Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,154,117 members, 7,821,832 topics. Date: Wednesday, 08 May 2024 at 07:48 PM

.. - Culture (40) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1829636 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (37) (38) (39) (40) (41) (42) (43) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by Nobody: 11:09pm On Dec 07, 2015
x

2 Likes 2 Shares

Re: .. by Nobody: 11:11pm On Dec 07, 2015
omoalade144:
ejoo nibo ni a o gbe ipese na lo,atipe sebi woni ti eyan ban je okete,awon agbalagba yio ma ri ifun re,yio si rorun funwon lati baja??.Koni baje o

Ipese wo le n so?
Re: .. by keyguy59(m): 11:17pm On Dec 07, 2015
AKOYA ABENU GONGO TOGBONA: ewe ailu, ewe
kilofefimise, ewe mafowokan omo mi, ewe
atikaparare, ewe gbegbe, ewe tete, awo ekun die,
epo obo, odidin atare kan, ao lo wa ikaraun ibin to tobi
ninu igbo, (ibi ti won ba ge imo ewe ope eyin si, ni eti
le saba ri ikaraun ibin, tabi ki e so fun awon elewe o mo ki won ba yin wa, amo ko je ti korofo ikaraun ibin
tinu igbo gan gan, ao ko gbogbo awon eroja yi sii
ikaraun ibin na. Ao fi aso pupa bo ooo loju, a o fi owu
dudu ati funfun di ni iko bere ti ara re ko ni han sita,
(owu iranso lao lo) ao lo ri mole si orita meta ni oru
(night) fun ojo meta, to ba ti di ojo keta, ao lo wu kuro nibe ni ale, ao jo lai tu, ao lo kunnaa, ao da si meta, afi
idan kan: sin gbere yii abadi wa ka, ao wa sin bere
ejiogbe si (center) lona meta si isale re.
||
||
|| Ao fi idakeji: ao ko lose dudu, ao ko sinu iba funfun,
after 7days, lao fi we ni ago kan osan lekan soso.
AO FI IDA KETA: ao da sinu awo funfun ao we ni tira
pelu owu dudu ati pupa, ao fi aso pupa ran ni olounde
ao wa fi owu ibile dudu ati funfun we round ti olounde
yen ko ni han jade, ao ma wo si ibadi, after 7days ti aba ti fi ose yen we ni ao ma wo siidi.
AKIYESI: ao ni je ki omi kan oju gbere yen fun ajo meje
gbako, amo ele ma shin apa shin ese. Ao si ni ma fi
olounde yen we, ao ma bo (remove) ti aba fe we.
ISE OGUN YII: apota: se eyin gbo pe omi ti eyin wo igbin
lenu re ni ? ti won ba sa ogun siwa lati fi pe ori wa ni bi, oso ni, aje ni, elebologun ni, tabi emere, walahi
eninaa yio pa arare ni ooo.
Maran: ogun yii deenaa kiko aisan ni pa ibasun tabi ti
won ba le magun fun obinrin, ti aba ba ni ajosepo, tabi
ti won ba fi ogun gbawa, ko si nkan ti yo se wa
aforan: ojo ti ijanba ba fe sele si wa, o le je ija n ba MOTO, tabi OLE, or OGUN (war) ti nkan ba sele si gbo
gbo won, ko si ikan ti yio o sele si wa, lai fi arapa. Etc
Asegbe: ibi ti won ba niki gbegbe ma gbe ibe ni gbe,
ibi ti won ba ni ki tete ma te ibe ni n te, ti aba wuwa
ibaje ko si eni ti yio bi wa ooo

2 Likes 1 Share

Re: .. by fbabs(m): 12:25am On Dec 08, 2015
healthFirst:

Rara o...eo re oruka yen snu e ni o pelu awon eroja to ku.

E seun o
Re: .. by Hoyehwummy: 12:48am On Dec 08, 2015
Pls we nid 2 chat in private.
Re: .. by Nobody: 1:58am On Dec 08, 2015
keyguy59:
e jo...eni to ba ni ogun ti omo yahoo fi gbowo lowo client e todaju....orisa oke agbe wa ooo

ejo wo e bawa fi ero email yin sita
elekeji ni wi pe ogun ti e fun awa ololufe yin,i yen ogun igbin to bonu ati ose dudu fun oko lomokurim to kere ko sise rara funmi oo. ejowo kini mo tu le se?
Re: .. by omoalade144(m): 8:28am On Dec 08, 2015
IMULE FUN EYONU AYE 109 ni ipese ti mon so nipare o
Re: .. by Nobody: 8:54am On Dec 08, 2015
omoalade144:
IMULE FUN EYONU AYE 109 ni ipese ti mon so nipare o

Ipese yen, orita meta ni ao gbe lo.

1 Like

Re: .. by francisbarrack(m): 12:35pm On Dec 08, 2015
healthFirst:


OOGUN ALEKO
ori eJo sebe kan, ori alabahun kan. odidi Atare kan, ao Jo papo, ao wa lo ebu ogun po mo etu ibon gidi, ao ma fi fo eko tutu mun.

Sugbon eto itoju to muna doko wa fun ohun te beere sugbon kii se inkan ta le fi sori afefe. Orisi eto meta wa ti a ma n se ni sise n tele fun inkan omokunrin to ba kere tabi ko sise daada. E kan si mi lori e-mail...sugbon kii se ofe o.

Biiii eloooo niii.
Re: .. by Nobody: 1:40pm On Dec 08, 2015
[quote author=francisbarrack post=40804016][/quote]

E KAN SI MI LORI E-MAIL.
Re: .. by Ifadamilola30: 2:50pm On Dec 08, 2015
healthFirst:


Ewe laa yato si lapalapa...ti n ri picture re, ma post re later.

E seun lopolopo baba!! Ewe a ma je!!
Re: .. by aone4(m): 7:02pm On Dec 08, 2015
healthFirst:
110
Bi eeyan ba n je ounje loju oorun, ibere osi ile aye ni eyi, ifasehin ati aisan nla ni o ma n fa. Otito Oogun re niyi;

KI WON FE FUN WA NI ONJE LOJU ORUN KI AMA LE LANU GBA.
Isawuru kan, ao jo po pelu odindi atare kan ao fi sin gbere si isale ete wa. Gbere eyo kan.
Moki gbogbo eyin Awo owo aye koni tewa, no fi ELEDUWA beyin kini ale lo fun eni ti nba je nkan loju orun fun ojo pipe ti o nri apere osi (poverty) gege bi baba health se so?

1 Like

Re: .. by Shomar: 7:15pm On Dec 08, 2015
[font=Lucida Sans Unicode][/font]ajatuka ?
Re: .. by aone4(m): 7:23pm On Dec 08, 2015
healthFirst:
110
Bi eeyan ba n je ounje loju oorun, ibere osi ile aye ni eyi, ifasehin ati aisan nla ni o ma n fa. Otito Oogun re niyi;

KI WON FE FUN WA NI ONJE LOJU ORUN KI AMA LE LANU GBA.
Isawuru kan, ao jo po pelu odindi atare kan ao fi sin gbere si isale ete wa. Gbere eyo kan.
Moki gbogbo eyin awo ama juwa se o Mofi Eledumare beyin ti eyan ban ti je nkan loju orun fun ojo pipe ti osi ri apere osi (poverty) gege bi baba health se so, afikun eni yi tun so funmi pe enu (mouth) o man run. Edakun eti mi leyin fun ase yori fun eni yi emaje ki oju ti omo awo mofi Awan to laye be yin.

1 Like

Re: .. by omoalade144(m): 9:50pm On Dec 08, 2015
ise onje oju ala yi se eyan meji lelo.
Re: .. by Nobody: 3:41am On Dec 09, 2015
omoalade144:
ise onje oju ala yi se eyan meji lelo.

Isawuru kan, Eeyan kan.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 3:41am On Dec 09, 2015
aone4:
Moki gbogbo eyin awo ama juwa se o Mofi Eledumare beyin ti eyan ban ti je nkan loju orun fun ojo pipe ti osi ri apere osi (poverty) gege bi baba health se so, afikun eni yi tun so funmi pe enu (mouth) o man run. Edakun eti mi leyin fun ase yori fun eni yi emaje ki oju ti omo awo mofi Awan to laye be yin.

E wa ori abala yi fun awon eyi ta ti fi sita tabi ke kan si mi lori e-mail.
Re: .. by systembayo: 11:28am On Dec 09, 2015
ejoo eyin awo mo need itusile ti mo le se loni ti awon Iya yonusi mi .ti ko ni na mi lowo
Re: .. by Shomar: 12:59pm On Dec 09, 2015
E jor sir. Ti customer wa koni fiwa sile. Ajoo wo la le se.
Re: .. by omoalade144(m): 2:28pm On Dec 09, 2015
Moki gbogbo wa patapata pe aku dede asiko yi, ayo lao fi se odun tuntun lagbara eledumare.Ejowo moni ibere kan ti mo fe bere.Ibere mi na ni pe,ti eyan ba lala pe ohun ya igbe loju orun ejowo ki lo tumo si.koni baje o
Re: .. by Nobody: 2:54pm On Dec 09, 2015
Shomar:
E jor sir. Ti customer wa koni fiwa sile. Ajoo wo la le se.

Opolopo Awure lo ti wa lori abala yi sugbon te ba fe awon Aworo Nla tabi Afaro Nla, e kan si wa lori e-mail.

1 Like

Re: .. by sasxy(m): 5:01pm On Dec 09, 2015
ejo baba se eniyan pupo le lo.
Re: .. by omoalade144(m): 6:47pm On Dec 09, 2015
Ago onile o,ejowo moni ibere pataki kan,se ti eyan ba fi ogun owo tabi any ogun si apo ti obirin ton se nkan osu bafi owo kan yan se ole ba ogun na je.
Re: .. by Nobody: 8:04pm On Dec 09, 2015
sasxy:
ejo baba se eniyan pupo le lo.

le lo kini?
Re: .. by Nobody: 8:04pm On Dec 09, 2015
omoalade144:
Ago onile o,ejowo moni ibere pataki kan,se ti eyan ba fi ogun owo tabi any ogun si apo ti obirin ton se nkan osu bafi owo kan yan se ole ba ogun na je.

kii se gbogbo oogun ni inkan osu obinrin le baje
Re: .. by sasxy(m): 9:14pm On Dec 09, 2015
healthFirst:


le lo kini?
Ise ti e post pe eyan oni le gba ounje loju orun ni o.
Re: .. by Oluokunoluwole: 11:10pm On Dec 09, 2015
Baba healthfirst se eniti iyawo re ni oko orun emere,se oko orun le maa fa ifaseyin fun oko aye re ni,ti o bari bee,kini eeyan lese si.eran wa lowo oo
Re: .. by Nobody: 11:13pm On Dec 09, 2015
sasxy:
Ise ti e post pe eyan oni le gba ounje loju orun ni o.

Eeyan kan ni.
Re: .. by Nobody: 11:15pm On Dec 09, 2015
Oluokunoluwole:
Baba healthfirst se eniti iyawo re ni oko orun emere,se oko orun le maa fa ifaseyin fun oko aye re ni,ti o bari bee,kini eeyan lese si.eran wa lowo oo

Beeni...won yio ma di oko re lowo, won le fa aisan si lara...o tun seese ki iru okunrin bee ma le se deede gege bi okunrin lodo iyawo re. wahala nla ni. ki iru eni be mura gidi ni o.
Re: .. by Bostilo: 3:09pm On Dec 10, 2015
E kasan o baba healthfirst. E jowo monilo email address yin tabi nomber yin mofe ba ifa ni gbolohun. My own email is(abosedenaomi@gmail.com) please baba get back to me
Re: .. by Hybrid01: 4:35pm On Dec 10, 2015
e Jo baba,egbon mi kan ni isoro yi:nkan omokunrin e kii sise pelu iyawo e.o ti to bi odun merin bayi.won ti jo bimo kan ki wahala yi to bere o.won si ti wa solution titi won ko ri.kini a le se si?oko re a ma le ni ta!
Re: .. by systembayo: 4:46pm On Dec 10, 2015
ejo egba mi ooo eyin awo e fun mi ni Ogun ti Ori abami ban fo yan edakun e sanu mi ooooooo

(1) (2) (3) ... (37) (38) (39) (40) (41) (42) (43) ... (99) (Reply)

Viewing this topic: 1 guest(s)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 33
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.