Obasolape's Posts
Nairaland Forum › Obasolape's Profile › Obasolape's Posts
1. N‘nu gbogbo ayida aye Ayo on wahala; Iyin Olorun ni y‘o ma Wa l‘enu mi titi 2. Gbe Oluwa ga pelu mi, Ba mi gb‘oko Re ga: N‘nu wahala, ‘gba mo ke pe O si yo mi kuro 3. Ogun Olorun wa yika Ibugbe Oloto; Eniti o ba gbekele, Yio ri igbala 4. Sa dan ife Re wo lekan ‘Gba na ‘wo o mo pe, Awon t‘o di oro Re mu Nikan l‘eni ‘bukun 5. E beru Re, eyin mimo, Eru miran ko si; Sa je ki ‘sin Re j‘ayo yin On y‘o ma toju yin Amin. |
B’o ti dun lati gba Jesu Bi iwo ba gbagbo, iwo o ri ogo Olorun. Jn. 11:40 1. B’o ti dun lati gba Jesu Gbo gegebi oro Re; K’a simi lor’ ileri Re, Sa gbagbo l’Oluwa wi Jesu, Jesu, emi gbagbo, Mo gbekele n’gbagbogbo, Jesu, Jesu, Alabukun Ki nle gbekele O si. 2. B’o ti dun lati gba Jesu, K’a gb’eje ‘wenumo Re Igbagbo ni ki a fi bo Sin ‘eje wenumo na. 3. B’o ti dun lati gba Jesu, Ki nk’ara ese sile, Ki ngb’ayo, iye, isimi Lati odo Jesu mi. 4. Mo yo mo gbeke mi le O, Jesu mi, Alabukun; Mo mo pe O wa pelu mi, Ntoju mi titi dopin. Amin. Tis so sweet to trust in Jesus If thou wouldest believe, thou shouldest see the glory of God. John.11:40 1. 'Tis so sweet to trust in Jesus, Just to take Him at His word: Just to rest upon His promise: Just to know, 'Thus saith the Lord. Jesus, Jesus, how I trust Him! How I've proved Him o'er and o'er Jesus, Jesus, precious Jesus! O for grace to trust Him more! 2. O how sweet to trust in Jesus, Just to trust His cleansing blood; Just in simple faith to plunge me 'Neath the healing, cleansing flood! 3. Yes, ‘tis sweet to trust in Jesus, Just from sin and self to cease; Just from Jesus simply taking Life and rest, and joy and peace. 4. I'm so glad I learn'd to trust Thee Precious Jesus, Saviour, Friend; And I know that Thou art with me, Wilt be with me to the end. Amen. |
“lba mase pe Oluwa ti o ti wa ni tiwa” - Ps. 124:1 1. lBASE p’Oluwa Ko ti wa ni tiwa Lo ye k’awa ma wi Nigbat’ese gbogun tiwa. Egbe: Ope ni f'Oluwa Oba wa Olore A ke kabiyesi A f'ope fun Jehofa T'o gba wa Iowo ota, A dupe Oluwu. 2. Nwon ‘ba bo wa mole Pelu agbara won, Ope ni f ’Oluwa, Ti ko jeki t’esu bori. Egbe: Ope ni f'Oluwa... 3. Okan wa yo b'eiye Nin' okun apeiye Okun ja, awa yo, E yo Jesu da wa sile. Egbe: Ope ni f'Oluwa... 4. Tire ni Oluwa Lati gbe wa leke Gbogbo awon ota, T'o wu ko tile yi wa ka. Egbe: Ope ni f'Oluwa... 5. Ara f ’okan bale Sodo Olugbala B’esu ti gbon to ni, Ko to kini kan fun Jesu. Egbe: Ope ni f'Oluwa... 6. Iranlowo wa mbe L'Oruko Oluwa T’O d’orun on aiye Oba awon eni Mimo. Egbe: Ope ni f'Oluwa... 7. Ogo fun Baba wa, Ogo fun Omo Re, Ogo f’Emi Mimo Metalokan jo gbo tiwa. Egbe: Ope ni f'Oluwa Oba wa Olore A ke kabiyesi A f'ope fun Jehofa T'o gba wa Iowo ota, A dupe Oluwu. Amin |
B’ORUKO JESU TI DUN TO 1. B’oruko Jesu ti dun to, ogo ni fun Oruko Re o tan banuje at’ogbe ogo ni fun oruko Re ogo f’oko Re, ogo f’oko Re ogo f’oruko Oluwa ogo f’oko Re, ogo f’oko Re ogo f’oruko Oluwa 2. O wo okan to gb’ogbe san Ogo ni fun oruko Re Onje ni f’okan t’ebi npa Ogo ni fun oruko Re 3. O tan aniyan elese, Ogo ni fun oruko Re Ofun alare ni simi Ogo ni fun oruko Re 4. Nje un o royin na f’elese, Ogo ni fun oruko re Pe mo ti ri Olugbala Ogo ni fun oruka Re. |
FI IYIN FUN JESU OLURAPADA WA 1. Fi iyin fun Jesu, Olurapada wa, Ki aye k’okiki ife Re nla ; Fi iyin fun ! eyin Angeli ologo, F’ola at’ogo fun oruko re, B’olu’agutan, Jesu y’o to omo Re L’apa Re l’o ngbe won le l’ojojo Eyin eniyan mimo ti ngb’oke Sion Fi iyin fun pelu orin ayo 2. Fi iyin fun, Jesu Olurapada wa, Fun wa, O t’eje Re sile, O ku On ni apata, ati reti ‘gbala wa, Yin Jesu ti a kan m’agbelebu; Olugbala t’O f’ara da irora nla Ti a fi ade egun de lori Eniti a pa nitori awa eda Oba ogo njoba titi laelae. 3. Fi iyin fun, Jesu Olurapada wa Ki ariwo iyin gba orun kan Jesu Oluwa njoba lae ati laelae, Se l’oba gbogb’eyin alagbara A segun iku; fi ayo royin na ka Isegun re ha da, isa oku? Jesu ye ko tun si wahala fun wa mo ‘tori O l’agbara lati gbala. Amin. |
ITAN IYANU T’IFE ! 1. Itan iyanu t’ife ! So fun mi l’ekan si Itan iyanu t’ife E gbe orin na ga ! Awon angeli nroyin re Awon oluso si gbagbo Elese, iwo ki yo gbo Itan iyanu t’ife Iyanu ! Iyanu ! Iyanu ! Itan iyanu t’ife 2. Itan iyanu t’ife B’iwo tile sako Itan iyanu t’ife Sibe o npe loni Lat’ori oke kalfari Lati orisun didun ni Lati isedale aye Itan iyanu t’ife 3. Itan iyanu t’ife Jesu ni isimi Itan iyanu t’ife Fun awon oloto To sun ni ile nla orun Pel’awon to saju wa lo Won nko orin ayo orun Itan iyanu t’ife. Iyanu ! Iyanu ! Iyanu ! Itan iyanu t’ife Amin. |
1. ISUN kan wa t’o kun f’eje O yo n’iha jesu, Elese mokun ninu re, O bo ninu ebi. 2. ‘Gba mo f’igbagbo r’isun na, Ti nsan fun ogbe Re, Irapada d’orin fun mi Ti ngo ma ko titi. 3. Ninu orin t’odun julo, L’emi o korin Re: ‘Gbat’ akololo ahon yi Ba dake n’iboji. 4. Mo gbagbo p’O pese fun mi (Bi mo tile s,aiye ) Ebun ofe t’a f’eje ra, Ati duru wura. 5. Duru t’a tow’ Olorun se, Ti ko ni baje lai; T’a o ma fi yin Baba wa, Oruko Re nikan. |
ITAN IYANU T’IFE ! 1. Itan iyanu t’ife ! So fun mi l’ekan si Itan iyanu t’ife E gbe orin na ga ! Awon angeli nroyin re Awon oluso si gbagbo Elese, iwo ki yo gbo Itan iyanu t’ife Iyanu ! Iyanu ! Iyanu ! Itan iyanu t’ife 2. Itan iyanu t’ife B’iwo tile sako Itan iyanu t’ife Sibe o npe loni Lat’ori oke kalfari Lati orisun didun ni Lati isedale aye Itan iyanu t’ife 3. Itan iyanu t’ife Jesu ni isimi Itan iyanu t’ife Fun awon oloto To sun ni ile nla orun Pel’awon to saju wa lo Won nko orin ayo orun Itan iyanu t’ife. Amin. |
ORE WO L’ANI BI JESU ORE WO L’ANI BI JESU Ore wo l’ani bi Jesu, ti o ru banuje wa! Anfani wo lo po bayi lati ma gbadura si! Alafia pupo l’a nsonu, a si ti je rora po, Tori a ko fi gbogbo nkan s’adura niwaju re. Idanwo ha wa fun wa bi? A ha nni wahala bi? A ko gbodo so ’reti nu; sa gbadura si Oluwa. Ko s’oloto orebi re ti ole ba wa daro, Jesu ti mo ailera wa; sa gbadura s’Oluwa. Eru ha nwo wa l’orun bi, aniyan ha po fun wa? Olugbala je abo wa, sa gbadura s’Oluwa. Awon ore ha sa o ti? Sa gbadura s’Oluwa. Yo gbe o soke lapa re, Iwo yo si ri itunu WHAT A FRIEND WE HAVE IN JESUS 1. WHAT a friend we have in Jesus, All our sins and griefs to bear; What a privilege to carry Ev’rything to God in prayer. Oh, what peace we often forfeit, All because we do not carry Ev’rything to God in prayer. 2. Have we trials and temptations? Is there trouble anywhere? We should never be discouraged, Take it to the Lord in prayer. Can we find a Friend so faithful. Who will all our sorrows share? Jesus knows our ev’ry weakness, Take it to the Lord in prayer. 3. Are we weak and heavy laden, Cumbered with a load of care? Precious Saviour, still our refuge,- Take it to the Lord in prayer. Do thy friend despise , forsake thee? Take it to the Lord in prayer: In His arms He’ll take and shield thee, Thou wilt find a solace there. |
Yin Olorun Abra’am (Yoruba Hymn) May 5, 2021 by Mayowa Leave a Comment 1. Yin Olorun Abra’am Ti O njoba l’oke Enit’o ti wa titi lai Olorun ‘fe “Jehofa nla l’Emi” Gbogbo eda jewo Mo f’ibukun f’Oruko Re Titi lailai 2. Yin Olorun Abra’am Nip’ase Eniti Mo dide, mo si wa ‘tunu Lowo ‘tun Re Mo ko aiye sile Ogbon at’ola re On nikan si ni ipin mi At’asa mi 3. On na ti seleri Mo gbekele eyi Ngo fi iye idi goke Lo si orun, Ngo ma wo oju Re Ngo si yin ipa Re Ngo korin ‘yanu t’or’ofe Titi lailai 4. B’agbara eda pin T’aiye at’esu nde Ngo dojuko ona Kenaan Nip’ase Re, Ngo re odo koja Bi Jesu wa lokan Ngo k’oja n’nu igbo didi Lo s’ona mi 5. Oba oke orun Olor’angeli nke Wipe “Mimo, mimo, mimo” Oba titi Eniti ki pada Ti y’o si wa lailai Jehofa, Baba, “Emi ni” Awa nyin O 6. Gbog’ egbe asegun Nyin Olorun l’oke Baba, Omo at’Emi ni Nwon nke titi Yin Olorun Abra’am Ngo ba won korin na Tire l’agbara at’ola, Pelu iyin |
Jesu mo wa sodo Re 1. f JESU mo wa sodo Re, Je ki nle ma to O lehin Bi 'ni mi gbogbo po si Ti ero mi gbogbo soji. Egbe: E yin logo, eyin Mimo E f'ope fun Baba loke Da wa si l'egbe Serafu, Ni kehin gba okan wa la. 2. mf Keferi, Imale, e wa Onigbagbo, ma kalo K'a jo yin Olorun wa, K'a le d'ade ni 'kehin. Egbe: E yin logo, etc 3. mf A dupe lowo Olorun T'o fi Jesu Kristi fun wa Lati ra araiye pada, Lowo ese at'Esu. Egbe: E yin logo, etc 4. mf Egbe Serafu damure Egbe Kerubu kun f'adura Olugbala yio gba wa la Oluwosan yio wo wa san. Egbe: E yin logo, etc 5. Nigbati 'pe kehin ba dun Jesu y'o ko wa de Kenaani, Je ka l'ayo lodo Re Fi wa s'agbala itura. Egbe: E yin logo, etc 6. E f'ogo fun Baba loke E f'ofo fun Omo pelu E f'ogo fun Emi Mimo Metalokan lope ye fun. Egbe: E yin logo, etc Amin |
1. K’ A to sun, Olugbala wa, Fun wa n’ ibukun ale; A jewo ese wa fun O, Iwo l’o le gba wa la. Bi ile tile su dudu, Okun ko le se wa mo; Iwo Eniti ki s’are Nso awon enia Re. 2. B’ iparun tile yi wa ka, Ti ofa nfo wa koja, Awon angeli yi wa ka, Awa o wa lailewu. Sugbon b’ iku ba ji wa pa, T’ ibusun wa d’ iboji, Je k’ ile mo wa s’ odo Re L’ ayo at’ Alafia. 3. Ni irele, a f’ ara wa Sabe abo Re, Baba; Jesu, ‘Wo t’o sun bi awa, Se orun wa bi Tire. Emi Mimo, rado bow a, So wa l’ okunkun oru, Tit’ awa o fi ri ojo Imole aiyeraiye. |
1. B'eru ese re ba nwo o lorun, Pe Jesu wole okan re; B'o nd'aniyan isoji okan re, Pe Jesu wole okan re, Le 'yemeji re sonu, Ba Oluwa re laja; Si okan re paya fun, Pe Jesu wole okan re. 2. Bi o ba nwa iwenumo kiri, Pe Jesu wole okan re; Omi 'wenumo ko jina si o, Pe Jesu wole okan re. 3. B'igbi wahala ba ngba o kiri Pe Jesu wole okan re; B'afo ba wa ti aye ko le di, Pe Jesu wole okan re 4. Bi ore t'o gbekele ba da o Pe Jesu wole okan re; On nikan ni Olubanidaro, Pe Jesu wole okan re, 5. B'o nfe korin awon olubukun Pe Jesu wole okan re, Bi o nfe wo agbala isimi, Pe Jesu wole okan re. 'Yemeji mi ti fo lo, Mo b'Olorun mi laja, Mo s'okan mi paya fun, Jesu ti wole okan mi. Amin. |
1. Bukun 'le wa at'ebi wa, at'ara wa/2ce Ibukun orun, iranwo, Re, Ibukun orun ko fi kari awa, K'O fi fun wa o, l'aye l'orun o, Baba orun 2. Tu wa lara, Alagbara, se 'toju wa/2ce Itunu Re, alafia Re, Ike Re, K'O fi toju wa, ye, Awa mbe O o, gbo adura wa, Oba Ogo. 3. Baba fun wa l'Emi mimo at'agbara/2ce Iranse orun, ebun lat'orun Itunu Baba, k'o wonu okan wa, K'o gbe 'nu wa o, k'o fun wa l'ayo, Oba Orun. 4. Awa f'iyin at'ope fun Baba l'orun/2ce Iyin fun 'ranwo, ope fun anu, Ayo fun 'dasi ti a nri lojojo, Ope fun O o, a tun juba Re, Baba awa. Amin |
TOLUWA NILE ATEKUN RE T'Oluwa Nile at'ekun re Aye at'ekun 'nu re O fi idi re sole lor'okun At I lori isan omi Egbe Gbe ori yin soke, eyin ilekun Ka gbe yin soke K'Oba Ogo wole wa Tani yo gori oke yi lo? Ori oke Oluwa Tani yo duro niwaju Re? Niwaju Oluwa wa Eni ti o ni owo mimo To so ni aya funfun Ti ko gb' okan re soke s'asan Ti ko si bura etan Awa ni iran ti nsaferi Re Saferi Re Oluwa Awa yo si ri ibukun gba Lowo Olorun Jakob A! Tani Oba awon oba Ti'se Oba Ogo yi? Oluwa awon omo Ogun Oun naa l'Oba ogo |
1. Jesu mimo Ore airi Oluranlowo alaini N'nu ayida aiye, ko mi K'emi le romo O. 2.Ki nsa n‘idapo mimo yi, Gba ohun t‘O fe ugo kun bi? B‘okan mi b‘eka ajara Ba sa le ro mo O. 3. Are ti m'okan mi pupo Sugbon o wa r'ibi simi T'ori t'o room O 4. B'aiye d'ofo mo mi loju Ba gba ore at'ara lo Ni Suri ati laibohun L'emi o romo O 5 ‘Gba t‘o k‘emi nikan soso, Larin idamu aye yi, Mo gb‘ohun ife jeje na Wipe, “Sa ro mo Mi 6 B‘are ba fe mu igbagbo, T‘ireti ba si fe saki, Ko si ewu fun okan na Ti o ba ro mo O. 7 Won ko beru ‘rumi aye Nitori ‘Wo wa nitosi; Won ko si gbon b‘iku ba de ‘Tori won ro mo O. 8 Ire sa ni l‘ohun gbogbo, Ko s‘eni le daya fo mi ‘Gba mo fi O s‘Olugbala, Ti mo si ro mo O. |
1. GBO-GB’ ogo iyin ola, Fun O oludande, S’ Eni t’ awon omode Ko Hosanna didun! ‘Wo l’ Oba Israeli, Om’ Alade Dafidi, T’ O wa l’ Oko Oluwa, Oba olubukun. Gbogb’ ogo iyin ola Fun O, Oludande, S’ Eni t’ awon omode Ko Hosanna didun! 2. Egbe awon maleka, Nyin O l’ oke giga; Awa at’ eda gbogbo Si dapo gberin na. 3. Awon Hebru lo, saju, Pelu imo ope, Iyin, adura, at’ orin, L’ a mu wa ‘waju Re. 4. Si O saju iya Re, Nwon korin iyin won; ‘Wo t’a gbega nisiyi, L’ a nkorin iyin si. 5. ‘Wo gba orin iyin won: Gb’ adura t’a mu wa, ‘Wo ti nyo s’ ohun rere, Oba wa Olore. |
Bi Krist ti da okan mi nde Aye mi ti dabi orun Larin 'banuje at' aro Ayo ni lati mo jesu Chorus: Halleluya Ayo l'o je Pe mo ti ri 'dariji gba Ibikibi ti mo ba wa Ko s'ewu Jesu wa nibe Mo ti ro pe orun jinna Sugbon nigba ti Jesu de L'orun ti de 'nu okan mi Nibe ni yo'o si wa titi Nibo l'a ko le gbe l'aiye L'or'oke tabi petele L'ahere tabi agbala Ko s'ewu Jesu wa nibe |
Ninu irin ajo mi, beni mo nkorin Mo n toka si kalfari, N’ibi eje na Idanwo lode ninu, l’ota gbe dide Jesu lo nto mi lo, isegun daju Egbe: A! mo fe ri Jesu kin ma w’oju re, Ki nma korin titi nipa ore re Ni ilu ogo ni ki ngbohun soke Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi. Stanza 2 Ninu ise isin mi, b’okunkun basu Un o tubo sunmo Jesu, y’o tan imole Esu le gb’ogun ti mi, kin le sa pada Jesu lo nto mi lo, ko se’wu fun mi. Egbe: A! mo fe ri Jesu kin ma w’oju re, Ki nma korin titi nipa ore re Ni ilu ogo ni ki ngbohun soke Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi. Stanza 3 Bi mo tile bo sinu afonifoji Imole itoni Re, Yio Mole simi Yio na owo re simi, Yio gbe mi soke Un o ma tesiwaju, b’o ti nto mi lo Egbe: A! mo fe ri Jesu kin ma w’oju re, Ki nma korin titi nipa ore re Ni ilu ogo ni ki ngbohun soke Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi. Stanza 4. Nigbati iji aye yi ba yi lu mi Mo ni abo t’o daju, labe apa re Y’o ma f’owo re to mi titi de opin Ore ododo ni, A! mo ti f’e to. Egbe: A! mo fe ri Jesu kin ma w’oju re, Ki nma korin titi nipa ore re Ni ilu ogo ni ki ngbohun soke Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi. |
11. Recessional Hymn Akokun 22 “B’o ba ni Jesu k’o dimu” B’o ba ni Jesu k’o dimu, K’o si toro imuduro, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Mu mi duro, mu mi duro, Mu mi duro dopin, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Ninu ofi-ola aiye, Pelu danwo arotele, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Nigba ‘banuje ile B’a d’ori okan mi kodo; Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Nigba wahal’ aiye l’otun Idanwo Esu li osi, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Nigba Esu gbe mi soke, T’o fe k’emi k’o teriba, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Nigbat’ o ku emi nikan, Ti ko si alabaro mo; Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. |
1 Nigbati ‘gbi aye yi ba nyi lu o, To si dabi enipe gbogbo re pin, Ka ibukun re, siro won l‘okokan, Ise Oluwa yo je ‘yanu fun o Ka ‘bukun re, ka won l‘okokan, Ka ‘bukun re, wo ‘se Olorun; Ka ‘bukun re, ka won l‘okokan, Ka ‘bukun re, wa ri ‘se t‘Olorun se. Eru aniyan ha nwo ‘kan re l‘orun! Ise t‘a pe o si ha soro fun O; Ka ‘bukun re, ‘yemeji yo si fo lo, Orin iyin ni yo si gb‘enu re kan. 3 ‘Gbat‘ o ba nwo awon oloro aye, Ronu oro ti Jesu ti se leri; Ka ibukun re, owo ko le ra won, Ere re l‘orun ati ‘le re l‘oke. 4 Ninu gbogbo ayidayida aye, Mase foya, Olorun tobi julo; Ka ‘bukun re, awon angel‘ yo to o Won yo si ran o lowo titi d‘opin. Amin. |
11. Recessional Hymn Akokun 22 “B’o ba ni Jesu k’o dimu” B’o ba ni Jesu k’o dimu, K’o si toro imuduro, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Mu mi duro, mu mi duro, Mu mi duro dopin, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Ninu ofi-ola aiye, Pelu danwo arotele, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Nigba ‘banuje ile B’a d’ori okan mi kodo; Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Nigba wahal’ aiye l’otun Idanwo Esu li osi, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Nigba Esu gbe mi soke, T’o fe k’emi k’o teriba, Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. Nigbat’ o ku emi nikan, Ti ko si alabaro mo; Jesu, Oluwa mi, Mu mi duro dopin. |
Nigba igbi aiye ba dide si o, T' okan re baje pe gbogbo nkan segbe, Siro ibukun re, ka won lokokan, Enu y'o ya o fun nkan t' Oluwa t'se. Refrain Ro 'bukun re ka won lokokan, Ro ohun t' Olorun se fun o; Ro 'bukun re, ka won lokokan, Ro 'bukun re, ri nkan t' Olorun ti se. Eru aniyan ha ti n pa okan re? Agbelebu ti 'wo nru ha si wuwo? Siro ibukun re le 'yemeji lo, Iwo y'o si korin b' ojo ti nkoja. Nigbat' ini elomi kun o loju, Ranti Krist n 'oro aimoye fun o, Siro ibukun re t' owo ko le ra, At' ere re lorun, ile re l' oke Beni larin ija b' o ti wu ko ri, Mase ba okan je mo p' Olorun mbe, Siro ibukun re, Angeli y'o wa, Fun ranwo on 'tunu d'opin ajo re. Source: YBH #658 When upon life’s billows you are tempest tossed, When you are discouraged, thinking all is lost, Count your many blessings name them one by one, And it will surprise you what the Lord hath done. Refrain: Count your blessings, name them one by one; Count your blessings, see what God hath done; Count your blessings, name them one by one, And it will surprise you what the Lord hath done. Are you ever burdened with a load of care? Does the cross seem heavy you are called to bear? Count your many blessings, every doubt will fly, And you will be singing as the days go by. When you look at others with their lands and gold, Think that Christ has promised you His wealth untold. Count your many blessings, money cannot buy Your reward in heaven, nor your Lord on high. So amid the conflict, whether great or small, Do not be discouraged, God is over all; Count your many blessings, angels will attend, Help and comfort give you to your journey’s end. |
B’o ti dun lati gba Jesu Bi iwo ba gbagbo, iwo o ri ogo Olorun. Jn. 11:40 1. B’o ti dun lati gba Jesu Gbo gegebi oro Re; K’a simi lor’ ileri Re, Sa gbagbo l’Oluwa wi Jesu, Jesu, emi gbagbo, Mo gbekele n’gbagbogbo, Jesu, Jesu, Alabukun Ki nle gbekele O si. 2. B’o ti dun lati gba Jesu, K’a gb’eje ‘wenumo Re Igbagbo ni ki a fi bo Sin ‘eje wenumo na. 3. B’o ti dun lati gba Jesu, Ki nk’ara ese sile, Ki ngb’ayo, iye, isimi Lati odo Jesu mi. 4. Mo yo mo gbeke mi le O, Jesu mi, Alabukun; Mo mo pe O wa pelu mi, Ntoju mi titi dopin. Amin. Tis so sweet to trust in Jesus If thou wouldest believe, thou shouldest see the glory of God. John.11:40 1. 'Tis so sweet to trust in Jesus, Just to take Him at His word: Just to rest upon His promise: Just to know, 'Thus saith the Lord. Jesus, Jesus, how I trust Him! How I've proved Him o'er and o'er Jesus, Jesus, precious Jesus! O for grace to trust Him more! 2. O how sweet to trust in Jesus, Just to trust His cleansing blood; Just in simple faith to plunge me 'Neath the healing, cleansing flood! 3. Yes, ‘tis sweet to trust in Jesus, Just from sin and self to cease; Just from Jesus simply taking Life and rest, and joy and peace. 4. I'm so glad I learn'd to trust Thee Precious Jesus, Saviour, Friend; And I know that Thou art with me, Wilt be with me to the end. Amen. |
1. Mo nduro lori ileri Krist' Oba Eniti a o ma yin titi laelae Ogo f‘Olorun, emi yo ma korin Mo nduro lori ileri Re. Emi nduro...... (Mo nduro de ‘leri, Mo nduro de ‘leri) Emi nduro lori ileri Oluwa Emi nduro...... (Mo nduro de ‘leri, Mo nduro de ‘leri) Emi nduro lori ileri Re. 2. Mo nduro le ileri ti ko le ye Gbati iji 'yemeji at‘ eru ba de Nipa Oro Re li emi yo segun Mo nduro lori ileri Re, 3. Ileri Re la mi loju lati ri Iwenumo pipe ninu eje Re Ileri Re so okan mi d‘om'nira Mo nduro lori ileri Re. 4. Mo nduro le ileri Krist' Oluwa Ife lo fi so mi po mo ara Re Nipa oro Re mo nsegun lojojo Mo nduro lori ileri Re Amin. |
ONIBU ORE HYMN LYRICS Verse 1 Oluwa orun on aye Wo Niyin atope ye fun Bawo la ba ti fe o to Onibu ore Verse 2 Orun ti nran atefefe Gbogbo eweko nso fe re Wo lo nmu irugbin dara Onibu ore Verse 3 Fun ara lile wa gbogbo fun gbogbo ibukun aye Awa yin o, a si dupe a onibu ore Verse 4 O ko du wa li omo re o fi fun aye ese wa o si f'ebun gbogbo pelu onibu ore Verse 5 O fun wa l'Eni Mimo re Emi iye atagbara O rojo ekun ibukun re Le wa lori Verse 6 Fun idariji ese wa, ati fun ireti orun Ki lohun ta fin fun o O je isura ti taye Onibu ore Verse 7 Owo ti anna, ofo ni Sugbon eyi tafin fun o O je isura ti taye Onibu ore Verse 8 Ohun ta bun o Oluwa Wo o an le pada fun wa Layo la ta o lore Onibu ore Verse 9 Ni odo re lati san wa olorun olodumare Je ka le ba O gbe titi Onibu ore |
Blessed Assurance Oda mi loju, mo ni Jesu! Itowo adun oorun l’eyi je! Mo di ajogun igbala nla, Eje Re we mi, a tun mi bi. Egbe: Ngo so itan na, ngo korin na, Ngo yin Olugbala mi titi; Ngo so itan na, ngo korin na, Ngo yin Olugbala mi titi. Ngo teriba fun tayotayo, Mo le ri iran ogo bibo Re; Angeli nmu ihin didun wa Ti ife at’anu Re si mi. Egbe: Ngo teriba fun, ngo simi le Mo di ti Jesu, Mo d’eni ’bukun, Ngo ma sora, ngo si gbadura, Ki ore Re ma fi mi sile. Egbe: Amin. |
OGO NI F'ORUKỌ OLUWA 1. Jesu ala-bu-kun a-wa yin ọ A kò kiki 'fẹ́ oore rẹ Alagbara, ẹni mímọ Ogo nla ni f'orukọ rẹ Chrs.. Óòoo...........ogo. Óòoo.........ogo Ogo ni f'orukọ~Oluwa Óòoo...........ogo. Óòoo.........ogo Ogo ni f'orukọ rẹ 2. Olurapada nla, oluwa wa Imọlẹ ọjọ ~ayeraye Jẹ k'awọn mimọ ni gbogbo aye Kọrin iyin ailopin rẹ 3. Lat'ori itẹ ogo ti ọ́run S'ori agbelebu itiju E'n tó kù, to ra wa pada Ki ẹlẹṣe ba tun le ye 4. Sọkalẹ wa, ọba àìkú Wa gba' jọba ogo re Wa ma jọ́ba, titi lailai Ki gbogbo 'jọba jẹ tirẹ |
Ninu irin ajo mi, beni mo nkorin Mo n toka si kalfari, N’ibi eje na Idanwo lode ninu, l’ota gbe dide Jesu lo nto mi lo, isegun daju Egbe: A! mo fe ri Jesu kin ma w’oju re, Ki nma korin titi nipa ore re Ni ilu ogo ni ki ngbohun soke Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi. Stanza 2 Ninu ise isin mi, b’okunkun basu Un o tubo sunmo Jesu, y’o tan imole Esu le gb’ogun ti mi, kin le sa pada Jesu lo nto mi lo, ko se’wu fun mi. Egbe: A! mo fe ri Jesu kin ma w’oju re, Ki nma korin titi nipa ore re Ni ilu ogo ni ki ngbohun soke Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi. Stanza 3 Bi mo tile bo sinu afonifoji Imole itoni Re, Yio Mole simi Yio na owo re simi, Yio gbe mi soke Un o ma tesiwaju, b’o ti nto mi lo Egbe: A! mo fe ri Jesu kin ma w’oju re, Ki nma korin titi nipa ore re Ni ilu ogo ni ki ngbohun soke Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi. Stanza 4. Nigbati iji aye yi ba yi lu mi Mo ni abo t’o daju, labe apa re Y’o ma f’owo re to mi titi de opin Ore ododo ni, A! mo ti f’e to. Egbe: A! mo fe ri Jesu kin ma w’oju re, Ki nma korin titi nipa ore re Ni ilu ogo ni ki ngbohun soke Pe mo bo, ija tan, mo de ile mi. |
C.M.S. 563, S.O. ED D7s (FE 135) "Iwo ki ise eru mo, Iwo di arole Olorun nipase Kristi" - Gal. 4:7 1. EWE ti Oba orun, Korin didun be ti nlo Korin ‘yin Olugbala Ologo ‘nu ise Re. Egbe: A nlo ‘le sodo Olorun Lona t'awon Baba rin Nwon si nyo: nisisiyi Ayo won l'awa o ri. 2. A nlo sodo Olorun Lona t'awon Baba rin Nwon si nyo: nisisiyi, Ayo won l'awa o ri. Egbe: A nlo ‘le sodo... 3. Korin agbo kekere E o simi n'ite Re, ‘ Bit'a pese 'joko nyin Ibe si n'ijoba nyin. Egbe: A nlo ‘le sodo... 4. W'Oke, omo imole Ilu Sion wa lokan Ibe n‘ile wa titi; Ibe l'ao r'Oluwa. Egbe: A nlo ‘le sodo... 5. Kerubu, tesiwaju Serafu, ma jafara Kristi Omo Baba nwi Pe laifoiya ka ma lo. Egbe: A nlo ‘le sodo... 6. Jesu, a nlo l'ase Re, A ko‘hun gbogbo sile lwo ma j‘ amona wa, A o si ma ba o lo. Egbe: A nlo ‘le sodo... 7. A f’ogo fun Baba wa, A f'ogo fun Omo Re; Ogo ni f’Emi Mimo, Mu wa de ‘le ayo na. Egbe: A nlo ‘le sodo Olorun Lona t'awon Baba rin Nwon si nyo: nisisiyi Ayo won l'awa o ri. Amen |
Emi o kokiki Re, Oluwa" - PS. 30:1 1. EMl o kokiki Re, Oluwa Iwo li o da mi n'ide lwo ni ko je ki ota yo mi Ogo ni f'oruko Re. Egbe: lyin, Ola, Ogo ni fun O Agbara ati ipa je Tire Egberun ahon ko to yin O A Wole, a juba Re. 2. Oluwa mi, emi kigbe pe O lwo si mu mi lara da O yo okan mi ninu sa oku O si pa mi mo l’aiye. Egbe: lyin, Ola, Ogo... 3. Korin s'Oluwa enyin Serafu K’e si dupe n‘iwa mimo Re lbinu Re ki pe ju ‘seju kan lye l’oju rere Re. Egbe: lyin, Ola, Ogo... 4. Bi ekun tile pe di ale kan Sibe ayo de I‘Owuro Alafia si de li osan gangan Mo tun di ipo mi mu. Egbe: lyin, Ola, Ogo... 5. Nigbat‘Oluwa pa oju Re mo Enu ya mi mo si kigbe A! kil'ere eje mi, Oluwa Gba mba koja s'isa oku? Egbe: lyin, Ola, Ogo... 6. Bayi l'Oluwa mi gbo igbe mi O si so kanu mi d‘ijo O bo aso ofo kuro l‘orun mi O f’amure ayo di mi. Egbe: lyin, Ola, Ogo... 7. A! Ogo mi dide si ma korin Ma fi ayo korin s’oke Oluwa ngo fi ope fun O Ngo si ma yin O lailai. Egbe: lyin, Ola, Ogo ni fun O Agbara ati ipa je Tire Egberun ahon ko to yin O A Wole, a juba Re. |