₦airaland Forum

Welcome, Guest: Join Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 2,007,815 members, 4,256,252 topics. Date: Wednesday, 23 May 2018 at 05:38 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! - Culture (3) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! (115185 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (1) (2) (3) (4)

(0) (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) ... (72) (Reply) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Orilee9ice(m): 10:42am On Nov 27, 2009
wink e kaaaaa rooooooooo o gbogbo eyin eniyan mi , e ku dede iwoyi o e dee ku ipalemo opin ose, fun awa ara 9ja, mo gbo pe e tun ti gba anoda public holide,  e maan'gbadun o! e ku odun ileya o,
awa naa gbaradi fun "Holy Ghost nite" ti redeemed  ni Excel Docklands ni ale yi, a maa gbadura fun gbogbo yin o! cheesy, so ki lon'sele eyin guys?? wink

@ chamotexi, paddi mi so waa pa? bawo ni mo rii pe o acknowledge mi lee kan, awon iyawo n'ko se won je tibi se won sin' muu 'koo pelu, wink wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by chamotex(m): 12:31pm On Nov 27, 2009
Orilee9ice:

wink e kaaaaa rooooooooo o gbogbo eyin eniyan mi , e ku dede iwoyi o e dee ku ipalemo opin ose, fun awa ara 9ja, mo gbo pe e tun ti gba anoda public holide,  e maan'gbadun o! e ku odun ileya o,
awa naa gbaradi fun "Holy Ghost nite" ti redeemed  ni Excel Docklands ni ale yi, a maa gbadura fun gbogbo yin o! cheesy, so ki lon'sele eyin guys?? wink

@ chamotexi, paddi mi so waa pa? bawo ni mo rii pe o acknowledge mi lee kan, awon iyawo n'ko se won je tibi se won sin' muu 'koo pelu, wink wink

Egbon, mo gbedi fun yin . . . Twaile!!!

Festival of Life - Emi gan ma debe . . . gbogbo adura ni mo ma gba.
Awon omo radarada ti won redi kiri iwaju ile mi, mi o fe ma ri won mo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Orilee9ice(m): 12:39pm On Nov 27, 2009
@ CHA-MO TEXXXX IIII!!,

Egbon, mo gbedi fun yin . . . Twaile!!![/[/b]quote]

O SEE JARE ABURO MI, WAA DAGBA BI EMI NAA JARE, kin n'je Twaile o, cheesy

Festival of Life - Emi gan ma debe . . . gbogbo adura ni mo ma gba.
[b]Awon omo radarada ti won redi kiri iwaju ile mi, mi o fe ma ri won mo
.
CHAMOTEXI, HUMMMMMMMMM, Ti o ba je omo jesu, oju wo lo fin'ri awa omo radarada ti won ju'di kiri niwaju e, dee dee o, wink di bible says if ya eye cause u to sin cut am off o cool, se adugbo mi lo waa ni? grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by chamotex(m): 12:51pm On Nov 27, 2009
^^^^
Twaile = Mo beri (salute)

Emi o le yo oju temi o. Kini mo fe fi ma ka bible? cheesy

Mo wa ni Kent - Belvedere
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Orilee9ice(m): 1:04pm On Nov 27, 2009
shocked shocked@ Chamotex, Its a lie oh!!,  o waa ni Belvedere ke, itosi ile mi ni yen, mo man mu train in Belvedere Station laa raa roo paa paa!! o see see pe mo ti ri e ri o, Erith-Kent ni emi waa,  cool

Mi o ni koo jo oju e o, literarily speaking,  grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by chamotex(m): 1:15pm On Nov 27, 2009
Erith-Kent? Enkule mi ni yen
Oye ki emo omo kan to n je Patience ni beyen - omo yen dun ju
Stella nko?

Area! Area!! Area!!! cheesy grin

Elenu bi Enugu . . . Te ba ti ri mi, e ti dami mo - Swagga poju cheesy cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by jaybee3(m): 1:19pm On Nov 27, 2009
patience abi? hmmmmmm
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by chamotex(m): 1:22pm On Nov 27, 2009
^^^^
U know am?
Oyan e o tobi pupo sugbon omo yen mo ere se baje baje
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Orilee9ice(m): 1:28pm On Nov 27, 2009
Erith-Kent? Enkule mi ni yen
Oye ki emo omo kan to n je Patience ni beyen - omo yen dun ju
Stella nko?

Area! Area!! Area!!!

Elenu bi Enugu . . . Te ba ti ri mi, e ti dami mo - Swagga poj[/b]u


Chamotex, so iwo ni mo ri ni [b]SANKOFA opp Belvedere Station
ni party ore kan ti won se ni Oct 24th, mo fe soo bee pe swagga e poo gann o, cheesy
.owo repete, omo repete, oba to'joba lo, swagga lo'mo gaa, abajo ti o fin'ri awon omo radarada ti won koja niwaju ile e, iwo ni won waa, wink nice 2 know pe mo ni neighbour lori tiredi yi, amo emi o kin so isokuso o, Omo Jesu le'mi o, wink wink grin .ori yato so'ri,
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Orilee9ice(m): 1:32pm On Nov 27, 2009
@ Chamotex, come to think of it, iwo ni Wosilat, Ramota ati Mulikat n'rohin pe o gaa fun e oh! Area Belvedere yen naa ni won gbe .u see now!! wink, swagga poju loo too wink cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Remii(m): 1:44pm On Nov 27, 2009
^^^^^ Se e ngbo oro le nu awon "Ade'ko d'ere" lipsrsealed
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Orilee9ice(m): 1:48pm On Nov 27, 2009
^^^^^ Se e ngbo oro le nu awon "Ade'ko d'ere"


@ Remii, o gaa o a tun gbo titun o, ki lon je "Ade'ko d'ere" jare o, wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by koredey(m): 12:18am On Nov 28, 2009
iroyin
Barack Hussein Obama Jr. (ojoibi 4 August, 1961) je oloselu ati Aare orile-ede ile Amerika. A bí Barack Obama ní ọjó ìkérin, oṣù èkéjọ (ògún), odún 1961. Ó jé òṣèlú orílè èdè Améríkà, ọmọ ilé ìgbìmó aṣòfin láti ìpínlè Illinois, ọmọ ẹgbé òṣèlú Democrat. Barack Obama jé òkan nínú àwọn òṣèlú méjì tí wón figa gbága láti je Àrẹ ilè Amerika. Ẹni èkejì ni John Mccain. Ni ojo kerin osu kokanla odun 2008 Obama wole ibo fun ipo Aare ile Amerika. Obama gori oye ni ogun jo osu kinni odun 2009. Barack Obama jé ènìyàn dúdú àkọ́kọ́ tí òkan nínú àwọn egbé òṣèlú nlá ti ilè Amerika fún ní ànfàní láti kóra nínú eré ìje àti di Ààrẹ ilè Amerika láti ẹgbẹ́ òṣèlú Demokratiki.

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by kolaoloye(m): 2:47pm On Nov 28, 2009
Mi o mo wipe won ti si tiredi miran.
Mo ki gbogbo ile laida enikan si. A ku alaja odun. grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tubabie(f): 8:07pm On Nov 28, 2009
Orilee9ice:

wink e kaaaaa rooooooooo o gbogbo eyin eniyan mi , e ku dede iwoyi o e dee ku ipalemo opin ose, fun awa ara 9ja, mo gbo pe e tun ti gba anoda public holide,  e maan'gbadun o! e ku odun ileya o,
awa naa gbaradi fun "Holy Ghost nite" ti redeemed  ni Excel Docklands ni ale yi, a maa gbadura fun gbogbo yin o! cheesy, so ki lon'sele eyin guys?? wink

Ha iwo naa wa nibe? emi naa lo si ibe cheesy

chamotex:

Festival of Life - Emi gan ma debe . . . gbogbo adura ni mo ma gba.
Awon omo radarada ti won redi kiri iwaju ile mi, mi o fe ma ri won mo.

LMAO!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by chamotex(m): 1:16am On Nov 29, 2009
tubabie:

Ha iwo naa wa nibe? emi naa lo si ibe cheesy

LMAO!Tubabie, se iwo na wani be ni?
Ibi eyin patapata ni mo joko si . . . ni ibi N3 yen
Gbogbo ijo ni mo jo . . . mo si gba ibukun pupo lo si ile.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by goodass(m): 1:19am On Nov 29, 2009
@2babie
anty a-lo-ma-dagbere,se alafia ni o?ku ojo 3

@chamoIsrael
wa sere paddy mi.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by TheSly: 1:23am On Nov 29, 2009
Suegbe ni gbogbo yi. . . . cool
Eyin alainikanse won-won yi. . . . . tongue
E ma lo wa ise se. . . . .Eyin onisekuse oniranu lasan lasan. tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by chamotex(m): 1:25am On Nov 29, 2009
goodass:

@chamoIsrael
wa sere paddy mi.

Onikunlomoka . . . TWaile!!!

The Sly:

Suegbe ni gbogbo yi. . . . cool
Eyin alainikanse won-won yi. . . . . tongue
E ma lo wa ise se. . . . .Eyin onisekuse oniranu lasan lasan. tongue

Awon 36 kiniun ni mo ma ran si yin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 1:25am On Nov 29, 2009
In kale lube o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by chamotex(m): 1:28am On Nov 29, 2009
FL Gators:

In kale lube o

O ma n be. . . O ma n be
Oya!
Se won pe e si ibibayi nsiyin?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 1:30am On Nov 29, 2009
ee se mi luwa n ba wi.


*excuse my rough ekiti*
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by TheSly: 1:32am On Nov 29, 2009
chamotex:


Awon 36 kiniun ni mo ma ran si yin
Iwo ati tani. . . .
Ti eyin ba fi ori so apata. . . . .O ma tuka ni! cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by chamotex(m): 1:38am On Nov 29, 2009
FL Gators:

ee se mi luwa n ba wi.


*excuse my rough ekiti*

your ekiti is poor, go brush up on ur skills

The Sly:

Iwo ati tani. . . .
Ti eyin ba fi ori so apata. . . . .O ma tuka ni! cool

Awon agba na lo sowipe, "Oro shunukun, oju shunukun laafi n wo" cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 1:39am On Nov 29, 2009
hehehhe how can you tell its poor if you cnt even speak it?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by TheSly: 1:40am On Nov 29, 2009
chamotex:

Awon agba na lo sowipe, "Oro shunukun, oju shunukun laafi n wo" cool
Oro ti okete ba ba ile so. . . .Ni Ile ngbo. . . . .
Mo pa laase wipe ko funmi ni number Iyawo e nisin!!! cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by bluespice(f): 1:41am On Nov 29, 2009
wow another thread exists?
toyin o kare
ekule eyin onile oh
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by chamotex(m): 1:47am On Nov 29, 2009
The Sly:

Oro ti okete ba ba ile so. . . .Ni Ile ngbo. . . . .
Mo pa laase wipe ko funmi ni number Iyawo e nisin!!! cool

eyi tobawi fun ogbo logbo ngbo
eyi ta bawi fun ogba logba ngba
kose kose ni lakose
oya ma kuru ma ga cheesy cheesy grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 1:49am On Nov 29, 2009
bluespice, iyawo wa, o to ojo meta.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by bluespice(f): 1:52am On Nov 29, 2009
toyin ore mi
so wa?
oje merin at'abo jare
bawo lara?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by TheSly: 1:53am On Nov 29, 2009
chamotex:

eyi tobawi fun ogbo logbo ngbo
eyi ta bawi fun ogba logba ngba
kose kose ni lakose
oya ma kuru ma ga cheesy cheesy grin
 cheesy cheesy cheesy cheesy

Eeewo Orisa. . . . . cool
Biri-Biri Lojun Ri. . . . . .Boun-Boun Ni agutan n wo. . .
Yio Bale. . .Yio Bale.  . . .Ni labalaba fin wo igbo lor. . .

Ajibola Ni oruko ti a n pe Ebo.
Ojigirigiri ni oruko ti a n pe awon Iya mi oshoronga.

Oya!. . .Fun mi ni number Iyawo e . . . Mo Pa Lase ni!!!! angry cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 1:57am On Nov 29, 2009
ara wa.
se chamotex ni ko ti e ki e beyen?
se o fe ki n fi egba si?
omo ye ma go o, ah ahn

(0) (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) ... (72) (Reply)

Post Pics Of Fulani Girls! / A Picture Gallery Of Igbo Traditional Marriage Ceremony "Igbankwu" / Akan Of Ghana And Cote D'ivoire

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (0) (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2018 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 95
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.