Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,150,608 members, 7,809,223 topics. Date: Friday, 26 April 2024 at 05:53 AM

Do You Speak Yoruba? - Culture (4) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Do You Speak Yoruba? (102108 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (43) (Go Down)

Re: Do You Speak Yoruba? by topeteadr(m): 10:49am On Oct 20, 2007
Mo ti man so pe gbogbo wa ti ya were.
Re: Do You Speak Yoruba? by excel12(m): 11:53am On Oct 22, 2007
tope_teadr:

Mo ti man so pe gbogbo wa ti ya were.

Tope,bawo lo se go bayi? Omo alaileko ni e.

Richdad, owo wo loro pe o ni?Boya lomo pe owo ko nife.Emi ni mo ma lo Tawa gbo!!!!
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 1:28pm On Oct 22, 2007
@richdad & excel12

grin grin grin grin grin grin cheesy cheesy cheesy cheesy

Se nitori emi Tawakalt Temitope ni gbogbo eleyi se nsele?

E jowo, e'jebure, efiye denu,

E ma je ndaku si bi bayi pelu erin, inu ti nro mi ooooooo. grin grin grin cheesy cheesy
Re: Do You Speak Yoruba? by RichDad1(m): 4:09pm On Oct 22, 2007
excel12:

Richdad, owo wo loro pe o ni?Boya lomo pe owo ko nife.Emi ni mo ma lo Tawa gbo!!!!
O mo anything,owo ati ife omo iya kan ni won infact ibeji ni won grin grin grin grin grin grin. Nitori na tepa mo se owo e wink wink wink wink

Tawa-Temi:

@richdad & excel12

grin grin grin grin grin grin cheesy cheesy cheesy cheesy

Se nitori emi Tawakalt Temitope ni gbogbo eleyi se nsele?

E jowo, e'jebure, efiye denu,

E ma je ndaku si bi bayi pelu erin, inu ti nro mi ooooooo. grin grin grin cheesy cheesy

Tawa-temi ,sa ma gbadun si mi lorun ,se o ri bobo Excel yen?ko lenu ni be rara, Ki lo n sele now?Mo n so e nu ooo (I am missing you) kiss kiss kiss kiss kiss kiss kiss kiss kiss kiss
Re: Do You Speak Yoruba? by excel12(m): 4:17pm On Oct 22, 2007
Richdad, ki lo n worry e naa? Tawakalitu ,o ti dun ju lomo .Nitorinaa ni mo se n ba richdad ja

Re: Do You Speak Yoruba? by excel12(m): 4:19pm On Oct 22, 2007
Iwo na wo Tawakalitu!!!

Omo pupa rodorodo,aponbepore,ibadi aran.

Richdad,sun siwaju joo.
Re: Do You Speak Yoruba? by RichDad1(m): 4:38am On Oct 23, 2007
Excell,
Mo ma ba e ja,Se o mo wipe oga awon Soja ni mi ni? mo ma ni ki won gbe e lo si Liberia or Iraq ,nitori na fi Tawa sile ki o de gbe aworan yen kuro ni kia kia angry angry angry angry angry angry angry angry
Re: Do You Speak Yoruba? by excel12(m): 8:15am On Oct 23, 2007
Rich Dad:

Excell,
Mo ma ba e ja,Se o mo wipe oga awon Soja ni mi ni? mo ma ni ki won gbe e lo si Liberia or Iraq ,nitori na fi Tawa sile ki o de gbe aworan yen kuro ni kia kia angry angry angry angry angry angry angry angry


Ma make sure pe mo ba Yaradua soro,Darfur ni Sudan ni ma ni ki won post e lo.
Re: Do You Speak Yoruba? by RichDad1(m): 8:34am On Oct 23, 2007
excel12:

Ma make sure pe mo ba Yaradua soro,Darfur ni Sudan ni ma ni ki won post e lo.

Yepa!!! shocked shocked shocked shocked,Ko soro mo le lo si anywhere sa fi Tawakalith sile fun mi,infact mo ma gbe salo fun e grin grin grin grin grin grin grin grin grin grin Ika buruku ,Sudan ko sudan niiii [size=8pt]hissssssssssssssssssssssss[/size]
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 4:23pm On Oct 24, 2007
Dafur ke? shocked shocked shocked
Nibi ti won ti pa awon omo ogun meje Nigeria?

Kini aridaju pe o ma jagun ye? (probability that he will survive the war)

Ha ko da be o.


Iyen eni.

Kinni aworan mi nse ni be yen?

Eti gbe mi le aye lowo!

Awon ton yo mi lenu ti poju.

Won je kin sinmi.
Nitorina, mo ma yipada(change it) si omiran, boya won afi mi le lorun.

Ejo wo, emase ja mo, efi ife so ra yin po.

Erin ti mo rin ti to ge. grin grin grin
Re: Do You Speak Yoruba? by Atuluku(m): 6:03pm On Oct 24, 2007
Tawa,nitori ti e,Seun ti ban excel12
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 10:32pm On Oct 24, 2007
Iro ni o(its a lie) shocked shocked shocked shocked

Seun jo ma se be yen?

Haba! Seun jo, mo ba bebe.


Ma je ko so mi loruko ooooo

Da excel12 pada sori eto yi ooo.
Re: Do You Speak Yoruba? by showbobo(m): 10:35pm On Oct 24, 2007
yam pepper scatter scatter ;d ;d ;d ;d
Re: Do You Speak Yoruba? by Seun(m): 4:17pm On Oct 26, 2007
e je ki excel12 bebe funra tire.
Re: Do You Speak Yoruba? by topeteadr(m): 4:22pm On Oct 26, 2007
@admin ejo ni itori olorun mon kun le lowo ni o. Admin idobale ni mo wa ejowo ejeki o padawa.
Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 4:35pm On Oct 26, 2007
@seun
Jowo darin jin bobo yii
Mo ro wipe , o wan banned fun ojo kan pere ni shocked
mi ko mope oma pe to bayii
Ti aba fi owo otun ba omowi, ao si fi osi famora grin
Gbogbo wa lo mope omo buruku ko ya lupa ni excel12 grin
Re: Do You Speak Yoruba? by topeteadr(m): 4:37pm On Oct 26, 2007
Admin ejo wo oh.
Re: Do You Speak Yoruba? by RichDad1(m): 1:42pm On Oct 27, 2007
Oga Seun,
E jo wo e dari jin Excel12 cry cry cry cry Bytheway ki lo se?? mo lo si irin ajo mo sese de ni, Ore mi pataki ni excel o ooo grin grin grin
Re: Do You Speak Yoruba? by GeeCee(m): 5:32pm On Oct 29, 2007
Se nitori pe o sope oun lohun ni Nairaland ni won se begi fun? Oga Seun, iyen o to tori ke. To ba wun mi mo le sope emi ni olori orile ede yi, iyen ko yo Yaradua loye, inu ara mi ni mo n dadun; bee ara mi ni mo n tan.
Nitori idi eyi, e da omo naa pada logan.
Re: Do You Speak Yoruba? by ajileko: 7:13pm On Oct 29, 2007
Eka le o. Emi ajileko ni mo n soro. Ejo se emo obinrin kan ni nairaland to feran Oko nla. Nitoripe oko mi ati epon mi tobi gigigi ati pe ti oko yen
ba ti le tan yi o wa dabi irin (iron rod). Ejo eba mi wa arabinrin kan ni nairaland ti o ma fi oko mi sere lalale. Ko si ma gbe ha nu bi ase n gbe ese adiye hanu ni jo keresimesi.

Eso pupo.
Re: Do You Speak Yoruba? by gbogboade(f): 12:02am On Oct 30, 2007
Ekale o.Gbogboade loruko temi. Mi n gbadun eto yi gan ni. Eto n wa n lati ile-ise Nairaland. Mi un gbadun egan ni. E jo ekari go
Re: Do You Speak Yoruba? by gbogboade(f): 12:05am On Oct 30, 2007
Mi ki gbogbo ebi Arabanbi ati gbogbo ebi Olufimo. No long thing
Re: Do You Speak Yoruba? by gbogboade(f): 12:05am On Oct 30, 2007
Mi ki gbogbo ebi Arabanbi ati gbogbo ebi Olufimo. No long thing
Re: Do You Speak Yoruba? by alagbin(m): 6:16pm On Oct 30, 2007
@ajileko

Eka le o. Emi ajileko ni mo n soro. Ejo se emo obinrin kan ni nairaland to feran Oko nla. Nitoripe oko mi ati epon mi tobi gigigi ati pe ti oko yen
ba ti le tan yi o wa dabi irin (iron rod). Ejo eba mi wa arabinrin kan ni nairaland ti o ma fi oko mi sere lalale. Ko si ma gbe ha nu bi ase n gbe ese adiye hanu ni jo keresimesi.

Boni Oko re yan se tobi to se ole fi picture re ranse to ri mo ni sister kan to feran oko nla grin
Re: Do You Speak Yoruba? by kanmosyl(m): 6:30pm On Oct 30, 2007
Haba, eyin omo aye ode oni
oma je se fun yin ni ke, eke je ma wo bi bobo Alagbin yii
se n so isokuso lenu ke.
Hahaha oba tie ko suru ke, tio ba tie je pe bi o se gun e
lo se nso, oba tie kora re ni ijanu die, abi orope ile asewo ni
Nairaland ni, aha awu ki lo to bayii,abi o ti gbagbe pe owo
die die bayi ni aranfe.
Eje kia aro re tori ojo ola ati ojo iwaju awon omo wa.
Re: Do You Speak Yoruba? by alagbin(m): 6:38pm On Oct 30, 2007
emi mako moso be bobo ajileko kan lo sobe mon bere pe bawo ni oko re se to bi to temi ma ni ejo oh
Re: Do You Speak Yoruba? by kanmosyl(m): 6:46pm On Oct 30, 2007
Alagbin,
Mabi nu jo mo fi Olorun be o,
Mio ka idahun re dada ni o
mabi nu ki o si dariji mi
sugbon bami ja ore re Ajileko si ikan ti mo so tan
ko le mo pe omoluabi onso isokuso lenu.
Lekan si mabinu simi.
Re: Do You Speak Yoruba? by topeteadr(m): 7:49pm On Oct 30, 2007
Wo ni binu si e.
Re: Do You Speak Yoruba? by topeteadr(m): 7:49pm On Oct 30, 2007
Wo o ni binu si e.
Re: Do You Speak Yoruba? by ajileko: 12:47am On Oct 31, 2007
Ogbeni kanmosyl, Ejo eda ri ji mi. Mi o kin se onisokuso. Omo oluabi ni mi mo de mope e gbadun mi ti eba momi daradara.
alagbin, Se omo pupa ati omo to lewa ni sista yin ti efe gbe oko mi fun. Nitori wipe nko fe ki enikeni fi oko mi sere. Obinrin
to ba kawe daradara to oba de ni ilosiwaju ni mo fe ko mu oko mi. Ese pupo. Mi o wa duro de asi yim ki n to fi aworan oko mi ronse si yin.

Ese sir.
Re: Do You Speak Yoruba? by MEGASTAR2(m): 3:12am On Oct 31, 2007
Eyin temi ejeun soke bi igi ireke
Re: Do You Speak Yoruba? by biggerboy(m): 12:22pm On Nov 05, 2007
Ki lo n sele si gbogbo yin naa?

(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) ... (43)

Ife Queen Wuraola With Her Lebanese Husband / Nigerian Native Names And Their Meanings / History Of Nsibidi The Ancient Igbo Alphabets Britain Destroyed Ibo Civilization

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 29
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.