Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,162,709 members, 7,851,408 topics. Date: Wednesday, 05 June 2024 at 06:48 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (119) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (377444 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (116) (117) (118) (119) (120) (121) (122) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by i4serious: 8:56pm On Oct 02, 2007
EYIN OMO IJEBU OJU YIN DA E JE KA RI OJU YIN OOOOOOOOOOOOOO[font=Lucida Sans Unicode][/font]
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by i4serious: 9:01pm On Oct 02, 2007
i je a ri omo egba lisabi ni ori eto yi bi?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by i4serious: 9:05pm On Oct 02, 2007
eyin om o yoruba oooooooooooooooooooooo.e je ki a se RIDDLES ni ori eto yi ki asi ma dahun awon ibere ti o ba tele.
Ki ni RIDLES NI EDE YORUBA?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 9:17pm On Oct 02, 2007
i4serious:

i je a ri omo egba lisabi ni ori eto yi bi?
bawaaaaaaaaaaaaaaaaaaa

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by jintujinta(m): 4:41pm On Oct 03, 2007
Anyway, mo kan ni kin bayin dasi ni. nitori wipe won so pe aisi nibe ni aibawon dasi. Funmeme, eyi ti o so yen kin se yoruba o. Ede ekiti abi ibo niyen na? Anyway, o gbiyanju sha.

O digba kan na!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by replenish(f): 4:57pm On Oct 03, 2007
@ IYA AJE,
EGBA WA,
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by NaijaDub(f): 8:09pm On Oct 03, 2007
Inu mi dun pupo lati ri ibi kan ni ibi yi ti a ti gba ede geesi si apa kan!
O buru jai wipe pupo ninu awa omo abinibi yoruba ni aa le so, o ma se o!

Mo ri yin na o!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by TawaTemi1(f): 2:39pm On Oct 04, 2007
Iroyin naa re lekunrere,
Aimoye awon obi lo kojale lati ko awon omo won lede abinibi nigba ti won wa ni kekere.
Eyi lo sokunfa ti awon omo bibi ile oodua fin so ede oke okun dipo ede Yoruba wa.
Eko awon omo yin lede Yoruba nigba ti won wa ni ewe, ki won ma baa je ajoji nile baba won nigba ti won ba dagba tan.
Nitori " Kekere lati peka Iroko, to ba dagba tan, apa oole ka mo".

Yeeepaaaaa!, I try ooooooooooooo
Tanx to my Parents kiss & Yoruba teachers . wink smiley grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bolorunfem(f): 6:18pm On Oct 04, 2007
O seun Richylaw, sugbon se ni ododo ni o fi Scotland se ibugbe ti ede abinibi re si dan moran to bayi i?Omo oko ni e o, inu mi dun si e, koda mo le fi o yangan pe ojulowo omo Oodua ni o. Idi ti o fi jo mi loju ni pe awa ti a fi Naija se ibugbe, ede elede la nso ni opolopo igba. Mo se ijewo wipe ori okun yi ni mo ti ma nni anfaani lati so (ko) ede yi laisi ikose kankan. Ni ibi ise, geesi ni bi i ti opeere. Ofin tile de wa lati so ede miran yato si geesi, ti o ba seesi so Yoruba si omo Oduduwa bi i tire, wiwo ni awon t'o ku yio wo o bi eni pe oro won l'o nso. Ni ile paapa oyinbo naa ni bii ti opeere, bi a ko tile so o geere a ko le se lai so amulumala bii y'know, so understand, mi i get e, ok, ati bee bee lo. Ki Olorun sa a gba wa lowo asa alasa ti a ko ara wa si yi jare. Mo ri e na. Ba mi ki ebi ati ara re. Layo ni Segoye yio de ba wa.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bolorunfem(f): 6:22pm On Oct 04, 2007
Mo ki gbogbo eyin ojulowo omo Yoruba ti o wa lori okun yi o. Eyin ti a si ngbiyanju lati so sugbon ti ko dan moran to mo ki eyin naa, e ku iyanju. Mo tun ki eyin ore ati ololufe wa naa kaabo.Gbogbo oje titun mo ki yin e ku ife o. Ajose wa ko ni baje o. Yoruba dun lati so, e ma a so niso.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by femi6(m): 6:25pm On Oct 04, 2007
mo ki yin o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 8:00pm On Oct 04, 2007
singing and humming, omo asiko ron mi lowo oluwa lo wa,
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 2:17am On Oct 05, 2007
e ka le oooo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 2:29pm On Oct 05, 2007
Unleash the dragon ni grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 5:57pm On Oct 05, 2007
LOL!clowns all over the forum.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 6:14pm On Oct 05, 2007
minute:

LOL!clowns all over the forum.
yes oooooooooooooooooooo and you are the nomba one clown grin
funlover:

Iya aje,se Bakassi e lo tobi bayi

Ti e ti ba e o,

Se tooto ni pe madam speaker (onidiri) ko owo je?
asawo ni e,olorun ma je kidi pa e,
ti o ba je ki oko mi ra e gba,you go hear weeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeeen
replenish:

@ IYA AJE,
EGBA WA,
honestly i,m not HAPPY WITH YOU.,but i still like u kiss

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by i4serious: 12:44am On Oct 06, 2007
Iya aje
Ba waaaaaaaaaaaaaaaaaa oooooooooooooooooo.Egba meji kin je ara won niyan oooooooooooooooooooo
Apa meji ni eyele fin nfo ni awon agba man so.E mi fara pe egba ni ooooooooooooooooooo .
So (eng) mo ni ipin ni egba ni .Awon egba lo N soko fun mi oooooooooooooooo .Won dara lopolopo, sugbon won ma n ni aroma lori.
Awon egba se die ninu oro Nigeria awon bi Sonekan,Abiola,Obasanjo,Bola Kuforiji Olubi ati bebelo
Egba dara ka mun ti e gan kuro.
Sugbon ju gbo e lo IJEBU NI OKO EGBA OOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOO

Se ba wa ?Iya aje
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 7:15pm On Oct 06, 2007
i4serious:

Iya aje
Ba waaaaaaaaaaaaaaaaaa oooooooooooooooooo.Egba meji kin je ara won niyan oooooooooooooooooooo
Apa meji ni eyele fin nfo ni awon agba man so.E mi fara pe egba ni ooooooooooooooooooo .
So (eng) mo ni ipin ni egba ni .Awon egba lo N soko fun mi oooooooooooooooo .Won dara lopolopo, sugbon won ma n ni aroma lori.
Awon egba se die ninu oro Nigeria awon bi Sonekan,Abiola,Obasanjo,Bola Kuforiji Olubi ati bebelo
Egba dara ka mun ti e gan kuro.
Sugbon ju gbo e lo IJEBU NI OKO EGBA OOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOO

Se ba wa ?Iya aje
so nijo wo ni ijebu ma da oko{penis}egba pada fun won?
se ijebu o ni oko tiwon ni abi oko won kere ni won se nlo ti tawon egba?
awon bi ti sonekan,abiola,obasanjo ati bebe lo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 10:14pm On Oct 06, 2007
the dragon ti unleashed. kare cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Owugal(f): 9:52pm On Oct 08, 2007
Yoruba eyin kaan ni ibi bayi fe serious gaan oo. Ejo, if you never studied how to read or write yoruba, jo ma ko nkan nkan oo. ori n fo mi bayi nitori mo un gbiyanju lati ka nkan ti awon kan ko. ye mo n lo,
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by i4serious: 2:56am On Oct 09, 2007
iya aje,
U didn't get my message oko (privates) that u thought was not the one I was talking about .
I said"IJEBU LO N SOKO FUN EGBA O)which means Ijebu is the husband of egba which can mean connotatively that Ijebu is the master of Egba or Ijebu is the leader of Egba/or Ijebu is the one dealing with Egba.That irrespective of d popularity or wealth or whatever u can think of that Egba normally claims that Ijebu still transcends them in all .
O ma se ooooooooooooooo aile ka yoruba wa dada ati aile ko yoruba wa dada ma n da wahala sile ooooo ki olorun ma je ki a so ede wa nu o ni generation wa yi oooooooo.My self inclusive e mi na wa lara awon ti o yeki o lo ri dokita yoruba nitori mo need improvement.Did u get my message no I was n't talking about the privates that u thought .
holla back at me ok

Thanks.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishooo(m): 11:32am On Oct 09, 2007
E ku ile oo. O to ijo meta ti mo ti de agbala yi kehin. Balle richylaw, oloye Segoye ati be bee lo. Inu mi ko dun si awon alakoso okun yi ni tele sugbon agba ti o binu ni omo re npo jojo. lo je ki n fi owo wonu. Ni igba ti aaro okun yi wa nsan mi ni mo ni ki n wa be yin wo. Se alafia ni mo ba yin oo.

i4serious:

iya aje,
You didn't get my message oko (privates) that u thought was not the one I was talking about .
I said"IJEBU LO N SOKO FUN EGBA O)which means Ijebu is the husband of egba which can mean connotatively that Ijebu is the master of Egba or Ijebu is the leader of Egba/or Ijebu is the one dealing with Egba.That irrespective of d popularity or wealth or whatever u can think of that Egba normally claims that Ijebu still transcends them in all .
O ma se ooooooooooooooo aile ka yoruba wa dada ati aile ko yoruba wa dada ma n da wahala sile ooooo ki olorun ma je ki a so ede wa nu o ni generation wa yi oooooooo.My self inclusive e mi na wa lara awon ti o yeki o lo ri dokita yoruba nitori mo need improvement.Did u get my message no I was n't talking about the privates that u thought .
holla back at me ok

Thanks.

Eeee, oo nilati se alaye fun iya aje pupo ju. Nnkan ti oun so kuku ye e. Sugbon bi o se fe gbe oro tire gba niyen. Ara abule yi na ni. Sebi won ni omo eni o le buru ka fi fun ekun paje.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Bblak(f): 1:42pm On Oct 09, 2007
O ga o.ewo bi everybody se serious pelu yoruba ti won n so.o show pe a wa proud of our mother tongue.that's extremely great
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 4:17pm On Oct 09, 2007
E kasan o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by NaijaDub(f): 4:21pm On Oct 09, 2007
@Nana

Eyan kan ni mo mo ti o nje Nana laye mi, Ibo de ni eni yen. Se yoruba ni Nana ti e?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 4:25pm On Oct 09, 2007
Omo Yoruba ni mi. Awon Ti mo mo tin won je Nana wa lati ilu Ghana.
Se dada lo wa sha?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 7:02pm On Oct 09, 2007
awon afa wa ni lorin ni lorin ni lorin

tiwon ko wa ni kewu ni kewu ni kewu

olola won lawanje lawanje lawanje

sorry guys i know tday is not friday,but i just remembered one of the alasalatu songs i used to listen to on the radio back in Nigeria

hmmm aiye nlo anto.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 7:57pm On Oct 09, 2007
minute, ba wo ni, u called me once and never call again, is my voice scary?, grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 8:05pm On Oct 09, 2007
mowa o brother.sha ku igbadun.


so iwo naa mo bee?
voice ee afi biti konko.lol. cheesy cheesy cheesy wink wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 8:07pm On Oct 09, 2007
minute:

mowa o brother.sha ku igbadun.


so iwo naa mo bee?
voice ee afi biti konko.lol. cheesy cheesy cheesy wink wink
mogbe, my voice gbogbo obinrin lo ku fun, well se igbadun ni iwo na wa, no school or work?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 8:14pm On Oct 09, 2007
mosheshe kuro nibi ishe ni-,mon lo schl laipe.

oni awon obinrin nku fun voice ee? shocked shocked shocked

awon naa daa? toba tanrae tan jekin mo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 8:14pm On Oct 09, 2007
minute:

mosheshe kuro nibi nio,mon lo schl laipe.

oni awon obinrin nku fun voice ee? shocked shocked shocked

awon naa daa? toba tanrae tan jekin mo.
TAN RE MI?, girl,its the fact, well hit me up again, hope u still have my number?

(1) (2) (3) ... (116) (117) (118) (119) (120) (121) (122) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 39
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.