Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,243 members, 7,818,833 topics. Date: Monday, 06 May 2024 at 06:16 AM

.. - Culture (34) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1829123 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (31) (32) (33) (34) (35) (36) (37) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by kadunasouth(m): 3:00pm On Nov 23, 2015
bwayomide:
eejo baba,ki ni oruko miran ti a npe ewe firiganmu?olohun a ran yin se oooooo.

Ewe olomuyinrin

3 Likes

Re: .. by lawani: 3:19pm On Nov 23, 2015
E ku ise opolo o. Olodumare a ma ran yin lowo o. Ase Edumare.
Re: .. by lawani: 4:09pm On Nov 23, 2015
Baba, m o ni ibeere kan ti m o fe beere ti e ba ni idahun is. E jowo kini itumo ala (mi mi) ti o jeyo ninu Obatala ati Orisaala. M o m o wipe ala (do do) tumo s i funfun, ala (do mi) tumo s I dream ni ede Geesi. Sugbon emi ko m o itumo ala (mi mi) ti owa ninu orisaala ati Obatala. M o ro wipe nla (big) ni tele sugbon ko da mi loju m o bayi. E se pupo.

Ibeere yi ko je m o ohun ti okun oro yi da le lori sugbon inu mi yio dun ti e ba le la mi loye. E seun.
Re: .. by Shomar: 4:44pm On Nov 23, 2015
E jowo. E fun mi ni ogun Agbara. Teyan nfi le koju awon enibi. Email mi niyi ajayioyewoles@gmail.com. Gbogbo ogun tebanfe, e le bimi. Ma se tinbani.
Re: .. by mondaylyno(m): 8:23pm On Nov 23, 2015
E jowo. E fun mi ni ogun Agbara. Teyan nfi le koju awon enibi. Email mi niyi Mondaylyno335@gmail.com. Gbogbo ogun tebanfe, e le bimi. Ma se tinbani.
Re: .. by kadunasouth(m): 10:39pm On Nov 23, 2015
bwayomide:
eejo baba,ki ni oruko miran ti a npe ewe firiganmu?olohun a ran yin se oooooo.
Ni oke oya niwan ti mani feriganmu kuwara nilorin wa ma ni feriganmu sugbon abeokuta ni west wan aman peni olomuyinrin, ewe olomunyinrin oni bi seed kinkin lara

2 Likes 2 Shares

Re: .. by keyguy59(m): 11:47pm On Nov 23, 2015
ASIRI NLA TI MO RI NINU IWE EGBGI AWON BABA MI.........NI AYE ATIJO BI OBINRIN LO ILE OKO....AWON BABA WA YIO FI MO BOYA IBALE RE YI WA NI BEE....KI OKUNRIN NA TO FE.......SUGBON BI OMO OBINRIN NA BA JEWO FUN BABA RE....OGBON AGBA WA TI WON YIO FI DAA IBALE NA PADA...............DANWO KI O FUN ILE LAABO RE BI OTI RI ...................Ogun ti ibale fin pada Sara obinrin( to regain
virginity>
Ewe ege were, owu Elena, lilopo, ao fipa ara eyin
adie, ao fi owu Elena yi eyin adie na, ao fi aso osu ti
obinrin na lo lowolowo we lawetan, ao mulo sinu
okiti ogan, ti okiti ogan yi babo, ibale(virginity ) yio padabo Sibe. ...................ASIRI NLA NI EYI OOOO...

3 Likes 1 Share

Re: .. by keyguy59(m): 11:53pm On Nov 23, 2015
<OGUN KI OBINRIN MABI ABIKU MO> Egbo sapo, egbo peregun, ako eyele, ose, igba olomori, ao ha ara awon egbo yen, ao gun mo ose dudu, ao la eyele yen laya, a ko ose yen sinu aya eyele yen, ao wa gbe sinu igba olomori yen, obinrin tabi omo tobi naa yio mafiwe. Ofore :- Ododun ni sapo nwu ewe, ososo ni peregun nse ofo iyare, ako eyele kini isimi, gbogbo eni toba nse oun buburu simi koma ni isimi.

1 Like

Re: .. by keyguy59(m): 12:33am On Nov 24, 2015
olorun ni oda owun gbogbo.......iba oooo....:........,.aye yi alo ni ojo kan......aye bo wa wo ewu enaa....aye bo wa sa.........aye bo wa fa ya ke de re.........iwa ibi o pee laye.....reeree lo yee ka ma se.........itori ojo ti aba ku.......ini tori ojo ti a ba file saso bo ra....owun lo di fa fun baba lawo to lo sogun aiku....egbo baba hearthfirst inje eni kan wa ti o niku saa..........eje ka ma ran ti atunbotan...........baba hearthfirst.........ese mi oooooooo mo ti te ate ji se si yin......ese wun ooooooooo
Re: .. by Nobody: 5:23am On Nov 24, 2015
ineedhelpfast:
E ku ise ni ibi yi o.
Iyalenu gbaa lo je Funmi wipe iru thread bayi wa ni Nairaland.

Ejowo, ibeere kan ti n gbe mi lokan tipe:
Mo se ise ni ile ise kan, won si ji owo ile ise na mo mi ni owo. 1.5million.

Ishele yii shele ni odun 2010.

QUESTiON
Nje o shi she se ki awon aye Bami mu eni ti o gbe owo naa, ki onitohun ka, ko she eleya and if possible, ko da owo na pada fun mi abi ko wa be mi?

Oro yi je ogbe okan nla funmi.

Eseun gan.

Awaiting response(s).


E kan si mi lori e-mail tabi ke call mi. Time and space have no control over the spiritual but the other way round. No secret is hidden from Esu laalu.
Re: .. by Nobody: 5:26am On Nov 24, 2015
keyguy59:
olorun ni oda owun gbogbo.......iba oooo....:........,.aye yi alo ni ojo kan......aye bo wa wo ewu enaa....aye bo wa sa.........aye bo wa fa ya ke de re.........iwa ibi o pee laye.....reeree lo yee ka ma se.........itori ojo ti aba ku.......ini tori ojo ti a ba file saso bo ra....owun lo di fa fun baba lawo to lo sogun aiku....egbo baba hearthfirst inje eni kan wa ti o niku saa..........eje ka ma ran ti atunbotan...........baba hearthfirst.........ese mi oooooooo mo ti te ate ji se si yin......ese wun ooooooooo

Kini a fi se yin? E ma binu si mi o, E jebure, Awo Olugbebe... Mi o ti ri e-mail yin o...bya ke tun send.
Re: .. by Lionhearted: 6:19am On Nov 24, 2015
keyguy59:
.
Bawo mo sele kan si yin?
Re: .. by keyguy59(m): 10:18am On Nov 24, 2015
awo kin binu si awo.....baba hearthfirst.......emi ni mo bee re fun ogun kan lowo yen lo ri email......
Re: .. by simlek: 11:59am On Nov 24, 2015
Àgò onílé o, onílé mo kágò o, Ewúré tó wolé tíò kágò deran àmú b'ofá, Ìran àgùntàn bòlòjò tó wolé tíò kágò deran àmú s'ètùtù. Áá júwaáse o, Àgbà ò sì níí tán l'órílè, bí àgbà ò bá tán l'órílè, Àá f'oláa won rìn, Àá sì fi yan fa-nda. Mo kí alàgbà ''Healthfirst, kàdúnásouth, keyguy59 etc'' àti gbogbo omo egbé ìkànnì yí lápapò, kò níí bàjé o, (Àse èdùmàrè).

1 Like

Re: .. by simlek: 12:27pm On Nov 24, 2015
keyguy59:
<OGUN KI OBINRIN MABI ABIKU MO>
Egbo sapo, egbo peregun, ako eyele, ose, igba
olomori, ao ha ara awon egbo yen, ao gun mo ose
dudu, ao la eyele yen laya, a ko ose yen sinu aya
eyele yen, ao wa gbe sinu igba olomori yen, obinrin
tabi omo tobi naa yio mafiwe. Ofore :- Ododun ni sapo nwu ewe, ososo ni peregun
nse ofo iyare, ako eyele kini isimi, gbogbo eni toba
nse oun buburu simi koma ni isimi.
Ekú isé takuntakun l'órí ìtàkùn yí o.
Re: .. by kayponpy20: 1:27pm On Nov 24, 2015
Ejowo oruko wo ni atunle mo Asunwon oyinbo si,Ajuse funwa o
Re: .. by ineedhelpfast: 3:16pm On Nov 24, 2015
Mail sent, kindly reply me. Thanks,


healthFirst:


E kan si mi lori e-mail tabi ke call mi. Time and space have no control over the spiritual but the other way round. No secret is hidden from Esu laalu.
Re: .. by ineedhelpfast: 3:24pm On Nov 24, 2015
Kini eyin tun fin shere bi omo ejo yi?

I ve gone to numerous alawos, pabo ni gbogbo e jasi, mo tun waste owoni. i had to gba kamu. olosanyin ti ko ba tun rami lowo so fun wa pe awon o kin mu ole but won fi ishele naa she akoba funmi ni lenu ise.

Deep down in my heart, i feel cheated, cos for anyone to steal such a huge amt and go scot free is d height of wickedness.

i hope to get REAL help on this thread sha.




Bosville:
Ki len wo lati ojo yii?? Eto awon alawo lo....Won ma fiyin mona.
Re: .. by Bosville(m): 5:03pm On Nov 24, 2015
ineedhelpfast:
Kini eyin tun fin shere bi omo ejo yi?

I ve gone to numerous alawos, pabo ni gbogbo e jasi, mo tun waste owoni. i had to gba kamu. olosanyin ti ko ba tun rami lowo so fun wa pe awon o kin mu ole but won fi ishele naa she akoba funmi ni lenu ise.

Deep down in my heart, i feel cheated, cos for anyone to steal such a huge amt and go scot free is d height of wickedness.

i hope to get REAL help on this thread sha.




Odo awon alawo te lo, iru awon ajo wo lo se funyin gan??
Re: .. by keyguy59(m): 7:56pm On Nov 24, 2015
se ri gbogbo ile.....eni ti won ji owo re yi...ti won ba ni kin so....ko le ri owo re mo....awon babalawo ako ma gba owo lowo re ni.....tori oti koja ojo meje......ka ni ko ti koja ojo meje ni...ise kan wa ti mole se si ti oni towun yio gbe owo na wa fun ara re... Sugbon oti koja......ema fi si adura.....
Re: .. by sammyjay76(m): 9:38pm On Nov 24, 2015
Eku dede asiko yi o gbogbo ile... ejowo eba wa fi Ogun apa o ka to daju sita ATI oGUN TI A LE SI MO TI WON BA GBE NKAN BURUKU SI ARA OBINRIN. ILU TI MO WA OPOLOPO NKAN NI WON SE FI GBA IYAWO ENIYAN, BI KI WON FI ERO, TABI MAGUN S LARA , TI OKO BA LU KI IYAWO LE JE TI WON.
Ejowo apa ota oni ka gbogbo wa o. Amin ASE.
Re: .. by rubber: 10:08am On Nov 25, 2015
healthFirst:
Oju Okun ko ni buru ki o mo lee fe ilele ilele awalawulu oju orun o ni wu koriko awon lo difa fun olokun seniade lojo ti gbogbo omi so pe awon ko niba se mo won ni ki o rubo ki gbogbo awon ti won lawon o ni ba se le maa ba se won yan lebo o rubo laipe laijina gbogbo awon omi ti won lawon o ni base yi ohun pada won wa nba olokun se wo si fi joba won won teriba fun un olokun seniade njo, o ni yo ooo ni bee lawon babalawo to se fa fun oun wi awon oju okun ko ni buru ki o mo lee fe ilele ilele awalawulu oju orun ko ni wu koriko awon lo difa fun Olokun Seniade lojo gbogbo omi so pe awon o niba se mo nje e ba mi se loni atewe atagba ewe asesere loni ki e ba mi se eku olose loni ki e ba mi se ogbo loni ki e maa gbo te mi ewe apada loni ki e padi ire gbogbo da si odo mi loni nitori ti moriwo ope ba yo a koju si Olodunmare Atewe Atagba e maa ba mi se

Ejowo baba kini gbolohun yi duro fun?
Re: .. by Ifadamilola30: 6:31pm On Nov 25, 2015
MOJUBA OLODUMARE!!! IBA Osanyin!! Orunmila, IBA!! Esu odara, IBA!! Eyin Iyami Eleye, IBA!! IBA agba, IBA Omode!! Moki gbogbo ile oo!! IBA gbogbo Eyin Awo oo!! Moki awon Ogberi pelu.!! IBA baba Healthfirst, baba Kanosouth, keyguy59, ati gbogbo eyin Awo ire/Onisegun ti e finnu-findo ti e si fowosowopo lati ko Ise lorisirisi sita lori thread yii..!! E ku ise takuntakun!! Orunmila a gbewa ooo. Gbogbo eni to ba fi tie sile to ngbo teni eleni, Odaju wipe OLODUMARE yio gbo tiwon na!! smiley cool

1 Like

Re: .. by Ifadamilola30: 6:34pm On Nov 25, 2015
cool
Re: .. by Ifadamilola30: 7:01pm On Nov 25, 2015
Baba Healthfirst, baba Kanosouth ati eyin Awo te wa nibi, e dakun awon aafani wo lowa ninu ki enia KO-FA, (Ki enia wo igbodu, ko si ni ifa ti a ma bo ninu ile Re) IFA KIKO! .. Awon aafani wo lo ro mon...
Re: .. by Nobody: 7:45pm On Nov 25, 2015
ineedhelpfast:
Mail sent, kindly reply me. Thanks,



I haven't seen it.

1 Like

Re: .. by ayokomi1010(m): 12:29am On Nov 26, 2015
E karo oooo,baba,ati Gbogbo omo odua,Igba akoko mi re Lori ikanni yi o,ama ju wa se o
Re: .. by ayokomi1010(m): 12:40am On Nov 26, 2015
Ogun Adodun Nla.ao toju aiyan kan ao lo ni enu ona wa ao wa fi ori po,ao ma fi wo nkan omokunrin wa ti a ba ti fe ba Obinrin ni ajosepo,be na ni Obinrin na le lo fun OKUNRIN ki o Sa ti fi pa oju ara re saju ki OKUNRIN to ba ni ajosepo,Adodun yi ni agbara pupo,Iba eyin agba oooooo,ewe ama je o.

2 Likes 1 Share

Re: .. by ayokomi1010(m): 3:04am On Nov 26, 2015
OGUN OSOLE AWORO WO OWO
Ao toju alangba tako tabo,owo eyo kudi 16,ao wa ya enu ako alangba na ao ko owo kudi 9 si ninu,ao ko meje sinu abo alangba na,ao wa fi ako tele inu ikoko ao gbe abo le,bi igbati won Jo se asepo ao wa fi igi nla die si egbe osi,odidi atare ni egbe otun,ao Jo papo,ao ni ro po rara ti a fi jo tan o,ao lo kunna Dada ao ma fi oti lo laro laro,opo ero ama wa si odo eni pelu owo nla. pelu ogo Olorun yio ri be odaju Dada,iba eyin agbalagba o

2 Likes

Re: .. by Ifadamilola30: 7:31am On Nov 26, 2015
smiley
Re: .. by Ifadamilola30: 7:32am On Nov 26, 2015
ayokomi1010:
Ogun Adodun Nla.ao toju aiyan kan ao lo ni enu ona wa ao wa fi ori po,ao ma fi wo nkan omokunrin wa ti a ba ti fe ba Obinrin ni ajosepo,be na ni Obinrin na le lo fun OKUNRIN ki o Sa ti fi pa oju ara re saju ki OKUNRIN to ba ni ajosepo,Adodun yi ni agbara pupo,Iba eyin agba oooooo,ewe ama je o.

Ewe a ma je oo!! E dakun se a ma gbe olo ti a o fi lo ise na si Enu Ona wa ni?? Abi ao lo ni ilele enu Ona wa ni??
Re: .. by ayokomi1010(m): 10:33am On Nov 26, 2015
[quote author=Ifadamilola30 ,ti aba fe lo Ogun adodun na,ale lo ni ori simenti tabi Ki a gbe olo lo enu ona

1 Like

(1) (2) (3) ... (31) (32) (33) (34) (35) (36) (37) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 41
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.