Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,693 members, 7,816,832 topics. Date: Friday, 03 May 2024 at 06:13 PM

Do You Speak Yoruba? - Culture (10) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Do You Speak Yoruba? (102215 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (7) (8) (9) (10) (11) (12) (13) ... (43) (Go Down)

Re: Do You Speak Yoruba? by ennyluv6(f): 1:42pm On Dec 05, 2007
@ others

e jowo e gbami se nairaland forum ni anpe forum wa yi ni abi Rich Dad and friends forum. nitoripe nkan ti mo nri ni pe Rich dad, Tawa-Temi, bimbliss and co lan ri. o ga gan ni ooooooooooooooo.
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 3:42pm On Dec 05, 2007
@ennyluv

Iwo naa darapo mo awon to wa lori eto yi , after all, aibawon sinibe, lai bawon dasi  cheesy cheesy cheesy cheesy cheesy

Oyinbo lo si soro ni ede geesi pe:

'If u can't beat them, you join them' .   grin grin grin
Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 3:49pm On Dec 05, 2007
Mo ki gbogbo eyin agba to wa nibi, ekasan, e de ku ise oni. Layo la ma de le loni. Ise oni di ishe mo wa lowo oo(amin)

Mo de ki yin ku ipalemo awon odun to'nbo, a ba wa laiye, a ba wa lalafia o. Gbogobo nkan ta ma fi se odun yin lolohun ma pese fun wa.

Asheisamodun o.
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 3:52pm On Dec 05, 2007
@ilugunboy,

ose pupo, adara fun e gidi ganni,

amin.
Re: Do You Speak Yoruba? by bimbliss(f): 9:39pm On Dec 05, 2007
ennyluv_6:

@ others

e jowo e gbami se nairaland forum ni anpe forum wa yi ni abi Rich Dad and friends forum. nitoripe nkan ti mo nri ni pe Rich dad, Tawa-Temi, bimbliss and co lan ri. o ga gan ni ooooooooooooooo.
fun eti re nairaland forum la wa ki see tawa, richdad bimbliss and co forum sugbon opo la pe, di e la yan ninu di e na ki baba ka e mo won ni so tete yara wa bi wa she di ara wa. ose gan ni o

Tawa-Temi:


Yeparipa, mogbe shocked shocked shocked shocked shocked
Rich Dad:

ma beru Tawa wo mo toju bobo yen gan ju bo she ro lo ni faa!! grin grin grin

Oga o Bim-Bim,
Lati ojo yi ti Tawa-mi ti lo se idanwo mi o ri brake light e at all ,aye o ri be yen o cry cry cry cry cry cry cry cry cry cry cry

o de wa tu mi si ta bi omo ojo mejo
haba!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!
Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 10:48am On Dec 06, 2007
Ekaaro o! ajibi? se dada la ji, eema ya se o. Oloriburuku ko ni ko ba wa lenu se.

Ke rora je gbadun party ni weekend yio. grin
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 11:19am On Dec 06, 2007
[size=40pt]Ekaaro oooo[/size]
Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 11:30am On Dec 06, 2007
@tawa-temi,

Bawo ni, so wa pa, o pe kin to dele lana, traffic ti poju ni western avenue. torina ni mo se le reply e. Ba wo ni se.
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 2:34pm On Dec 06, 2007
Haaa!!!! oma seeoo


Emi ooo kin face traffic rara lati ile lo si ibise nitori wipe ile mi ko jina si ibise mi rara.

Infact mo le fi ibinu fi ese rin lati ile lo si ibise mi to ba wun mi.

But ti mo ba nlo si ile iwe, ikunmu otun mi abo si ti osi nitori traffic ti o wa lori 3rd mainland bridge pelu ti Adekunle area.

Anyway, ise nlo dede sa, ko si wahala.


Bimbliss, Richdad, & others Eku ise ooooo
Re: Do You Speak Yoruba? by cashoggy(f): 5:16pm On Dec 10, 2007
Tawa-Temi, Ohun ti oju omo eniyan nri lori 3rd mainland bridge ti o mu enu ba yen ko ma kere o. a ko kuku mo oun ti on maa nfaa, o ti wa a di baraku bayi o. Lato iyana Adekunle titi lo de iyana Oworo ni sun-keere-gba-keere oko ti nwaye lojoojumo. Koda ti mo ba ranti iriri oju ona yi, ile kii wu mi lati lo. Ti kii baa se ti awon omo olomo ti o wa nile, boya 'iyawo opin ose' ni mi o ba maa se. Emi ko kuku mo ise ti awon LASMA nse nibe yen o! Boya ki ba san ka ni won ko si nibe. Awon oko ti ara won ko da to, awon wonyi a daku sona ti enjinni won ba ti gbona! Aanu awon awako bee a tile maa se mi, paapa julo ti o ba je awon nikan lo wa ninu oko, tabi ti iru awako naa ba je obirin. Too, ona ofun ona orun, beeni Yoruba wi, ki Olorun sa maa se aanu wa. Sugbon okan mi bale wipe ti a ba fi maa mu ose ti o mbo, ogunlogo ibi ise ni yio ti gba isinmi ipari odun, eleyi yio je ki igboke-gbodo oko rorun lori afara 3rd mainland. Mo ri e na, ki Olorun ma ko atunrin wa. O dabo.
Re: Do You Speak Yoruba? by topeteadr(m): 5:17pm On Dec 10, 2007
Walahi, gbogbo wa ti ya were.
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 5:36pm On Dec 10, 2007
@Cashoggy

Ooto loku so, sugbon awon LASTMA guys yen de ngbiyanjuo, omi poju oka loni.
Anu mi ma nse awon to ngbe ni mainland and environs ti won de nsise ni Island.

Infact ti mo ba wa ni ile nigba mi mo ma nri ori 3rd mainland bridge anu ade se mi nitori stress ti awon eniyan ma go through ni ojojumo.

Oluwa akuyo gbogbo wa, amin.

Awon colleagues mi ni ibise ti won ba nso nkan ti oju won ma nri, anu mi ade ma se won, ti mo ba go through the same stress lojojumo, mo le daku. undecided undecided

Ki Oluwa sa ma kowayo , pele oooo.

Sa take care arare.  Oluwa adaosi oooo
Re: Do You Speak Yoruba? by bimbliss(f): 8:23pm On Dec 10, 2007
oro traffic ti e nso oti nshele ni abj na. but nkan to wa ni be ni pe aki pe ni nu e bi ti eko sugbon to ba continue bayi ni iwo yi odun meji si bi ilu yi na oni se gbe pelu traffic


@ Tawa
pele , bawo ni mummy e nko?
she oun jeun
ku jo meta oh!
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 12:04pm On Dec 11, 2007
@Bimbliss

Bawo ni?
mo wapa ooooo
Mo njeun si awon parents mi lorun ki won to le mi lo ile oko mi very soon.


Ise nko?
Pele ti traffic Abuja, Olorun akowayo.
Re: Do You Speak Yoruba? by topeteadr(m): 12:49pm On Dec 11, 2007
Gbògbö wâ ti ya wèré sé
Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 2:44pm On Dec 11, 2007
@tope,

to ba ti ya were, o de ya were tie siwaju!, kilode to so wipe gbogbo wa ti ya were?. Kin so oto fun e, mi o ro  wipe o funny at all, lati ma so wipe awon eyan ti ko se e ti ya were, haba!, e je ka ma ronu dada ka to ma post, the fact wipe a o mo ra wa ko de ni ka kan ma post rubbish ke!.
Re: Do You Speak Yoruba? by GeeCee(m): 4:12pm On Dec 11, 2007
E jowo e ma binu si Tope, ki se oun na. Infact emi gan ti n binu si tele sugbon o dabi pe ori e ti wale bayi. Nitori idi eyi, e bami dari ji ko ni se radarada mo.
E se pupo.
Re: Do You Speak Yoruba? by funmeme(f): 4:46pm On Dec 11, 2007
grin grin grin grin grin grin mio le so bi inu mi se dunto lati ba ede abinibi mi pade lori eto yiiiiiii ah adafun eniti orori lati post e.

aku imura odun ooo ati musulumi ati chritiani odun aya booooooo ani bodunlo gbogbo wa ooooo

ile o ni le wa sode

aasi ni gbe saajo.

ire ni gbogbo wa a ma ri oooo (amin)
[color=#000099][/color]
Re: Do You Speak Yoruba? by kosiie: 5:16pm On Dec 11, 2007
oda b'ayi o. awon yoruba nse tiwon nbi awon ibo nse ti wan no
mo ki gbogbo aara ile o
ada fun gbogbo yin, sheri, omo to n'so ede t'ofi bi lenu omo na ma dagba
aaagh, ede yi le o
arira
Re: Do You Speak Yoruba? by ndumart: 5:21pm On Dec 11, 2007
Awon eyan o tie wa ni ise mo bayi. kini awa ti a o gbo yoruba wa se bayiooo? Oda wi pe gbogbo wa ma ma so ede wa. E ku oro enu.
Re: Do You Speak Yoruba? by topeteadr(m): 12:15am On Dec 12, 2007
E ma binu si mi oh!.
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 11:06am On Dec 12, 2007
[size=40pt]Ekaaro nile ooooooo[/size]
Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 12:28pm On Dec 12, 2007
tope_teadr:

E ma binu si mi oh!.
a ti dari ji e, sugbon iwo ko gbodo ma soro koro mo nibi yi, to ba fe ma play game, forum wa fun yen!.

So wapa!.

@fun gbogbo ara ile,

EKARO OOOO![b][/b]
Re: Do You Speak Yoruba? by kochito(m): 12:45pm On Dec 12, 2007
Eyin temi omo kaaro ojiree,se a wapa? A de ku ipa le mo odun, mo gbadura pe odun ayabo fun gbogbo wa, gbogbo ohun ti a le lo ma bosi ninu odun titun to nbo, odun titun na yio s'oju emi wa(amin)
Yoruba bo won pa lowe wipe ti elese ba mo ese lese ki npe lori ikunle, nitori na eja ka dariji tope. Omode kin mo eko je ko ma ra lowe, omo de lonse tope.
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 3:12pm On Dec 14, 2007
EKu ise eni oooooo


Ki gbogbo yin ni nice weekend.

Re: Do You Speak Yoruba? by Nobody: 4:02pm On Dec 14, 2007
@tawa -temi,

Ba wo ni, ku jo meta, ise nko ati family?.

mo love weekend pic to attach yen, se o mind kin download e sinu phone mi grin.

Se wo ti pin rice xmas ni office yin, ka le wa si ile e nijo odun grin
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 11:51am On Dec 18, 2007
@ Home

Eku Ojo meta ooooooo

Ede ku ipalemo odun

Abawa laiye ati ni aiye wa.

Olorun awa pelu wa ninu odun 2008

Oluwa a mu ileri re se laiye wa ninu odun titun yi ooooo


@ilugunboy

bawo ni se o wa pa?

Ku ipale mo odun.

@bimbliss,richdad, biggerboy,

se ewa pa?
e ku ipalemo odun yi ooooo.

Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 11:53am On Dec 18, 2007
Eku ipale mo oooooo

Re: Do You Speak Yoruba? by ndumart: 12:25pm On Dec 18, 2007
Ese o, emi a se opo re
odun a ba wa layo
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 1:05pm On Dec 18, 2007
[size=40pt]E ku odun ooooooooo[/size]

Re: Do You Speak Yoruba? by DTruth1(m): 1:12pm On Dec 18, 2007
@ Tawa Temi
Shey awon oro inu picture yen o se ko ni yoruba ni

Awon pics naa ne wa lopo lopoo
Re: Do You Speak Yoruba? by TawaTemi1(f): 1:15pm On Dec 18, 2007
se oro wipe thred yi nikan ni pics naa wa fun ni?

mi o le se wahala jooo


nevertheless, ose pupo lati so wipe o wapa



D Truth:

@ Tawa Temi
Shey awon oro inu picture yen o se ko ni yoruba ni

Awon pics naa ne wa lopo lopoo

(1) (2) (3) ... (7) (8) (9) (10) (11) (12) (13) ... (43)

I Want To Learn Igala Language, Get In Here. / Ife Queen Wuraola With Her Lebanese Husband / History Of Nsibidi The Ancient Igbo Alphabets Britain Destroyed Ibo Civilization

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 39
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.