Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,245 members, 7,815,352 topics. Date: Thursday, 02 May 2024 at 11:08 AM

Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju - Health (6) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju (558506 Views)

Civil Servant Killed By Thunder In Oro, Kwara (Photos) / Ogun Ibile To Daju / The Bad Shape Of Oro General Hospital, Kwara State (Exclusive Photos) (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (27) (Reply) (Go Down)

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:27pm On Feb 09, 2016
aktab:


Baba e jo se ojo meta la a o fi lo ise yi tabi a le lo leyin ojo keta.
Ojo meta lao filo

2 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:47am On Feb 10, 2016
Eyonu todaju
Epo obo, igi Asorin, Ewe ola ao lo gbogbo re papo ao da sinu lonfida ao ma fi ra owo ati oju die die




A
W
U
R
E
Eyonu odara pupo
Ewe ewuro taja lojo eru alamo, epo obo ao gun gbogbore papo ma ose ao fi ororo malu ati ori po, ao ma fi we lararo pelu adua nkan to ba fe

7 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by aktab: 1:39pm On Feb 10, 2016
kadunasouth:
Ogun arisiki
Koro owu akese topo, eyin ororo kan odidi atare kan ao jo ao lo kuna ao ma fi miliki lo die die odaju

Baba e jo se eyin adie ibile tabi ti agric ni kaa lo,
ki lo n je eyin ororo se omo inu re (yolk) ni.eseun pupo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kemkem303: 1:48pm On Feb 10, 2016
Ewe ama je o! Baba kadunasouth a o ma ri yin ba o. Ase o! E dakun e jowo e fun mi ni ogun ti ma fi ri ise. Mo tin wa ise oti to odun meta bayi. E dakun e sanu mi. Elekeji, e jowo se mo le ri ogun ti won ma fi contract nla nla be oko mi? Nitori wipe nkan fe ri bakan lenu ojo meta yi. Ese gan ni o.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:57pm On Feb 10, 2016
Ogun Arisiki
Aidan meji Epo obo Atare odidi kan ao jo papo ao ma to sowo pelu adua ao ma fi omin lo lararo

7 Likes 2 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:31am On Feb 11, 2016
Gbere Ebe Awon Agba
Igo ngori ewe Agogo igun ao ja 99 odidid atare kan ao jo papo ao fi sin gbere si igbaya otun gbere meta, eyin meta, igbaya osi meta eyin igbaya osi na meta opari odaju

6 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Bosville(m): 6:46am On Feb 12, 2016
Ejowo baba kadunasouth kini iyato to wa larin ogun "Arisiki" ati "Awure"??

1 Like 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:07pm On Feb 12, 2016
Bosville:
Ejowo baba kadunasouth kini iyato to wa larin ogun "Arisiki" ati "Awure"??
Awure ati Arisiki wan jo arawon sugbon iyato die wa nibe gbo gbo eniyan lole se ogun arisiki sugbon kokin se gbogbo eyan lole se awure, awure wa fun onise owo ki ise re le gboro ki opolopo awan eyan ma wa be nise, ati onisowo ati oludasile ile eko ki awan omo akeko le po dada ati bebelo oluko ilewe kolese awure yio kan man sise fun onise ni sugbon olese arisiki yio mari anu gba lodo awan eyan osise ijoba kolese awure sugbon olese arisiki yio ri anu ati igbega lenu ise laifa orogun gbogbo eniyan lolese arisiki sugbon ki ise gbogbo eyan lolese awure, sugbon gbogbo eniyan tulese awure ti akoba bikita lati gbe oriyin fun ilese ti ki se tiwa bi apejuwe sale girl tolose awure oun gba egberun mewa losu sugbon oun wata oja million fun ogare pelu awure tose seriwipe oga nilosiwaju oun faseyin, sugbon tobase arisiki yio pade alanu,
Sugbon awure na tun pe lorisi risi, awure owo itaja okiki pebelo otun depend ti kobaye ole pemi fun ekunrere alaye, abi kio kan simi lori ero aye lujara

7 Likes 4 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by belatoxx: 7:14pm On Feb 13, 2016
Aboru boye oo @Babakaduna ejowo ti eni yan ba un se were were ti o tun mu oti ati siga kiri ki ni a le lo fun iru enibee ejowo e fi si ita fun wa ewe a maje fun yin lase edumare
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 3:12pm On Feb 15, 2016
Eyonu Asina
Kowe kan, eye kanakana kan, eye elulu, okete oojo eyin adie ororo mewa, epo obo, ewe ewuro oojo, ao jo po ao ma fi ogere epo pupa la ni aro ati ale

5 Likes 2 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ALIUDAVID: 7:26pm On Feb 15, 2016
Ekale baba kaduna south, ejo oruko wo ni won tun pe "olu ogan" iba eyin to laye, iba agbagba..
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:11pm On Feb 15, 2016
belatoxx:
Aboru boye oo @Babakaduna ejowo ti eni yan ba un se were were ti o tun mu oti ati siga kiri ki ni a le lo fun iru enibee ejowo e fi si ita fun wa ewe a maje fun yin lase edumare

Ogun fun Oniwa npale ati omuti ati iwakiwa ti afe kiwan fi iwa na sile
Akara ori atan pelu odidi atare kan ao jo ao lo yio kuna ao wa lo sugar onikoro 7/9 meje fun okunrin, mesan fun obinrin yio ma la koto ba eniyan soro laro kutu, gbogbo iwa ti kodara leni na yio kosile

5 Likes 3 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by aktab: 10:59pm On Feb 15, 2016
kadunasouth:
Eyonu Asina
Kowe kan, eye kanakana kan, eye elulu, okete oojo eyin adie ororo mewa, epo obo, ewe ewuro oojo, ao jo po ao ma fi ogere epo pupa la ni aro ati ale
.

Babakadunasouth,Olohun a tunbo ma fun yin se oo. e joo e ma binu si ibeere mi yi,
1.se eyin adie ibile la maa lo ni tabi ti Agric.
2.E jo e se alaye fun mi n kan to nje eyin ororo se pupa inu eyin ni (yolk)tabi funfun inu e?
ewe a maa je o, ESE
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:54am On Feb 16, 2016
aktab:
.

Babakadunasouth,Olohun a tunbo ma fun yin se oo. e joo e ma binu si ibeere mi yi,
1.se eyin adie ibile la maa lo ni tabi ti Agric.
2.E jo e se alaye fun mi n kan to nje eyin ororo se pupa inu eyin ni (yolk)tabi funfun inu e?
ewe a maa je o, ESE
Eyin adie ibile (adie tiwan sin nile) to sese ye ti koti baje niwan peni eyin ororo

2 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by belatoxx: 1:21pm On Feb 16, 2016
Babakadunasouth@ Ki ni won pe ni Akara ori atan e jo e la ye mi adura wa yio gba
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 1:24pm On Feb 16, 2016
belatoxx:
Babakadunasouth@ Ki ni won pe ni Akara ori atan e jo e la ye mi adura wa yio gba
Imi gbigbe(igbe ti wan ya sori atan toti gbe dada)

3 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by belatoxx: 1:31pm On Feb 16, 2016
Ese pupo babakadunasouth agba yin a di ale o, mo dupe pupo lowo yin


Baba ki ko fa to je wi pe ti mi ko ba na owo kan tan mi ko kin ri emiran egba mi e sa nu mi.

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 12:24pm On Feb 17, 2016
Eni ti kokini kule, onlopadanu ekaabo, lafi nki ojogbon wa, baba nkaduna ati gbogbo Omo awo pe: Ago'onile'o!. Olorun ama fun yin se, lase edumare. Fun eniti obere idi Ti ofi jepe owo Ki duro si lowo, oroyi pinsi ona topo, pataki ibe nipe onilati se akiyesi arare, Ki ole mo iru ogun Ti walo,
. AKIYESI PATAKI
. 1) Iru ise ti onse
. 2)bi isere se nmun owo wole si
. 3)awon bukata to nfi owo re gb
Toba sepe bukata to nfi owore gbo koba poju ere isere lo, Ti owo koba tun wa duro lowore, ajepe kotun ye ojo ibi re wo, Toba bosi June, oni lati otun Ni lati mo awon asiri kokan nipa arare lati ma kiye si, Ki ona re leba rorun laye.
Ti koba wa ba awon ibeyen lo, oni lati se atude daada, bi awon ide onje oju oorun, ibalopo oju oorun, jankariwo oju oorun tabi oju aye, ijakadi oju oorun, ati ise agbana ti ma nmun Ni na ikan tan keyan otorikan, tabi Ki eyan sise odindi kan wa so owo di owo guguru ati epa moni lowo, ati opolopo ebe awon agba.

Gbogbo ise Ti mo ndaru koyi loti wa Nita, kefara bale ka oju iwe lati here pepe, ohun Ti koba ye wa ka tun beeree. AJUWASE'O!

2 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ALIUDAVID: 12:59pm On Feb 17, 2016
baba kaduna south, ejo oruko wo ni won tun pe "olu ogan" iba eyin to laye, iba agbagba..
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 5:51pm On Feb 17, 2016
08101646045atwp:
Eni ti kokini kule, onlopadanu ekaabo, lafi nki ojogbon wa, baba nkaduna ati gbogbo Omo awo pe: Ago'onile'o!. Olorun ama fun yin se, lase edumare. Fun eniti obere idi Ti ofi jepe owo Ki duro si lowo, oroyi pinsi ona topo, pataki ibe nipe onilati se akiyesi arare, Ki ole mo iru ogun Ti walo,
. AKIYESI PATAKI
. 1) Iru ise ti onse
. 2)bi isere se nmun owo wole si
. 3)awon bukata to nfi owo re gb
Toba sepe bukata to nfi owore gbo koba poju ere isere lo, Ti owo koba tun wa duro lowore, ajepe kotun ye ojo ibi re wo, Toba bosi June, oni lati otun Ni lati mo awon asiri kokan nipa arare lati ma kiye si, Ki ona re leba rorun laye.
Ti koba wa ba awon ibeyen lo, oni lati se atude daada, bi awon ide onje oju oorun, ibalopo oju oorun, jankariwo oju oorun tabi oju aye, ijakadi oju oorun, ati ise agbana ti ma nmun Ni na ikan tan keyan otorikan, tabi Ki eyan sise odindi kan wa so owo di owo guguru ati epa moni lowo, ati opolopo ebe awon agba.

Gbogbo ise Ti mo ndaru koyi loti wa Nita, kefara bale ka oju iwe lati here pepe, ohun Ti koba ye wa ka tun beeree. AJUWASE'O!
alaye ye koyewa dada esoro lori osu June ebawa yonana re koyewa Dada tori egban mi kanwa June ni Toni Iru isoro be mama reti esi

..
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Naturewonders: 1:17pm On Feb 18, 2016
Baba ejowo mo need ogun eni to nba obirin sun loju orun.eseun
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 2:59pm On Feb 18, 2016
Turare itaja
Ewe tagiri ati iru woro niwanba die ewe tagiri yio poju iru lo ni ilopo meta ao ma businu ogu ina ao mafi ninu shop wa tabi ile
Odara pupo

3 Likes 3 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:37am On Feb 19, 2016
Ogun isori
Egun esusu ori oka odidi atare kan ao jo papo ao mala pelu epo pupa lalale . Apa ota koni kawa o lase odumare

4 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:44am On Feb 19, 2016
Ogun kokoro omun
Etu ibon gid,i iyere ao lopo ao pomo ori ao mafi wo (ao ma fi pa omun na ao ma fiwo, yio pa kokoro na)

4 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by alabosian(m): 11:24am On Feb 19, 2016
baba mo need ogun to ma boost sperm count. ti o ma je ki sperm ni eyin ninu dada
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 4:28pm On Feb 19, 2016
Fun eni tio bere ibere nipa osu June, oropo nibe, sugbon kage kekeke, bio baje omo June, bio koba mo awon asiri yii, owo kole duro lowo'e, fun idi eyi, Kii se nka Ti ale fi si ori afefe, nitori naa, elekan si ojogbon wa, kadunasouth, lati bere ekun rere alaye, tabi kekan si wa Lori wasp. Ifin wo! Ikoro wo! Ntaba jijo wo, gigun Ni ngun. Ajuwase'o
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by simpleworld: 7:55pm On Feb 19, 2016
baba pls mo nilo phone yin
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 10:11am On Feb 20, 2016
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ajuwase'o
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Abiola10: 10:25am On Feb 20, 2016
Eku ise o,baba ejowo sir e fun wa ni oogun koko omu obinrin(breast lump).
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by possible26: 1:45pm On Feb 20, 2016
BABA e jowo mo need oogun quick expulsion
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Hafyz23(m): 4:53pm On Feb 20, 2016
kadunasouth:
Tude todaju
Epo obo, iku ojia, igi nla ata ijosi ati eru alamo ati aidan ao gun gbogbo re month ose dudu ao ma fi we gbogbo ide aye larawa loma tu danu pelu ase Alayelorun
Edakun baba,kini je "epo obo"?
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by dominique(f): 7:08pm On Feb 20, 2016
This is the health section not the culture section, plesee post in English so others can gain from your contributions.

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (27) (Reply)

Causes Of Seeing Menstrual Period Twice A Month / Postinor 2 - How Effective Is It? / Doctor in the House: Free Medical Advice Available

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 44
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.