Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,137 members, 7,814,977 topics. Date: Thursday, 02 May 2024 at 03:34 AM

Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju - Health (5) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju (558488 Views)

Civil Servant Killed By Thunder In Oro, Kwara (Photos) / Ogun Ibile To Daju / The Bad Shape Of Oro General Hospital, Kwara State (Exclusive Photos) (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (27) (Reply) (Go Down)

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 8:33am On Jan 26, 2016
kadunasouth:

ẸYỌNU AWỌN AGBA
Ifunni ekete kan, egbo akerejupon , ati ewe ajẹọbale, ao jo papọ̀, ao po ma ọṣẹ dudu oni apo nkan, ao ma fiwẹ leralera.

akoko wo lodaraju ti ale malo ise yi? or igba kugba ni?
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 11:02am On Jan 29, 2016
Eni ti kokini kule, onlopadanu ekaabo, lafi nki ojogbon wa, baba nkaduna ati gbogbo Omo awo pe: Ago'onile'o!. Olorun ama fun yin se, lase edumare, awon enion nri akitiyan yin ati opolopo igbi yanju yin ninu block, ninu block yi nimotiri awon Awo ti nwa nje fawo egbe'e, ati ninu awon opolopo block toje ti omo awo!, ati Alfa ati Woli ati onisegun omo awo lomo awo amaje lailai. Mowa nfi asikyi be gbogbo omo awo patapata Lori oogun tabama fisi block kama se aye wore daada, komaje eyi toma mu okan kuro tomafi mewa paro, fun apere, eni tonwuko tani kolo ewe minsinminsin pelu esore ati opolopo atare sinu oti, apa ikolotito sugbon esominsin misin tamo si oju olongbo kogbudo poju Lara, seloma tun wu nkan miran sile, fun idieyi gbogbo omo awo eje kakiye Sarao, bakan na fun iwo ogberi ti okomo ojutu ogun, tio bari nkan ti koyeo ninu block ti koyeo beere, won kimuyan sibere, odara Ki won bue juki ofi owo arare serare lo, bakana gbogbo oloro alufansa Lori awon ikan Ni, eje ka kiye Sara. Ajuwase'o. Letter timo koyi kiise fun blocks nikan kiisise fun eebu tabi oro iwosi rara, bikose fun Akiyesi, ogbon ologbo Ni kiije kapagba Ni were, fun awon opolopo blocks toje ti omo awo ni. Akoni se asise lola Eledumaawon.by P.Arojah

3 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 12:13pm On Jan 29, 2016
08101646045atwp:
Eni ti kokini kule, onlopadanu ekaabo, lafi nki ojogbon wa, baba nkaduna ati gbogbo Omo awo pe: Ago'onile'o!. Olorun ama fun yin se, lase edumare, awon enion nri akitiyan yin ati opolopo igbi yanju yin ninu block, ninu block yi nimotiri awon Awo ti nwa nje fawo egbe'e, ati ninu awon opolopo block toje ti omo awo!, ati Alfa ati Woli ati onisegun omo awo lomo awo amaje lailai. Mowa nfi asikyi be gbogbo omo awo patapata Lori oogun tabama fisi block kama se aye wore daada, komaje eyi toma mu okan kuro tomafi mewa paro, fun apere, eni tonwuko tani kolo ewe minsinminsin pelu esore ati opolopo atare sinu oti, apa ikolotito sugbon esominsin misin tamo si oju olongbo kogbudo poju Lara, seloma tun wu nkan miran sile, fun idieyi gbogbo omo awo eje kakiye Sarao, bakan na fun iwo ogberi ti okomo ojutu ogun, tio bari nkan ti koyeo ninu block ti koyeo beere, won kimuyan sibere, odara Ki won bue juki ofi owo arare serare lo, bakana gbogbo oloro alufansa Lori awon ikan Ni, eje ka kiye Sara. Ajuwase'o. Letter timo koyi kiise fun blocks nikan kiisise fun eebu tabi oro iwosi rara, bikose fun Akiyesi, ogbon ologbo Ni kiije kapagba Ni were, fun awon opolopo blocks toje ti omo awo ni. Akoni se asise lola Eledumaawon.by P.Arojah
ki epe baba amaju yin se good observation leleyi Joe o! adura yio gba awo nki awo

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:01pm On Jan 29, 2016
ATUDE
Ewe akoko ati ewe ewuro ao gbo ao mu die ao fi iyoku we opari

4 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MyLady11(m): 5:22am On Jan 30, 2016
kadunasouth:
ATUDE
Ewe akoko ati ewe ewuro ao gbo ao mu die ao fi iyoku we opari
ATUDE means what sir?
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 3:21pm On Jan 31, 2016
Fun anfani eni to bere itumo Atude, yioda fun'o, ntani emosenun, opolopo nkan lama ngbo, sugbon Ti aomo itumo re, tabi Ti amo itumo re tojepe ao kakun. Edakun gbogbo omo Awo, emaje kojepe gbogbo ibere Ti awon eniyan ba nbere emojeka nilero pe Awo toni block nikan logbodo danu, tori Awo ni gbawo ni gbuo, aoni te lawujo Awo. (IDE) ipinle ideni wipe nigba ti eniyan ba nfi oju ko owu alantakun (Elena) tabi ti oba njeun loju oorun, tabi nla ala biba ara eni sun ni gbogbo saa, tabi otito akoko toye ki obi omo inu re, ti okobii, tabi okori owo deedee bi oti senri tele mo tabi onjawe koje funo biti telemo, itumo IDE ni yen, bia bawa fe se atude, nkankan nio koko siwaju. Aoni sasise'o.

4 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 3:26pm On Jan 31, 2016
Ibo gan ni ibiti (IDE) ngba wole Sara eniyan ga?
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 3:31pm On Jan 31, 2016
Ona wo Ni IDE ngba wole Sara eda eniyan? Atipe kini alelo tole dekun IDE lago arawa?
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by belatoxx: 6:16pm On Jan 31, 2016
ABORU BOYE: BABAKADUNASOUTH EGBAMI OO


osole nla to nsoni di Olowo
okan malu ao ki ori igun si iho kan, aotun fi egberun kan naira we Igbo ao kisi iho elekeji , ao wa ki atare si iho eleketa ao jo ninu ikoko tuntun ao mafi foko mu lararo,
lowo bade

EJOWO SE ISE YI KO NI ABURU KAN KAN


2. MO NI LO OGUN ITAJA TO JE BI IDAN AGBAYIN ADI ALE OOOO

3 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ALIUDAVID: 10:09pm On Feb 01, 2016
Ekale gbogbo ile ejo eni ti o ba ni ogun arobi todaju(BACK TO SENDER) ko ju sita fun afani gbogbo wa... Iba agbagba iba eyin to laye..

2 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 12:10am On Feb 02, 2016
Notice! Notice!! Notice!!!

Read and ask not side effect of my post

OSO... also called money rituals or blood money. Some people don't know the differences between oshole and awure.. oso is what they use human being for the preparation of the wealth... and some of the results of oso it's. . E.g.. to see money inside big pot by chanting the name of the person you used. The money will dissappear inside the pot within some hours. And also can be used by sending ghost or spirit of such person to goto the bank or anywhere to bring u huge money.. or carried calabash on top of such person head and be picking money And it has big repercussions like. E.g.. not live long. Suddenly death. .earing ghost voices anywhere you go. And some people's got mad immediately they did it. Because it's not compatible with his star......
 beware of wicked people they will told you that it's basiri ( good fortune ) or oshole ( wealth booster ) what u have to notice from their talk. It's to know how it will work for you. Once u detect how it will works. So try and run for your life....

 OSHOLE or AWURE NLA or  AKO AWURE or OSHOLE TUTU ( wealth booster) this is the best thing to do it has no repercussions and powerful than AWURE.. any OSHOLE it's require ANIMALS AND SOME LEAFS OR BARKS no human blood shed.. it's good for those who is looking for progress especially the person that has the particular job that his doing. Oshole can not drop money in front of you oo.. it's not a magic or miracle it will just boost you work and your progress.

 AWURE ALSO CALLED APEDE. ... Awure it's good it's also work for progress of anything human being his doing.. it's has no blood shed of HUMAN BEING or ANIMALS. It's only has some leafs , barks .. and anything that has no blood.. though some required Ants.insect..e.t.c no repercussions


 N:B... my advice for people's that is reading this blog. Is to be careful of all those uselss people that need you to run business. Everybody need money. Why can't he did it for himself.. so be careful thanks.....

9 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by belatoxx: 12:19pm On Feb 02, 2016
MO NI LO OGUN ITAJA TO JE BI IDAN AGBAYIN ADI ALE OOOO

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:03pm On Feb 02, 2016
Asiri Ola (ki ona owo le lakanwa)
Ako ati Abo eye ega owo eyo mesan ewe ola ati ewe sawerepepe odidi atare kan ao ko gbogbore sinu fitila oloju merindinlogun inure lao tijo ao lo ao mafi miliki lo lararo iseyi daju fun owo ati okiki and connection

7 Likes 2 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by belatoxx: 12:14pm On Feb 03, 2016
@kadunasouth EJOO MO NI LO OGUN ITAJA TO JE BI IDAN AGBAYIN ADI ALE OOOO

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Nobody: 11:39pm On Feb 03, 2016
kadunasouth:
Asiri Ola (ki ona owo le lakanwa)
Ako ati Abo eye ega owo eyo mesan ewe ola ati ewe sawerepepe odidi atare kan ao ko gbogbore sinu fitila oloju merindinlogun inure lao tijo ao lo ao mafi miliki lo lararo iseyi daju fun owo ati okiki and connection


IBEERE.
1.E jowo baba, se owo eyo ailuju ni a maa lo ni tabi eyi to lu oju
2. Mo bayin so nnkankan, e si se ileri wi pe e o kan simi. Nko i tii ri esi yin. E se pupo.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:49pm On Feb 06, 2016
Ogun Itaja 1
Egugun agbari aja ao lo po ma ewe ola ao lo yio kuna dada ao da si inu ipara ao popo dada ao tun wa da turare to balorun si ao ma fi para losi ibi ojawa ata jere lao ma ta o amin Ase iba fun gbogbo eyin agbagba oju anu ni kie mafi womi omo yin ni month nse mojuba o!

Itaja 2
Opolopo ewe sawerepepe ati opolopo ibose adie odidi atare kan ao jo papo ao ma da sinu omin fi wan le lararo eleyi daju, tabati fi wan le bayi ero abere si mawa raja nio iba eyin ajunilo ti ekolo bajuba ile ile alanu nio efi oju ire womi

7 Likes 3 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by belatoxx: 10:54pm On Feb 06, 2016
@kadunasouth ese pupo fun idaun yin ejowo kini alelo si eni to oko re kere ti yio fi tobi dada ejowo oo iyawo ile mi tin komplani
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by belatoxx: 11:03pm On Feb 06, 2016
EJO EFUN WA NI OGUN TI OKO OKUNRIN BA KERE SI OJO ORIRE.MO SE IBA AGBA OO
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 4:55am On Feb 07, 2016
Turare Jalabi, Itaja, Afa orewole Odara Fun Onile ati Onirin Ajo
Ori Agiliti, ori aparo, ori musu eyi toni irun, Ewe ajade, eru alamo, koro owu kopo die, oyin bi sibi meji ao gun gbogbo re sakasaka ao mafi lararo Danwo oje bi idan

5 Likes 3 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 5:26am On Feb 07, 2016
Atude Asina todaju
Ewe tude Egbo tude Epo obo ao gun gbogbo re month ose ti aba ti fe sun ni ale ojo alakoko ao fi epo rara ojo keji ao fi ori rara ojo keta ao fi oyin rara kato lore mawe odaju

5 Likes 2 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:30pm On Feb 07, 2016
Awure ati Asiri bibo
Epo obo ao lo kuna dada ao fi omin agban po month ose dudu ao ko sinu awo ipese awo dudu ao ma fiwe

4 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by sannies(m): 10:59pm On Feb 07, 2016
Good evening sir, what can someone use for fibroid (iju). Thanks

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 4:43am On Feb 08, 2016
Awise
Ewe ogbo ewe alupaida eyo atare kan ao lo ao fi sin gbere si isale ete wa, gbere eyokan lago kan oru lojo sunday, ebu toba ku ao fe sinu ategun

7 Likes 3 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:06pm On Feb 08, 2016
Ose itaja
Egbo tude ata pupa ati ata dudu ao gun ao pomo ose dudu ao ma fiwe
Ikilo ata die die lama lo bi eyo meta meta kogbodo poju koma ba ma tawa lara ale fi epo rara kato mawe odaju

6 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:13pm On Feb 08, 2016
Ogun isoye
Ewe eran die kuluso 7/9 (obinrib/okunrin) eja abori ao jo ao mafi fo eko tutu mu die die lalale

4 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:21am On Feb 09, 2016
Ogun itaja
Ajesi adie ati oko atare kan ao lo papo month epo obo ao gun month ose dudu taba gun tan ao fi epo obo gun ose na lori leyin ojo keta tati se ogun yi lao wa bere si nilo ao ma fi we opari

5 Likes 2 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 2:15pm On Feb 09, 2016
Atude ati Asina kia kia
Egbo tude ako eye iga, odidi atare ao jo ao lo yio kuna ao ma fi ogede omini je ebu na die die ise yi daju dada

5 Likes 2 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 3:32pm On Feb 09, 2016
Ogun Agbana ati Anabo todaju reo!
Ati ki owo le duro lowo wa odaju
Egbo ako ati abo rere ao lore wu lagokan osan alubosa elewe odidi atare kan ao jo ao fi sin gbere yipo orun owo wa mejeji
Opo eniyan lolelo ninu iseyi
Ti oba ri gbere yi sin kosiye meji nibe oti segun agbana niye o
Ibare olodumare
Iba agbagba

6 Likes 2 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by aktab: 6:37pm On Feb 09, 2016
kadunasouth:
Atude Asina todaju
Ewe tude Egbo tude Epo obo ao gun gbogbo re month ose ti aba ti fe sun ni ale ojo alakoko ao fi epo rara ojo keji ao fi ori rara ojo keta ao fi oyin rara kato lore mawe odaju


Baba e jo se ojo meta la a o fi lo ise yi tabi a le lo leyin ojo keta.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by aktab: 6:40pm On Feb 09, 2016
kadunasouth:
Atude Asina todaju
Ewe tude Egbo tude Epo obo ao gun gbogbo re month ose ti aba ti fe sun ni ale ojo alakoko ao fi epo rara ojo keji ao fi ori rara ojo keta ao fi oyin rara kato lore mawe odaju
kadunasouth:
Atude Asina todaju
Ewe tude Egbo tude Epo obo ao gun gbogbo re month ose ti aba ti fe sun ni ale ojo alakoko ao fi epo rara ojo keji ao fi ori rara ojo keta ao fi oyin rara kato lore mawe odaju


Baba e jo se ojo meta la a o fi lo ise yi tabi a le lo leyin ojo keta.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Bosville(m): 8:13pm On Feb 09, 2016
Agba yin adale baba kadunasouth....Mo ni lo ogun ti a fin mu ole to ba ji nkan wa....Eseun sir
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:23pm On Feb 09, 2016
Ogun ta nfi gbe Aburu kuro lara tabi inu ile
Isu gbegbe odidi atare kan ao jo papo ao fi ro ekuru je opari

7 Likes 2 Shares

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (27) (Reply)

Causes Of Seeing Menstrual Period Twice A Month / Postinor 2 - How Effective Is It? / Doctor in the House: Free Medical Advice Available

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 41
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.