Mishoo's Posts
Nairaland Forum › Mishoo's Profile › Mishoo's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 ... 27 28 29 30 31 32 33 (of 33 pages)
i have a good biz idea in importation but need cash to start up. Where do i go?? |
otito ponbele. Ore mi kan wa ti abi si ilu oba - maryland, US. ibe ni won dagba si, bi o tile jepe kole so yoruba daradara, o ma ngbo daradara nitori mama won man fi yoruba bawon soro, baba won a si ma fi geesi bawon soro. nitori na kini a le se si oro to wa nile yi ![]() |
go to www.sms.ac. register free and start sending 3 texts messages every day. |
@richylaw, o ku ogbon, ku laakaye, abudi ni todo, opolo re o ni gbe ooo!! @dapo4u, ti o ba wa ni ilu wa, o nilo lati so oyinbo fun awon omo re nitori yoruba ni won a kuku gbo ni ita.o si dara pupo ki won le mo ede mejeeji nso. Sugbon to ba se pe oke okun lowa, a dara ki o fi Yoruba ko omo re ooo. Eyi dara pupo ki won ma ba sonu ninu ede elede!! |
Dapo4u:Ase oo. Omo tiyin na o ni sanku oo!! iwonba ti a le se ni a nse oo. Mo gbe bi igba oti fun ogidi omo yoruba bi @richylaw & @haywhy, ki won ba mi pari eyi toku. |
Ekeji ti mo le soro re ni Penkelemesi.eyi wa lati oro awon eniyan wa. Ikan lara awon Oloselu atijo (Ade___ Adegoke) ti o ma so geesi to po ni o ma nso "peculiar mess" ni gbogbo igba. Ni awon eeyan wa ba soo ni penkelemesi. Nibi ni o ye mi mo! |
Dapo4u:Okookan la ma mun. Osomaalo seyo lati awon eya yoruba kan. ti won ba ya ra won lowo, ati gba ma n nira, o si gbudo je alagidi eniyan ki owo re ma ba lo gbe raurau. ti won ba ti wa gba owo won, ti won ko ba ba o nile, won o ni joko rara. won a so pe "oso ni maalo" (meaning i'll prefer to squat) ki eni na ma ba sope won ti joko, nitori na won nilo lati sanwo ijoko. Bi ose ye mi re oo !! |
arabinrin roonie-slimz, ko to ibinu rara oo. Omo eni ko le buru ka le fun ekun paje. Alaye !richylaw ni ki o gba, ki osi bu omi suuru mu. agba to ba ni suuru ni omo re npo joojoo. |
ronnie-slimz:ewo ni isokuso ninu owe? A dara ti o ba yan oo!! |
Agilinti ti nse ginni ginni, iku npa a, ambotase opolo to n fi ojojumo gbe ra re sanle !! Jeje laye gba ooo!! |
ronnie-slimz:Arabirin roonie-slimz, e kaabo oo.Ki ni emu ti ode bo? |
segoye2:o se mi lanu pe o ti pe ti motiri eru awon iwe ti an soro re wonyi.koda alagbamu re (hard copy) ko si si sakani mi.Ma binu oo!! |
haywhy:@hawwhy, ewo gangan ninu awon irunmole lo n soro re.Awon irunmole kii gbe ebo lorun oo.Awom ebora lo fe so bi?? |
@ segoye, ma roora oo. ki o ma lo mu imu kumu. Ki ipe ki eniyan to ta teru nipa lati ibe yen ooo. Ki olorun ma so eee |
richylaw:Ooto ni oooo!ni iwe alako bere karun (Primary 5) ni mo wa ti mo fi ka iwe na. Nko le gbagbe lailai |
o ya mi lenu, osi tun jo miloju pe o ko ka ju ile iwe girama lo ni ilu wa yi. Tire ni mo riri ooo. Ako ri eleyi ri, a fi nda eru ba oloro ni. Amon, kiise bi tire. O wu mi lori pupo? Se be ni o feran ede to ni abi o tun fi nse nkan miran?? |
Talo ti ka " ogboju ode ninu igbo olodunmare" ![]() |
iko oro re ranmi leti awon iwe oga mi ninu yoruba - Adebayo Faleti. Abi oti pa iwe re pade ri ni?? |
@richylaw, gbona, bawo ni oro re se ni agbara to bayi. Ko dami loju pe Glasglow lo wa oo. Amon o ti pe ni ile wa yi sa ko to lo ![]() |
richylaw:Gbiri lologun nji. Aki ri okunrun eiye lori ite. ara mi le. @richylaw, a pade loni. Gbogbo ile nko? |
Olarrylaw:pls get in touch with me at olumatthias2002@yahoo.co.uk . am interested. Thanks |
@aylala, Thanks for the great info man. they are always priceless !! |
My people, i dey hail oooo!! Na who dey for this house ![]() I don land gidigba !! |
o wu mi ki ntile pade awon olusoro lori okun (thread) yi, sugbon nigba ise mi ki i raye. afi ki ise to bere ati ti ise ba ti pari. Amon sa mo ngbadun yin, |
Eku ile ooooo. Ewo lo fa eebu ati oro alufansa ti o wa loju iwe meji-meta sehin?? Sebi omo yoruba ni gbogbo wa.Kilo wa fa gbon mi si, omi o too?? E ja ka bu omi suuru mu ooo. Nitori agba kii wa loja kori omo tuntun wo. @Haywhy,minute&richylaw, mo sa ma ngbadun yin ni gbogbo igba ni sa. Owo yin a ma roke oooo. E ee ri batise. E ee rona gbeegba. Owo yin o ni wo ajadi apo oo. @gbogbo eniyan toku e se dara dara oo. Aiyefele se suuru oooo. Agba to ni suuru ni omo re npo joojoo. A aa tun ma ri ra. ipade tun di igba kanna. |
you would be tying the money down for what sake Even putting the money in shares would pay you more. Besides nothing can be predictable in Naija.What if kero & Diesel prices dont rise for 8 months ![]() |
then the pressure was on. but thank God i neva forgot the son of whom i am and i didnt mess up!! Service year was too much but God saw me through. |
I think all these boils down to family values and upbringing. In fact places unlike Lagos & other developed places, where thay hardly show bad movies or there are little bad influences aroud, they hardly disvirgin their females until wedding day. I know this because i grew up in one. I got to the university before i realised there is a thing called Boyfriend & girlfriend. not as if i didnt hear about sex but you just believe its for the ashawos et al |
O dabi eni pe ko si enikankan ninu ile yi. @richylaw ooo! @richylaw ooooooo!! emeji mo pe e ooo. Baba fe omo loju ariran, @richylaw ooooooooooooooo!!! |
mo ti de bi ati nde oo. E ku ile |
i wan go do work, make una tell them make dem no try that kain thin again oo. Lailai. If na pidgin make we yearn pidgin well!! abi, my people for obodo naija ![]() |
smile4kenn:omo ibo, kaabo. Aje okuta ma mumi !! pele !1 se o fe kako e ni ede ni abi kilo wa wa oo ![]() |

