Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,651 members, 7,958,967 topics. Date: Thursday, 26 September 2024 at 08:25 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! (176330 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (69) (70) (71) (72) (73) (Reply) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by EzePromoe: 10:55pm On May 11, 2013 |
ekale o, awon omo Yoruba, inu mi dun lati mo yin |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 8:03am On May 13, 2013 |
Eze Promoe: ekale o, awon omo Yoruba, inu mi dun lati mo yinBoo ni oo je e Eze puomo, se dada lo wa ? O ku ojumo !!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by EzePromoe: 1:41pm On May 13, 2013 |
donroxy: Boo ni oo je e Eze puomo, se dada lo wa ? O ku ojumo !!!E jo o, ko ye mi, N kò le ye èdè Yorùbá daradara, emi ni learner |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 9:02pm On May 14, 2013 |
donroxy: Boo ni oo je e Eze puomo, se dada lo wa ? O ku ojumo !!!How are you Eze promoe,Hope u re fine,Good morning !!! Eze Promoe:eh eh eh Nle oo jee omo Nna ....... Emi nio ye o nbe ? Laa hon mi kin salaye fun o ? O kun ooo !! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by EzePromoe: 3:51am On May 15, 2013 |
donroxy: How are you Eze promoe,Hope u re fine,Good morning !!!You were using Boo ni instead of Bawo ni, that is you're using your dialect, that's why i got confused. THANKS ANYWAY! Mo wa pa! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 12:43pm On May 16, 2013 |
Eze Promoe:Tis not a Dialect but a way of shortening ''Bawo ni'' while speaking Yoruba ''Boo ni'' Just like shortening Yoruba=Yooba !!!! Ndewo ooo !!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by topazjosh(m): 10:08pm On Sep 13, 2013 |
Ejoo o,ogbeni seun ogagun abga NAIRALANDI,e so fun awon modireto kan gbe tiredi yii lo is fronti peji,"koko oju iwe"mo n. Fiili e,in other words Ale o,ke n ti ri in ondo dialect! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by lushvox: 6:45pm On Dec 11, 2013 |
in the days of the colonial era - ni aiye awon ekolo ati ira gone are the days - ibon ni awon ojo na when things were good - ni igba ti agolo dara but when things were bad - sugbon ni igba ti agolo baje hence forth - adiye nja ... I forgot the rest... 2 Likes |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by abiolz(m): 11:50am On Sep 01, 2014 |
E ku osu titun yi o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by fuckluv(f): 7:29am On Sep 04, 2014 |
lushvox: in the days of the colonial era - ni aiye awon ekolo ati iraYooba dun gan ooo! Ewo tiransilation aye! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by CokerAnne(f): 10:42pm On Sep 08, 2014 |
E ku ale gbogbo ile o! E ku ise atooro o, se ko re ara ju? Oruko mii ni omo-obabirin Adediwura Adeola, mo wa lati ilu kekere kan ni ipinle Ogun, mo je omo odun mejidin logbon, mo feran lati maa ka, iwe, mo is tun maa ngbadun ere alafe, mp je eni ti o ko eniyan mora lopolopo, mo is ni emi irele ati iteriba eleyi lo mu ki ifee mi l'okan omode ati agba. Month fee lati danu duro nibi yi naa. Ngo maa tesiwaju ni ojo miran. O daaro o, Oorun ire la o sun.... |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 9:08am On Sep 09, 2014 |
CokerAnne: E ku ale gbogbo ile o! E ku ise atooro o, se ko re ara ju? E ni aamu s'aya |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by bolorunfem(f): 4:23pm On Nov 26, 2014 |
Eyin temi, ibo le wa? O to jo meta? Se alafia ni e wa gege bi emi naa se wa nihin? Se ise nlo? Ile nko? E de ku ipalemo odun, a a ba wa layo ati alafia. E jowo e ma je ki okun yi ku o, e je ko maa lo bee. Yoruba dunn ka, Yoruba dun lede. One Love! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by bolorunfem(f): 7:40am On Mar 25, 2015 |
lushvox: Well, well, well - Kanga, kanga, kanga Who knows? - Imu tani Nobody knows - Kii se imu enikeni Only God knows - Imu Olorun ni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Carriacou1985(f): 5:04pm On Mar 25, 2015 |
Greetings to you all, I am trying to learn more about my culture, although I am not of Nigerian or even African blood but I hope maybe someone can help me. I have recently created a post here to find out if some ancient songs and dances originated from the Igbo people of Nigeria passed down to us from our ancestors taken from west Africa in the slave trade. I had 2 replies which said that the language of the songs sounded more like Yoruba than Ibo. So maybe someone here can clarify it for me? In our tradition we perform a big drum dance for weddings and funerals and other events to receive blessings from our ancestors gone before us. The song is called: Ibole Ibole woy yo Gongo banan plantain Me wo yo Ibole Ibole woy yo Hele bu Legba wo yo We also have another song entitled: Ogun maa se sile wa Can someone pls tell me if this could be the Yoruba language? Many thanks in advance |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by seedorfg(m): 6:20pm On Apr 04, 2015 |
e ku iyaleta o, eyin omo ile kaaro o'jire, se dada lawa, e si ku osu titun yi o, emi ishola agbo, omo a'ji lala eso, a'fi gbogbo ara da bi egbin, ala i gbagbe oju o r'eje, fi gbogbo oju sunkun omi, nki gbogbo yin oooo ! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by tpiadotcom: 12:54am On May 12, 2015 |
tunnytox: where did an ogbomoso man learn to speak ekiti? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Nobody: 11:07pm On May 13, 2015 |
tpiadotcom: iwo ko tie le ko ede abinibi re. geesi ni ki o ma a so nibe. ko ra re kuro lori tiredi yi jare. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Ousmaf(m): 7:43am On Sep 14, 2015 |
Eku ojumo nle se alafia laji bii? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Ousmaf(m): 7:45am On Sep 14, 2015 |
Ekaaro nile yi o se dada laji? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by minato015(m): 10:50am On Nov 11, 2016 |
[color=#000099][/color] E karo ni yara yi oo... She gbogbo yin wa pa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Olu317(m): 2:40pm On Nov 11, 2016 |
E ka san eyin eyan mi, se da da ni awa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by YourNemesis: 6:03pm On Nov 11, 2016 |
Olu317: Beeni, dada ni a wa. Bawo ni gbogbo nkan se n lo? E ku asiko ti a wa yii o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Olu317(m): 7:54am On Nov 12, 2016 |
E kaaro o gbogbo omo oduduwa. Mo dupe lowo Eledumare fun ore ofe ati abo e lori ebi mi ara ati oju lumo. Aku ifarada ijoba Buhari. Anu olorun a yiwa ka |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by scholes0(m): 8:07am On Nov 12, 2016 |
Olu317: Inu mi dun lati ri wipe Yoruba kiko le ti owo omo Oodua dun ka bi eleyii. Pupo ninu wa ni ko mo ede Yoruba kiko bi o se to, ati bi o ti ye. Ki n maa fa oro gun sa, E ku ise. Olorun yio so agbara yin di otun. 1 Like |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Rilwayne001: 8:30am On Nov 12, 2016 |
topazjosh: Aayan Ogbufo yin buru jai 1 Like |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Rilwayne001: 8:34am On Nov 12, 2016 |
Eku owuro ni ahin o. Oruko tawa ni Riliwanu Adigun. Inun mi dun, ayo mi kun lati ti ri awon omo iya mi lori tiredi yii. Oodua agbewa ooo! Ogagun Sukkot, a nreti yin nikale o 1 Like |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by haffaze777(m): 8:49am On Nov 12, 2016 |
L'esi omo oluware iyi da iru eleyi l'asa?too Dede eyin ojogbon iyi wa Ni ikale ree mo kii.Emabinu pe ede egba re emi fi ki yin oooo,ba ra'se n se n'ile lisabi agbongbo akala,ololajulo oba rilwayne001 e wa ko ede egba |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Rilwayne001: 9:15am On Nov 12, 2016 |
haffaze777: Ede Yoruba ponbele la n so ni ori tiredi eleyi. Ede egba yii le pupo, o yato gedegbe si Yoruba tiwa n'Ibadan. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by sukkot: 11:27am On Nov 12, 2016 |
Rilwayne001:ekaro Sir. ekugbogbo e. shey gbogbo e nlo Sir ? akoba adaba oloun majari lolzzzzz <<< THE BOLDED IS HAUSA PRAYER WHEN I WAS DOING TIME IN LAGOS 2 Likes 2 Shares |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! by Justiceleague1: 5:18pm On Nov 12, 2016 |
Rilwayne001:ahhhh! Shebi mo sò tèlé. Mo mò pe orukò yi riliwanu.....haaahahahahaha.... Èèle,ooo, gbo gbo òmó ègbé..well orukò mi ni dafidi.. mo kii gbogbo yii o...ka se ma dupè fun òlòhun fun Trumpu to ti di president ni ilu America. Gbogbo awa,afonja,inu awa dun.. 1 Like |
(1) (2) (3) ... (69) (70) (71) (72) (73) (Reply)
Owe Ile Yoruba -some Lovely Yoruba Proverbs And Their Meanings. / Yorubas, Please Help Me Translate These Words. / Most Frequently Used Insult In Nigeria
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 40 |