Mishoo's Posts
Nairaland Forum › Mishoo's Profile › Mishoo's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 ... 23 24 25 26 27 28 29 30 31 (of 33 pages)
E jowo e bami da si oro yi: Ni aye ode isin, se dandan ni ki egbon lo si ile oko saaju aburo ni. Mo setan lati gbe arewa mi wole, ni egbon re ba faariga pe oun ko iti lo ile oko oo. nitori na aburo oun ko le lo saaju oun. E gba mi. Ewo ni ti idogbe ninu ibeji ![]() ![]() Emi o kuku ran an tele nigbati ki i se oun ni yio sanwo ori ati ti igbeyawo. Sugbon Mama Iyawo mi ko fe bu iyan egbon re keere ooo. Kini ki n wa se bayi ?Eyin agba, aye ti di aye olaaju, eewo ni eleyi ![]() |
E kaaro ooo eyin omo oodua. |
Naugthy girl. Try it now since you love them all especially the Tit ones. |
Kare iyalaje. Tire o ni baje. awon fabu ati adura re nmu inu mi dun, Kaabo si ori okun wa yi. Wa a pe fun wa ooo. |
ikamefa:Ikamefa nibo lo tiri ayajo.Mu suuru ka nkan ti won ko now.a mo wipe yoruba ko se saare ka bi oyinbo sugbon ko si eni to pe ogede ooo. Ore mi Baale richylaw, bawo ni oo. Se ara le?? |
nana:Yangan is corn.awon kan ma n pe ni agbado. |
You have to go to him my dear, thats if you love him. One of the sacrifices of love. It'll pay you later, though you might not love it now. Believe me. |
Nana bawo ni?? o ma to ijo meta?? Se ara le?? Se enu n gbe yangan ![]() |
OSANOBUA !!! OLODUNMARE OOOO!! CHINEKE MEI!!! AGBABIAKA OOOO!!!! WHERE WORLD DEY GO SELF?? I HOPE THOSE THINGS GO CLEAN SHA ![]() |
i dont think u need to be apprehensive cos its a matter of his friends becoming your friend and you'll gain more friends cos u wont loose touch with those in Naija. If you can even join a class or club the better. but i think you'll compromise before he does. |
E ku ile oo |
SMC:oro gidi loso SMC A ye o kale. Ore mi tafari bawo ni? Se alafia ki le wa bi?? |
iyalaje:@Iyalaje, e kaabo. E ma da omo ti oun je chichi8 yen loun ooo. Omode loun see.Katikati si ti poju lenu re. E baa wi oo. Ko ba koja aye re. |
![]() chichi81:RAVING MEGALOMANIAC LUNATIC E waa wo were loja |
E ku ile ooo Gbogbo yin ni mo ki pe e ku ijade ojo iwuye segoye. Oloye tuntun, oye a mori oo.E ku anawo nara. A ye o kale oo. Ore mi Baale, se ara le? Singing ijo ti mo jo lara yanke gbogbo ara lo n ro mi yanke baba o gbudo gbo yanke mama o gbudo gbo yanke yanke yanke yanke kooda ijo ojo na o derun.Odidi wakati meje ni mo fi sun nigba ti mo dele. Baale, E ku alejo oo. Ke pe lori oye. |
@seun 001, sorry to disappoint you, but that would bring the number of Area boys to the multiple of 5. Believe me as there would be more homeless people nad they will take to drugs more. Find a better solution. I believe one exists. |
ikamefa:iyaafin ikamefa nibo lo wa lati ijo mefa ![]() |
Eyin eeyan gidi, e kabo ejoo, kini ao je ni iwuye segoye gan?? ko ma lo je ounje oyinbo ni ![]() |
honsule pls am expecting tooo. olumatthias2002@yahoo.co.uk it is double t. thanks in anticipation. |
![]() thank God REAL people are back!! E ku ile ooo. Nibo ni gbogbo eyin eniyan lo lati ojo meta??Haywhy, Ikamefa, Desola, Nana, Ikomi ati be be lo. E ku irin ajo ooo. e kabo. Inu Baale na dun pe e ti pada wa si ori okun yi.a je ki awon alaini ise se bi obowunmi et al wa ibomiran gba lo. Ki lon sele?? |
i would like the wap settings too pls mail me at olumatthias2002@yahoo.co.uk Thanks in advance |
richylaw:Ibi ise ni emi na wa sugbonki nkan ba le to ni ko je ki nraye. Mon gbadun aiyefele ori Konputa enikeji emi na lowolowo bayi. Eku eeto ilu yi. obowunmi: ![]() Kik jero nwi ganan ![]() |
Baale Richylaw se alafia ni??Ki ara ole oo!! |
tafari:mo ma n gbadun agbado sunsun gan ni. Epa oyinbo na a si ma dun. sugbon eyi to ku e fun elomiran. |
Ogbeni tafari, se alafia lo wa. Se oko ko je epo oo?? Kini o mu bo lati irin ajo?? |
@OdodoFunfun je ki won de ki won ro ejo funra won, sugbon won kii se omode rara oo. TI OMO BA TO LOKO, A MA NFUN LOKO NI Ohun to ba wun won lokan ni won le se. Ilu yi ko si lodi si rara. Ire ooo |
Iru katikati ati kantankantan wo ni agannigan ti won n pe ni MIRACH nse yi?? o wa da mi loju pe ogbeni yi ko ni laakaye kankan ninu kolofo yi o pe ni ori re. kooda kii se omo oko rara, o da mi loju. IKUN N JE OGEDE, IKUN N REDI. IKUN KO MO PE OUN TO DUN LO N PANI A a dara ko lo ba awon ara ile re ki o si bewon daradara ti eni to ba nse o ko ba i ti ku.Se etutu to ye ko se ki alufansa yi le fi o sile ki o ma se ba aiye ara re je oo. Baale, gbogbo looko looko ilu mo kin yin.Sugbon SABITIU ti won npe ni MIRACH yi lo n mu inu bi mi pelu oro opoonu ti oun so ati iwa jagidi jagan re. A du yin se oooo!!! |
Na so now |
Ndewo ooo Jisiyike nu !! Ikomi, i envy you, speaking on the Yoruba & Ibo forum fluently. |
abi ore mi segoye, radarada ponbele ni yi oo. ibo ni ati ri eniyan ti o se wipe nkna ti o koko ko ni ori okun yi bi awon eniyan ninu. Ogbeni mirach, se suuru ooo. ki o ma lo fidi fana. |
ibkn:Whats GIS ? |
i think you should try and meet him with a recorder or even in an hotel with a hidden camera, then after recording, duplicate the conversation or video, then threathen him to report to the police with the proofs or go public in the dailies if he doesnt desist from worrying you. |
1 2 3 4 5 6 7 8 ... 23 24 25 26 27 28 29 30 31 (of 33 pages)

