Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,786 members, 7,810,051 topics. Date: Friday, 26 April 2024 at 07:27 PM

Ifa, The Enchanted Verses - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Ifa, The Enchanted Verses (2283 Views)

Nigerian Origin Of Internet (ifa) In Yoruba Land / Origin Of Ifa / Ifa - The True Religion Of The Yorubas? (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Ifa, The Enchanted Verses by ladionline: 4:45am On Jan 01, 2014
Aboru, boye o...
Re: Ifa, The Enchanted Verses by ladionline: 4:49am On Jan 01, 2014
Olodumare, Oba ateni-lege-lege fori sapeji omi, iba o. Oba t'onile t'olaye, kabio osi Olodumare.
Re: Ifa, The Enchanted Verses by ladionline: 4:55am On Jan 01, 2014
Iba Akoda Aye, iba Aseda Orun. Iba yeye Iba baba. Iba iyami, Ajibola abeni Olotu-fe. Eye rere tii waje fawo.
Re: Ifa, The Enchanted Verses by ladionline: 5:01am On Jan 01, 2014
Iba atiwaye ojo, iba atiwo Oorun. Iba awon tonile tolaye, iba omo Alade gbogbo. Eje o ju mi se ooo.
Re: Ifa, The Enchanted Verses by ladionline: 5:09am On Jan 01, 2014
Asodunmodun nii sawo asodunmodun. Asosumosu nii sawo asosumosu. Eyin ajogun, eye E je kodun yi sanwa o, kilu tuba kotushe, kaboyun ile bi were, kagan o towo ala bosun, kire gbogbo 'o wawa wale tako-tabo. Ayunlo ayunbo, ni ko maa ba kowa wa, atero Ipo, atero Ofa, kamaa barawa ni ti harara ebo. kafefe rere o tugi oko lara, geru~geru.
Re: Ifa, The Enchanted Verses by ladionline: 5:16am On Jan 01, 2014
Ifa ori mi o gbebo, oran mi o gba etutu. Ere o lori agberu le o! Ori rere ntemi. Odu Irete nimo koko foni te, ire, ire. Oyeku mo ma ba o mule, bojumo ti nmo, Kiku o remi kete, karun o remi kete. Irete nimo te, Ire nitemi, iran ataare kan kii di tie laabo. Akii bale ayo laikun, e~wole ayo, e~womo.
Re: Ifa, The Enchanted Verses by ladionline: 5:23am On Jan 01, 2014
Igi kii da loko ko para ile, aja kii jin ko pero ona, efun ii fonjo koma la peregede! Nkasai la, peregede!
Re: Ifa, The Enchanted Verses by ladionline: 5:38am On Jan 01, 2014
Odi meji ni mo mo da o, ifa baba mi ni, Erigialo, Ifa, Barapetu nii koni loran bi iyekan eni, Ifa, Olokun-seni-Ade, Ope abise wara: Ifa ti mo ko te Odi nii je, ire nifa nfenu re so koto simi lenu, ire owo ire omo ire aiku jin~jin: ile ni mo joko si, ni gbogbo ire nwo tuurutu waa ba mi.
Re: Ifa, The Enchanted Verses by ladionline: 5:47am On Jan 01, 2014
Here now and forever more, peace and joy has met. This is the year of my dream, to usher in dreams beyond my wildest imaginations! So shall it be for you too, and I shall dwell in the house of God for ever more. Amen.

(1) (Reply)

Why Do Igbos Always Travel Every December / Post Your Favourite Videos Of Nigerian Girls Dancing / Does Westernization Equate To Civilization?

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 11
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.