Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,156,518 members, 7,830,536 topics. Date: Friday, 17 May 2024 at 02:39 AM

.. - Culture (55) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1830726 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (52) (53) (54) (55) (56) (57) (58) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by mondaylyno(m): 6:14am On Feb 13, 2016
Ekaro baba healthfirst .se kaba JO OGUN lori "kerosine stove" se oma sise abi ko ni sise
Re: .. by Nobody: 10:23am On Feb 13, 2016
mondaylyno:
Ekaro baba healthfirst .se kaba JO OGUN lori "kerosine stove" se oma sise abi ko ni sise

A le jo awon ogun kan lori kerosene stove sugbon eo gbudo lo Aluminium Pot rara. Ikeji ni wipe, awon oogun kan wa to je dandan ori aaro meta le ti gbudo jo won.

2 Likes

Re: .. by femiafolorunsho: 3:01pm On Feb 13, 2016
I will like to join the group also +22554828638

1 Like

Re: .. by asmondy(m): 3:29pm On Feb 13, 2016
healthfirst add me whatsap group 08024329020
Re: .. by Ginius95(m): 4:44pm On Feb 13, 2016
Creating a whatsapp group can't help matters on as regards the issues we are addressing, This thread should be allowed to continue as it assists numerous people all over the world, and it makes it accessible to numerous Yoruba indigenes far and wide also to promote our culture and heritage, we shouldn't allow this to be cut short which is the essence of a forum, where we would be able to share ideas and also make corrections, if there is any cause for us to correct those posting incomplete stuffs, then it should be noted and people can be notified as regards that, we should allow this thread to continue and people who are real Yorubas would be able to access it. We already have rules that stuffs should be written in Yoruba language which makes it comprehensible to only the Yoruba indigenes. Creating a whatsapp would be killing the essence of this thread. Thanks

3 Likes 1 Share

Re: .. by gbengaeba007: 6:49pm On Feb 13, 2016
[quote author=bosrote post=34909873]

Awon tolaye a ma ranyinlowo sir ....E jowo sir se lepo niyo lama se ise yen je abi bawo ni ase ma se je? e se pupu
Re: .. by Bostilo: 6:49pm On Feb 13, 2016
Titiloye247:

Am interested to join the group. Username: Titiloye247. Cellphone: 08034039830. Thanks sir.

Am interested too.

Numeber mi niyi- 07065707337

1 Like

Re: .. by gbengaeba007: 7:01pm On Feb 13, 2016
kadunasouth:

Awon tolaye a ma ranyinlowo sir ....E jowo sir se lepo niyo lama se ise yen je abi bawo ni ase ma se je? e se pupu

ASEJE OWO KIAKIA
Ata ijosi isu dandan ao lo po ao fi se odidi igbin kan je ao pe ohun yi si lodin din nio

Olu igbo fi igbin toro fun ero ona, gbogbo nkan ti dandan ba tenu mo, dandan ni kose, eyin to laye moni bukata iye owo bayi ki oto to ojo bayi . Ao je igbin na ni odindin, opari

3 Likes

Re: .. by gbengaeba007: 7:05pm On Feb 13, 2016
kadunasouth:

Mojuba eyin agbalagba o ewe a ma je o ejowo sa se lepo niyo lama se ise yen je abi bawo ni ase ma se je? e se pupu

ASEJE OWO KIAKIA
Ata ijosi isu dandan ao lo po ao fi se odidi igbin kan je ao pe ohun yi si lodin din nio

Olu igbo fi igbin toro fun ero ona, gbogbo nkan ti dandan ba tenu mo, dandan ni kose, eyin to laye moni bukata iye owo bayi ki oto to ojo bayi . Ao je igbin na ni odindin, opari

1 Like

Re: .. by Diamond666(m): 7:41pm On Feb 13, 2016
Inu mindun latidara po IFALOLA Diamond-666(08147119943)
Re: .. by belatoxx: 8:22pm On Feb 13, 2016
Babahealth first pls STOP this watapp things this forum was created to help people not like tis
Re: .. by Nobody: 11:07pm On Feb 13, 2016
healthFirst:

Did you read our rules on the first page about writing Ogun in English or any other Language apart from Yoruba? If you haven't, pls go back and read. It's against the rule of this thread to type Ogun in English...you may type in English you questions or observation but NEVER the Ogun.

This is the last warning.

Baba healthfirst : ee jowo ema binu fun ede englisi ti mo tayipu ni bi peji melo kan seyi... mo ti gba gbeni... ti eba pada seyin, mo ti lo paa re o. ee se o. ema binu lekan si
Re: .. by Nobody: 11:12pm On Feb 13, 2016
eejowo e bami modify post ti eti quote ti mi
Re: .. by kadunasouth(m): 11:32pm On Feb 13, 2016
[quote author=gbengaeba007 post=42895489][/quote]
Beeni lepo niyo

1 Like

Re: .. by kadunasouth(m): 11:35pm On Feb 13, 2016
Beeni lepo niyo
[quote author=gbengaeba007 post=42895587][/quote]

3 Likes

Re: .. by Nobody: 2:33am On Feb 14, 2016
Ginius95:
Creating a whatsapp group can't help matters on as regards the issues we are addressing, This thread should be allowed to continue as it assists numerous people all over the world, and it makes it accessible to numerous Yoruba indigenes far and wide also to promote our culture and heritage, we shouldn't allow this to be cut short which is the essence of a forum, where we would be able to share ideas and also make corrections, if there is any cause for us to correct those posting incomplete stuffs, then it should be noted and people can be notified as regards that, we should allow this thread to continue and people who are real Yorubas would be able to access it. We already have rules that stuffs should be written in Yoruba language which makes it comprehensible to only the Yoruba indigenes. Creating a whatsapp would be killing the essence of this thread. Thanks

This is a reasonable opinion, I would have love to adopt it as the solution to the issue of fake posters but you did not address the reason why I wanted to go on whatsapp. I would appreciate it if you or others could suggest ways to get these spoilers off the thread. The other time when I complained, thank God it yielded result; I saw some of them have created other similar threads...it's okay, as long as they desist from corrupting our work here.

Please suggest ways to keep them off then we can have solid reason to continue with the thread. It's better not to have this thread than to come here and copy incomplete oogun, waste money on them and create more problems for someone who came for solution.

2 Likes

Re: .. by starlord1(m): 4:30am On Feb 14, 2016
Ekaro o gbogbo omo odua. Ejowo oruko wo ni won tun pe EWE OJILE OLOSAN tori month bere lowo awon elewe omo won ni pe awon ko mo.
Re: .. by alhajialhaji(m): 8:28am On Feb 14, 2016
healthFirst:
IKEDE PATAKI:
Ao gbe eto yi lo sori whatsapp group nitori awon opuro ti won n fowo soya lori ayederu ogun lori ikanni yi ki o le seese fun wa lati ma yo won kuro bi a ba ti ri won. Ogun sise ati lilo kii se inkan ti o ye ki a ma pa iro fun awon eeyan. Bi oogun o ba pe tabi o je ayederu, o lewu pupo fun enikeni to ba je iru ogun be. Ao de fe ki awon epo to wa laarin alikama ba oruko wa je.
E dara po mon wa lori whatsapp number yi 08148398067, tabi ki e fi number yin sile nibi, ki a le add yin sinu group na. Iwulo Ewe Ati Egbo ni oruko group na. E dara po mon wa fun ojulowo oogun ati idaabobo lowo awon Oloogun eke.

07052905575....e add mi sori whatsapp group yin sir..
Re: .. by admolfemx(m): 10:57am On Feb 14, 2016
janle:
[FUN ANFANI ENI TON WA AYETA TO DAJU] ewe efirin, osedudu bi oni.[100]naira pelu oju olongbo kopo die. Ao gun ewe yi mo osedudu yi, ao te oju olongbo yi si lara. Ao ma fi we. Pelu kaninkan adayeba. Osi tun sise fun ada. Ao bu die sinu oti schnapes. Sugbon oni eewo o. Aye mo juba o.
E jo baba se pelu oju olongbo towa lara ose ye ni a maa fi oti lo,ekeji kini ewo re sir,e se pupo.
Re: .. by elegushichilling: 12:58pm On Feb 14, 2016
iba olodunmare, iba eyin agba gba ni ikani yi o. Lai fa oro gun. Eja (dog) ge mi je ni itan osi mi, lati igba ti ositi sele ni oti dabi pe kini kan jamije ni ese ibi ti oti ga mije, lehin ose die, kini na se mi ni owo osi, nigba ti ositun ya, obere sini se mi ni orun osi ati ori osi. Lasiko yi ni mo sare lo si ile iwosan, lehin ojo kejidinlogun (18 days) ti eja ti gemije. Won bere sini funmi ni rabbies vaccine. Ola ni yo pe igba ikeyin ti malogba abere (injection) toku. Sugbon dokita na fiyemi wipe, ohun ko le so boya otipeju. Nkan ti oje iya leni funmi niwipe, gbogbo ara apa osi ni on dunmi (pain) ti owa dabi wipe ori apa otun nikan lo'n sise.

Ejowo se agbo kan wa ti molemu tabi nkan ti molese wa ti olemu ailera yi kuro?

Ni ida keji, won ta ofa mo eniti oje oga mi lenu ise ni ese osi ti ese na siwu buruku lapa isale. Sugbon won gbe orisirisi nkan wa bi mumu ati fifi raa, ti won si tun fi ewe gbo, ositi faa, oti waale bayi. Se ofa yi na le nise pelu emi naa ni? Nibayi kata, era riro apa osi ati ori fifo apa kan lo'n bami ja. Ejowo eyin agba gba kini ero yin?
Lehin ose kan ati die ti eja gemije ni itan osi mi naa ni ese osi oga mi bere sini wu ti osi pariwo ara riro. Kosi enikankan ti otile mo ohun ti mohun la koja bayi ni ilewa. Omode ni mi o, eran mi lowo.
Re: .. by ALIUDAVID: 7:29pm On Feb 15, 2016
Ekale baba HEALTHFIRST, ejo oruko wo ni won tun pe "olu ogan" iba eyin to laye, iba agbagba..
Re: .. by heritagesat: 11:06pm On Feb 15, 2016
E da kun add mi 08134215966
Re: .. by Nobody: 4:39am On Feb 16, 2016
ALIUDAVID:
Ekale baba HEALTHFIRST, ejo oruko
wo ni won tun pe "olu ogan" iba eyin
to laye, iba agbagba..

E beere lowo awon elewe omo. Inu Okiti Ogan ni won ti man ri Olu Ogan...Ikan ni sugbon isale patapata lo ma n wa, o soro lati ri die.

1 Like

Re: .. by Ade231(m): 7:27am On Feb 16, 2016
kadunasouth:

Ogun to wa nisale yi egbiyanju kese gbogbo arun toropo ma nkan osu obinrin kia kia iwosan ati alafia yio de ba ni kia kia koda eni tiko se nkan osuri to ba ni anfani lati lo ogu yi kia kia ni yio bere si se nkan osu, nkan osu yio wa lasiko toye yio si mowo duro lasiko toye

ogun Obinrin ti kori nkan osure Tabi orun tabi onse segesege
Egbo paran pupa ati paran funfun ati bara nla kan ati enu opiye ose dudu bi oni 100 naira tabi 50naira babase fe kiopo si ni ati kanhun bilala epo osan wewe tabi kage osan wewe si meji meji ao jo papo yio month fi omin oronbo wewe mu ogun yi daju saka
Otun sise fun atosi, Aremo ati obinrin ti inu ma nrun lasiko to nse nkan osure odaju odaju
NB ta base ogun yi tan ao bu sibi meji sinu igo oronbo kan yio mamun dede cup toma nwa ninu schinap aimaye eyan lolelo ninu iseyi.

Baba healthfirst ese pupo esi Ku Ojo meji meta otipe ti emi na ti wa ori ikanni yi nipase kan tabi ekeji mo dupe pupo ewe yio ma je o gbogbo adawole yin yio ma yori si rere lagbara eledua ibaje koni to siyin ma lo se ise yi mo si mope yio je bi idan ni e o pe fun wa o Ase edumare

1 Like

Re: .. by Nobody: 8:47am On Feb 16, 2016
AKIYESI:

Eeyan kan san owo Iwe Iwulo Ewe Ati Egbo lati Ibadan sugbon address ti eni na fun wa ti sonu lori phone, e joo, ki eni na ba wa fi address ranse ki a le fi iwe ranse si. E seun.
Re: .. by Nobody: 11:42am On Feb 16, 2016
AKIYESI ATI IKILO PATAKI

Awon kan npe mi fun Oshole ti won ri lori abala yi...mo fe ko je ami idaniloju fun gbogbo wo wipe emi gegebi oludasile abala yi ko fi Ogun Oshole kankan sita ri rara. Idi ni wipe Ogun Oshole kii se Ogun lasan ti a le se bo ti wu wa. O lewu pupo fun eni ti ko mon nipa re daada. Orisirisi Oshole lo wa ati wipe eyi to ba Eleda re sise nikan lo le lo. Ki Babalawo to se Ise oshole fun yin, e je ki won se iwadi boya eyi ti won fe se ba Eleda yin sise. Opolopo lo n fi owo ati akoko sofo lori Oshole ti ko ba Eleda re sise. E je ka kiye sara. Inkan ti won n pe ni ogun kii se inkan amusere.

Emi gegebi enikan o le fi Osole sita nibi, sugbon te ba fe se Ise Oshole eyikeyi, ki e kan si mi lori e-mail tabi whatsapp, ao beere lowo Eleda yin ki a to dawole. Looto, a ma beere owo lowo yin sugbon e ma titori owo die te ma san ki e lo je inkan tio ye ke je. Ikilo mi ree o.

1 Like 1 Share

Re: .. by Kalamklm4ever(m): 1:07pm On Feb 16, 2016
healthFirst:
IKEDE PATAKI:

Ao gbe eto yi lo sori whatsapp group nitori awon opuro ti won n fowo soya lori ayederu ogun lori ikanni yi ki o le seese fun wa lati ma yo won kuro bi a ba ti ri won. Ogun sise ati lilo kii se inkan ti o ye ki a ma pa iro fun awon eeyan. Bi oogun o ba pe tabi o je ayederu, o lewu pupo fun enikeni to ba je iru ogun be. Ao de fe ki awon epo to wa laarin alikama ba oruko wa je.

E dara po mon wa lori whatsapp number yi 08148398067, tabi ki e fi number yin sile nibi, ki a le add yin sinu group na. Iwulo Ewe Ati Egbo ni oruko group na. E dara po mon wa fun ojulowo oogun ati idaabobo lowo awon Oloogun eke.

Numeber mi niyi- 08020407962
Re: .. by Nobody: 4:13pm On Feb 16, 2016
healthFirst:
AKIYESI:

Eeyan kan san owo Iwe Iwulo Ewe Ati Egbo lati Ibadan sugbon address ti eni na fun wa ti sonu lori phone, e joo, ki eni na ba wa fi address ranse ki a le fi iwe ranse si. E seun.
.
Re: .. by Nobody: 5:34pm On Feb 16, 2016
x

1 Like

Re: .. by elegushichilling: 10:32pm On Feb 16, 2016
elegushichilling:
iba olodunmare, iba eyin agba gba ni ikani yi o. Lai fa oro gun. Eja (dog) ge mi je ni itan osi mi, lati igba ti ositi sele ni oti dabi pe kini kan jamije ni ese ibi ti oti ga mije, lehin ose die, kini na se mi ni owo osi, nigba ti ositun ya, obere sini se mi ni orun osi ati ori osi. Lasiko yi ni mo sare lo si ile iwosan, lehin ojo kejidinlogun (18 days) ti eja ti gemije. Won bere sini funmi ni rabbies vaccine. Ola ni yo pe igba ikeyin ti malogba abere (injection) toku. Sugbon dokita na fiyemi wipe, ohun ko le so boya otipeju. Nkan ti oje iya leni funmi niwipe, gbogbo ara apa osi ni on dunmi (pain) ti owa dabi wipe ori apa otun nikan lo'n sise.

Ejowo se agbo kan wa ti molemu tabi nkan ti molese wa ti olemu ailera yi kuro?

Ni ida keji, won ta ofa mo eniti oje oga mi lenu ise ni ese osi ti ese na siwu buruku lapa isale. Sugbon won gbe orisirisi nkan wa bi mumu ati fifi raa, ti won si tun fi ewe gbo, ositi faa, oti waale bayi. Se ofa yi na le nise pelu emi naa ni? Nibayi kata, era riro apa osi ati ori fifo apa kan lo'n bami ja. Ejowo eyin agba gba kini ero yin?
Lehin ose kan ati die ti eja gemije ni itan osi mi naa ni ese osi oga mi bere sini wu ti osi pariwo ara riro. Kosi enikankan ti otile mo ohun ti mohun la koja bayi ni ilewa. Omode ni mi o, eran mi lowo.

ejowo baba healthfirst, ebami fesi si ibere mi loke yi. Mo ti gba abere rabies na pe, sugbon ojo to ye ki'n gba ti ikeyin ko ni mogba. Oye kin gba ni monday, mo wa gba ni tuesday, oni. Ni gba ti molo ni ala monday, won nipe awon ko ni abere na ni ile, wipe kin pada wa ni aro tuesday.

Ejowo Sir healthfirst, agbo wo ni mo lelo to le mu oro aja yi kuro lara mi patapata.
Re: .. by Nobody: 1:45am On Feb 17, 2016
A se atunko Akole abala yi fun awon idi ti yio di mimon fun gbogbo wa laipe. E ma binu wipe a ko wi fun yin ki a to se.
Re: .. by Nobody: 4:03am On Feb 17, 2016
healthFirst:
AKIYESI:

Eeyan kan san owo Iwe Iwulo Ewe Ati Egbo lati Ibadan sugbon address ti eni na fun wa ti sonu lori phone, e joo, ki eni na ba wa fi address ranse ki a le fi iwe ranse si. E seun.
.

(1) (2) (3) ... (52) (53) (54) (55) (56) (57) (58) ... (99) (Reply)

Viewing this topic: 1 guest(s)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 56
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.