Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,154,175 members, 7,821,982 topics. Date: Wednesday, 08 May 2024 at 11:34 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (11) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (197963 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (8) (9) (10) (11) (12) (13) (14) ... (100) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:43am On Mar 03, 2009
HeatFusion:

rotflmao, awe, without the translation, I wouldn't have been able to understand your yoruba ekiti.

Mehn, I read it like 5 times, still didn't get it grin grin

E se n o, sugbon, ko n se emi le feron. Moyola lo [own heart] yin, nkan te so fun mi ni ye ooooooooooooooo.

n gba te so fun mi, mo sukun di e, then mo yo yin kuro lo kan mi cry cry cry E hurt mi o, e hurt mi gidi gan gan ni. sad sad

B.T.W, se omo Ekiti tabi omo Oyo ni yin? wink

Omo ipinle Ondo lemi o, sugbon ilu mi (Ijare - ti a mo si I.J. city) pelu Ikere Ekiti dijo ni ala kan ni. Nitorinaa ede kan na ni awa ati Ekiti nso.

Iwo naa mo wipe mo feran re tokan tokan, iwo saa ti se temi; mo ma fi gbogbo aye mi fun o ni wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 1:41am On Mar 04, 2009
farotika:

Omo ipinle Ondo lemi o, sugbon ilu mi (Ijare - ti a mo si I.J. city) pelu Ikere Ekiti dijo ni ala kan ni. Nitorinaa ede kan na ni awa ati Ekiti nso.

Iwo naa mo wipe mo feran re tokan tokan, iwo saa ti se temi; mo ma fi gbogbo aye mi fun o ni wink
ahhh awan omo Ondo. . . .awam rivals mi tongue tongue

lol o feran mi ke? oje stop am o, se o moh pe iyawo ogebi kan ni mi shocked shocked

Ahhhh gbogbo aye e ke? omo, maa se yen o. . . . shocked shocked
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 2:05am On Mar 04, 2009
Heatfusion,

Ewo ni epe, Toyosi ko ni ko mi sile o. A le breakup.

Mo ri wipe iwo ati farotika tin plan nkan cool cool wink wink wink wink wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 2:09am On Mar 04, 2009
Eyah, broda dayo, mo ti miss yin gan. . . .

Like, where have you been hiding sef? Hope everything dey kampe.

Since my sis is away, I gotta look after you now eh. Yippe grin grin

Anywaz, I got ur message, just listened to it. . . . I still dnt know what my oriki is oooooooo.

Farotika? ema da lo hun jare. That boy dey do ashewo plenty, get women for every corner of this forum.

e think say I go fall for his tricks sad sad tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 8:00am On Mar 04, 2009
HeatFusion:

Eyah, broda dayo, mo ti miss yin gan. . . .

Like, where have you been hiding sef? Hope everything dey kampe.

Since my sis is away, I gotta look after you now eh. Yippe grin grin

Anywaz, I got ur message, just listened to it. . . . I still dnt know what my oriki is oooooooo.

Farotika? ema da lo hun jare. That boy dey do ashewo plenty, get women for every corner of this forum.

e think say I go fall for his tricks sad sad tongue

Se o ri nibi ti o ti do ashewo ri ni

O je jawo ninu apon ti o yo, dayo o feran re rara, o ti ni ololufe tie. Iwo se temi leni ki o wa ri bi mo se ma fi adun s'aye e grin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 4:05pm On Mar 04, 2009
Farotika,

Di omo yen mu daada O feran re gidi gaan ni Ojojumo lo man soro nipa iwo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Hauwa1: 4:57pm On Mar 04, 2009
e ku isime o ara ile.

awon ara adugbo, kilon shele ni bi yi?

humming . . . guguru perere epa perere
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 10:41pm On Mar 04, 2009
Mo nrii yin o! cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 1:13am On Mar 05, 2009
farotika:

Se o ri nibi ti o ti do ashewo ri ni

O je jawo ninu apon ti o yo, dayo o feran re rara, o ti ni ololufe tie. Iwo se temi leni ki o wa ri bi mo se ma fi adun s'aye e grin cheesy
rotfl

Yes na, mo ri e o. . . .nibi to tin "holla at them gals" tongue

Talo feran bro dayo? abeg, that's my brother oooooooo shocked shocked

adun aye bawo. . . .bi eyin okurin se n soro ni ye tongue tongue tongue

dayokanu:

Farotika,

Di omo yen mu daada O feran re gidi gaan ni Ojojumo lo man soro nipa iwo
shocked shocked shocked shocked shocked ehrrrm ehrrrm. . . .hmmmmmm angry angry shocked shocked Our secret grin

*Hauwa*:

e ku isime o ara ile.

awon ara adugbo, kilon shele ni bi yi?

humming . . . guguru perere epa perere
You, you. . . .why I dey mind you sef. No be Dayo u dey find for here grin grin tongue

Moyola:

Mo nrii yin o! cool
I sure hope so o. . . .no be 4 eyes u get? shocked shocked shocked
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 1:21am On Mar 05, 2009
HeatFusion:

I sure hope so o. . . .no be 4 eyes u get? shocked shocked shocked

Yu knw!!. . . hehe! sowa? Okoh e nko? cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 1:22am On Mar 05, 2009
Moyola:

Yu knw!!. . . hehe! sowa? Okoh e nko? cheesy
aburo mi, mowa pa jare.
Oko wo? se e fe fun mi ni rich brother yin ni? cool grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Hauwa1: 2:52am On Mar 05, 2009
Heat how you dey smiley dayo ke? is he in the SEAL?
if only grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 3:55am On Mar 05, 2009
*Hauwa*:

Heat how you dey smiley dayo ke? is he in the SEAL?
if only grin
I dey o. . . .
Yes na, dayo is in the SEAL. . . .don't you see his rippling muscles from cleaning the unit floors? shocked
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 8:05am On Mar 05, 2009
E ku deede iwoyi o. Se ara nle
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 3:39pm On Mar 06, 2009
HeatFusion:

aburo mi, mowa pa jare.
Oko wo? se e fe fun mi ni rich brother yin ni? cool grin

Se o l'oko (koboko) ni shocked shocked shocked
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 6:46pm On Mar 07, 2009
farotika:

Se o l'oko (koboko) ni shocked shocked shocked
Ahhhhhhhh ejo ooooo. . . .see this ashewo bobo. tongue
I meant oko as in husband ni o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bababuff(m): 6:18pm On Mar 09, 2009
Dede omo yoruba, ki ti gbe o!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 9:32am On Mar 10, 2009
bababuff:

Dede omo yoruba, ki ti gbe o!

O gbe iree undecided
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by FBS: 1:25pm On Mar 11, 2009
pls is o4kasibe a yoruba word? grin

omo Egba se wa?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 2:51pm On Mar 11, 2009
FBS:

pls is o4kasibe a yoruba word? grin

omo Egba se wa?

Beeni o, pelu amii:

mi mi mi mi do.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 2:58pm On Mar 11, 2009
ogbeni farotika

oto'jo meta ti a soro gbeyin

ema binu si mi rara. Ise lantu lantu ti Obatalapipipi Oluwaseun gbe le mi l'owo ni ko ke ki n'raye yoju si ori eto yii.

Nise ni awon obirin ati okurin ti won wa ni ipinle oroife (romance section) ni ilu nairaland ni ko je ki n'gbadun.  sad

N'je eti ri ogbeni goodasi to pa jesu oyingbo je tabi babsongudus ni adugbo yii? Mo ni oro pataki ti mo fe ba won so o, eni keni to ba ri won ko ba mi so fun won o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 3:48pm On Mar 11, 2009
lol! pele di e!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 5:00pm On Mar 11, 2009
Moyola:

lol! pele di e!
maa so pele fun omo ti ori e gbeske ye.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 5:08pm On Mar 11, 2009
Ebony-Silk:

maa so pele fun omo ti ori e gbeske ye.
s'emi lo n'bawi? Iwo omo alaileko yii, ma f'ejo e sun farotika.

To ba setan pelu e, waa je iyan e n'isu. angry tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 7:01pm On Mar 11, 2009
debosky:

s'emi lo n'bawi? Iwo omo alaileko yii, ma f'ejo e sun farotika.

To ba setan pelu e, waa je iyan e n'isu. angry tongue
emi ni omo alaileko? wowwwwwwwww, debo, o ti n hurt mi o. pelu ebubu e.

Kini Farotika a se? A kan so fun mi "baby mi, ko da now, jo, take e easy on debo". grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 7:20pm On Mar 11, 2009
Ebony-Silk:

maa so pele fun omo ti ori e gbeske ye.

Hehe! kilo se fun e nau? sha take e eazy pelu e! tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:51pm On Mar 12, 2009
debosky:

ogbeni farotika

oto'jo meta ti a soro gbeyin

ema binu si mi rara. Ise lantu lantu ti Obatalapipipi Oluwaseun gbe le mi l'owo ni ko ke ki n'raye yoju si ori eto yii.

Nise ni awon obirin ati okurin ti won wa ni ipinle oroife (romance section) ni ilu nairaland ni ko je ki n'gbadun. sad

N'je eti ri ogbeni goodasi to pa jesu oyingbo je tabi babsongudus ni adugbo yii? Mo ni oro pataki ti mo fe ba won so o, eni keni to ba ri won ko ba mi so fun won o.

Baba ni debo, bawo ni ore, se o njolifikeeti.

Nipa ti ogbeni judaasi, rara o , goodaasi, o dabi pe omo naa ti lo p'okunso o nitoripe o pe ti mo ti gbo nipa re gbeyin.

Awon omo onidi regede yen nkan, se won o jasi sa wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 12:53pm On Mar 12, 2009
Ebony-Silk:

maa so pele fun omo ti ori e gbeske ye.

Haba iyawo mi, se arugbo ni o npe ni olori gbeske shocked shocked Jowo ma se be mo o kiss
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 1:06pm On Mar 12, 2009
farotika:

Baba ni debo, bawo ni ore, se o njolifikeeti.

Nipa ti ogbeni judaasi, rara o , goodaasi, o dabi pe omo naa ti lo p'okunso o nitoripe o pe ti mo ti gbo nipa re gbeyin.

Awon omo onidi regede yen nkan, se won o jasi sa wink
ore mi atata farotikky mo n'jolifikeeti gidi gaani. Koda igbadun ti fe yi mi lorun! grin

Oro buruku ma leyi o! Ejoo ki le ro pe ole fa ki goodaasi lo p'okunso? Se awon omoge o fun ni adun ti n'be laarin itan won ni tabi se o je gbese nla ti ko le san ni? Ara adugbo e dami lohun o! Ema dake je ki a ma ri ogbeni goodaasi o!

Sori omo ti o n'pe ni aya re Ebony yen, omo onibaje gbaa ni. Kilo fe fa ki omo ikoko yen ma w'enu si agbalagba lara? Abi arifin ileegbe ko ni a n'pe yen ni? Sora ko si kilo fun daa daa o. Ibinu mi kii da rara o.

Bawo ni e de se yanju oro dayokanu ati ennyluv? Nje omo yen ti pada si ile oko re DK sha?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by farotika(m): 1:31pm On Mar 12, 2009
debosky:

ore mi atata farotikky mo n'jolifikeeti gidi gaani. Koda igbadun ti fe yi mi lorun! grin

Oro buruku ma leyi o! Ejoo ki le ro pe ole fa ki goodaasi lo p'okunso? Se awon omoge o fun ni adun ti n'be laarin itan won ni tabi se o je gbese nla ti ko le san ni? Ara adugbo e dami lohun o! Ema dake je ki a ma ri ogbeni goodaasi o!

Sori omo ti o n'pe ni aya re Ebony yen, omo onibaje gbaa ni. Kilo fe fa ki omo ikoko yen ma w'enu si agbalagba lara? Abi arifin ileegbe ko ni a n'pe yen ni? Sora ko si kilo fun daa daa o. Ibinu mi kii da rara o.
Bawo ni e de se yanju oro dayokanu ati ennyluv? Nje omo yen ti pada si ile oko re DK sha?

Je ki nso ooto oro fun o nipa goodaasi: Nigbati awon omoge elese teere yen ti bere si fi baba s'ako (nfi tage) ni o ti gba ile oloti lo ti o si fi ara re fun oti guda.

Ti o ba ri bobo yen nisinyi, aanu re maa se e. Oti ti yi ori e patapata cry cry

Nipa ti adumaradan temi nikan, jowo saanu iyawo mi o. Se o mo 'pe eyin agba le ma nso wipe: Omode o ni mo eko ije ki o ma ra lowo. Omode ni o nse; mo maa ba soro nigbakugba ti a ba ti wo yara lo cool

Se o ri ogbeni dayo yen, oro e ti sun mi patapata, nitooto, won ni kinni re tobi tobee ge ti ennyluv ko jale pe oun o ni le fi i sile. Ennyluv ti di mario si dayo lorun o, nibe lo maa ku si lipsrsealed
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 10:38pm On Mar 12, 2009
farotika:

Haba iyawo mi, se arugbo ni o npe ni olori gbeske shocked shocked Jowo ma se be mo o kiss
oje warn ore e dada. ori e bi ori gbeske grin grin
e dey vex me jare. bawo ni? wink

debosky:

Sori omo ti o n'pe ni aya re Ebony yen, omo onibaje gbaa ni. Kilo fe fa ki omo ikoko yen ma w'enu si agbalagba lara? Abi arifin ileegbe ko ni a n'pe yen ni? Sora ko si kilo fun daa daa o. Ibinu mi kii da rara o.

Bawo ni e de se yanju oro dayokanu ati ennyluv? Nje omo yen ti pada si ile oko re DK sha?
se iibunu mi lo wa dara? oje ma try e. . . .ta ba wo sokoto kan, emi ni ma koko jade ni nu e. beware tongue

and BTW, leave my bro alone o. dayo gotz berra taste than ennyluv cool cool cool

farotika:

nipa ti adumaradan temi nikan, jowo saanu iyawo mi o. Se o mo 'pe eyin agba le ma nso wipe: Omode o ni mo eko ije ki o ma ra lowo. Omode ni o nse; mo maa ba soro nigbakugba ti a ba ti wo yara lo cool

Se o ri ogbeni dayo yen, oro e ti sun mi patapata, nitooto, won ni kinni re tobi tobee ge ti ennyluv ko jale pe oun o ni le fi i sile. Ennyluv ti di mario si dayo lorun o, nibe lo maa ku si lipsrsealed
emi ni omode? shocked shocked shocked shocked am old enough to born you twice shocked shocked shocked angry angry hmmm.
mo ti biinu
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 12:40am On Mar 13, 2009
debosky:

Bawo ni e de se yanju oro dayokanu ati ennyluv? Nje omo yen ti pada si ile oko re DK sha?

Ori Ennyluv ni DK wa bayi, tori e ni ko se le respond cheesy

(1) (2) (3) ... (8) (9) (10) (11) (12) (13) (14) ... (100)

Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá / Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 51
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.