Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,161,496 members, 7,847,038 topics. Date: Saturday, 01 June 2024 at 09:55 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1832595 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (46) (47) (48) (49) (50) (51) (52) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by omoalade144(m): 6:15pm On Jan 15, 2016 |
Inu mi dun gidigidi si iwe tie gbe jade yi, nitori pe, iwe yi wa gege bi agbara fun omo yoruba tooto, nitori idi eyi, moro gbogbo wa pe kia nipin ninu iwe yi. Emi gan papa n tiraka lati nipin ninu iwe yi .mosi mope lagbara OLORUN ELEDUMARE emi na ani iwe yi lowo.ASE. |
Re: .. by Zenlife: 9:11pm On Jan 15, 2016 |
Re: .. by tpiar: 11:31pm On Jan 15, 2016 |
Agbero means tout, you should know that nah. why pretending here. |
Re: .. by emmyjahzy: 1:56am On Jan 16, 2016 |
Walai elo igbe adie eyikeyi kokuna daada kefi ma fo enu, yo lo patapata |
Re: .. by autoboy20: 5:12am On Jan 16, 2016 |
e se gan mr. emmyjahzy, sugbon ejowo e se alaye funmi lekunrere bi mo se ma lo ogun yi, se ma po igbe adie na mo tooth paste ni abi bawo, ejowo e salaye funmi lekunrere |
Re: .. by Nobody: 8:36am On Jan 16, 2016 |
autoboy20: E lo ma je Ata ile leemeta laarin ose...te ba je fun ose meji, ke pada wa fun wa labo...o da mi loju wipe eo ni gburo enu rirun mon. 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 8:39am On Jan 16, 2016 |
tpiar:Rara o...Agbero iyen yato si Agbero ti a n so o. Agbero( A/gbe/ro) do mi mi. while the Agbero(Tout) is (A/gbe/ro) Re do do. 3 Likes |
Re: .. by Nobody: 1:55pm On Jan 16, 2016 |
x 1 Like 2 Shares |
Re: .. by Youceemeri: 2:27pm On Jan 16, 2016 |
Baba Healthfirst at babawa Kadunasouth Mo ki yin e ku ise takun takun lori i kanni yi ogbo ato. Ejowo efun wa ni ogun to okunrin oni le fi ko arun ibalopo lara obinrin bi Magun ati ti won ba fi unkan si ara obinrin naa lati wa bani lajo sepo ejowo mo fi orunmila be yin. |
Re: .. by seye4nii(f): 7:13pm On Jan 16, 2016 |
thanks |
Re: .. by Victorolami: 7:18pm On Jan 16, 2016 |
Baba Healthfirst Ati Baba Kaduna South Egbami ooo.... Oni omobirin kan ti ati nfe arawa bi odun marun bayi... laipe yi ni awon obi re fale awon kan lowo lati murin irin ajo losi ilu Spain tiko sii gba ilana toto... omobirin yii ko mon pe awon ti won ko awon obirin losi ile okere lati loma fi won se owo asewo lon kosi lowo... won siti dey Sahara Desert bayii....Ije oni ise ti e lese funmi lati GBE omobirin yii kuro ni ibi towa bayii si ilu bi Ibadan tabi Eko,,, ti yio file pada wale... tori awon obi re gan tin kaba mon bayii Lori igbese ti won GBE... ejowo esanu mi, tori moni ife omobirin yii gidigidi. |
Re: .. by Nobody: 10:13pm On Jan 16, 2016 |
Victorolami: Te ba ti mon oruko awon to fe mu arabinrin na lo si irin ajo...e kan si mi lori e-mail. |
Re: .. by autoboy20: 10:46pm On Jan 16, 2016 |
Eseun baba, se mo le ri ata ile na ra ni odo awon elewe omo? |
Re: .. by sakius10: 11:27pm On Jan 16, 2016 |
autoboy20:baba mo kin yin lori ise takutaku ti e se lori ikoni yi o,aji nde ara amaje yi o,baba edaku ogun aworo ti ale ri mon lele ilu shop ni mofe ati ogun kalonko todaju,koni tan nibiti eti mu lagbara edumare oo |
Re: .. by Nobody: 11:33pm On Jan 16, 2016 |
autoboy20: Ata Ile tabi Atale ni Ginger...o po kaakiri. |
Re: .. by Victorolami: 11:40pm On Jan 16, 2016 |
E seun gan baba, awon tolaye yio ma tiyin leyin.... Sugbon mi o Mon oruko arakunrin ti oun mu won rin irin ajo yii... ati wipe won ti kuro ni Nigeria ni odo wa nibi won si ti wani DESERT ni orile ede Niger... Ejowo se kosi oun tele bami fii GBE omobinrin yii kuro larin won si ilu towa ni Nigeria nibi... Ojo yin yio dale ooo. |
Re: .. by autoboy20: 7:05am On Jan 17, 2016 |
baba mo dupe lowo yin gan |
Re: .. by Victorolami: 11:10am On Jan 17, 2016 |
E seun gan baba healthfirst, awon tolaye yio ma tiyin leyin.... Sugbon mio Mon oruko arakunrin ti oun mu won rin irin ajo yii... ati wipe won ti kuro ni Nigeria ni odo wa nibi won si ti wani DESERT ni orile ede Niger... Ejowo se kosi oun tele bami fii GBE omobinrin yii kuro larin won si ilu towa ni Nigeria nibi... Ojo yin yio dale ooo... Ejowo eran mi lowo. |
Re: .. by sakius10: 1:15pm On Jan 17, 2016 |
Victorolami:baba edakun eki fi esi si iberemi ,baba mofi awon toni aye beyi |
Re: .. by Victorolami: 1:25pm On Jan 17, 2016 |
E seun gan baba healthfirst, awon tolaye yio ma tiyin
leyin.... Sugbon mio Mon oruko arakunrin ti oun mu won
rin irin ajo yii... ati wipe won ti kuro ni Nigeria ni odo wa
nibi won si ti wani DESERT ni orile ede Niger... Ejowo se
kosi oun tele bami fii GBE omobinrin yii kuro larin won si
ilu towa ni Nigeria nibi... Ojo yin yio dale ooo... Ejowo
eran mi lowo. |
Re: .. by omoalade144(m): 2:47pm On Jan 17, 2016 |
Ekasan o baba,ejowo baba efunmi ogun eyonu togbona ti ale fi si ara ti aba fe jade |
Re: .. by Nobody: 5:43pm On Jan 17, 2016 |
Victorolami: O ye ke mon oruko eni to mu afesona yin lo irin ajo. |
Re: .. by Nobody: 5:44pm On Jan 17, 2016 |
Awon Eyonu po sori ikani yi daada. omoalade144: |
Re: .. by Nobody: 5:46pm On Jan 17, 2016 |
Fun anfani awon to wa ni ilu Eko ati agbegbe re, Iwe Iwulo Ewe, Egbo ati Eranko ti wa ni agbegbe Iju-Ishaga fun tita bayi. 1 Like
|
Re: .. by omoalade144(m): 9:52pm On Jan 17, 2016 |
Ejowo sir moni ibere kekere kan torumi loju,ejowo ti obirin balo ogun adodun fifo abe re,ti okunrin balo CONDOM ba obirin na sun se ogun na yio sise.Eseun sir, agba yin adale o |
Re: .. by dominicson: 11:02pm On Jan 17, 2016 |
Youceemeri: Abeleeku eye aparo, atare kan, a o jo papo, a o fi sin igbere yipo idodo. Igbere naa ko ni iye. Eniyan meji ko le pin lo. Iba! 1 Like |
Re: .. by Nobody: 1:24am On Jan 18, 2016 |
x 1 Like |
Re: .. by belatoxx: 1:36am On Jan 18, 2016 |
Youceemeri: Baba ejowo efun wa ni ise yi emi naa ni fe si ese pupo. |
Re: .. by Nobody: 2:05am On Jan 18, 2016 |
Youceemeri: O ti wa lori ikani yi, e pada sehin. |
Re: .. by Nobody: 2:23am On Jan 18, 2016 |
healthFirst: E Jowo e juwe address na fun wa ati wipe eni ti yi o bayi ta iwe na, yi o wulo funmi nigba ti n ba fe gba ise yen, n o kan si yin laipe, e seun |
Re: .. by Nobody: 2:27am On Jan 18, 2016 |
healthFirst: 1 Like |
Re: .. by Nobody: 3:06am On Jan 18, 2016 |
x 2 Likes 1 Share |
(1) (2) (3) ... (46) (47) (48) (49) (50) (51) (52) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 43 |