Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,151,888 members, 7,814,007 topics. Date: Wednesday, 01 May 2024 at 12:33 AM

Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju - Health (8) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju (558409 Views)

Civil Servant Killed By Thunder In Oro, Kwara (Photos) / Ogun Ibile To Daju / The Bad Shape Of Oro General Hospital, Kwara State (Exclusive Photos) (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) ... (27) (Reply) (Go Down)

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:58pm On Feb 28, 2016
possible26:


BABA ejowo e fun mi ogun premature ejaculation


Ewe lapalapa funfun ati pupa ewe egele funfun ao gbo dada ao se ao ma mun laro ati ale
NB ewe egele yi kiki egun ni gbogbo arare ale ko gbogbore sinu odo kagun kia bu omi si dada ki awa se pelu ase tabi ki aki ora toba lagbara bowo kafi gbo odara

5 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by admolfemx(m): 10:20pm On Feb 28, 2016
kadunasouth:

Ewe na oloruko meji rekureku kifa kokoja ona
Ewe na common lodo awan elewe omo eko sinu pepa ewe rekureku ki efun wan, wan ofun yin
Baba kadunasouth e kale o,olorun yio ma wa pelu yin o amin.ibere mi ni wipe e jo bawo ni mo se lewo akosejaye eni ati pe iru igbese wo ni mole gbe lati wo,ejo eran mi lowo fun ibere mi yii,e se pupo.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Zenlife: 10:45pm On Feb 28, 2016
Baba, ejowo mo fe ki e bami se ise kan. Mo ni card fun yin lowo. Ago abanisoro yin o lo, se e o lo whatsapp mo ni? O se pataki gan. E jo ki e kan mi sori e-mail

Ossezx@gmail.com
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by systembayo: 10:37am On Feb 29, 2016
baba ejo mo need Ogun eni to wa girl friend tabi iyawo.ewe amaje oooo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by geejayjax: 2:25pm On Feb 29, 2016
kadunasouth:

Copy it out and take it to elewe omo u can't spend more than 300 give then five hundred to bust their moral they will prepare it for u and take it morning and night very effective
Pls, if u don't mind translate it. Thanks
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:16am On Mar 01, 2016
geejayjax:

Pls, if u don't mind translate it. Thanks
Translation of ogun is not allow on this thread

3 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:29am On Mar 01, 2016
Aseje Owo (money)
Abo adie alawo meta(3 color) ao pa ao ge kekeke si ona to ba wuwa, iru iyere ata ijosi ewe ologosese ao gun gbogbo re ao fi se adie yi lepo niyo
To ba tutu ao fi iyere osun te ifa eji ogbe ao pe ofore si ao dasi ao koje
Arin igi oko lo longosese nti de ade tie gbogbo ibi ti month badurosi ni kiwan ti ma de mi ni ade owo nla nla, eji ogbe baba ifa wa gbe alanu temi komi nibi ti mobaduro si Ase

7 Likes 2 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by possible26: 1:08pm On Mar 01, 2016
BABA edakun e funwa no ogun iba jedojedo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by systembayo: 3:36pm On Mar 01, 2016
baba ese fun ise ti efuwayi olorun aba wa dupe fun yi oooo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Zenlife: 7:38am On Mar 02, 2016
Baba ejowo e funwa no oogun obinrin ti o yan ale pelu oogun awise. Adupe.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by wale259(m): 3:11pm On Mar 11, 2016
Sir,e ku atunse,olorun oba ko ni da ile ati ona yin ru,e jo month fe ki e salaye arin yi ni (toto ikuku to badi aru ao fise sara sita)ati wipe se a ma so igbin yen nu ni.
kadunasouth:
TUDE ASINA
Ekuru funfun, igbin kan ao lu igbin ni idi ao jo omisi ekuru pelu ori(sea butter) toto ikuku to badi aru ao fise sara sita
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by wale259(m): 3:20pm On Mar 11, 2016
Baba,e jo kini itumo ki ma gba ogorun eyan lelo oseyi.
kadunasouth:
Ogun Atude Ituwo tiwan bade owo eniyan mejeji
Odidi bara kan ao gesi 16 ao ko tele ape ao wa gbe ori musu tonirun le lori ao fi odidi atare kan si legbe ao jo ao popo ma ose ao mafi we owowa mejeji
Iba akoda iba aseda iba eyin aye ewa tumi nide edi kidi bara ki gbogbo ide owomi kotu danu ki owo mi bere si ya fun owo nlala ki magba
Ogorun eyan lelo oseyi



Moju ba re olodumare

1 Like 3 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by MJAhmed(m): 10:20am On Mar 12, 2016
wale259:
Baba,e jo kini itumo ki ma gba ogorun eyan lelo oseyi.
baba Kaduna south means that ogorun eyan lelo(hundred people can use it) that many people can use the soap

2 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 5:40pm On Mar 12, 2016
Ogun iferan ki gbogbo aye le nife wa
odidi eyele funfun,ao fi ori ra gbogbo arare, ewe alupayida ewe egele, ewe ewuro oojo, Odidi atare meta, a Jo gbogbo re po, a po mose ao tun fi ori die si, a maa fi we lararo.

5 Likes 3 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ousmaf(m): 12:36pm On Mar 13, 2016
kadunasouth:
Asiri Ola (ki ona owo le lakanwa)
Ako ati Abo eye ega owo eyo mesan ewe ola ati ewe sawerepepe odidi atare kan ao ko gbogbore sinu fitila oloju merindinlogun inure lao tijo ao lo ao mafi miliki lo lararo iseyi daju fun owo ati okiki and connection

Ejo baba Agba yin a dale e o sini ri ogun akoba, oruko miran wo latule pe 'ewe ola', ese Olohun Oba to ga julo aman ran yin se, ameen.
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 2:23pm On Mar 13, 2016
Ousmaf:


Ejo baba Agba yin a dale e o sini ri ogun akoba, oruko miran wo latule pe 'ewe ola', ese Olohun Oba to ga julo aman ran yin se, ameen.
Ewe oja tabi ewe igbo tiwan nmu

5 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by wale259(m): 5:12pm On Mar 13, 2016
Sir, e jo se inu fitila na lati ma lo kuna abi ale lo lori olo...
kadunasouth:
Asiri Ola (ki ona owo le lakanwa)
Ako ati Abo eye ega owo eyo mesan ewe ola ati ewe sawerepepe odidi atare kan ao ko gbogbore sinu fitila oloju merindinlogun inure lao tijo ao lo ao mafi miliki lo lararo iseyi daju fun owo ati okiki and connection

2 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Seylad2009(m): 5:41pm On Mar 13, 2016
kadunasouth:

Ewe oja tabi ewe igbo tiwan nmu
E jo wo mo ni lati bayi soro lori ago. E Jo wo e fi numba iba araeni soro yin rese si mi lori seylad2009@gmail.com tabi 08066717262.
Ese pupo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Zenlife: 2:32am On Mar 14, 2016
kadunasouth:
Ogun iferan ki gbogbo aye le nife wa
odidi eyele funfun,ao fi ori ra gbogbo arare, ewe alupayida ewe egele, ewe ewuro oojo, Odidi atare meta, a Jo gbogbo re po, a po mose ao tun fi ori die si, a maa fi we lararo.

eiyele ti aye tabi to ti ku?

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:07am On Mar 14, 2016
Zenlife:


eiyele ti aye tabi to ti ku?
Ao le mole ti yio ku le kanna tabi kadu sinu koko ijo nkan ao sese wa fi ori pa lara

2 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:38am On Mar 14, 2016
Seylad2009:

E jo wo mo ni lati bayi soro lori ago. E Jo wo e fi numba iba araeni soro yin rese si mi lori seylad2009@gmail.com tabi 08066717262.
Ese pupo
09090305775

2 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by grinface98(m): 6:32am On Mar 15, 2016
kadunasouth:

09090305775
Ekaaro Baba Agba. Agba yin yio dale oo. E jowo mo nilo ILIAMU to daju gidigidi lati owo yin. Alfa ni mi ni Osun sugbon baruufu ni pupo ninu awon ILIAMU ti mo ni. Ese gaan baba. Ewe aje oo!!
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by wale259(m): 9:23am On Mar 15, 2016
Baba kaduna,e jo e fesi si ibeere mi yi...se inu fitila na lati ma lo kuna abi ale lo lori olo...
wale259:
Sir, e jo se inu fitila na lati ma lo kuna abi ale lo lori olo...
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:33am On Mar 15, 2016
wale259:
Baba kaduna,e jo e fesi si ibeere mi yi...se inu fitila na lati ma lo kuna abi ale lo lori olo...
Ale lo lori olo

3 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 11:39am On Mar 15, 2016
Ejo sir, kini oruko miran ti akopa jen?
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 12:28pm On Mar 15, 2016
kadunasouth:
Gbere Ebe Awon Agba
Igo ngori ewe Agogo igun ao ja 99 odidid atare kan ao jo papo ao fi sin gbere si igbaya otun gbere meta, eyin meta, igbaya osi meta eyin igbaya osi na meta opari odaju

Ejo sir, ki lo je igo ngori, e salaye?

1 Like 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 12:50pm On Mar 15, 2016
zenith329:

Ejo sir, ki lo je igo ngori, e salaye?
Ododo ori re, flour to wa lori agogo igun, eo ri oun ma te condoro yio gun yio wa kako oun lema ja 99

3 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by wale259(m): 1:16pm On Mar 15, 2016
E jo sir,se opolopo eyan lelo.
kadunasouth:

Ododo ori re, flour to wa lori agogo igun, eo ri oun ma te condoro yio gun yio wa kako oun lema ja 99
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 5:33pm On Mar 15, 2016
wale259:
E jo sir,se opolopo eyan lelo.
Beeni

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 9:45pm On Mar 15, 2016
kadunasouth:
Eyonu Ebe Awon Agba
Igi Asorin(igi nla)) epo obo iye igun akopa eyokan ao lo gbogbore ti yio kuna ao wa dasinu adi eyan ao ma fi para odaju sugbon oni eewo eyokan ijo kijo tabati lo ise yi akogbodo lo turare yala fi para abi fi saso odaju
Ejowo baba kadunasouth, mo ti bere akopa lowo awon elewe omo sugbon woni awon ko mo ohun ti o jebe, ejowo sir, kini oruko miran ti akopa je?
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:52pm On Mar 15, 2016
zenith329:

Ejowo baba kadunasouth, mo ti bere akopa lowo awon elewe omo sugbon woni awon ko mo ohun ti o jebe, ejowo sir, kini oruko miran ti akopa je?
Eye gunugun(eye igun) iye apare to gun dada ni wan peni akopa
Eyokan ni wan ma bayin tu, wan sile ti tu kale fun tita

3 Likes 2 Shares

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Zenlife: 4:23am On Mar 16, 2016
kadunasouth:
Awise
Ewe ogbo ewe alupaida eyo atare kan ao lo ao fi sin gbere si isale ete wa, gbere eyokan lago kan oru lojo sunday, ebu toba ku ao fe sinu ategun

baba se ese mejeji ni a ma sin gbere eyokan si? Bo je okan, osi tabi otun?

(1) (2) (3) ... (5) (6) (7) (8) (9) (10) (11) ... (27) (Reply)

Causes Of Seeing Menstrual Period Twice A Month / Postinor 2 - How Effective Is It? / Doctor in the House: Free Medical Advice Available

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 51
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.