Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 6:38pm On Nov 09, 2023 |
Ẹiyẹ Afìyẹ́lúlù — Hummingbird
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 6:26pm On Nov 09, 2023 |
Àkókó — Woodpecker
Popular Proverb:
1. A ùn Pe Gbénàgbénà, Ẹiyẹ Àkókó Na ùn Yọjú
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 6:12pm On Nov 09, 2023 |
Ìbákà — Canary bird
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 4:13pm On Nov 09, 2023 |
Ògòngò — Ostrich
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 4:13pm On Nov 09, 2023 |
Àparò — Partridge
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 3:42pm On Nov 09, 2023*. Modified: 4:01pm On Nov 09, 2023 |
Adìyẹ — Chicken
Akọ — Àkùkọ Abo — Abo Adìyẹ Awọn ọmọ — Òròmọ Adìyẹ
Popular Proverb: 1. Kíkere L'abẹ́rẹ́ un kere, Ko kìí ṣe mímìn Fún Adìyẹ
2. Adìyẹ t'ó ṣu Tí kò tò, Ara rẹ̀ l'ó wà
3. Bi Ojú Akátá bá Li Ewo, Ṣe Ẹnu Adìyẹ L'ó yẹ K'á ti gbó-ọ
4. Àyè Kìí Há Adìyẹ, K'ó má lè dé ibi ti ẹyin to wà
5. Jàmbá Ti ó un kó Ẹyin lọ l'óri Àba, Ti A bá Dáké, Gbogbo Àkùkọ ìlú L'o ma lọ Síi
6. ìfẹ́ tí A fẹ́ adìyẹ kò de'nú, L'eyin kó dágbà K'a pa-a jẹ — Ibi pípajẹ L'o Mọ
7. Àgbà t'o so yàngán mọ ìdí, L'o sọ ara rẹ̀ di aláwadà fún Adìyẹ
8. Adìyẹ un sunkún Aìlẹ́yin, Àjànàkú ùn sunkún Ai-r'étè bo ti ri
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 3:18pm On Nov 09, 2023 |
Yanja-yanja — Snakebird/Anhinga
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 2:50pm On Nov 09, 2023 |
Àkàlàmàgbò — Ground Hornbill
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 2:48pm On Nov 09, 2023 |
Àtíòro/Àtíàla — Hornbill
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 2:36pm On Nov 09, 2023 |
Alápáǹdẹ̀dẹ̀ — Swallow
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:43pm On Nov 09, 2023 |
Ẹiyẹ Awó/Ẹtù — Guinea fowl
Akọ — Ẹtù Abo — Awó
Popular saying: 1. Àgbà L'ẹtù
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:40pm On Nov 09, 2023 |
Tòlòtólò — Turkey
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:30pm On Nov 09, 2023 |
Àdán — Bat
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:26pm On Nov 09, 2023 |
Ẹiyẹ Ìwó — Raven
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 1:15pm On Nov 09, 2023 |
Ologoṣẹ́ — Sparrow
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:56pm On Nov 09, 2023 |
Òdèrekókò — Laughing Dove
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:48pm On Nov 09, 2023 |
Ẹyẹ Ẹ̀gà — Weaver
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:47pm On Nov 09, 2023 |
Òwìwí — Owl
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:46pm On Nov 09, 2023 |
Pẹ́pẹ́yẹ — Duck
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:25pm On Nov 09, 2023 |
Zimri: Boya Monitor lizard Thanks bro |
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:48pm On Nov 08, 2023 |
Àdàbà — Dove
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:48pm On Nov 08, 2023 |
Lékeléke — Cattle egret
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:44pm On Nov 08, 2023 |
Ẹyẹlé — Pigeon
Popular Proverb :
1. Ẹyẹlé Ò ni ba onílé mu, K'ó bá Onílé jẹ, K'o wa di ọjọ́ ikú, K'o yẹ'ri
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:36pm On Nov 08, 2023 |
Idì — Eagle
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:31pm On Nov 08, 2023 |
Odídẹrẹ́/Ayékootọ́ — Parrot
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:28pm On Nov 08, 2023 |
Ọ̀kín — Peacock
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:27pm On Nov 08, 2023 |
Igún/Igúnugún/Àkàlà — Vulture
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 12:21pm On Nov 08, 2023 |
Àṣá — Hawk
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 11:44am On Nov 08, 2023 |
Àwòdì — Yellow-billed kite
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:52pm On Nov 07, 2023 |
Àlégbà —
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:48pm On Nov 07, 2023 |
Ìjàpá — Tortoise
|
Culture › Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos(op): 7:44pm On Nov 07, 2023 |
Ọmọnílé — Wall gecko
|