₦airaland Forum

Welcome, Guest: Register • Login • With Google • Trending • Recent • New

Stats: 3,344,219 members, 8,510,740 topics. Date: Friday, 30 October 2026 at 11:31 PM

Toggle theme

Raydos's Posts

Nairaland Forum › Raydos's Profile › Raydos's Posts

1 2 3 4 5 6 7 8 ... 15 16 17 18 19 20 21 22 23 (of 239 pages)

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op):
Adìyẹ — Chicken

Akọ — Àkùkọ
Abo — Abo Adìyẹ
Awọn ọmọ — Òròmọ Adìyẹ

Popular Proverb:
1. Kíkere L'abẹ́rẹ́ un kere, Ko kìí ṣe mímìn Fún Adìyẹ

2. Adìyẹ t'ó ṣu Tí kò tò, Ara rẹ̀ l'ó wà

3. Bi Ojú Akátá bá Li Ewo, Ṣe Ẹnu Adìyẹ L'ó yẹ K'á ti gbó-ọ

4. Àyè Kìí Há Adìyẹ, K'ó má lè dé ibi ti ẹyin to wà

5. Jàmbá Ti ó un kó Ẹyin lọ l'óri Àba, Ti A bá Dáké, Gbogbo Àkùkọ ìlú L'o ma lọ Síi

6. ìfẹ́ tí A fẹ́ adìyẹ kò de'nú, L'eyin kó dágbà K'a pa-a jẹ — Ibi pípajẹ L'o Mọ

7. Àgbà t'o so yàngán mọ ìdí, L'o sọ ara rẹ̀ di aláwadà fún Adìyẹ

8. Adìyẹ un sunkún Aìlẹ́yin, Àjànàkú ùn sunkún Ai-r'étè bo ti ri

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 3:18pm On Nov 09, 2023
Yanja-yanja — Snakebird/Anhinga

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 2:50pm On Nov 09, 2023
Àkàlàmàgbò — Ground Hornbill

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 2:48pm On Nov 09, 2023
Àtíòro/Àtíàla — Hornbill

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 2:36pm On Nov 09, 2023
Alápáǹdẹ̀dẹ̀ — Swallow

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:43pm On Nov 09, 2023
Ẹiyẹ Awó/Ẹtù — Guinea fowl

Akọ — Ẹtù
Abo — Awó

Popular saying:
1. Àgbà L'ẹtù

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:40pm On Nov 09, 2023
Tòlòtólò — Turkey

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:30pm On Nov 09, 2023
Àdán — Bat

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:26pm On Nov 09, 2023
Ẹiyẹ Ìwó — Raven

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:15pm On Nov 09, 2023
Ologoṣẹ́ — Sparrow

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:56pm On Nov 09, 2023
Òdèrekókò — Laughing Dove

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:48pm On Nov 09, 2023
Ẹyẹ Ẹ̀gà — Weaver

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:47pm On Nov 09, 2023
Òwìwí — Owl

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:46pm On Nov 09, 2023
Pẹ́pẹ́yẹ — Duck

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:25pm On Nov 09, 2023
Zimri:
Boya Monitor lizard
Thanks bro
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:48pm On Nov 08, 2023
Àdàbà — Dove

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:48pm On Nov 08, 2023
Lékeléke — Cattle egret

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:44pm On Nov 08, 2023
Ẹyẹlé — Pigeon

Popular Proverb :

1. Ẹyẹlé Ò ni ba onílé mu, K'ó bá Onílé jẹ, K'o wa di ọjọ́ ikú, K'o yẹ'ri

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:36pm On Nov 08, 2023
Idì — Eagle

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:31pm On Nov 08, 2023
Odídẹrẹ́/Ayékootọ́ — Parrot

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:28pm On Nov 08, 2023
Ọ̀kín — Peacock

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:27pm On Nov 08, 2023
Igún/Igúnugún/Àkàlà — Vulture

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:21pm On Nov 08, 2023
Àṣá — Hawk

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 11:44am On Nov 08, 2023
Àwòdì — Yellow-billed kite

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:52pm On Nov 07, 2023
Àlégbà —

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:48pm On Nov 07, 2023
Ìjàpá — Tortoise

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:44pm On Nov 07, 2023
Ọmọnílé — Wall gecko

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:41pm On Nov 07, 2023
Aláyànbẹ́rẹ́/Aláǹbẹ́rẹ́ — Skink

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:35pm On Nov 07, 2023
Ọ̀gà/Alágẹmọ — Chameleon

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:33pm On Nov 07, 2023
Aláǹgba — Lizard

Akọ is Adárípọ́n
Abo is Abo Aláǹgba

Popular Proverb:

1. Gbogbo Aláǹgba L'ó Da inú De ilẹ̀, Ṣùgbọ́n Aò mọ Èyi ti inú ùn ro

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:22pm On Nov 07, 2023
Ìṣáwúrù — Fresh water snail

Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:20pm On Nov 07, 2023
Ìgbín — Snail

1 2 3 4 5 6 7 8 ... 15 16 17 18 19 20 21 22 23 (of 239 pages)