Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,206 members, 7,818,704 topics. Date: Sunday, 05 May 2024 at 10:11 PM

Osole Owo Todaju - Culture - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Osole Owo Todaju (16011 Views)

Osole Owo Toje Gbewa Pelu Alajo To Daju / Osole Owo Tutu / Oro Nipa Osole Owo Nla (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Osole Owo Todaju by Laniretiawoagba: 11:32am On Feb 27, 2018
opo eniyan lowa , tiwon koni igbagbo ninu Ogun ibile, tabi bi eniyan se ma nlowo lowo, ni irorun, Erin won paami pupo, ejeki a Dan osole kekere yii woo, Awo ti ejo bo sile, iye eye okin, imi ojo, Ikun ojia, abeere,alagemo kan, ao lo papo, ao fi te IFA eji ogbe, ao pe ofo ree sii, kato pomo ose, OFO REE iji nji timoji mo wee owo tenin , mo mun aso tokin roo, mo wo ewu tokin sorun, morin bi olounyere, mo rin bi olounyoro, woni tani mo nwa kiri , moni IFA ni mo nwa kiri, woni IFA nbe ni kaa ketadinlogun, mode kaa ketadinlogun moba IFA, IFA ni nje mo Mon oun, moni mo Mon iwo IFA ni elepo pupa bi ikode, IFA ni ojia loniki omo araye owa fi ire temi jimi Nile mi loni, baba Niki unmo sise Mon, tori alagemo ki sise tifi daa igba aso, gbogbo aso ejo nibo fun ile, ire gbogbo Niki OMA temi lowo lati oni loo, lorigun mererin Agbanla aye, Fun imoran tabi iwadi tabi oun Miran ti e Lee fe bami soo, Ki e pemi sori number yii, 08037492173 tabi whatsapp. Ire o
Re: Osole Owo Todaju by Pearlyakin(m): 9:57am On Mar 02, 2018
Hello, are you on WhatsApp
Moreso can you see the result of just 5 matches I mean the scores that the team will play.

(1) (Reply)

I Never Said Benin Owned Lagos – Oba Akiolu / The Relationship Between The Isoko And Ndiigbo( Ukwuani-anioma). / Court Orders Osun CP To Arrest Oluwo

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.