Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,016 members, 7,817,994 topics. Date: Sunday, 05 May 2024 at 02:40 AM

Yoruba- Oro Agba - Literature - Nairaland

Nairaland Forum / Entertainment / Literature / Yoruba- Oro Agba (2862 Views)

"Oro's Victim" A Short Story By Tosan Tarre / Chronicles Of Woli Agba: No Dulling (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Yoruba- Oro Agba by fatigs88: 2:43pm On Dec 01, 2015
Adura Alufa Borode gba:

Tani ko tun maa tan ara re bi Alfa Mosalasi Otun. Leyin irun ale lo gbadura si Oluwa pe ki O le oun ati janmo jina kuro lodo esu- eni eko eni egbe. Alufa Borode o ye muti bee ko ye tefa- wose fun awon 'alejo'. Aya- alaya lo n ba se asepo. Isele kan to bami ninu je ju ni eyi ti o sele ninu Osu Lamulana. Omoge binrin kan lo n wa oko. Dindinrin omoge yii ti mo fi oruko bo lasiri wa oko de odo Alfa Borode. Kii se pe oun naa ni lokan lati fe Alufa yii, oun ti o gba lero ni pe Borode yoo ba ohun se 'ise' ti yoo fa oko wa ba oun. Ka ma soro gun, meji ninu awon janmo ka Alufa Borode po pelu omoge yii ninu mosalasi losan gangan awe! Ibanuje okan gbaa. Ibere nla ni pe: Bawo ni bi ba Alufa ni ajosepo yoo se di oogun aje-bi-ina fun oko fife? O ma se o. Aimokan mokan a si maa da awon eeyan lamu. Bee ni oro Alufa Borode ri. Ko tuba, bi o se n se tele naa lo si tun n se. Igba mo n koja legbe mosalasi ni irole ana, ti mo gbo ti Borode n sadura fun ara re ati 'janmo' re ni mo ba mi kanle. Adura yoo gba looto pelu ogelete ese ti o moomo da, tiko si tun jawo.

#AyF™
©2015

1 Like 1 Share

Re: Yoruba- Oro Agba by fatigs88: 6:21pm On Dec 08, 2015
Ojo ibi o ra gaari loja Akesan. Nonba lasan ni ojo ori. Ohun a gbe ile aye se lo pataki.
Re: Yoruba- Oro Agba by OYAY(m): 1:16pm On Dec 09, 2015
A dara fun yin pelu ede abinibi wa ti e fi n ko itan Alfa Borode yii. Oodua a gbe wa oooo! ! !
Re: Yoruba- Oro Agba by fatigs88: 9:03am On Dec 14, 2015
OYAY:
A dara fun yin pelu ede abinibi wa ti e fi n ko itan Alfa Borode yii. Oodua a gbe wa oooo! ! !

E seun seun. E maa ba mi bo. Yoruba dun- un gbo s'eti fun eni ti o ba mo o.

(1) (Reply)

Pacesetters Novels - PDF Download / The Ghost In Our Compound / My Random Thoughts

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 11
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.