Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,350 members, 7,957,932 topics. Date: Wednesday, 25 September 2024 at 03:40 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Proudly Ekiti's Indigene Panegyric (oriki) (19711 Views)
The 'dying' Yoruba PANEGYRIC (Oriki), An Idea For Its Preservation. / Lets Know The Full Oriki Of Your Home Town.. / Oruko, Oriki And Orile, The Genius Of The Yoruba In Human Nomenclature (2) (3) (4)
Proudly Ekiti's Indigene Panegyric (oriki) by Bigajeff(m): 12:29am On Sep 19, 2016 |
Proudly Ekiti man. ORIKI PANEGYRIC OF EKITI INDIGENE; AAYE EKITI: Omo eleku lele lele ona Aaye,Eku Senu Omode Aaye o mu kete ö ra gburin. ADO EKITI: Omo Ado Oora Amukara sabe ewuje, Ikara se meji i temi lukoko, Ado mei yunle oni kobe osilo monu AGBADO EKITI: omo owa omo ekun omo alagbado orara, aimona gbe sinu agbado AISEGBA EKITI: aisegba aguda omo apalufin omo olulu orokeiroloru lasura omo odoja supon-na lasura ARA EKITI: Omo alara tin dara,ara la o mada ,awa o ni daran ARAMOKO EKITI: omo alaramoko l'ejidogbon agogo ude; alara m'oi pori isa okan i ki mi ' a roko aga o, ara ara pelu ife'jumo k'agbara ga k'ara ye wa' k'ara san wa; Ara ulu ayo ARAROMI-UGBESHIEKITI: omo elesi adu ile adu oko ARE EKITI: Omo oyi ajawa nfe murinmurin lule AWO EKITI: omo alagodo abeni memu,omo oloke ijisun eru ko yu.omo eguru sotita ona oke ijisun. AYEDE EKITI: Ayede geri attah, osoko ekiti soko akoko, o sakoko rigborigbo. AYEDUN EKITI: Omo elesun a payiya yeye AYEGBAJU EKITI: Ayegbaju obalu odagun lule odagun loko omo alale kemun tisan bomi AYEGUNLE EKITI: Omo amoro epa reni, Omo amuda sile mogun erun pani AYETORO EKITI: Elo ajana omo agbo o yo erun odi, Omo owa omo ekun, edu iju omo akin,omo ofabere gunyan ki idi gberigbe ona ma mo. Omo oluku k'aso ibo,omo abadin hanran hanran. EFON-ALAYE EKITI: omo oloke ko moke igun,oke ko malayei tile ogun,omo edu ule haun efon kumoye, Omo Oke Wa Foona Oke Sora Dotaa,Eji gberekede,Eji gbimorodun ERIJIYAN EKITI - Omo Elerii njiyan kan da’de, akun weji weji, Omo alaye more Oko ido ale iye, Omo Elegigun iwaju ji’ tehin nrina, Omo Elegigun le ju ade kan soso, Omo adegigunsori-eko weji weji EMURE EKITI: Omo Elemure aoro ora, elemure i japari usu, ei jemulolo udi re, aarin usu ni kan mu a kelemure mi aje, Emilomo eso orita egiri oke, Emure ijaloke afisu foloore EPE EKITI: Epemuke moale omo elepe lologun igi lasan lara oko unbo ERINJIYAN EKITI : omo oloja odo omo oloja odo aboyesun, omo erin adigunbo ERINMOPE EKITI: Omo eridu'ora omokuku be korantan i hanomo han ke bi han be i dun han Eeemope Omo Eridu 'ora ERIO EKITI: Èdú Èrìò ọmọ agbe mùsúù kẹlẹ, ọmọ ọtayeye lugbọn-ọn mibọbọ joye, ibọbọ jolodeode, ibọbọ jọta epo, ọmọ oloke meji takọ tabo, ajoji baa i gori olodeode, ọta epo larosi de a. ESUN EKITI : omo elesun oyinbo omo elesun orinjeyeweere ESURE EKITI: Omo Elesure okese. EWU EKITI: Omo Ewu Ogidi uda, omo amudasile mogun enupani EYIO EKITI: omo a muda sile kogun eni pani IDO EKITI: omo udo oganganmodu ama gbado ekuru resin, iha lomo alagbado ayaiya tan aiha a ya, aire a ya arimona gbe sinu agbado IDO-ILE EKITI: ile Omo Ajinare mope oye, omo owa omo ekun, omo ajisunhan,omo ajire ni, omo amojo gbogbo dara bi egbin,omo alagogo ajilu gbingbin ni sosi,omo onibata kero kalokabo lona adura omo oni bata kerokalo-kabo lugbi mo rusimi onigbagbo. IFAKI EKITI: Ifaki orinkinran, omo atijo ogun lele boorun maakin. Esi keejogun ijale udo ona ifaki lii ha. Omo okorobo lila isuko firi ona eyika more. IGBARA-ODO EKITI: Omo eleye i se weyeweye ati dori ogun IGBEMO EKITI: omo elefo sigbemo oba yii efo san bi eni releefo romi oko ra lona igbemo IGBOLE EKITI: omo olurara agbagba tile oyi biribiri goke lagbe igbole odo IGEDE EKITI - omo elemi nigede amadiye sereke, elemi igede niwi ki mi gbadiye sin, mowi me i sinye omi, oni laso mo mu kigede soro, agboku mariwo na mi selewo yuyu IGOGO EKITI: igogo obiri; omo awoko merin tia gbe foruru obe je egberin okele, ekiri oke omo amain urukan jaraba iyan igogo sebora onielaya edese IJAN EKITI: Omo ijanmodu alagada ogun, omi ki ijan i mu ni ijan we esi; omo elega arisagba.eru ko sagba nibe arija ayaba,ari sagba arija olori IJELU EKITI: Ijelu mojo omo olodi atalemo, omo alayuwa ajoji ko wese, ajoji koba wese adoni ebo lulera lono ije IJERO EKITI: omo owa Omo ekun, omo ejio omo oriomu,omo olose meji takotabo,omo amomohoko toutobo udi re IJESA-ISU EKITI: omo ijesamodu,omo eleni ewele,omo ameo usu dahun se,omo a woro labe usu yaa gbe lolo odikeji,omo ikaka i so'su diro diro loke amu,omo a muda silemogun erun pani.omo agbagba roke orire yaa lu, omo ehon kitipa ona 'jesa kii'jesa moja kii'jesa modeyo, laka ule ra lona IJURIN EKITI: Ijurin moje! Omo alaran ojiji, omo amuda sile mogun enu pani, akuku beni lori ya jogun enu lule ijurin omoagbara sa yaya lori eguru. IKERE EKITI: omo oloke meji takotabo, omo aba gbami eye gbami, agbagba fiafia alapa faari, omo oju kee boju leru omo eleo jeun ree omo ekun omo erukuluji, omo ukere kete oniyan ana olosunta orun ukere orole baba oke. IKOGOSI EKITI: omo olomi meji, gbigbona ati titu.. nibi o tipade IKOLE EKITI: Elekole o balaya aso, Ikole to tala bose, e i sepe hon run ma so se, eshi idale ti a ni, Ikole lomo olose meji gbarimi rimi kan le. Ikole run ma aso se kin tala mo sha; atala bose, keru ba adiye funfun. IKORO EKITI; Omo eso obe so ikoro mudapariko omo eruku yoyo onah obe yajogun enun lobe ooooo, ireke aragan idun bi ogan iyo, ireke aragan idun bi oyinmomo. IKUN EKITI: Emi lomo ikun amure,omo elero mumu ona oja,omo abeja i se wotowoto enu asoro ILAWE EKITI: omo alawe ko tori wiwe ko makuro soja,ko wi kun naja-naja kun bomi a lura lona Awe ILOGBO EKITI: ilogbo okere,abewe usu gbagangbagan ILORO EKITI: Omo oloro erijugbin Ari jugbin ranje mu karahun muni, omo olotorojo nse ori opalele ILUKUNO EKITI: ilukuno ose omo a min ranyin bi ogo iyo ILUPEJU EKITI: Ulupeju la me a, Omo Eso ooruta merun wese,Omo Oke lila ti moto layaa, omo egiri oke arogunse bi ega IPAO EKITI: ipao ileji ogbe omo amugbo sodi orogba omo onile imole ajeji kowo ajeji toba fipawobe laimepo laimuyo ammebose IPOLE ILORO EKITI: ipole omo asewi leremeta kale to le IPOTI EKITI: upoti ala, omo amewe eni j'iyan, awa lomo eleniewele,omo amekuru jeko. IRE EKITI: iremogun omo awuse, omo owu ti n wuko gbinrin-gbinrinlagbede. N ba tete waye omo enimeta ni n bamaa se, n ba jomo, , n ba jomo alakara maa ma roun fi wan enun, n tun jomo alagbede ma finanloju-finanle masagban isale woriwori IRO EKITI: Uro adidi,omo amugbayeo IROPORA EKITI: iropora ajija emure ule ewa ubi kan sewa iyunISAN EKITI: Isan moge, omo asote monru, oloro agogo, omoamuda sile mogun erun pani.omo owa omo ekun omo olodi,odi re atile mo,ooni ke mo rin un modi mo omo elepa omo awo ISAOYE EKITI: Isaoye akoko alakoko ororo giro omo amugba buwo ISE -EKITI- Omo Akin je'Efon. Omo a gbure Agudugbu s'oju odi k'ari j'Efon Use ya yan. Ugbo kan mo'sii si kan si d'Use, a mo foo oun le iijugbo Aje a l'Use. Adabalukosi lo ba loriigi l'oja Odo, kan p'ugba Ode jo. Oni mo tita libe, o ta ogun ifon. A ri mo tita libe, o t'oji akofa. Ugbogbo kukuruku la gbogi l'oja odo, k'Adabalukosi fo lo, Emi omo ogidan,o gun mo gara, Omo at'eran mo ta'ho. ISINBODE EKITI: isin obi omo olobedu woroworo,obe kan seke kute ule jerun omo oni simi ITAJI EKITI: omo Itaji òpó kìtìpà léyìn Èkìtì, mii k'opo ma ja kíEkiti mó dêyô, Èwí í bèmí ùdì, Ônítâjî í bèmí èsûn'sû ôkô, Èwímí yoo jùdì, Ônítâjî mí yoo mó ó jóná, un i kôsé ôlójà méjì màá bá tùbá mi Ônítâjî â lô ITAPA EKITI: Eso oruta ejiri oke,omo onimeya ule meya oko,omo asibeota yayinyo IWOROKO EKITI: Ihoroko de ile ouro ile ouro omolore la me ia ogun i pa ihoroko omo aroloyen IYE EKITI: Omo alagere kijipa suko firi ona, omo oloke meji tako tabo IYEMERO EKITI: OMO ni sedo ewa,omo ori mogun je,awa lomo awo foo sise..ofi omo foko to n ti kini abere, Omo onihun didun lodo di. IYIN EKITI: Awa lomo eso orita Egirioke. Uyin logun Uyin lota. Ulu kan rije rimu tan ke i deni lora; Omo alaede KOTA EKITI: Omo Elekota ogunroyin soye, agun soye bi oyinbo. Omo oriire d'ade. ODOOWA EKITI: omo eleni ewele,omo oke lila ti moto laya, olegin lodoyin ololua lode udogun. omo abu oba ma se, omoala ideu,omo egin,omo epa, omo otokorojo sori opa lelele OGOTUN EKITI: omo ologotun ojorube, omo eleni ateeka,omo eleni ewele,omo amuru ekun sere nibuje,Eja gbogbo dade,towena dade akun. OKE-AYEDUN EKITI: omo adagbalu, omo adelila pa OKE-ORO EKITI: omo alaure ladao para seji,omo alaure san yaya gunta. Omo amekikun modi,omo alaure la Okeoro paraseji aka kan tolokore,okan re ti apetu OKEMESI EKITI: omo oloja oke ni di ogun,omo fabunmi orara lada. omo afaganja omo arogun yo. omo oke agbonna,omo oke ludi ogun atiri ogun OMU EKITI: Omo olomu aperan omo oloro,Agogo omo amuda sile mogun erun pani akuku beni lori san jogun erun lo lona omu OMUO EKITI: Omo eleye meta oro kashakasha, iko ina, iko oorun, iko koku osupa a tani yayaya, Omo olomuo kerejekereje omuo ore, OMUOOKE EKITI: Omo Olomi Ajire,omo alaroju ja ka, omo gbo gbo bi oro, omo o ba ma aja je tan o a ga ro bo ruu n oo,omo eleye meta o roo ka ta ka ta,meta la pa, meta la un la ORA EKITI: Omo Olora airijuru ugba, arijuru lora mo yogiri sapo ORIN EKITI: omo elero ajeja sanra ero sapodi supepe ero kun derun latete eru ibudo ORUN EKITI: Omo apariko odu ule aro omo ologba arin ko okoroti kion ti moni, ire joba lopoto o orire se ki moba sale ayare,awelejo mo ri lo sagbala yaa senu sogini miki weise libe nii meise ori re meise agbon re. OSAN EKITI: omo olosan mojo,olosan abedu omo inu odi, omo olosan mojo, omo arowora mo ra hin, omo aladodo,awo gbeseti lodo atiba, omo aforosinu bo atare lowo, omo amebi sinu ko nje OSI EKITI: Osi asise omo elegberin uwo, omo a meruko ude ba Ooni sala (agbe) ale, omo a muda sile m'ogun enu pa'ni, akuku be lori moyajogunenulo,omo olosimefu, omo afiju agbere suaa omo ameruko oko boonin sagbe ale, olumonle meji werewere OSUN EKITI: Omo olosun bipesi riro, omo Olosun ri tanna ode, Osun mokun Ijunmu, Omo Ajiboye OTUN EKITI : Otunmoba, Omo enireke agbejo; omo olodi atile mo, Omo Ireke Aragan Idun TunMayan Idun, Ireke Ria Idun Booyinmonmon, Omo Oloro An Se, Keran Mon Je, Kaaguntan Mon Je, OtunMoba Osere Omo Akinla Lotun, Omo Olorogbo Kiji Lotun OYE EKITI: omoloye morauife, kei tana osi gangan,mo asorosiku otutu si, omo alago ajilu gboin gboin nijo ose TEMIDIRE EKITI: omo onisopo omo oloke agunmootadi omoagesiwonwon boko USI EKITI: Usi oro, omo atoko bo mohun sibi kan ni USIN EKITI: omo aoyo yo oni gbo, gbo ti n ti eyin eku Ekiti Yeye oo, hin okun oo kete Ekiti se ala ni oo. ire oo! Feel free to comment which town in Ekiti you rep #irepekiti 5 Likes 1 Share
|
Re: Proudly Ekiti's Indigene Panegyric (oriki) by Bigajeff(m): 12:31am On Sep 19, 2016 |
I rep Ikole Ekiti |
Re: Proudly Ekiti's Indigene Panegyric (oriki) by Walionemperor(m): 2:26am On Sep 19, 2016 |
iRepIgboleEkiti |
Re: Proudly Ekiti's Indigene Panegyric (oriki) by ayitasitis(m): 5:35am On Mar 25, 2019 |
[quote author=Bigajeff post=49480475]Proudly Ekiti man. ORIKI PANEGYRIC OF EKITI INDIGENE; AAYE EKITI: Omo eleku lele lele ona Aaye,Eku Senu Omode Aaye o mu kete ö ra gburin. ADO EKITI: Omo Ado Oora Amukara sabe ewuje, Ikara se meji i temi lukoko, Ado mei yunle oni kobe osilo monu AGBADO EKITI: omo owa omo ekun omo alagbado orara, aimona gbe sinu agbado AISEGBA EKITI: aisegba aguda omo apalufin omo olulu orokeiroloru lasura omo odoja supon-na lasura ARA EKITI: Omo alara tin dara,ara la o mada ,awa o ni daran ARAMOKO EKITI: omo alaramoko l'ejidogbon agogo ude; alara m'oi pori isa okan i ki mi ' a roko aga o, ara ara pelu ife'jumo k'agbara ga k'ara ye wa' k'ara san wa; Ara ulu ayo ARAROMI-UGBESHIEKITI: omo elesi adu ile adu oko ARE EKITI: Omo oyi ajawa nfe murinmurin lule AWO EKITI: omo alagodo abeni memu,omo oloke ijisun eru ko yu.omo eguru sotita ona oke ijisun. AYEDE EKITI: Ayede geri attah, osoko ekiti soko akoko, o sakoko rigborigbo. AYEDUN EKITI: Omo elesun a payiya yeye AYEGBAJU EKITI: Ayegbaju obalu odagun lule odagun loko omo alale kemun tisan bomi AYEGUNLE EKITI: Omo amoro epa reni, Omo amuda sile mogun erun pani AYETORO EKITI: Elo ajana omo agbo o yo erun odi, Omo owa omo ekun, edu iju omo akin,omo ofabere gunyan ki idi gberigbe ona ma mo. Omo oluku k'aso ibo,omo abadin hanran hanran. EFON-ALAYE EKITI: omo oloke ko moke igun,oke ko malayei tile ogun,omo edu ule haun efon kumoye, Omo Oke Wa Foona Oke Sora Dotaa,Eji gberekede,Eji gbimorodun ERIJIYAN EKITI - Omo Elerii njiyan kan da’de, akun weji weji, Omo alaye more Oko ido ale iye, Omo Elegigun iwaju ji’ tehin nrina, Omo Elegigun le ju ade kan soso, Omo adegigunsori-eko weji weji EMURE EKITI: Omo Elemure aoro ora, elemure i japari usu, ei jemulolo udi re, aarin usu ni kan mu a kelemure mi aje, Emilomo eso orita egiri oke, Emure ijaloke afisu foloore EPE EKITI: Epemuke moale omo elepe lologun igi lasan lara oko unbo ERINJIYAN EKITI : omo oloja odo omo oloja odo aboyesun, omo erin adigunbo ERINMOPE EKITI: Omo eridu'ora omokuku be korantan i hanomo han ke bi han be i dun han Eeemope Omo Eridu 'ora ERIO EKITI: Èdú Èrìò ọmọ agbe mùsúù kẹlẹ, ọmọ ọtayeye lugbọn-ọn mibọbọ joye, ibọbọ jolodeode, ibọbọ jọta epo, ọmọ oloke meji takọ tabo, ajoji baa i gori olodeode, ọta epo larosi de a. ESUN EKITI : omo elesun oyinbo omo elesun orinjeyeweere ESURE EKITI: Omo Elesure okese. EWU EKITI: Omo Ewu Ogidi uda, omo amudasile mogun enupani EYIO EKITI: omo a muda sile kogun eni pani IDO EKITI: omo udo oganganmodu ama gbado ekuru resin, iha lomo alagbado ayaiya tan aiha a ya, aire a ya arimona gbe sinu agbado IDO-ILE EKITI: ile Omo Ajinare mope oye, omo owa omo ekun, omo ajisunhan,omo ajire ni, omo amojo gbogbo dara bi egbin,omo alagogo ajilu gbingbin ni sosi,omo onibata kero kalokabo lona adura omo oni bata kerokalo-kabo lugbi mo rusimi onigbagbo. IFAKI EKITI: Ifaki orinkinran, omo atijo ogun lele boorun maakin. Esi keejogun ijale udo ona ifaki lii ha. Omo okorobo lila isuko firi ona eyika more. IGBARA-ODO EKITI: Omo eleye i se weyeweye ati dori ogun IGBEMO EKITI: omo elefo sigbemo oba yii efo san bi eni releefo romi oko ra lona igbemo IGBOLE EKITI: omo olurara agbagba tile oyi biribiri goke lagbe igbole odo IGEDE EKITI - omo elemi nigede amadiye sereke, elemi igede niwi ki mi gbadiye sin, mowi me i sinye omi, oni laso mo mu kigede soro, agboku mariwo na mi selewo yuyu IGOGO EKITI: igogo obiri; omo awoko merin tia gbe foruru obe je egberin okele, ekiri oke omo amain urukan jaraba iyan igogo sebora onielaya edese IJAN EKITI: Omo ijanmodu alagada ogun, omi ki ijan i mu ni ijan we esi; omo elega arisagba.eru ko sagba nibe arija ayaba,ari sagba arija olori IJELU EKITI: Ijelu mojo omo olodi atalemo, omo alayuwa ajoji ko wese, ajoji koba wese adoni ebo lulera lono ije IJERO EKITI: omo owa Omo ekun, omo ejio omo oriomu,omo olose meji takotabo,omo amomohoko toutobo udi re IJESA-ISU EKITI: omo ijesamodu,omo eleni ewele,omo ameo usu dahun se,omo a woro labe usu yaa gbe lolo odikeji,omo ikaka i so'su diro diro loke amu,omo a muda silemogun erun pani.omo agbagba roke orire yaa lu, omo ehon kitipa ona 'jesa kii'jesa moja kii'jesa modeyo, laka ule ra lona IJURIN EKITI: Ijurin moje! Omo alaran ojiji, omo amuda sile mogun enu pani, akuku beni lori ya jogun enu lule ijurin omoagbara sa yaya lori eguru. IKERE EKITI: omo oloke meji takotabo, omo aba gbami eye gbami, agbagba fiafia alapa faari, omo oju kee boju leru omo eleo jeun ree omo ekun omo erukuluji, omo ukere kete oniyan ana olosunta orun ukere orole baba oke. IKOGOSI EKITI: omo olomi meji, gbigbona ati titu.. nibi o tipade IKOLE EKITI: Elekole o balaya aso, Ikole to tala bose, e i sepe hon run ma so se, eshi idale ti a ni, Ikole lomo olose meji gbarimi rimi kan le. Ikole run ma aso se kin tala mo sha; atala bose, keru ba adiye funfun. IKORO EKITI; Omo eso obe so ikoro mudapariko omo eruku yoyo onah obe yajogun enun lobe ooooo, ireke aragan idun bi ogan iyo, ireke aragan idun bi oyinmomo. IKUN EKITI: Emi lomo ikun amure,omo elero mumu ona oja,omo abeja i se wotowoto enu asoro ILAWE EKITI: omo alawe ko tori wiwe ko makuro soja,ko wi kun naja-naja kun bomi a lura lona Awe ILOGBO EKITI: ilogbo okere,abewe usu gbagangbagan ILORO EKITI: Omo oloro erijugbin Ari jugbin ranje mu karahun muni, omo olotorojo nse ori opalele ILUKUNO EKITI: ilukuno ose omo a min ranyin bi ogo iyo ILUPEJU EKITI: Ulupeju la me a, Omo Eso ooruta merun wese,Omo Oke lila ti moto layaa, omo egiri oke arogunse bi ega IPAO EKITI: ipao ileji ogbe omo amugbo sodi orogba omo onile imole ajeji kowo ajeji toba fipawobe laimepo laimuyo ammebose IPOLE ILORO EKITI: ipole omo asewi leremeta kale to le IPOTI EKITI: upoti ala, omo amewe eni j'iyan, awa lomo eleniewele,omo amekuru jeko. IRE EKITI: iremogun omo awuse, omo owu ti n wuko gbinrin-gbinrinlagbede. N ba tete waye omo enimeta ni n bamaa se, n ba jomo, , n ba jomo alakara maa ma roun fi wan enun, n tun jomo alagbede ma finanloju-finanle masagban isale woriwori IRO EKITI: Uro adidi,omo amugbayeo IROPORA EKITI: iropora ajija emure ule ewa ubi kan sewa iyunISAN EKITI: Isan moge, omo asote monru, oloro agogo, omoamuda sile mogun erun pani.omo owa omo ekun omo olodi,odi re atile mo,ooni ke mo rin un modi mo omo elepa omo awo ISAOYE EKITI: Isaoye akoko alakoko ororo giro omo amugba buwo ISE -EKITI- Omo Akin je'Efon. Omo a gbure Agudugbu s'oju odi k'ari j'Efon Use ya yan. Ugbo kan mo'sii si kan si d'Use, a mo foo oun le iijugbo Aje a l'Use. Adabalukosi lo ba loriigi l'oja Odo, kan p'ugba Ode jo. Oni mo tita libe, o ta ogun ifon. A ri mo tita libe, o t'oji akofa. Ugbogbo kukuruku la gbogi l'oja odo, k'Adabalukosi fo lo, Emi omo ogidan,o gun mo gara, Omo at'eran mo ta'ho. ISINBODE EKITI: isin obi omo olobedu woroworo,obe kan seke kute ule jerun omo oni simi ITAJI EKITI: omo Itaji òpó kìtìpà léyìn Èkìtì, mii k'opo ma ja kíEkiti mó dêyô, Èwí í bèmí ùdì, Ônítâjî í bèmí èsûn'sû ôkô, Èwímí yoo jùdì, Ônítâjî mí yoo mó ó jóná, un i kôsé ôlójà méjì màá bá tùbá mi Ônítâjî â lô ITAPA EKITI: Eso oruta ejiri oke,omo onimeya ule meya oko,omo asibeota yayinyo IWOROKO EKITI: Ihoroko de ile ouro ile ouro omolore la me ia ogun i pa ihoroko omo aroloyen IYE EKITI: Omo alagere kijipa suko firi ona, omo oloke meji tako tabo IYEMERO EKITI: OMO ni sedo ewa,omo ori mogun je,awa lomo awo foo sise..ofi omo foko to n ti kini abere, Omo onihun didun lodo di. IYIN EKITI: Awa lomo eso orita Egirioke. Uyin logun Uyin lota. Ulu kan rije rimu tan ke i deni lora; Omo alaede KOTA EKITI: Omo Elekota ogunroyin soye, agun soye bi oyinbo. Omo oriire d'ade. ODOOWA EKITI: omo eleni ewele,omo oke lila ti moto laya, olegin lodoyin ololua lode udogun. omo abu oba ma se, omoala ideu,omo egin,omo epa, omo otokorojo sori opa lelele OGOTUN EKITI: omo ologotun ojorube, omo eleni ateeka,omo eleni ewele,omo amuru ekun sere nibuje,Eja gbogbo dade,towena dade akun. OKE-AYEDUN EKITI: omo adagbalu, omo adelila pa OKE-ORO EKITI: omo alaure ladao para seji,omo alaure san yaya gunta. Omo amekikun modi,omo alaure la Okeoro paraseji aka kan tolokore,okan re ti apetu OKEMESI EKITI: omo oloja oke ni di ogun,omo fabunmi orara lada. omo afaganja omo arogun yo. omo oke agbonna,omo oke ludi ogun atiri ogun OMU EKITI: Omo olomu aperan omo oloro,Agogo omo amuda sile mogun erun pani akuku beni lori san jogun erun lo lona omu OMUO EKITI: Omo eleye meta oro kashakasha, iko ina, iko oorun, iko koku osupa a tani yayaya, Omo olomuo kerejekereje omuo ore, OMUOOKE EKITI: Omo Olomi Ajire,omo alaroju ja ka, omo gbo gbo bi oro, omo o ba ma aja je tan o a ga ro bo ruu n oo,omo eleye meta o roo ka ta ka ta,meta la pa, meta la un la ORA EKITI: Omo Olora airijuru ugba, arijuru lora mo yogiri sapo ORIN EKITI: omo elero ajeja sanra ero sapodi supepe ero kun derun latete eru ibudo ORUN EKITI: Omo apariko odu ule aro omo ologba arin ko okoroti kion ti moni, ire joba lopoto o orire se ki moba sale ayare,awelejo mo ri lo sagbala yaa senu sogini miki weise libe nii meise ori re meise agbon re. OSAN EKITI: omo olosan mojo,olosan abedu omo inu odi, omo olosan mojo, omo arowora mo ra hin, omo aladodo,awo gbeseti lodo atiba, omo aforosinu bo atare lowo, omo amebi sinu ko nje OSI EKITI: Osi asise omo elegberin uwo, omo a meruko ude ba Ooni sala (agbe) ale, omo a muda sile m'ogun enu pa'ni, akuku be lori moyajogunenulo,omo olosimefu, omo afiju agbere suaa omo ameruko oko boonin sagbe ale, olumonle meji werewere OSUN EKITI: Omo olosun bipesi riro, omo Olosun ri tanna ode, Osun mokun Ijunmu, Omo Ajiboye OTUN EKITI : Otunmoba, Omo enireke agbejo; omo olodi atile mo, Omo Ireke Aragan Idun TunMayan Idun, Ireke Ria Idun Booyinmonmon, Omo Oloro An Se, Keran Mon Je, Kaaguntan Mon Je, OtunMoba Osere Omo Akinla Lotun, Omo Olorogbo Kiji Lotun OYE EKITI: omoloye morauife, kei tana osi gangan,mo asorosiku otutu si, omo alago ajilu gboin gboin nijo ose TEMIDIRE EKITI: omo onisopo omo oloke agunmootadi omoagesiwonwon boko USI EKITI: Usi oro, omo atoko bo mohun sibi kan ni USIN EKITI: omo aoyo yo oni gbo, gbo ti n ti eyin eku Ekiti Yeye oo, hin okun oo kete Ekiti se ala ni oo. ire oo! O seun omo ‘ye mi. Agba re a dale, wa si kere oko dele. I represent #Kota Ekiti |
Re: Proudly Ekiti's Indigene Panegyric (oriki) by MetaPhysical: 1:59am On Mar 26, 2019 |
Wow! Impressive! Great job bro. |
(1) (Reply)
Iru Kingdom: The End Of A Dominating Dynasty / List Of Obas In Yoruba Land (ranking Of Yoruba Monarchs) / Igbo Monarchs Set To End The Osu Caste System Come December 28
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 52 |