Welcome, Guest: Join Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 2,379,416 members, 5,305,065 topics. Date: Saturday, 07 December 2019 at 11:14 AM

.. - Culture (95) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1572836 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (92) (93) (94) (95) (96) (97) (Reply) (Go Down)

Re: .. by engrkaz(m): 5:21pm On Mar 10, 2018
olaking34:
E jowo, no ni lo Ogun ti a fi n tu ejo(case) ka, tabi ti a fi le mu ki a won oga ile ise ka oju Ku to ni ejo(case).
Ti e ba ri Ogbeni Magu, e digbolu.. E ti si konga....bi e ba ti le se bayi, abuse buse, ejo ba tuka
Re: .. by Canme4u(m): 8:54am On Mar 13, 2018
08101646045atwp:
ATUDE OSE"
ewe lapa funfun mesan, ewe ewuro ojoo mesan, ewe efinrin mesan, ewe ajaobale mesan, yerupe ago kan osan ati toru, ao gun mose, ao fiwe fun ojo meta pere lori ni ago kan oru ni wiwe re o, ti abatiwe ose ye pari, ao tu kanhinkanhin yeka, ao sonu ni o. Odaju


ITUWO ATUDE- aowa ewe ajeobale, epo igi ajeobale, egbo ajeobale, aolopo mose aopin ose na si ona meje, ti abafe we aowa ajadi apere kan aoko sinu re aowa we ose mejeje na lekan na telera won ninu apere yi kain kain meje ni aofi we ooo, AKIYESI, ti aba nwe lowo aogbodo soro, aosi gbodo siju le afi ti aba wekan tan ti atun fewe imin

ATUDE TODAJU Ewe tude egbo tude iyere ao lo ti yio kuna dada ao ra isasun tuntun ao fi se odidi igbin kan je lepo niyo lodidi ni ao se igbin yi o akoni ge ti obajina ao so kale ao je ko tutu ao wa bo gbogbo aso orun wa ati oruka ao wa ni ihoho omoluabi ao wa da aseje na si ilele ao kunle ti ao wa ka owo wa mejeji seyin wa ao wa se adua itusile ao wa fi enu gbeje lodindi iseyi daju danwo kori botiri Ike oloun ola oloun komaba alayelorun NB ori ilele cement or tiles lamada aseje yi si leyin ti ati nunu dada ao dasi ao waje

EYONU AWON AGBA TODAJU
Ao wa Opolopo ewe imi esu ao japo ma ododo ati itanara ao jo po ma atare odidi kan ao mafi la epo pupa lalale pelu adua odara pupo atude ni pelu odaju

EYONU¤ Ewe Akoko ati Itanna re, epo ati egbo re ao jo pelu odindi ataare kan, ao maa fi epo la ki a to sun... Ti o baa di ojo keje ti a lo ise yii ao fi Akara elepo se sara fun enia meta pere odaju

EYONU¤ Eru oju aro, epo obo ao lo kuna daadaa ao mo mo ose Lux ao maa fi we lalale.... Odaju

EYONU AWON IYAMI TURARI NI O¤ Eku asin meta, Epo Obo, Epo Igi nla, Korowu ao gun papo, ao daa sinu try kan ao waa daa adin gidi si ao ro papo daadaa, ao saa si ategun, ao maa fin ni alale ki a to sun.... Awon Agba won yi maa yonu siwa

EYONU ASINA TIPATIPA¤ Ao gun ewe Afelorun kuna daadaa, ao waa po pelu Ose dudu, ao te Ifa Eji Ogbe si ori iyere Osun, ao se Adura Isina si daadaa ao waa po pelu ose yen ao ko sinu igba Olomori, ao maa fi we ni gbogbo igba..... Walahi Odaju

EBE/IMULE AWON AGBA TODAJU
Alubosa elewe tutu kopo die ao gun dada ao popo ma ose dudu ao wa eyin adie Oojo ao do gbon fo lori die ti korofo eyin yi konibaje ao jo omin eyin yi sinu ose yi ao tun gun dada ao wa igba olomori ao ko ose yi si ninu ao wa fi korofo eyin yi gun ose yi lori logan gan ibi ti ati fo eyin na ni yio koju sinu ose, ao ti koko dogban fowo jin ibibe kato fi eyin na gun ki korofo eyin na maba fo. Ao ma buwe nigba toba wuwa. Iseyi daju ijo taba bere wiwe re ojona ni yio bere ise

EYONU
Oga3,asin3,opolo3,eso ido,eso werenjeje,ewe ajeobale, ewe orijin,ewe kileofimise,odindi atare 3,ao Jo po ao ma fi epo ogere la ninu fitila oloju kan. Tested ok
IMULE AGBA
Akara elepo16,eran menu,ao to akara yi round ninu ape ao fi eran sarin re ati odindi atare kan ao Jo po ama fi otin lo lalale
Eyonu ,ogede omini ati epo obo ati igbo mimu ao gun papo mo ose ,odaju

Etutu awon eleye kan reo:- alubosa funfun ao fi din eran namo tikoiti womi tiagesi ona merindinlogun, ao jo ako alangba kan pomo odidi atare kan ao lokuna ao da sori ipese na ao da epopupa lelori ao daniyan si ao gbelo sorita loru oganjo, odaju

Tour!
Eyin isoro ope eyin nikiee bawa toroyise'o
Tori eku Ni awon ko nko nfilele awa'omon
Kaye omo olufe lebaagun gege nio
Kiya maba jomo'olufe nio
Edakun edabo efiye denu'o
Etanti imule'o
Bawobapawo ile loda'o...
Moseba agba.. Mowari faye'ooo

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
FUN ALAYE LEKUN RERE 08101646045
Ajuwase o
MAJEMU LAILAI?
Se omo odun mokandinlogbon naa le WO agbo yii?
Re: .. by skoolguy: 3:27pm On Mar 15, 2018
Eejowo ti aba uko ogun ki ari pe ako Eewo re pelu tori pe awon omiran ni eewo ti ako gbodo se sugbon ti ako ni ko si be eleyi buru lopolopo ao nite oju ile mole oh
Re: .. by dplanner: 12:32pm On Mar 16, 2018
Awon asiri tI eyan ma fi sI le nibi asiri bibo lo je ko le mu e Kuro ninu OsI toripe asiri to daju sugborn ale ma fi sI ta nibi be o ya Egba asina owo awure to daju yi ki e fun ile nI abo re e o owo tuntun orisi risi meta a o Han aya watuhibuna LiMala uba Janmo sI gbogbo ara owo na a o sa gbe a o wa orI okete kan ati irun asirì a o lo wòn po Mo Ihere tabI at a ijosin a o se je Edo Malu fun ojo3 omI aye nì omì re oooo. Fun ibere tabi nkan kan pe 07067796292, 07055595911 .
Whatsapp number 09062199194 .
Re: .. by dadamonie150(m): 7:35am On Apr 02, 2018
Eku Ile ooo gbogbo ara ileooo, gbogbo eyin agba wa to wa ni ikale eku dede asiko yi ooo, opolopo odun laaa ma seee ooo, olorun atubo ma gba fun waa... Amin
ejowo mo need ogun afako to daju ejowo e shanu mi, olorun ko ni dayin da bukata yin
Re: .. by DeDaniels1: 6:56pm On Apr 06, 2018
Baba, e ku ise nla ti e nse lori eto yi, eledua a maa tubo ranyin lowo o. E jowo bawo ni a se le bayin soro lori ohun pataki kan to je wa logun. eseun.
Re: .. by dplanner: 6:47pm On Apr 07, 2018
iwo ti o ba nwa ipo kan tabi ofe ki ola ti oni ki oma di ohun igbagbe laye, ki ola na ma lo bee, toripe opo ni ola won ati oruko won ti di ohun igbagbe, kan si mi kajo soro lori 07067796292 tabi whatsapp no 09062199194.
Re: .. by authlas: 1:23pm On Apr 22, 2018
Eku ise o baba, olohun a maa funyin se o, a dupe pupo.

Ejowo , mo fe ki e dakun ki e funmi ni oogun ti o sise dajudaju fun AKO NARUN(nettle rash/hives). Narun yii ndamilaamu debiwipe otijade simi ni abe ti ojewipe ti mo ba nho, abe yen ti nbo pelu, abere kosi ran rara. Edakun mo fe ki e funmi ni eyi todaju ti yoo paa lati inu wa, yoo si tun je anfaani funn elomiran ti kokoro yii lee maa yo lenu ninu forum YII....ESE PUPO
Re: .. by dplanner: 1:55pm On May 02, 2018
Asina owo gidi to daju a o Han suratul wakia meta ewe abamoda 99 ewe ati egbo ogbo ati odindi atare kan a o jo po a o fi omì ti
eyele mu ku fo Hantu yi a o fi omì hantu yi lo ebu ogun ti ajo yi ni ago kan oru ni ihoho lekan na walahi odaju gan .e je ki a ma se bere dada ki a to ma se awon ise ki ale mo awon ise to ba irawo wa mu toripe opolopo ti lo ise to po ti ko sise fun , ese ibere dada .fun ibere Lori anything pe si ori 07067796292 , 07055595911 tabi what's app number yi 09062199194 .E ku oju lona asiri wakia to je gbewa owo to daju .

2 Likes

Re: .. by dplanner: 3:50pm On May 12, 2018
Adura ise fatiah ati turari re pelu sara ti a le fi gba unkohun Lodo olorun, ko da bi ise wa kolo dede tabi ise wa ti ku Yanyan ko si nkan ti ale lo fun, ko da mo ba awon oga aloso dudu ati awon eyan kan lati America pari ise yi ti won si ti ri ise re bayi , o daju pupo awon nkan turari adura yi ni iye agbe 16, aluko 16, Ikode 16, ewe lapalapa funfun 16, bomubomu 16 , sara re agbo funufun nla kan, fatiah na ni ise yi sugbon oni bi ati ma se fun ojo meje, ko si ibi ti oluwa re ba wa ni orile aye yi, ise yi ma kan lara ,nkan ti aba fi bere ni yi o je fun, ale fi bere owo nla, agbega, ipo, ilosiwaju,ejo kotu,contract, anything at all .wallahi adura wa awon eni olorun na si wa , ko da ewe ati egbo nbe to nje bi igi se je fun idana. Iwo to ba nife si ise yi o le kan si mi lori ero ibanisoro mi 07067796292, 07055595911, yala ofe ki nba e ko eto adua jo ni tabi ofe ki n jowo re fun ooo sugbon adura ti ko si iyemeji nibe ni ,awon eyan mewa ni mo ti se adura yi fun ti gbogbo re se ise ti a ran pe kose.

1 Like

Re: .. by dplanner: 12:40pm On May 27, 2018
GBEWA OWO WAKATI MEJI 2HOURS Odindi eiye elulu aye kan, oga aye kan, ewe alupaida meje, ewe abamoda kan, owo 1000 note kan , ao la elulu yen laya, a o fi owo tele , a o be oga le , a o ko ewe alupaida si, ao fi ewe abamoda si, ao fi owu funfun we gbogbo re po, a o be lo si ile ijalo fun 3 days or 7 days leyin ojo yen , a o gbe wale a o gbe sinu ape a o tu gbogbo owu ara re ape tuntun ni o odijijo, ao ro sinu ado ide, a o gbe ado ide yen sinu awo sobi ao wa pa ewure kan sori ado yen ninu awo sobi yen, a o fi ewure yen se Sara ni o, eni toni ise yi o gbudo je ninu ewure yen oooo . Lilore: gbogbo igbati aba fe lo ise yi , a o da agbado funfun sinu awo funfun ti ko lami. A o fi 1000 le lori a o wa to ebu ninu ado ide yen sori owo yen ninu awo funfun yen a o so pe : Alupaida parada ki o lo gbe owo wa fun mi, a o wa de fun bi 2hours ao lo si wo leyin wakati meji yen pelu ogo olorun owo 1000 yi o ti kun inu awo yen. O daju pupo. Mo ki wa pe aku awe yi , emi ari eyin osu allahumo amin. Pe mi fun ekunrere alaye ti ko baye oooo nkan ti mo fi ise sita ni pe ola awe atipe anu Eyan se mi pupo ju to ri ise to lagbara to si daju ni. 07067796292, 07055595911.
Re: .. by Wonder0803(m): 6:34pm On May 28, 2018
Ejowo enitimonife si lo travel kuro Nile Yi, ejowo, Ogun wo mole se toje wipe eni no koni nife elomiran Mo tabi ko ma lala ife simi
Re: .. by fridayakanb1(m): 1:52pm On Jun 09, 2018
Aku awe yio,a si ku ipalemo odun,a bawa laye,a bawa laaye,Ase Edumare. coolAku awe yio,a si ku ipalemo odun,a bawa laye,a bawa laaye,Ase Edumare.
Re: .. by absoluteSuccess: 11:49am On Jul 14, 2018
absoluteSuccess:
Ago o, mo ki tewetagba lori ikanni yi o, eku oro iwosan ati ilera lori ewe ati egbo o. Inu mi dun lati so nipa egbogi ajebiidan kan ti mo sese pile re. Mo pe oruko egbogi naa ni 'Allicin Pride', ah, egbogi naa dara yeye! Pupo awon ara mi ti won ti too wo ni won'gboriyin fun iwulo Allicin Pride gege bii immune booster tabi 'awogba-arun'. Lowo yi, mo ni obinrin kan ti mo nlo Oogun naa fun lati wo 'iko fee'. Ogun ti a wi yi mumi feran lati wa imo sii lori bi a tile fi ewe ati egbo Ile Ibi Wa se iwosan fun koowa. Sombo ati beebeelo wa ninu oun ti a fi pelo Allicin Pride. Akoja ewe mi re o, Ki Eleduwa o je ki egbogi naa di ilumooka. Aye wa a dara, ewe a maa je funwa o, Ase.


Looking back in time, all I have to say is, to God be the glory.

1 Like

Re: .. by dplanner: 9:38pm On Jul 14, 2018
ekale ninu ile yi mo ki tewe agba mo tun fe ran wa leti pe ayewo la se kato se ohun ko hun idi nipe elo mi ti we orisirisi ose ati orisirisi ise ti ko ja si dada fun kaka ko san fun o tun buru si ni, oko bere irawo to mu wa ye, iru ise to le ba kadara re mu, tabi iru ogun to n ba o ja , ki won le ba e wa solution re, e lo mi ti ko ba ara re lati ibi ogun ori net sise lai mo pato nkan ti n se, e lo mi ti sora da onisegun osan gan lai mo owo otun yato si tosi mo duro na 07067796292, 07055595911
Re: .. by dominicson: 12:05am On Jul 17, 2018
Indications: diabetes, typhoid, general infections, Hormonal imbalance, mensural disorders.


contact: 08145802864, 08072331475

Re: .. by dominicson: 12:07am On Jul 17, 2018
dominicson:
Indications: diabetes, typhoid, general infections, Hormonal imbalance, mensural disorders.


contact: 08145802864, 08072331475

Re: .. by mtechlogo: 4:33pm On Jul 24, 2018
Ejo baba Adeesu yi mori opolopo ise yi ti wan sope epe baba fun ofo ise Adeesu yi ya to si eyi ti e so fun wa se otun ni ofo Miran ni baba ela mi loyee baba o IFA agbe wa ooo
Re: .. by dplanner: 8:49am On Aug 12, 2018
Eyonu oshole tako tabo to daju taara
Ako alangba 16, abo na 16, egbo tude ti won di si ona 16, opolopo eso yerepe, opolopo ewe ewuro oojo, atare odindi 16, akuko adire totobi kan, abo adire to ti bimo ri kan, alelo alangba tutu tabi gbigbe kosi wahala ,a o ko sinu ape tuntun kan, a o ko egbo tude si, a o ko eso yerepe si, a o ko ewe ewuro si, atare a o ko si , a o ma jo taba jo tan , a o lo to yi ooo kuna dada, a o pin si ona meji , a o po idakan mo ose dudu , eje abo adire yen lama fi po ose yen a o ko sinu ise funfun , a o wa sere ado kan, a o ro idakeji ogun yen si, ao pa eje akuko adire yen si, ao le iyere mo sere yen lara , ao gbe mejeji si aye owo , a o ma fi ose yen we lararo kutukutu , a o si ma fi ebu yen fo eko tutu mu leyin re .Akiyesi ti olorun ba fun yin ni iyonda iseyi se, kosora pupo toripe o ma ko obinrin wa pupo ju, to ba tinlo iseyi , ti ara ba tin hun wa, a o gba alejo toni owo lowo niyen, akogbudo hun ara na, teyan ba hun ara na, alejo ma wa sugbon koni mu owo wa, iseyi daju pupo ninu awon oshole to n je lowa. Awon adire mejeji yen a o fi se sara fun enikeni, sugbon enitoni ise kogbudo je nibe .07067796292 fun anything
Re: .. by oluseun98: 1:21pm On Aug 15, 2018
pls mo need oogun bet9ja to wining game bet9ja help me
Re: .. by dplanner: 1:08pm On Aug 23, 2018
Iwo to ba fe mo akosejaye lati mo irawo re pelu ise ti o ba irawo re mu ,ti o mu o kuro ninu idamu , to ri opo ti lo orisi risi asiri tabi ogun , ti ko ri ona abayo, eyan to ba nife si ko pe number yi 07067796292, 07055595911tabi whatsapp number 07062199194 ka soro .
Re: .. by dplanner: 9:41am On Aug 27, 2018
OGUN OSHOLE OWO FUN ENI TO N LO IRAWO INA TO DAJU PA
a o wa eyele funfun kan , oga aye kan , Orogbo kan, obi pupa alawe 4 kan, obi funfun alawe 4 kan, odindi atare kan , a o ko sinu igba ibile kekere kan , a o fi omo ri re de , a o wa fi aso funfun ilaji opa we papo , a o gbe pamo di ojo keji ,ti ko ni kanle, to ba di aro kutu , a o lo gbe si inu ape tuntun ti a gbe kana , a o lo kuna ,a o ro sinu ado ato , a o gbe ko enu ona wa, a o fi lo omi aye laro kutu hai lowo ba de oooooo. Sugbon ise yi se ise fun awon to ba lo irawo ina ju , mo iru irawo wo re ko to dawo le oooo, tabi ko pe lati mo akosejaye re 07067796292 , 07055595911.
Re: .. by dplanner: 10:28am On Aug 27, 2018
OGUN OSHOLE OWO FUN IRAWO YEPE TO DAJU PA
A o wa awo ekun die, ori ati ese asa mejeji ti won ti si lenu gbigbe ,ogongo ori akitan meta , imi osunmare die , a o gun po mo ose dudu , a ko sori owo #1000 , a o ma fi omì toloworo we lararo fun ose meji , Ilele la gbe owo yen si ni igun yara, a o wa ko ose le lori nibe ni a o to ma bu we lararo , ki ose meji ko to pe , a o ri owo ni owo nla o daju pa .mo akosejaye re ko to dawo le o ooo, e le pe fun akosejaye re 07067796292, 07055595911 .
Re: .. by Dami08188603491: 1:24am On Aug 28, 2018
mo nilo ise aluyo ti ilu gangan.
Re: .. by hainaroju: 9:50pm On Aug 30, 2018
Ejowo mo need ogun iferan to lagbara gan, obinrin ti monife si julo, mo ka pelu okunrin miran, sugbon ko wun mi kin padanu ee, nitoripe esu olojo pipe san ju angeli ti eyan komo lo, ese o
Re: .. by hainaroju: 10:09pm On Aug 30, 2018
hainaroju:
Ejowo mo need ogun iferan to lagbara gan, obinrin ti monife si julo, mo ka pelu okunrin miran, sugbon ko wun mi kin padanu ee, nitoripe esu olojo pipe san ju angeli ti eyan komo lo, ese o
Re: .. by dplanner: 10:56am On Sep 01, 2018
Iwo to ba mo pe ohun wa ogun kan , wa pe ni tori ko si aye lati ma post gbogbo ogun , e pemi si ori 07067796292 tabi ki e ba mi soro lori whatsapp mi lori 07062199194 .to ba fe ba mi soro lori whatsapp so oruko re , ilu to ngbe , ati ogun to n wa
Re: .. by dplanner: 4:52pm On Oct 04, 2018
OSO AJO OJOJUMO (AKEESU) TO DAJU PA
A o lo wa ole Inu eran ewure oojo, ewe alupaida 7, atare aja odindi 7, aso funfun opa kan , a o ko gbogbo re sinu aso funfun yen, a o wa di lenu , a o jo p.o., a o wa da sibi kan, a o lo wa ewure abo eyiti ko ti bimo ri , a o so mole sinu yara kan , a o se ise ti a jo yen , a o da papo mo eeri ogi ti ewure yi ba ti waaje ounje yi tan , a o lo pa ewure na , a o la ikun ewure yi , a o ba ise ajo yen lodindi ,sugbon kise jijo lama ban be pada ooo, a o wa kan apoti igi iroko kekere kan fun ise na, a o ko opolopo owo ti a fi da loko, leyin ojo keje , a o ma lo mu owo nibe ,sugbon ilaji ni owo ti a o ma mu nibe , yi o ma seku ilaji nibe .Eran ti a lo yen eniti aba se ise yen fun eni na kogbudo je ninu eran yen o toripe sara lama fi eran na se .07055595911, 07067796292.
Re: .. by dplanner: 9:42am On Nov 09, 2018
OSHOLE OOJO GBEWA 1-10 MILLION TO DAJU GAN
Patako ese esin , ologbo dudu kan, ori igun kan, ori akala kan,iye agbe 11,iye aluko 11, ikode 11, abo adie funfun, a o jo po, a o po mo ose dudu ,a o ko sinu igba olomori, a o gbe igba yen sinu apo aso funfun , a o wa so kainkain tuntun ta fe fi we sinu apo aso funfun yen kale , dandan ni ki a pa eran kan ni ijo ti a ba pari ise yi, a o ko ma we ose na ni ago kan oru, ni Kete ti a ba we ose na tan, a o ko gbogbo Lajuba ti a fi we wa sile, a o wa pada losi baluwe yen , a o ba iya arugbo kan nibe, a o bere lowo re , million naira , ti o ba mu lowo , yi o lo , kama beru, a o lo jo ko de ninu Ile , o daju , yi o gbe wa. Iwo to ba fe dawo le ise yi pe 07067796292, 07055595911.
Re: .. by Yode138: 1:00am On Nov 13, 2018
Ifankaleluya:

Pls I need your phone number. I have sent you series of mails. Kindly respond. Thanks.

Iba Agba o.


I'l nt join any issue with you cos u'a nothing but jst a cockroach!
I do not come here 2 obtained money from pple under the false pretence that am this nd that. I come here 2 shed-light.

IWO-KE....IWO TI O TI E MO OJU-ODU NI MA MA BA SORO. Hiss!!

(1) (2) (3) ... (92) (93) (94) (95) (96) (97) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2019 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 156
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.