Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 4:23pm On Jul 03, 2007 |
richylaw: O ti o, Ferlie bi ti bawo, Tafari ni mo mo o. Ara awon iwa alumokoroyi ti a n so yen na re o. Yanana oro yi o, ba wo ni Tafari se tan mo ferlie? abi oo baale. Ododo oro le so. Ogbeni ferlie, tani yin ooo. E jowo e juwe ara yin.Ati ibi ti e ti wa oo. [s]Talo mo okolo yin loyo, afi ojo to dana sun ile.[/s] Inu wa o dun lati mon yin. |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:10pm On Jul 02, 2007 |
richylaw: E seun o, eyin ara ilu, Awon agba bo , won ni adan dorikodo o n wo se eye. E je ki a tun wo owo ti awe ti won n pe ni Olutomiwa yi , yio gbe ki a to da seria fun. o dara bee. sugbon eranti pe enu ti aja fi nba omo re sere na ni o fi nbuje oo. a o le fi awon eniyan kan le ki won ba okun yi je fun wa. E ku agba oo.Ki ade pe lori. |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:07pm On Jul 02, 2007 |
tafari: idahun mi
5 a kii bara eni tan ki a fa eni ni itan ya. Tafari, o tie gbiyanju. eyi sa tunmo si wipe oki i se omo igbo tabi ajeji yio ye o kale. |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 2:34pm On Jul 02, 2007 |
Baale, mo wa lehin yin bi ike lori awon oro te so si Olutomiwa. Enu agba ni obi ti n dun hanun. |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 1:49pm On Jun 29, 2007 |
Singing ta lo wa ninu ogba na omo kekere kan ni se kin wa wo ma wa wo iwo lopa iwo lo - - - - ----------------------- |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 9:00am On Jun 29, 2007 |
Anje ekuru ko tan lawo, o tun ngbon owo si. Tomiwa o ti to oo. se oya ni e ni? nitori oun be, ko to lo fi idi gun iso. Rora se ooo. Aabo oro laa nso fun omluabi, to ba de inu re adi odindin. |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:56am On Jun 29, 2007 |
|
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 6:32pm On Jun 28, 2007 |
olutomiwa: a ti ri se tie tobi to won abi o TOBI JU AWON YE LO?  Haba olutomiwa, a nilati pe igbimo lori oro re ooo. Boya ni a o fi jeki o pe ninu ilu wayi. A mo sa, temi ko ni lati dajo oo. Oloye segoye,Gnature, Iyalode ikamefa, ikomi, desolar kile riso si oro yi oo?? |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 6:29pm On Jun 28, 2007 |
richylaw: I'm fine, Oju abore kii ri ibi o, mo sare fi "sun shade" si oju ni bi mo se ko firi awon aworan afoniloju yen o. Ki Olorun ma ke de gba wa ke lowo bobo Olutomiwa yi ke! Ore mi Baale, koda eyin ni mo sapamo si. Ki oju ma ri ibi, gbogbo ara logun re. A fi bi eni wipe kobekobe baloon fe be. Ha, ao ro eru eleyi ri, - - - - - - |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:56pm On Jun 21, 2007 |
Mode mode ni ti ewe ade mobo mobo ni ti aboye ewure ile to ni aoni de ni ao ni deba aguntan ile to ni ao ni bo ni yio nu
eku ile oo segoye baba bawo ni ose wa? se arale?? baale nko? o to ijo meta ti mo ti wa si ori okun yi. inu mi dun pupo. |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:49pm On Jun 21, 2007 |
Mode mode ni ti ewe ade mobo mobo ni ti aboye ewure ile to ni aoni de ni ao ni deba aguntan ile to ni ao ni bo ni yio nu
eku ile oo segoye baba bawo ni ose wa? se arale?? baale nko? o to ijo meta ti mo ti wa si ori okun yi. inu mi dun pupo. |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:39pm On Jun 19, 2007 |
@desolar, mo wapa. oko e nko?? |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 4:32pm On Jun 19, 2007 |
Aago onile o |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 2:30pm On Jun 15, 2007 |
Baale. baale, baale ooo!! Abebora mutin yangan !! Igbakeji orisa !! Eku ile oo !!
Ogbeni tafari, bawo ni oo?? oo si je ki baale reju lagbala pelu atototnu re?? Mu suuru si oro re oo!! |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:27pm On Jun 14, 2007 |
richylaw: ha, ha, ha , eyin wo le n pariwo pipipi bantabanta lehin aafin ba n, e o mo pe baale n reju ni yewu ni? ekaabo ooo, nana ati baale. eyin mejeji wole bawa re |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:22pm On Jun 14, 2007 |
|
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:20pm On Jun 14, 2007 |
|
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:18pm On Jun 14, 2007 |
se o fe ji ni??  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:16pm On Jun 14, 2007 |
|
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 6:31pm On Jun 14, 2007 |
eku ile ooo. ot o ijo maeta ti mo ti wa si ori okun yi kehin. se alafia ni mo ba gbogbo yin o? iyalode ika, bawo ni oo?? desorlah, kaabo si oju agbo yi  desorlah: Baale, e seun wa o, ojo na a ba wa laye aba wa laaye. A o ni fi enikeni ninu wa se awati o. Awon olori na nko, se daada ni won wa. Desolah mofe gba o ni iyanju. gege bi omo oodua rere. dakun yago fun segoye ooo. hun, o ni ohun ti agba ri lobe to fi wa iru sowo oo. segoye a ma so kantan kantan bi eni ti o muy paraga ni igba miran oo. odara, ti o fe ti gba tire wa ni lati ko iwa re ni oo. Ore mi baale - ------ richylaw: Alagba Tafari, idunu nla ni o n je fun mi lati ri wipe oye ilu wa yii n wu iwo na . O si ti di dandan ki o ri oye je. Mo ti ba awon oloye ilu to ku soro nipa igbese nla yi, won si ti fi enu ko wipe kii a se idanwo fun o. Ti o ba ti we yan kainkain , o daju wipe kosewu legberun eko o. IDANWO FUN TAFARI: A. Pari owe yi: 1. Ailora ogongo, 2. Datoro,datoro, datoro, agba ti o da toro, 3. Idi ni iku igbin,, 4. Onibaje ko won,, 5. A kii bara eni tan ,,
B. Omo ilu wo ni o? C. Fun wa ni ila maarun pere ninu oriki orile ilu tabi iseda ebi yin.
Ogbeni Tafari , awon ibeere jekojeko yi ni mo nilo esi fun , lehin eyi o di dandan ki o joye ni Ilu Yoruba yi.
A fi bi eni wipe o gba enu mi soro, mo sese fe beere idi ti a kii fi ri oluaye Ile Naira Alagba Seun Osewa ni abala ti yoruba, mo sebi oruko yoruba ni Seun, ki wa lode? O di dandan ki o wa fun ti oye re o. Mosi tun fi asiko yi ro Segoye ati iyawo re desorlah wipe ki e fi aworan ara yin tabi eda re sowo ranse si baale o, awon oniroyin nilo re. on a more serious note  Howu, e o fe fi ogbeni tafari je oye rara oo. se e mo pe otioto ponbele ni emi oso fun yin. awon ibere yin ko mi ni ominu, kooda emi gan na o le dahun opo ninu won. E bu omi suuru mu oo, nitori agba to ba ni suuru ni omo re npo jojo. too emi ni tiyin, ire ooooo |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 4:55pm On Jun 12, 2007 |
segoye2: Si Mushoo,
Bawo ni, se iwo na ti ni interest si Aunty Nana ni?, Jo o So fun wa ooo, eje ka ri gbo, emi fe sare lo se road walk, ma pada wa in 1 hours time, Ogbeni segoye, eewo ti ni tiyin gaan na?? Won o sa ti fun yin ni nana patapata. E maa nbe saa. ksi eni to mo oko iyawo oju ona ooo. Ki e lo fi edo le ori orooro!! |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 4:51pm On Jun 12, 2007 |
richylaw: Mishoo temi ni kan soso, jowo ma wo nkan kan ninu ogba o, awon apayan ati gbomogbomo lowa nibe . Mo si ti so fun awon ode ati fijilante ilu ki won ma so inu ogba na. Enikeni ti a ba si mu ni a o fi imu re danrin. Emi ko ni fe ki ore baale tooto je iya ti ko mowo mese o. Howu, baale!! enikan o ki je ki ile o fe oo. omode gbon agba si gbon ni a fi da ile ife. Ti e ba nje, e ma fun ore yin ti e pe mi na je diedie sa. Mo kan ni ki n yoju wo inu ogba boya mo le ri nkan mu nibe ni, ki awon segoye,ikomi ati debosky to ma bere sini pe mi ni gbomogbomo. emi ki gbe omo oo. Agbalagba ni mo ma ngbe. Sugbon mo mon iwa ara mi, mi o je koja aye mi ni ibi ti baale ba wa. Ire oooo. |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 12:42pm On Jun 12, 2007 |
Talo wa ninu ogba nna?? Awon omo kekere kan ni se nwa wo won mon wa wo won -------------- |
Investment › Re: First Bank's 100 Billion Naira Share Offer by mishoo(m): 12:39pm On Jun 12, 2007 |
Good idea guys but even at the secondary market, people are holding tight to their shares. How can one get shares to buy  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 12:37pm On Jun 12, 2007 |
e ku ile ooo, @nana et al |
Business › Re: Transnational Corporation of Nigeria Plc (Transcorp) by mishoo(m): 1:31pm On Jun 11, 2007 |
easimoni: Transcorp could be a great stock in 5 years but even the prospectus showed that they intend to make a loss in the first yr of operation. why not invest in another stock and buy back transcorp when the they start to turn the company around? Do you invest out of pride or to maximize returns? transcorp won't help you maximize returns. but i cant even get the cert, so i've given up |
Business › Re: Transnational Corporation of Nigeria Plc (Transcorp) by mishoo(m): 2:22pm On Jun 08, 2007 |
Whatever people say, am still holding to my transcorp. It is for long term invetment and am sure i wont regret it in 5 yrs time, (if The world hasnt ended). |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 2:16pm On Jun 08, 2007 |
Too bale, e ba @nana se nkan si oro re oo. Won ti n ta si Nana ju. E ran lowo ooo  Be omo na si je omo daradara. |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 2:00pm On Jun 08, 2007 |
Eku ile ooo. @Richylaw. Okunrin meta. Se alafia ni owa. @Nana, obinrin to rewa, bawo ni ooo. Se alafia ni mo ba yin bi?? |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:41pm On Jun 06, 2007 |
|
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:39pm On Jun 06, 2007 |
Ikomi: Egbami Egbami won ti fi idi gba microphone lowo mi. @Ikomi mo kan fe so fun e kin to ma lo ile pe o ni isoro to po gannnnn ni? Ma gba ibi ti o gba wa saiye pada lo ooo  |
Culture › Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:35pm On Jun 06, 2007 |
ikamefa: asko oh?  @Gnature a fi igba ti o gba iso. Sori ooo |