Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,630 members, 7,816,599 topics. Date: Friday, 03 May 2024 at 01:44 PM

Itan Akonilogbon - Literature - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Literature / Itan Akonilogbon (2367 Views)

Itan Alajo Somolu / Itan Sebi Otimo (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Itan Akonilogbon by oloriireomo(m): 1:17pm On Sep 11, 2013
Olorire Omokotuojiire Ejiworo
ODAJU OBINRIN

Gbogbo sanmori tin woko ati eyi ti n waya e dakun e naa suuru si o.a o ni bo s'owo eletan o.
Ife ti akinkunmi ni si omoladun ko lafi we rara.oun se'ke atiige re sungbon isesi omoladun si akinkunmi buru jai.
Lako-labo won loni ise gidi lowo wonsi ri ipo to joju dimu n'ibise won.
Banki ni toko-taya won ti n sise,oko n sise ni fedeliti banki niigbati aya n sise ni oseniiki.
Sungbon kinni kan loba ajao awon ololufe yii je,e o bimi pe kinni?ani apa re gunju'tan lo.la todun ti wonti so yigi igbeyawo, omoladun ko royun ni,ko loyun aaro d'ale ri.sibe-sibe e o lemo ohun ti won n la koja idinipe won kii je ki eti meji bawon gbo ohun tin lo laarin won.won kii ba arawon ja nitori airomobi,akinkunmi gbagbo pe olorun nii s'omo osi daju pe yoo se tawon naa t'asiko bato.
Isele kan sele looro ojo isinmi kan,awon omo ipeere meta kan wa bawon lalejo.awon omo yii jo omoladun bi imumu afi bi eni pe omoladun se "ho,tosi powan sile ni.egan ni he,won jo omoladun -un po.
ara n fu akinkunmi si iyawo re boya oun loti bi awon omo yii si'bikan kawon o to pade .o beere lowo re sungbon o je koye pe kosi nkan to jobe ati pe awon omo aburo oun ni won.
Leyin isele yi,akinkunmi se iwadi siwaju-ati siwaju si.eyin oreyin o r'okodoro oro pe omoladun ti ni oko nii gbakan ri. Wonsi ni awon omo meta.ki oko re to re'wale asa ni won ti feto s'omo bibi leyin omo meta.leyin ti oko re ku ni awon ebi oko re gbogun ti,koto dipe won gbemi re lofi keru jade ti osi fiile okore sile.o ko awon omo re meta naa lo sodo awon alabojuto.leyinnaa lowa bere igbe aye otun koto wa s'alaba pade akinkunmi.akinkunmi to sese bere igbese aye re lotun.niigba ti akinkunmi dele,o gbinaje.ofi ibinu da eru omoladun bagbo.o tito odun meedogun gbako ti wonti so yigi ti kosi somo laarin won.omoladun kosi jewo pe oun ti feto somo bibi tabi jewo pe oun ti lomo siibi kan tele ri.e o roju aye bi??
Wewa n sele ni juniyan.ana ni a gbo nipa seniyan seranko.e dakun se ara ko fu yin si omoladun bayi?se kii se eranko?bii kii se eranko,iwa eranko towu yi n ko?akosi bero.
Kinni oro iyanju ti e nifun akinkunmi?
Eledua yoo mo saa nu fun wa o
Re: Itan Akonilogbon by Mynd44: 1:20pm On Sep 11, 2013
I need to sit down for this
Re: Itan Akonilogbon by oloriireomo(m): 1:23pm On Sep 11, 2013
How?u dnt get it right?
Re: Itan Akonilogbon by Mynd44: 1:34pm On Sep 11, 2013
oloriire omo: How?u dnt get it right?
I am on the road
Re: Itan Akonilogbon by oloriireomo(m): 2:44pm On Sep 11, 2013
Mynd_44:
I am on the road
alright!!
Re: Itan Akonilogbon by oloriireomo(m): 3:33pm On Sep 11, 2013
Alright
Re: Itan Akonilogbon by slimfit2(m): 4:29pm On Sep 11, 2013
o ba ni ko ti baje..ki Akinkunmi wa iyawo tuntun si waju

1 Like

Re: Itan Akonilogbon by oloriireomo(m): 6:03pm On Sep 11, 2013
E seun lae.b'oro ile aye se ri nun-un
Re: Itan Akonilogbon by Wesslier(m): 6:42am On Sep 12, 2013
I guess dis is "tribalistic"... No harm anyway
Re: Itan Akonilogbon by wizb: 12:11pm On Sep 15, 2013
Hmmm

(1) (Reply)

****stories By Luxguy**** / Mom's Best Friend And I (18+ Romance) / Bolaji Agbekoya (the Pain Behind The Smile)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 19
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.