|
FL Gators
|
I see that the other thread was locked since it reached 100 pages. Eyin Omo yoruba, eku ka le o. Special welcome to my Ekiti peeps Okun o 
|
|
|
|
|
|
IFELEKE (m)
|
E ku ojumo eyin eeyan mi, a'a jiire bi? A ku ibere tireedi tuntun, tireedi yi a san wa s'owo,a san wa s'omo, a san wa si aiku baale oro. E je ka pa owo po lati gbe tireedi wa laruge nitori teni n teni atiwipe agbajowo la fi n so ya. tope-lobi,toyin,dayo,remii,fbs,orile,pafati,ajenti,tubabie,faakay,posa,abbey,kamoteesi,blu,olu,segoye,. . .a.b.b.l. mo ki gbogbo yin oo Special welcome to my Ekiti peeps Okun o  orekelewa,adumaradan, ot'orun! se ala lu e se? o to jo meta, nibo lo sa lo lati ojo yi?
|
|
|
|
|
|
Krayola (m)
|
YYAAAYY!! tireedi tun tun  se a ma fa party ni, abi?
|
|
|
|
|
|
FL Gators
|
@ife Ahhhh, mo creati tiredi, mo gbagbe. Joo, maabinu simi  Mo wa pa o. mo wa n bi, iwo lo ti ssalo. Se i un ara ule wa, topsy nko? YYAAAYY!! tireedi tun tun  se a ma fa party ni, abi? LOL !!!! As long as you arrange and pay for the expenses  se maltina la fi ma wash e ni? 
|
|
|
|
|
|
Abbey_city (f)
|
Ekan san o!
|
|
|
|
|
|
|
|
dominique (f)
|
kilo de 
|
|
|
|
|
|
IFELEKE (m)
|
E n le nile oo
|
|
|
|
|
|
Oluschenco (m)
|
se alafia ni gbogbo ile wa, o ti to ijo meta.
|
|
|
|
|
|
|
|
IFELEKE (m)
|
pafati o tun ti de abi?
|
|
|
|
|
|
Ogaga4Luv (m)
|
Odaro oooo. . . . . . .
|
|
|
|
|
|
IYA NGBALI
|
pafati o tun ti de abi?
pervert da?where is he?o ti pe ti mo ti nwa bobo na 
|
|
|
|
|
|
faakay (m)
|
Ota waa ma shaun ku ni oo
|
|
|
|
|
|
Winnergal (f)
|
ekule o, eyin eyan mi . . .
|
|
|
|
|
|
faakay (m)
|
Tipe Tipe ni moti soji! emi o ki nse alakori  eni kan o le wa ma so fun mi wipe eja lowa ninu sandin  hen? Awon Temi Yapa! Odun ti bo ooooooo
|
|
|
|
|
|
dayokanu (m)
|
E ku ojumo nibiyi o
|
|
|
|
|
|
Ogaga4Luv (m)
|
Ekugbadure oooooo. . . . . . . . 
|
|
|
|
|
|
dominique (f)
|
oniranu ni e  odaaro awon eyan ore mi 
|
|
|
|
|
|
Remii (m)
|
pafati o tun ti de abi?
pervert da?where is he?o ti pe ti mo ti nwa bobo na  ^^^^^^ Iyangbali ati Ifeleke Apa keji , lol. Gbogbo ile en le ni bi oooo
|
|
|
|
|
|
IFELEKE (m)
|
remii, ma da bobo onisokuso yen lo'un jo, bawo ni? o to jo meta, se alaafia lo wa ? Gbogbo ile, E ku isinmi
|
|
|
|
|
|
Positivity (m)
|
E kaale oooh! E ku isinmi.
|
|
|
|
|
|
dominique (f)
|
e ku ale awon eyon mi. . . se gbogbo e ndun? 
|
|
|
|
|
|
FunmyKemmy (f)
|
E ku atijo oooooooooo. Se daadaa ni? Se alafia ni e wa? Gbogbo ile n ko o?
|
|
|
|
|
|
Abbey_city (f)
|
Eka saaaaaaaan ninu ile yi o
|
|
|
|
|
|
IYA NGBALI
|
kini mo se fun e domi nikun?  ^^^^^^ Iyangbali ati Ifeleke Apa keji , lol.ma da ifeleke onisekuse ye lohun jare  Eka saaaaaaaan ninu ile yi o
Gbogbo ile en le ni bi oooo @abbey city nijo wo lo ma je ki nwo inu city?se inu city e kere abi o tobi dada?se o de fine like washington dc this thing 
|
|
|
|
|
|
Oluschenco (m)
|
Iya Ngbali, nigbawo lo to fe dekun (stop) iso ku so, odun ma tin lo s'opin. 
|
|
|
|
|
|
IYA NGBALI
|
Iya Ngbali, nigbawo lo to fe dekun (stop) iso ku so, odun ma tin lo s'opin.  ojo oko iku lojo isimi 
|
|
|
|
|
|
dominique (f)
|
iru lyan wo ni iya ngbali yi gan? moo ro pe o wa alright  odaaro awon eyan mi 
|
|
|
|
|
|
FL Gators
|
kilo sele so gbogbo awan omo yoruba ti wan wa ni section yi tele? eku veteran's day o, eku isimi, ede ku joli joli o  @Dayo how far na?
|
|
|
|
|
|
Remii (m)
|
Odun nlo s'opin Baba rere F'iso re so wa t'omo t'omo Oun ti o pa ni lekun o, l'odun tuntun Maje ko se le siwa o Baba rere
|
|
|
|
|
|
nolongTing
|
Ekaro oooo eyin eyan mi se alafia le wa?
|
|
|
|
|
|