₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,327,150 members, 8,429,526 topics. Date: Friday, 19 June 2026 at 05:11 AM

Toggle theme

Raydos's Posts

Nairaland ForumRaydos's ProfileRaydos's Posts

1 2 3 4 5 6 7 8 ... 14 15 16 17 18 19 20 21 22 (of 238 pages)

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:41pm On Nov 07, 2023
Aláyànbẹ́rẹ́/Aláǹbẹ́rẹ́ — Skink

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:35pm On Nov 07, 2023
Ọ̀gà/Alágẹmọ — Chameleon

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:33pm On Nov 07, 2023
Aláǹgba — Lizard

Akọ is Adárípọ́n
Abo is Abo Aláǹgba

Popular Proverb:

1. Gbogbo Aláǹgba L'ó Da inú De ilẹ̀, Ṣùgbọ́n Aò mọ Èyi ti inú ùn ro

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:22pm On Nov 07, 2023
Ìṣáwúrù — Fresh water snail

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:20pm On Nov 07, 2023
Ìgbín — Snail

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:20pm On Nov 07, 2023
Ekòló — Earthworm

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:03pm On Nov 07, 2023
Alákàn/Akàn — Crap

Popular Proverb:

1. Ẹni Bá fẹ́ Wo Ishéjú Akàn, A pẹ́ L'éti Omi
2. Ojú Li Alákàn Fi ùn Sh'orí

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 6:59pm On Nov 07, 2023
Aláǹtakùn — Spider
Òwú Aláǹtakùn — Cobweb

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 6:52pm On Nov 07, 2023
Tanwínjí — Mosquito larvae

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 6:50pm On Nov 07, 2023
Àkeekèé/Òjògan — Scorpion

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op):
Àmọ̀tẹ́kùn — Cheetah

There's a lot of controversy surrounding if cheetah is amotekun or leopard or Tiger, But the true owner of the name amotekun is Cheetah

The reason behind this name is because of the resemblance between Leopard "Ẹkùn" And cheetah "Amotekun"


The meaning of:
Àmọ̀tẹ́kùn — The one who is known to look like Ẹkùn

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op):
Ẹkùn — Leopard

Ẹyá — Leopard Cub

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 6:32pm On Nov 07, 2023
Akika — Pangolin

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 6:19pm On Nov 07, 2023
Ewújù — hedgehog

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:03pm On Nov 07, 2023
Ikún — Ground squirrel

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:53pm On Nov 07, 2023
Àfè ìmòjò — Barbary striped grass Mouse

Àgó — Typical striped grass Mouse

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:52pm On Nov 07, 2023
Ẹ̀lírí — pygmy mouse

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op):
Ọṣà/Elégbédé — Chimpanzee

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op):
Ìlábùrù/irò — baboon

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:31pm On Nov 07, 2023
Akítì — Tantalus monkey

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:29pm On Nov 07, 2023
Ìnàkí — Gorilla

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:28pm On Nov 07, 2023
Òyo/Olóyo — Mona monkey

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:20pm On Nov 07, 2023
Ọ̀bọ Lágídò — White throated Guenon

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:19pm On Nov 07, 2023
Àáyá — Red colobus monkey

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:18pm On Nov 07, 2023
Òwè — collared mangabey

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:07pm On Nov 07, 2023
Ẹdun/Lámbẹ́/Alákẹdun — Ursine colobus

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:06pm On Nov 07, 2023
Ìjímèrè — Patas monkey

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:05pm On Nov 07, 2023
Ọ̀bọ — Monkey

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 11:48am On Nov 07, 2023
Ẹlẹ́dẹ̀ Igbó — Wild boar

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 11:40am On Nov 07, 2023
Ẹlẹ́dẹ̀ — Pig

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 11:39am On Nov 07, 2023
Túrùkú/Túùkú — River hog

CultureRe: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 11:31am On Nov 07, 2023
Ẹtu — Maxwell duiker

1 2 3 4 5 6 7 8 ... 14 15 16 17 18 19 20 21 22 (of 238 pages)