Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,163,140 members, 7,852,874 topics. Date: Friday, 07 June 2024 at 07:40 AM

Yoruba Commonwealth and Politics - Politics (90) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Yoruba Commonwealth and Politics (675700 Views)

OPC - Faseun & Adams Unite For Security Of Yoruba Commonwealth / SEUN - Re: Yoruba-commonwealth-politics / Goodluck Jonathan Returns From Commonwealth Assignment (photo) (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (87) (88) (89) (90) (91) (92) (93) ... (384) (Reply) (Go Down)

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by totit: 9:21pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:

Ki ni oruko wan lori forumu yii boya ka pe wan wa ka de fun won nii imoran nipa ona bi ile osun tile tesiwaju

"Raufaregbesola"
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ritchiee: 9:21pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:

Mii mo wipe o lokiki toyi oo de bi wipe awon oloselu wa no mo ni pa e.Iyen tumosi wipe o se n se ki won ri gbogbo nkan ta n nko nibi ba yii
Emi nigbagbo pe lara won ma nko akoranse kan tabi ikeji agaga ni asiko oro oselu...erinkeke(ekk=lol)
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:24pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:
O da bi eni wipe ogbeni razidi n bere lowo yin lano wipe ta ni e lero wipe o to lati pe oni oloori awon Yooba.Emi oni paro fun yin.ko si enikankan laarin awon oloselu wa to wumilori

Lati ojo ti Baba Abraham Adesanya ti d'oloogbe ni Yoruba ti padanu Asiwaju won. Mo duro fun atunse o (I stand to be corrected)
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by superstar1(m): 9:25pm On Oct 30, 2015
Gbawe, Oduavanguard and Shymexx ti so awon oko doro oro leni.

Ikan ti e mi fe fi kun ni pe, o ye ki awon oloselu wa je ki itesiwaju ilu jewon logun ju itesiwaju apo ti won lo.

O ye ki awon oloselu ma wo bi won se le ji ilosiwaju baba gbogbo kaaro o jire papo. Ki a ma ko gbogbo eyin sinu Eko nikan.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:26pm On Oct 30, 2015
Ritchiee:
Emi nigbagbo pe lara won ma nko akoranse kan tabi ikeji agaga ni asiko oro oselu...erinkeke(ekk=lol)

To ba je ni tooto ni gbogbo nkan te n wi yiii.iyen tumo si wipe aa gbudo mu gbogbo nkan ta nko ni bi yii ni yepere
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:29pm On Oct 30, 2015
marioking:

Lati ojo ti Baba Abraham Adesanya ti d'oloogbe ni Yoruba ti padanu Asiwaju won. Mo duro fun atunse o (I stand to be corrected)

Emi wa pelu yin lori ele yi.Awa Yooba aa lolori.mo mo wipe awon kan o ni finusokan pelu wa lori ele yi
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:33pm On Oct 30, 2015
superstar1:
Gbawe, Oduavanguard and Shymexx ti so awon oko doro oro leni.

Ikan ti e mi fe fi kun ni pe, o ye ki awon oloselu wa je ki itesiwaju ilu jewon logun ju itesiwaju apo ti won lo.

O ye ki awon oloselu ma wo bi won se le ji ilosiwaju baba gbogbo kaaro o jire papo. Ki a ma ko gbogbo eyin sinu Eko nikan.

Nkan gaan ti mo n so fun awon yan leleyi.kilode to se je wipe gbogbo nkan ta ba fe da sile nile yooba,aa gbudo lo se ko.kilo sele si awon ilu toku? eyin na ewo iyato ti nbe laarin eko ati awon ile yooba toku

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Musiwa419: 9:33pm On Oct 30, 2015
marioking:

Lati ojo ti Baba Abraham Adesanya ti d'oloogbe ni Yoruba ti padanu Asiwaju won. Mo duro fun atunse o (I stand to be corrected)
otito oro le so. Ologbe Abraham Adesanya ni asiwaju ti iran Yoruba ni gbeyin.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Musiwa419: 9:38pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:

Nkan gaan ti mo n so fun awon yan leleyi.kilode to se je wipe gbogbo nkan ta ba fe da sile nile yooba,aa gbudo lo se ko.kilo sele si awon ilu toku? eyin na ewo iyato ti nbe laarin eko ati awon ile yooba toku

se emo wipe ile ise epo ti ogbeni dangote fe kosi Lekki ni ipinle Eko, Olokola ni ipinle Ogun lo fe kosi tele
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by laudate: 9:40pm On Oct 30, 2015
*sigh* I give up....walking away. sad The dictionary isn't helping...
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:43pm On Oct 30, 2015
Musiwa419:
se emo wipe ile ise epo ti ogbeni dangote fe kosi Lekki ni ipinle Eko, Olokola ni ipinle Ogun lo fe kosi tele

Ara nkan ta n so ni yen.mo gbo wipe idi ti ko se kosi ipinle ogun ni wipe owun pelu awon ara ilu yen o fohunsokan lori ere ti won o je lata re e.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ritchiee: 9:44pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:

To ba je ni tooto ni gbogbo nkan te n wi yiii.iyen tumo si wipe aa gbudo mu gbogbo nkan ta nko ni bi yii ni yepere
Beeni o.Bo pe boya a nbo wa ri eso re nitori re ni mo se sope o ye ki a mu oro kan gboogi(lekokan)lati soro le lori.Onikaluku yoo ti mura dani.Ao so gbogbo edun okan wa ati oogun ti a o lo si i.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:47pm On Oct 30, 2015

Amoran gidi leleyi te mu wa yii sugbon iberu mi ni wipe to ba to asiko kan aa ni mo n kan ta fe soro nipa.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:47pm On Oct 30, 2015
Ara idi pataki ti Awon ile yoruba toku o fi tesiwaju niyen. Iba sepe bi won se n tu Eko se ni won se n se awon ipinle toku ni, ile oduduwa I ba ti goke agba.
O ye ki awon gomina wa gbogbo toku maa gbiyanju lati fa awon onisowo wa si ipinle onikaluku.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Firefire(m): 9:48pm On Oct 30, 2015
Eyin Ogidi Omo Odua, eku atotonu.

Aareonakakanfo, ani lati mu koko oro kan fun ijiriro yi, eyi lo ma fun wa ni idarii Ohun ti a o soro le lori.

Alafia, fun gbogbo Ile oooooo.

1 Like

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:49pm On Oct 30, 2015
marioking:
Ara idi pataki ti Awon ile yoruba toku o fi tesiwaju niyen. Iba sepe bi won se n tu Eko se ni won se n se awon ipinle toku ni, ile oduduwa I ba ti goke agba.
O ye ki awon gomina wa gbogbo toku maa gbiyanju lati fa awon onisowo wa si ipinle onikaluku.

Yato si ipinle ogun,mi o mo nkan to de ti awon ilu yooba toku o se lo anfani isunmo wan seko
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ritchiee: 9:50pm On Oct 30, 2015
Musiwa419:
otito oro le so. Ologbe Abraham Adesanya ni asiwaju ti iran Yoruba ni gbeyin.
Kilode ti a ko le fi eeyan bi Wole Soyinka se asiwaju yoruba lasiko yi?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 9:51pm On Oct 30, 2015
Musiwa419:
se emo wipe ile ise epo ti ogbeni dangote fe kosi Lekki ni ipinle Eko, Olokola ni ipinle Ogun lo fe kosi tele
Ki e pe baba fun wa. Ohun ti mo mo daju nipe Olokola kii se ti ipinle Ogun nikan. Ipinle Ondo ati Ogun ni won jijo ni labe akoso ijoba apapo nigba naa. Ogbeni Agagu ati Gbenga Daniel ni won jumo bere eto naa pelu isakoso Obasanjo. Sugbon kete ti Agagu ti kuro lori oye, ohun naa ni eto naa ti fori sanpo nitori wipe gomina to gba ise lowo e ko fi be fi ara mo eto naa. Eleyi lo fa ti ipinle Ogun naa fi ni ifasehin nipa Olokola.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:52pm On Oct 30, 2015
Firefire:
Eyin Ogidi Omo Odua, eku atotonu.

Aareonakakanfo, ani lati mu koko oro kan fun ijiriro yi, eyi lo ma fun wa ni idarii Ohun ti a o soro le lori.

Alafia, fun gbogbo Ile oooooo.

Ogbeni ritchiee ti mu amoran yin wa.boya maa lati gba pelu yin.se e ma fun wa ni ori oro lojoojumo ka ba le ma soro ni paa re.eyin ati ogbeni ritchiee
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:54pm On Oct 30, 2015
Ritchiee:
Kilode ti a ko le fi eeyan bi Wole Soyinka se asiwaju yoruba lasiko yi?

Wole soyinka kin se oloselu.oto ni keyan ni imo iwe.oto loro oselu
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 9:54pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:

Yato si ipinle ogun,mi o mo nkan to de ti awon ilu yooba toku o se lo anfani isunmo wan seko
Paapa ipinle Osun. Ojojumo ni mo maa n wo pe kilo se ti ko se si ona taara lati ipinle Osun si ilu Eko. Mo mo wipe Ogbeni Aregbe daba nnkan ti o jo be ni igba kan ri. Ona kan wa lati Gbongan (Wakajaiye) ti won so wipe o lo ja si apa kan ni oju ona Eko si Ibadan.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ritchiee: 9:56pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:

Amoran gidi leleyi te mu wa yii sugbon iberu mi ni wipe to ba to asiko kan aa ni mo n kan ta fe soro nipa.
Se eyin ti ri ojo kan ti awon oniroyin sope awon ko ri nkankan royin mo.O seewoO de le je ekokan...ire o.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:58pm On Oct 30, 2015
razid:

Paapa ipinle Osun. Ojojumo ni mo maa n wo pe kilo se ti ko se si ona taara lati ipinle Osun si ilu Eko. Mo mo wipe Ogbeni Aregbe daba nnkan ti o jo be ni igba kan ri. Ona kan wa lati Gbongan (Wakajaiye) ti won so wipe o lo ja si apa kan ni oju ona Eko si Ibadan.

Ki ti e n se ipinle osun ni kan,, oye ka ni oko irin reluwe to le gbe wa lati eko si awon ilu toku nile yooba.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ritchiee: 10:00pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:

Wole soyinka kin se oloselu.oto ni keyan ni imo iwe.oto loro oselu
Ema binu,se oloselu ni Pa Abraham Adesanya.Egbe wo ni won wa?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by zimoni(f): 10:00pm On Oct 30, 2015
totit:

Kikikikikikikiki grin

Baawa? Kire? lipsrsealed
Tiredi ke

Raara o

"Sétan tabi gbaradi" lan pe oo grin

Yooba yi lekenka oo grin

He's right.

Thread....English, Tiredi.....Yoruba.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:00pm On Oct 30, 2015
Ritchiee:
Se eyin ti ri ojo kan ti awon oniroyin sope awon ko ri nkankan royin mo.O seewoO de le je ekokan...ire o.

Oda na se gabaradi lati ma fun wa ni ori oro lojoojumo lati soro nipa?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 10:00pm On Oct 30, 2015
Ritchiee:
Kilode ti a ko le fi eeyan bi Wole Soyinka se asiwaju yoruba lasiko yi?
Ti e ba wo ohun ti mo so ni ana, asiko tito fun wa lati ni olori tuntun ti yoo maa fun awa omo Yoruba ni ilana. Gbogbo awon ti o ti ju Aadota odun lo ko le se ise naa rara tori wipe opolopo won ni won ni ikunsinu si ara won. Fun apeere, kosi ibasepo to dan moran laarin ojogbon Wole Soyinka ati Oloye Obasanjo. Awon Afenifere to je odo naa tun ti koju ija si ara won. Eyin e wo Yinka Odunmakin ati awon iyoku ti won jo bere, e o ri wipe awon naa n ba ara won ja ni. Eeyan kan ti mo fe damoran ni Baba Bolanle Gbonigi, sugbon awon naa n be lara awon iran agba ti a n soro re.

1 Like

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Musiwa419: 10:01pm On Oct 30, 2015
razid:

Ki e pe baba fun wa. Ohun ti mo mo daju nipe Olokola kii se ti ipinle Ogun nikan. Ipinle Ondo ati Ogun ni won jijo ni labe akoso ijoba apapo nigba naa. Ogbeni Agagu ati Gbenga Daniel ni won jumo bere eto naa pelu isakoso Obasanjo. Sugbon kete ti Agagu ti kuro lori oye, ohun naa ni eto naa ti fori sanpo nitori wipe gomina to gba ise lowo e ko fi be fi ara mo eto naa. Eleyi lo fa ti ipinle Ogun naa fi ni ifasehin nipa Olokola.
Alaye yin ye mi dara dara. Emi na mo wipe ipinle Ogun ati ipinle Ondo ni won jijo nii. Amo kilode ti awon ipinle mejeji ose fi owo sowopo lati fi le ri wipe eto yen wa si imuse ni isiyin. Se nitori wipe egbe oselu ototo lo wa ni ipinle ogun ati ondo ni?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by itstpia8: 10:03pm On Oct 30, 2015
Thread: English

Owu: Yoruba
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:04pm On Oct 30, 2015
Ritchiee:
Ema binu,se oloselu ni Pa Abraham Adesanya.Egbe wo ni won wa?

Beeni oloselu ni won.Lehin iku olori pataki obafemi awolowo ati adekunle ajasin, pa adesanya lo ropo won.Alliance for democracy loruko egbe won.awon pelu olori bola ige,ayo adebanjo,ganiyu dawodu ati bola tinubu
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 10:05pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:

Ki ti e n se ipinle osun ni kan,, oye ka ni oko irin reluwe to le gbe wa lati eko si awon ilu toku nile yooba.
O dabi eni pe gomina Amosun ti fowosi ise ode pelu awon oyinbo kan lati pese oko oju irin ti yoo lo lati Abeokuta si Sagamu ati titi de Ijebu Ode. Bakannaa ni lati Abeokuta lo si Ilaro ati Ayetoro. Ti iru eleyi ba wa nibe, sebi n se ni ipinle Ondo yoo ko dara po mo lati Ijebu Ode lo si Ore titi gba Ondo ati Akure ni.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by bolabolakemi(f): 10:05pm On Oct 30, 2015
The only future for keeping Yoruba culture and people is restoration of Oduduwa Republic ... embarassed

The long and short of the British fraud is that blacks are still slaves and they divided us into two-the house slaves and field slaves. The 1967 Biafra restoration was like a recaptured slave and how can a black monkey undo what the British did? They could not believe it. YOU PROBABLY HEAR GOWON AND OTHERS SAYING OJUKWU SHOULD HAVE SURRENDERED EARLY, IF BUHARI IS DOING WHAT HE IS DOING TODAY BECAUSE HE WAS DECLARED WINNER IN AN ELECTION, DO YOU NOW SEE WHY THEY STOLE PEOPLES HOUSES AND MONEY? The land Buhari owns in Port Harcourt that he said he does not know where it is, is probably one of the houses they stole but they will blame it on Ijaws or Ikwerres.

Before you criticise Biafra please take time and ask "Is Biafra different from Scotland and the UK? When they say loss of property and so on remind them there are Igbos in Ghana and Cameroon and in London and New York - they have not lost their property and we are not one country with them. The House slaves normally sabotage every effort of the field slaves to be free - you have to choose which one you are but don’t think we are free -the British uses the Hausa/Fulani to enslave everyone. - http://combatgeno
http://elombah.com/index.php/opinion/2067-biafra-or-black-emancipation-opening-the-eyes-of-black-people

1 Like

(1) (2) (3) ... (87) (88) (89) (90) (91) (92) (93) ... (384) (Reply)

Kenyans Are Far Behind Nigerians In Every Aspect – Fani-Kayode / Anambra light of the nation, eastern economy power house. / Enugu, The Pride Of The East.

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 48
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.