Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,687 members, 7,809,598 topics. Date: Friday, 26 April 2024 at 11:48 AM

.. - Culture (35) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1827312 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (32) (33) (34) (35) (36) (37) (38) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by ayokomi1010(m): 10:40am On Nov 26, 2015
E karo gbogbo Omo Awo,ejo ti nkan omokunrin enia ba kereju ti enia kosi le ba obinrin sun ju ekan lo,ejo Ogun wo lale lo fun to ma sise kiakia,ese ewe amajeo

1 Like 1 Share

Re: .. by Ayomidegbenga1(m): 10:44am On Nov 26, 2015
ayokomi1010:
Ogun Adodun Nla.ao toju aiyan kan ao lo ni enu ona wa ao wa fi ori po,ao ma fi wo nkan omokunrin wa ti a ba ti fe ba Obinrin ni ajosepo,be na ni Obinrin na le lo fun OKUNRIN ki o Sa ti fi pa oju ara re saju ki OKUNRIN to ba ni ajosepo,Adodun yi ni agbara pupo,Iba eyin agba oooooo,ewe ama je o.

ejoo sir,kini won n pe ni adodun ati wipe kini itumo aiyan.

1 Like 1 Share

Re: .. by Ifadamilola30: 11:06am On Nov 26, 2015
E seun lopolopo, ajagunmale a duro tiyin!!
Re: .. by Ifadamilola30: 11:18am On Nov 26, 2015
Ayomidegbenga1:


ejoo sir,kini won n pe ni adodun ati wipe kini itumo aiyan.

Adodun!! Ni kukuru, ti obinrin ba nfi Ogun adodun pa oju ara, oko re yio gbadun re ju nkan miran lo. Bee gege fun okunrin to ba nfi ise yi pa nkan omokunrin re, obinrin to ba lo fun yio fe ko tun ma ba oun lopo si ni!!

Aiyan ni awon oloyinbo npe ni Cockroach!!

2 Likes

Re: .. by ayokomi1010(m): 12:39pm On Nov 26, 2015
ejo ajowo lalelo bi oko ba kere,ati ti enia o le ba obinrin sun ju ekan pere lo,edakun gbogbo Omo awo
Re: .. by Ade231(m): 1:33pm On Nov 26, 2015
kadunasouth:


Ewe olomuyinrin

Baba kadunasouth eku ise takun takun o,eledua yio ma ran yin se o ase ni tedumare,ejowo mofe oogun ti eeyan le lo fun obinrin ti nkan osu re nle ojo ti o si je pe ki ri be tele,sogbon awon igba kan wa ti oje pe laarin osu merin si marun ole mari rara ti yio ba si ri nigba miran o le je ojo meta sugbon eleyi ti o nse lowo bayi ti nlo bi ojo meje abi mejo bayi,ejowo mofi eledua beyin ni ki e fun mi ni oogun ti a le lo si ti o ba wa,ma ma reti esi yin ojo.ese pupo ao ma ri yin ba ni agbara olorun,ase.
Re: .. by fbabs(m): 2:31pm On Nov 26, 2015
healthFirst:
OGUN TI OBINRIN KI FI KO OHUN ENIYAN
Eyin adie kan ao lu lori ao fi orii si, ao fi adi si, ao fi epo pupa sii,ao fi oruka si ao gbele ao ri mole ao loyo ni ojo keje ao ma ki bowo tia
ba fe ba obinrin soro
. Se a o da tinu eyin nu ni abi ao ko ni da tinu eyin nu

2 Likes

Re: .. by Nobody: 3:25pm On Nov 26, 2015
fbabs:
. Se a o da tinu eyin nu ni abi ao ko ni da tinu eyin nu

Rara o...eo re oruka yen snu e ni o pelu awon eroja to ku.

2 Likes

Re: .. by Nobody: 3:30pm On Nov 26, 2015
x

1 Like

Re: .. by Nobody: 3:52pm On Nov 26, 2015
x

1 Like

Re: .. by Nobody: 4:28pm On Nov 26, 2015
x

1 Like 1 Share

Re: .. by scholes0(m): 5:19pm On Nov 26, 2015
Ifadamilola30:


Adodun!! Ni kukuru, ti obinrin ba nfi Ogun adodun pa oju ara, oko re yio gbadun re ju nkan miran lo. Bee gege fun okunrin to ba nfi ise yi pa nkan omokunrin re, obinrin to ba lo fun yio fe ko tun ma ba oun lopo si ni!!

Aiyan ni awon oloyinbo npe ni Cockroach!!

Se Aiyan ni tabi Aayan?

1 Like

Re: .. by lanjum(f): 8:57pm On Nov 26, 2015
E jowo o kinni eniyan le lo nigbati Ato omokunri ko ba le domo.
Re: .. by kadunasouth(m): 9:50pm On Nov 26, 2015
Eyonu Ebe Awon Agba
Igi Asorin(igi nla)) epo obo iye igun akopa eyokan ao lo gbogbore ti yio kuna ao wa dasinu adi eyan ao ma fi para odaju sugbon oni eewo eyokan ijo kijo tabati lo ise yi akogbodo lo turare yala fi para abi fi saso odaju

3 Likes

Re: .. by bwayomide: 10:23pm On Nov 26, 2015
adagba yowokowo olohun o ni fi si inu oro yin baba,mo dupe fun idahun yin si ibere mi,mo dupe lowo olohun ati eyin baba mejeji ti e ntowa sonan,mo nri iyato ninu aye mi lowolowo,e jo ohun ti o ku fun mi ni alanu ati aranse,e jo baba,inu mi adun gidigidi ti e ba le fun mi ni ogun ti eeyan fi nri alanu.e sehun baba.olohun a ran yin lowo ooooooo.

1 Like

Re: .. by BookieMan: 10:37pm On Nov 26, 2015
kadunasouth: .

Pardon my use of English.

Sir, may God bless you for the good work but kindly avail us the use of comma to separate each and every items from each other.

Makes it easier to buy from the elewe omos.
Re: .. by Ifadamilola30: 11:22pm On Nov 26, 2015
healthFirst:
102
ALA WIPE OKUNRIN NI IBALOPO LOJU OORUN( Ifasehin ni Awon Aye ma n fi eyi se fun eniyan)
E lo wa osun abalaye ki e loo ni ileele pelu eyo ataare meta ki e fi sin oke inkan omokunrin yin si oke ki o je meta pere, eo ji laaro kutu ja ewe ewuro ki oorun to yo yoo je 201, ao gbo 200 sinu omi ao gbe si oorun laaro ao da eyo ataare 7 si ao fi owo meta daa bi agbelebu, ao fi sibe, ao gun eyokan ti o ku mose ti e le fi we leekannaaa ao se(sieve) omi yen n ao gbe omi yen ao lo fi we ose yen ni ale ki a to lo sun. Pelu ase Olohun gbogbo ona ti won ba di mon wa yo si patapata

Adura yin a gba, baba!! Edumare koni fiyin sile! E jowo iru osun wo ni osun abalaye??

1 Like

Re: .. by Ifadamilola30: 11:28pm On Nov 26, 2015
scholes0:


Se Aiyan ni tabi Aayan?

Inkankan na ni!!
Re: .. by omoalade144(m): 1:54pm On Nov 27, 2015
Moki gbogbo awo ati awa ogberi lori owu yio.Ejoo moni ibere pataki kan ti mofe bere o.Ejoo se awo ifa na ni awo tangaran atipe kini oruko miran ti awo tangaran nje
Re: .. by Nobody: 2:19pm On Nov 27, 2015
Ifadamilola30:


Adura yin a gba, baba!! Edumare koni fiyin sile! E jowo iru osun wo ni osun abalaye??

E beere lowo awon elewe omo.

1 Like

Re: .. by Nobody: 2:23pm On Nov 27, 2015
lanjum:
E jowo o kinni eniyan le lo nigbati Ato omokunri ko ba le domo.

A ko le dahun ibeere yin pelu Oogun kan pato...stages ni aisan low sperm count lara okunrin ati wipe, o je dandan ka koko treat aisan to fa aisan low sperm count ki a to le fun iru eni bee loogun low sperm count, bi beeko, yio kan ma lo oogun lasan ni. E kan si mi lori e-mail mi(check the first page for my e-mail)

1 Like

Re: .. by omoalade144(m): 6:15pm On Nov 27, 2015
ejoo se awo ifa ni awo tangaran ni
Re: .. by Snowealth: 7:35pm On Nov 27, 2015
E jowo mo ni lo atuwo to lagbara fun eniyan ti aye n da laamu, to be ti ise re daru. E jowo e fi ran mi lowo.
Re: .. by mondaylyno(m): 10:14pm On Nov 27, 2015
Baba ejo se mole ri ogun ti oko okunrin yho fi gborin dada yato si eyi ti efum waBaba ejo se mole ri ogun ti oko okunrin yho fi gborin dada yato si eyi ti efum waBaba ejo se mole ri ogun ti oko okunrin yho fi gborin dada yato si eyi ti efum wa
Re: .. by Sobandemojisola: 6:44am On Nov 28, 2015
mi
Re: .. by ayokomi1010(m): 10:23am On Nov 28, 2015
Aye mojuba o,moki gbogbo ojogbon ti olorun ni Ki won mafi tewetegbo se Omo araye lore,e Jo mobere Ogun kan tosi dunmi lokan,e si Dami loun ejowo mofi olodumare be gbogbo ile,Ogun na nipe ti nkan Omo kunrin ba kere ju OJO ori re lo,atipe oyun funfun Jade ni nu nkan omokunrin re,Ki le Ba obinrin lajosepo ju ekanlo ti a fi sunlo,kini mole lofun ejowo,baba ati gbogbo ojogbon e sanumi
Re: .. by Nobody: 2:08pm On Nov 28, 2015
.
Re: .. by Aluqman(m): 9:31pm On Nov 28, 2015
e dakun irufe oruka wo la le lo fun ise yi, se oruka irin ni abi eyikeyi. e seun
Re: .. by Aluqman(m): 9:49am On Nov 29, 2015
healthFirst:
OGUN TI OBINRIN KI FI KO OHUN ENIYAN
Eyin adie kan ao lu lori ao fi orii si, ao fi adi si, ao fi epo pupa sii,ao fi oruka si ao gbele ao ri mole ao loyo ni ojo keje ao ma ki bowo tia
ba fe ba obinrin soro


eku owuro o baba, mo n fe alaye lori egbogi yi daa daa mo fun eni mi kan kosi ri ise re. Mo lero wipe ko se ise na daadaa ni. Iru oruka wo ni ale lo se oruka irin ni abi eyikeyi, ti eyin adie na ba fo nigba ti aba fe yo jade leyin ojo meje se ko bawi. A ma ri yin ba o.
Re: .. by Aluqman(m): 10:32am On Nov 29, 2015
Iba Akoda Iba aseda. Iba Agba Iba omode Iba okunrin Iba obinrin Iba onile Iba alejo eje ko ju wa se o.
ONFA RIRISE (ITAJA)
A o pa omo onile kan iru re ko gbodo ge, a o so sinu ado kekere a o fi isebe die si a o fi paper di enu ado na, a o we ni owu dudu ati funfun fifi ko si enu ona shop tabi ile itaja. Egbogi yi kere amoo aje bi idan ni. Iba Agba o.
Re: .. by Aluqman(m): 10:33am On Nov 29, 2015
Iba Akoda Iba aseda. Iba Agba Iba omode Iba okunrin Iba obinrin Iba onile Iba alejo eje ko ju wa se o.
1.
ONFA RIRISE (ITAJA)
A o pa omo onile kan iru re ko gbodo ge, a o so sinu ado kekere a o fi isebe die si a o fi paper di enu ado na, a o we ni owu dudu ati funfun fifi ko si enu ona shop tabi ile itaja. Egbogi yi kere amoo aje bi idan ni. Iba Agba o.
Re: .. by kadunasouth(m): 11:34am On Nov 29, 2015
Ade231:


Baba kadunasouth eku ise takun takun o,eledua yio ma ran yin se o ase ni tedumare,ejowo mofe oogun ti eeyan le lo fun obinrin ti nkan osu re nle ojo ti o si je pe ki ri be tele,sogbon awon igba kan wa ti oje pe laarin osu merin si marun ole mari rara ti yio ba si ri nigba miran o le je ojo meta sugbon eleyi ti o nse lowo bayi ti nlo bi ojo meje abi mejo bayi,ejowo mofi eledua beyin ni ki e fun mi ni oogun ti a le lo si ti o ba wa,ma ma reti esi yin ojo.ese pupo ao ma ri yin ba ni agbara olorun,ase.
Ogun to wa nisale yi egbiyanju kese gbogbo arun toropo ma nkan osu obinrin kia kia iwosan ati alafia yio de ba ni kia kia koda eni tiko se nkan osuri to ba ni anfani lati lo ogu yi kia kia ni yio bere si se nkan osu, nkan osu yio wa lasiko toye yio si mowo duro lasiko toye

ogun Obinrin ti kori nkan osure Tabi orun tabi onse segesege
Egbo paran pupa ati paran funfun ati bara nla kan ati enu opiye ose dudu bi oni 100 naira tabi 50naira babase fe kiopo si ni ati kanhun bilala epo osan wewe tabi kage osan wewe si meji meji ao jo papo yio month fi omin oronbo wewe mu ogun yi daju saka
Otun sise fun atosi, Aremo ati obinrin ti inu ma nrun lasiko to nse nkan osure odaju odaju
NB ta base ogun yi tan ao bu sibi meji sinu igo oronbo kan yio mamun dede cup toma nwa ninu schinap aimaye eyan lolelo ninu iseyi.

2 Likes

(1) (2) (3) ... (32) (33) (34) (35) (36) (37) (38) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 34
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.