Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,194,804 members, 7,956,059 topics. Date: Sunday, 22 September 2024 at 11:01 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Post Yoruba Christian Hymns Here (226844 Views)
Post Your Favourite Christian Hymns / Share Your Best Hymns / Christian Hymns/songs And Copyrights (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (Reply) (Go Down)
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by tayotee(m): 11:29pm On Feb 26, 2012 |
Si o Olutunu Orun Fun ore at’agbara Re A nko, Aleluya Si O, ife eni t’Owa Ninu Majemu Olorun A nko, Aleluya 5 Likes |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by tpia5: 11:31pm On Feb 26, 2012 |
i know the songs in english and i have songs of praise even though i havent opened it in a while. will get ancient and modern maybe when i go to nigeria. |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by tayotee(m): 11:31pm On Feb 26, 2012 |
Ija d’opin ogun si tan Olugbala jagun molu Orin ayo lao ma ko – Aleluya Gbogbo ipa n’iku ti lo Sugbon Kristi f’ogun re ka Aye ! e ho iho ayo – Aleluya Ojo meta na ti koja O jinde kuro nin’oku E f’ogo fun Oluwa wa – Aleluya O d’ewon orun apadi O silekun orun sile Ekorin iyin ‘segun Re – Aleluya Jesu, nipa iya t’O je Gba wa lowo oro iku K’a le ye ka si ma yin O – Aleluya. Amin. 7 Likes 1 Share |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by moremi2008(m): 11:33pm On Feb 26, 2012 |
tpia@: I actually had my mum buy me a Yoruba/English Bible when last I was home. It's good for practicing Yoruba! 1 Like |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by tpia5: 11:36pm On Feb 26, 2012 |
hearing the bible read in yoruba is a very interesting/fascinating experience. will get the audio version as soon as i find one. |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Hibkay: 11:36pm On Feb 26, 2012 |
Igbagbo mi duro lori,eje ati ododo Jesu,nko je gbekele ohun kan,leyin oruko nla jesu. Chrs- Mo duro le kristi apata, ile miran iyanrin ni 2 Likes |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Nobody: 11:37pm On Feb 26, 2012 |
One from The Apostolic Church, attended a few times as a child and one of the hymns that stuck goes thus: Igba aye wa aro gbede gbede (2X) Kasa ti'beru Oluwa Oba ogo Inu buruku, aso kamu kuro Katoro fun suuru baba iwani Igba aye wa aro gbede gbede Kama se fi'wa ipa so ara d'egbin Ejo elejo odi kamu kuro Kayera fun rigimi, ipa osi ni Igba aye wa aro gbede gbede 3 Likes |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by moremi2008(m): 11:44pm On Feb 26, 2012 |
tpia@: http://www.faithcomesbyhearing.com/ambassador/free-audio-bible-download It might be dramatized though. |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by tpia5: 11:48pm On Feb 26, 2012 |
moremi2008: hmm, thanks |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by purpose100(f): 2:59am On Feb 27, 2012 |
Okan mi yin Oba orun Mu ore wa sodo Re. Wo ta wosan ta'darin jin tala ba a yin bi Re? Chorus Yin Oluwa Yin Oluwa Yin Oba ainipekun Yin Oluwa Yin Oluwa a Yin Oba ainipekun. Lai foya lapa Jesu Lai foya lese Re Labe ojiji 'fe e Re lokan mi o sinmi. Mo bo lowo banuje Mo bo lowo eru O ku idanwo die e ti n fi're koja a. Chorus Lai foya lapa Jesu Lai foya lese Re Labe ojiji 'fe e Re lokan mi o sinmi. 5 Likes 1 Share |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 3:02am On Feb 27, 2012 |
Are mu o, Okan re si koro So fun Jesu, So fun Jesu, Oun lore ti o mo Ko tun sore , tabi Iyekan bi re So fun Jesu nikan 1 Like |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 3:06am On Feb 27, 2012 |
E ma tesiwaju, Kristian ologun Sa teju mo Jesu, ton be niwaju Kristi Oluwa wa , Ni Balogun wa. Wo basia re wa niwaju ogun, Chorus E ma tesiwaju, Kristian Ologun Sa teju mo Jesu, to n be niwaju 3 Likes |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by purpose100(f): 3:29am On Feb 27, 2012 |
Mo fe kin dabi Jesu ninu iwa pele. Ko se ni to gbo'ro binu lenu Re lekan ri. 3 Likes |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by purpose100(f): 3:38am On Feb 27, 2012 |
Adua didun, Adua didun lo gbe mi lo kuro laye. Lo waju ite Baba mi kin so gbo edun mi fun. Ni gba banje ataro Adua labo fun okan mi. Emi si bo lowo esu gbati mo ba n gba adua didun. Itan iyanu ti 'fe so fun mi lekan. Itan iyanu ti 'fe e gbe orin kikan. Awon angeli royin Re Awon oluso si gbagbo elese iwo ki yo gbo Itan iyanu ti 'fe. Chorus Iyanu Iyanu Iyanu Itan iyanu ti 'fe. 4 Likes 1 Share |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 3:40am On Feb 27, 2012 |
En yin te fe Oluwa, E fi ayo yin han E jumo ko orin didun, E jumo ko orin didun Ke si yi te na ka, Ke si yi te na ka An yan lo si Sion, Sion to dara Julo oo An yan goke losi Sion, Ilu Olorun wa (Englsih version We are matching to Zion) |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by moremi2008(m): 5:20am On Feb 27, 2012 |
Does anyone have the rest of the lyrics for: Enikan be to feran wa, A o fe wa Ife re ju ti ye kan lo, A o fe wa Ore aye ko wa sile Bi oni dun, ola le koro Sugbon ore yi kii tan ni, A o fe wa Emi ni Jesu fe, ofe mi yeye Emi ni Jesu feran ju enikeni lo O ra mi pad lowo iku ekeji Ayo igbala mi wa di pupo repete 1 Like |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 6:40am On Feb 27, 2012 |
^^ Thats the full lyrics you posted |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by moremi2008(m): 6:55am On Feb 27, 2012 |
dayokanu: I want all the verses! I go hard, bros! |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 7:13am On Feb 27, 2012 |
Fun mi niwa pele Okan tutu Ifarabale bi to luwa mi Irele on suru ati opo iyonu Ninu ohun gbogbo Kin jo Jesu 1 Like |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 7:18am On Feb 27, 2012 |
moremi2008: Not sure I can help you though. Let me compose mine Ore ododo ni Jesu ah o fe wa O fe lati ma bukun wa A o fe wa Okan wa fe gbo ohun re Okan wa fe lati sun mo Ohun na ko si ni tan wa je A o fe wa 1 Like |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by TonySpike: 8:20am On Feb 27, 2012 |
Let me add this catholic hymn: Araiye e yoo, gbogbo agbaiye pipe ni ise, owo Oluwa Awa maa ri di ise re Otito sha ni oro re Iba Awimayehun I can't remember much of the song again, lol |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Vickivicki(m): 9:26am On Feb 27, 2012 |
purpose100: Wakati adura didun To gbe mi lo kuro laye Lo'waju ite baba mi Ki nso gbogbo edun mi fun Nigba banuje at'aro Adua l'abo fun okan mi Emi si bo lowo esu Gbat' mo gba adua didun , , Another childern church hymnal here: Ewe t'oba orun Korin didun be ti n lo Korin yin olugbala Ologo ninu ise re A nlo sodo Olorun lona t'awon baba rin, This i can remember for now |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Pororo(f): 9:27am On Feb 27, 2012 |
@ Dayokanu I've been looking for this hymn. [i]Fun mi niwa pele , okan tutu uuu Ifarabale bi, Toluwa mi Irele ohun suru, ati opo iyonu Ninu ohun gbogbo kin jo Jesu [i] Thanks so much. Do you happen to know the English version, please? |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by Chemmzy(f): 10:07am On Feb 27, 2012 |
Bi mo tiri, lai sa wawi sugbon nitori eje re bo si ti pe mi, pe kin wa Olugbala, mo de, mo de. Bi mo tiri, lai duro pe mo fe kokan mi mo to to so do re to le wemi mo Olugbala, mo de mo de WAKATI ADURA DIDUN. Wakati adura didun to gbe lo kuro laiye lo waju ite Baba mi, ki nso gbogbo edun mi fun nigba banuje at'aro adua la bo fun okan mi emi si bo lowo ewu} gbati mo ba gba dua didun}2ce. Wakati adua didun iye re yio gbe ebe mi lo sod'eni to seleri lati bukun okan adua bo ti komi, kin woju re ki ngbekele, ki nsi gbagbo ngo ko gbogb'aniyan mi le} ni akoko adua didun}2ce DURO Okan are ile kan nbe lona jinjin saiye ise ile tayi da, ko le de tani ko fe sinmi ni be chorus: Duro, roju duro masekun}2ce Duro, duro sa roju duro mase kun. Bi wahala ba bo o mole bi ipin re laiye ba buru woke sile ibukun na sa roju duro mase kun (repeat chorus). Bi eegun ba wa lona re ranti ori ta fe gun de bi ibanuje bo okan re o ti ri be folugbala (repeat chorus). Ma sise lo mase rope a ko gbadura edun re ojo isinmi nbo kokan sa ro ju duro mase kun. (repeat chorus) 5 Likes 1 Share |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by oferefe(f): 1:12pm On Feb 27, 2012 |
Wa sa Adura owuro kun le ka gba Adura! Adura ni opa Kristien lati bOlorun rin losan wo le labe je kawi li emi pe mosun sugbon okan mi ji lati ba o sona. Je kii gbo gbo Ile, Men i like this song,dats our family altar song in those days But personally,i like Gba taboluwarin n'u mole oro re ona wa yio ti mole to, Gbata ba nse fere Onyo maba wa gbe ati awon ti o gbeke le chorus Sa gbeke le ona miran kosi Lati layo'nu jesu jupe ka gbeke le 6 Likes |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by bukkytroni: 1:17pm On Feb 27, 2012 |
Apata Ayeraye Se ibi isadi mi Jeki omi on eje To san lati iha re Se iwosan fe'se mi Kosi so mi di mimo 5 Likes |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by bencobenz(m): 2:26pm On Feb 27, 2012 |
Olugbala gbohun mi Gbohun mi, gbohun mi, Mo wa s'odo re gbami, Nibi agbelebu Chrs Oluwa jo gbami, Emi ki yio bi o ninu mo, Alabukun gbami, Ni bi agbelebu. 4 Likes 2 Shares |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by bencobenz(m): 2:32pm On Feb 27, 2012 |
Aye si nbe nile odo aguntan, Ewa ogo re npe o pe ma bo, Wole wole, wole nisisiyi, Ewa ogo re npe o pe ma bo. Ki ile to su, ilekun na leti, Gbana o ka bamo pe o se Ose ose ko si aye mo ose Ewa ogo re npe o pe ma bo 5 Likes 2 Shares |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 2:42pm On Feb 27, 2012 |
Chemmzy: That was the song my grandma sang on her deathbed In her memory let me dedicate this song A o ha pade leti odo Tese angeli tite To mo gara bi Kristali To n san leba ite na A o pade leti odo, Odo didan, odo didan an na Pelu awon mimo leba odo to n san leba ite na 3 Likes 1 Share |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by purpose100(f): 3:26pm On Feb 27, 2012 |
Vickivicki: I think u posted either from CAC or Methodist hymnal. Because in Baptist hymnal we have it as 'Adua didun' not as 'Wakati Adura didun'. But they all mean the same thing sha. 1 Like |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by dayokanu(m): 4:31pm On Feb 27, 2012 |
Fun mi niwa pele Okan tutu Ifarabale bi Toluwa mi, Irele on suru ati opo iyonu Ninu ohun gbogbo, Kin jo Jesu |
Re: Post Yoruba Christian Hymns Here by abouqi(f): 5:02pm On Feb 27, 2012 |
This is interesting! So eyin omo kaa ro o jire po ni Nairaland bayi? Ese gan o, l appreciate the Poster also. So you guys still remember these Hymns like this? E fe k'ori awon ko gbo nkan t'a n so ko maa swell ni yi o. Well, let them post theirs. Thank you all! |
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) (Reply)
The First Britsh Slave Ship To Reach The Americas Was Called The Good Jesus! / Cultism, The Spiritual Consequences And Deliverance Through Christ / Gospel Hymns And Songs — ♫ Praise & Worship || All-Sufficient Jesus ♫
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 48 |