Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,151,579 members, 7,812,884 topics. Date: Monday, 29 April 2024 at 09:20 PM

E Je Ka So Yoruba - Culture (2) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / E Je Ka So Yoruba (12517 Views)

Oga Jona Shugaban Barayin Kasa, Me Ya Sa Ne Ka Je Ga Gaida Obassanjo? / Ndi Anambra Ka Anyi Gbakobanu Ebea Mata Onwe Anyi! Anambra Obodo Dike! / Omo Yoruba, E Je Ka Ki Ara Wa Wipe 'E Ku Something' (Yoruba Greetings) (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (Reply) (Go Down)

Re: E Je Ka So Yoruba by dayokanu(m): 11:00pm On Jun 30, 2010
Oya ka itan soke jor.
Abi se o n je dodo idi mi ni?
Re: E Je Ka So Yoruba by Idowuogbo(f): 11:08pm On Jun 30, 2010
ejo efimile oo
mo ka itan kankan soke
elo bawon ni strip club , teba fe ri itan ori shirishi
am sure , etun ke ere owo yin de ile
onishina
Re: E Je Ka So Yoruba by weblessyou: 12:01am On Jul 01, 2010
@idowuogbo
quote

, Awon taiye and ati kenny, Buhahahahahahahahaha!
Omo Yoruba atata
.
He he ee,
Aun-ti idowuogbo(WE ARE PUSHING IDOWUOGBO) chei!

Kin ma gbagbe, idogbe ati alaba n ko, se won ti jeun?

my sis, can u remember this rhyme or never sang it b4?
Sokoto pepe is a nicker, eja dindin is a fish, omi garri is water, e.g omi agbon. Funnily funny
Re: E Je Ka So Yoruba by dayokanu(m): 12:02am On Jul 01, 2010
Mo fe je kulikuli, Mo fe je kulikuli
Re: E Je Ka So Yoruba by Idowuogbo(f): 12:09am On Jul 01, 2010
^shey o je ofio

@weblessu
kilode to de fila askari so ri
omo yoruba sure banker ni mi , notin does me
omo awon obi mi oshere de idota, idopin , ori idowu lon ba ise de
and emi on shomo abe bridgeoo
so emi mo orin yen oo tongue tongue tongue tongue cheesy grin grin

emi ni tire nitoto
ogboski cheesy cheesy cheesy grin grin
Re: E Je Ka So Yoruba by dayokanu(m): 12:11am On Jul 01, 2010
Oya je ki awa se ere Idota, Idogbe, Idoha, ati Idopin
Re: E Je Ka So Yoruba by Idowuogbo(f): 12:18am On Jul 01, 2010
loll
egbon mi , ema je ki oro ribe
eti lo wa ju , ere o gbodo de gbogbo ibi ten gbe lo
mo sure pe awon omo ame ma yapa si yin lorun
so epa omo wednesday wa ko wa sere yen fun yi
mo juba oo , baba ti ko common
grin grin grin grin
Re: E Je Ka So Yoruba by weblessyou: 12:25am On Jul 01, 2010
mo sure e ni fe kan ba ojo ola yin je
Re: E Je Ka So Yoruba by weblessyou: 12:27am On Jul 01, 2010
ore mi, bi eleshe ban tan o, iwo ma se gba.
Re: E Je Ka So Yoruba by Idowuogbo(f): 12:29am On Jul 01, 2010
^lailai,wot can fa
eniway ,emi tife losun ore
kasun re kaji re oo
cool cool cool
Re: E Je Ka So Yoruba by weblessyou: 12:43am On Jul 01, 2010
@idowuogbo
oda aaro arabinrin
To ba di idaji a o ma ba ere wa lo ni iwon-tun-wonsi(moderation)
E gbinyanju lati ma fi awon oope si aye won, EMA SE FESI SI ORO WON.
Awon omode n ka tiredi wonyi O.
Fun ojo ola won, odaaro o!
Re: E Je Ka So Yoruba by weblessyou: 12:21pm On Jul 01, 2010
Bi omode ba shubu---Aa wo iwaju

Agba to jin si koto---Oko ara yoku logbon

Eni se ika tan to yi odo bori---bi oba aye ko rio 'torun wo o

Iyan ogun odun---
A ma jo ni lowo

Osika gba gbe ola--- o
gbagbe ojo ikeyin

Eni gbin ebu ika sile---omo re a je nibe

Ika yio ba onika---rere a ba eni rere

Ojo gbogbo ni tole--- ojo kan ni ti olo un.
Re: E Je Ka So Yoruba by weblessyou: 12:25pm On Jul 01, 2010
smiley
Re: E Je Ka So Yoruba by weblessyou: 12:29pm On Jul 01, 2010
Oun to ba gbin---ni iwo yio ka

Opipa mi pa ara re---o ni oun pa aja

Oni re---ni yio fi ola re han

Eni ta oja eepe---yio gba owo okuta

Esan a ke lori gbogbo---onise ibi

Ma fi oni ba ola re je--- ika ko pe, rere lo pe

Jawo ninu gbogbo---ise ibi

Ko i ti peju---fun atunse

To ba ko iwaju sio ta a, to ba ko eyin sio ta a---to ba ku iwo nikan tun ero ara re pa a

Eni a wi fun---oba je ko gbo.
Re: E Je Ka So Yoruba by weblessyou: 12:34pm On Jul 01, 2010
Omode gbon, agba gbon la fi da Ile-ife

Ogbon ologbon---la nfin sogbon

Ore ko si mon---ka ri eni ba rin loku

Amuni nje amuni---ewo ni o ni bo nibe

Ore dun la n ba ara eni jeko---ti ile oge to oge je

Anroju je eko obun---obun pon eko e kere

Ija lode---lorin dowe

Oun se mi, oun gba mi---ati se ndupe lowo eni to n se ni, to n tun gba ni

Eni rii nkan hee to fe ku pelu e---owo eni to ti sonu nko?

Agba ki wa loja---ki ori omo tun wo.
Re: E Je Ka So Yoruba by weblessyou: 12:35pm On Jul 01, 2010
smiley
Re: E Je Ka So Yoruba by Jenwitemi(m): 11:03pm On Jul 05, 2010
Aaloo o! Aaaloo!

Opa tinrin kanle, o kanrun! Kini o!
Re: E Je Ka So Yoruba by Jenwitemi(m): 11:05pm On Jul 05, 2010
Ma a koko bere,
Kini o ba oba jeun ti ki palemo?
Eshinshin ni o!
Re: E Je Ka So Yoruba by Idowuogbo(f): 11:14pm On Jul 05, 2010
oga jeni okarun magun grin grin grin
Re: E Je Ka So Yoruba by weblessyou: 3:49pm On Jul 06, 2010
Alo o o:- Aloo
kin lo koja niwaju ile oba ti ko ki oba o
Re: E Je Ka So Yoruba by weblessyou: 4:50pm On Jul 06, 2010
quote: jenwitemi: Aaloo o! Aaaloo!

Opa tinrin kanle, o kanrun! Kini o!

Ojo ni o!
Re: E Je Ka So Yoruba by Nimshi: 9:20am On Jul 08, 2010
Alo o o:- Aloo : kin lo koja niwaju ile oba ti ko ki oba o

Àgbàrá ni o!

Ire o.
Re: E Je Ka So Yoruba by Nimshi: 9:32am On Jul 08, 2010
Bí ajá bá lo ogún odún l'áyé, ẹran Ògún náà ṣì ni.

Ire o.
Re: E Je Ka So Yoruba by Nimshi: 9:33am On Jul 08, 2010
A fi ọ́ jọba ò ńṣàwúre o fẹ́ jẹ Ọlọ́run ni?

Ire o.
Re: E Je Ka So Yoruba by Remii(m): 9:37am On Jul 08, 2010
Aaaaaloooooooooo:


A ran omo ni akara, akara de ile saaju omo, kini oo
Re: E Je Ka So Yoruba by weblessyou: 11:24am On Jul 08, 2010
Aaalo o Aloo : kin lo koja niwaju ile oba ti ko ki oba o
Quote: nimshi: Àgbàrá ni o!
Agbara ati GJ ni o(ibadan visit)
Re: E Je Ka So Yoruba by weblessyou: 11:40am On Jul 08, 2010
@nimshi
Ejo wo, níbo le ti rí sofutiwear(software) ti efi fàmì sí gbogbo òró yin.

Kíni orúko sóftwarè yen

Ire o
Re: E Je Ka So Yoruba by dayokanu(m): 7:11pm On Jul 08, 2010
Ere ti aja fi ogun odun sa, irin faaji ni fun eshin.

ogun odun ti eshin fi n sare, Iwaju ni a ma ba Ile.
Re: E Je Ka So Yoruba by whiteroses(f): 7:18pm On Jul 08, 2010
emi komo ibi ti eboro de amo emi fe so alo.
Alo oh!
1. Kini yoruba pregnancy test, e ri chicken drum si inu obo re daada ki e si faa yo, omo n benbe ti won ba buje.
2. Olobo loloko, sokoyokoto
3. Oko tobasun, obo lomaaji
grin
Re: E Je Ka So Yoruba by Nimshi: 7:29pm On Jul 08, 2010
weblessyou:

Aaalo o Aloo : kin lo koja niwaju ile oba ti ko ki oba o
Quote: nimshi: Àgbàrá ni o!
Agbara ati GJ ni o(ibadan visit)


. . .  Nkò mọ̀ pé Gúdúlọọkù ò yà kí kábíyèsí . . .

Ṣé Gúdúlọọkù kò mọ̀ pe Àràbà ni bàbá, ẹni a bá lábà ni baba ni?

Àwọn àgbà sọ̀rọ̀ tán, wọ́n ní: àgbà ò sí nílùú ọ̀kẹ́rẹ́. . .

Gúdúlọọkù a mú ni bú ni, ẹran Ìbíyẹ; Ìbíyẹ fọ́jú ọ̀tún, ẹran rẹ̀ fọ́ tòsì.
.


Ire o
Re: E Je Ka So Yoruba by Nimshi: 7:39pm On Jul 08, 2010
weblessyou:

@nimshi
Ejo wo, níbo le ti rí sofutiwear(software) ti efi fàmì sí gbogbo òró yin.

Kíni orúko sóftwarè yen

Ire o

Nípa ti àwo-ìdarii kọ̀mpútà (èyí tí a mọ̀ sí 'software') tí ẹ sọ:

http://www.africanportal.net/Publications/ABD/mktut1.htm
http://www.facebook.com/apps/application.php?id=199889225883

Ire o.
Re: E Je Ka So Yoruba by Nimshi: 7:55pm On Jul 08, 2010
whiteroses:

emi komo ibi ti eboro de amo emi fe so alo.
Alo oh!
1. Kini yoruba pregnancy test, e ri chicken drum si inu obo re daada ki e si faa yo, omo n benbe ti won ba buje.
2. Olobo loloko, sokoyokoto
3. Oko tobasun, obo lomaaji
grin

Hmnnn, ọ̀rọ̀ ni whiteroses sọ sílẹ̀ yí o!

Kíni àwọn àgbà (àti ọmọdé tó kún ojú òṣùwọ̀n) rí sọ si?


Ire o
.

(1) (2) (3) (Reply)

Sultan Of Sokoto Attends Convocation Of International Islamic University, Uganda / Top 5 Traditional Dances In Nigeria / I Want To Learn Igbo

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 24
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.