Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,194,853 members, 7,956,194 topics. Date: Monday, 23 September 2024 at 07:31 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju (565221 Views)
Civil Servant Killed By Thunder In Oro, Kwara (Photos) / Ogun Ibile To Daju / The Bad Shape Of Oro General Hospital, Kwara State (Exclusive Photos) (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (8) (9) (10) (11) (12) (13) (14) ... (27) (Reply) (Go Down)
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 4:13am On Apr 04, 2016 |
kadunasouth:Ejo sir,se a le lo eyin agric Oojo? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:54am On Apr 04, 2016 |
zenith329:Elelo sugbon ise na koni daun dada, sugbon ti ibile yio tete daun 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Zenlife: 9:11am On Apr 04, 2016 |
Baba mo ki yin o. E jowo e fun wa ni oogun fun omo osun mefa ti o ni iko, otutu, cattarh, pelu congestion ni aya. Oogun oyinbo o sise fun. E jo baba, e ran wa lowo. Adupe. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 2:42pm On Apr 05, 2016 |
Aseje Atude Ao ra eyin agiriki meta ao bo yio jina dada to batutu ao bo epo eyin yi ao wa koko isasaun kekere kan ao lo ewe tude die ati egbo tude die ati iyere 16 ao lo ao da sinu koko isasun ao to omi oronbo die si akonifi epo si ati iyo ao gbe kana ao wa da eyin yi si ao se to ba tutu ao ra agban kan ao lu agban yi lona meta ao fi omiyi sin owo wa katoje aseje yi taba jetan ao fi owowa mejeji nu ara agbanna alefise sara tabi kalore jusi ori atan ide arawa yio tu patapata sugbon aseje yi osoro latije ama odaju NB taba jetan gbogbo arawa ni yio weak sugban leyin wakati die tabi ojo alafia yio de ona yio si si funwa ibare olodumare ati awan agbagba 4 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Dadsonval(f): 3:32pm On Apr 05, 2016 |
[quote author=Zenlife post=44390826]Baba mo ki yin o. E jowo e fun wa ni oogun fun omo osun mefa ti o ni iko, otutu, cattarh, pelu congestion ni aya. Oogun oyinbo o sise fun. E jo baba, e ran wa lowo. Adupe. E jowo baba, mo nilo egbo igi fun infections ara |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Dadsonval(f): 3:33pm On Apr 05, 2016 |
Baba mo ki yin o. E jowo e fun wa ni oogun fun omo osun mefa ti o ni iko, otutu, cattarh, pelu congestion ni aya. Oogun oyinbo o sise fun. E jo baba, e ran wa lowo. Adupe.[/quote] baba mo ki yin o, e bami wa ogun antibiotics sir |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Dadsonval(f): 3:35pm On Apr 05, 2016 |
Zenlife:baba mo ki yin o, e bami wa ogun antibiotics sir |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 11:37am On Apr 06, 2016 |
kadunasouth:Ekaaro sir, e jo kiloje omi oronbo? Se omi agbon yen a maa fi san (wash) owo wa ni? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Nobody: 6:43am On Apr 07, 2016 |
ohhhh 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:10am On Apr 07, 2016 |
zenith329:Osan wewe, tabi osan were , osan kekeke lonje oronbo(lime orange) Omin agban na ama fin san owowa mejeji ni wash hands 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by zenith329: 7:08am On Apr 08, 2016 |
kadunasouth:Good morning sir, e jo kini oruko imi ti koro isin tun je? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ETHIX(m): 7:56am On Apr 09, 2016 |
Good |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ade231(m): 10:20am On Apr 10, 2016 |
kadunasouth:baba ese pupo olodumare yio ma ti yin leyin o,ejo eyin ti e so yi se eyin oojo(new layed egg)ni abi eyin wo ni sir ese pupo hun ma reti esi yin sir. 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:35am On Apr 10, 2016 |
Ade231:Yes new layed egg for that day, d egg must be used on the same day 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:17pm On Apr 10, 2016 |
OSE AROBI/Awe ibi danu Ose dudu, ewe esiponla, oju oro, ewe alupaida, ao gun gbogbo re mo ose. Ao maa fiwe ori de orun. NB: ako gbudo fi ose yi we gbogbo arawa Ewo nio 5 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by AdiscoPele: 9:13pm On Apr 11, 2016 |
kadunasouth:Ejo baba, se ti a ba lo iseyi, se ibi na ko ni re si ori awon omo tabi ebi wa. Ejo sir, alaye yi wa fun awa ti a ko mo itunmo AROBI ni sir. Eseun pupo |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:27pm On Apr 11, 2016 |
[quote author=AdiscoPele post=44617688]Ejo baba, se ti a ba lo iseyi, se ibi na ko ni re si ori awon omo tabi ebi wa. Ejo sir, alaye yi wa fun awa ti a ko mo itunmo AROBI ni sir. Eseun pupo[/quote Ori ota ni ibi ma pada si Arobi means back to sender 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by AdiscoPele: 9:45pm On Apr 11, 2016 |
[quote author=kadunasouth post=44618051][/quote]Eseun sir |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Tevez83839: 11:08pm On Apr 11, 2016 |
Edakun baba oluyaworan nimi .lati igba timo ti si shop kosi oja edakun mofe maa ta gba ise nlanla .i tomode tagba ma gbe ise wa funmi ,ki ero ma da lodomi..boya eyi ti mo le se si shop ti maa rimole tabi gbeko tabi eyikeyi edakun .moje gbese mofee sanwo .monilo iranlowo yin ooo.kadunasouth ibao |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 11:26pm On Apr 11, 2016 |
Hybrid01:Mo ti post ise yen seyin emawo ni page by page eo ri (Ero teso, kia le ri iyawo wa basun) elo se kia ni ona yio si lati wole lati jade 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Tevez83839: 6:14am On Apr 12, 2016 |
Baba edakun e add mi ni whatxapp 08162736520..eko dami lohun ni.. Atipe ti oko okunrin ba kere baba health first soro lorire won ni ogun re todaju awon koni fe post e pe eyi to daju wa torii ayederu poni ita 08162736520.edakun titi ise shop yen eranmilowo nipae |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 10:49am On Apr 12, 2016 |
Tevez83839:Emi okin se whatsup group, ma post agbo lati fo idoti abe okunrin to ma nfa ki oko sunki ti awan idoti yi bati jade nkan omo okunrin yio wa bosiye kowa isere yio sipe dada 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by AdiscoPele: 11:21am On Apr 12, 2016 |
kadunasouth: Atude Asina Omundun ewe akoko 9 ata ijosi eyokan ao gun papo ma ose talewe tan lekan soso ao fiwe Ejo sir, se a le lo ise mejeji yi papo. Se a le fi ose ta ba gun fi we ewe akoko ati ewuro. 2 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 12:26pm On Apr 12, 2016 |
AdiscoPele:Beeni oda pupo yio fi tete daun omi agbo yen efi we osena kiewa funmi ni iroyin re leyin ojo die tie tilo 4 Likes 1 Share |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by AdiscoPele: 12:44pm On Apr 12, 2016 |
kadunasouth: Eseun pupo sir fun idaun noo. Otun ku kan sir, ewe akoko po ni adugbo mi, iya elewe omo kan ni o fi han mi, mo si tun ni igi ewuro ni inu compound mi ti mo gbin fun rara mi. Ibere mi ni wipe, se mo le ja awon ewe ni ori igi tabi kin lo re ra lowo elewe omo? Mo fe ke mo wipe gbigbe ni awon elewe omo man ta, atipe mio fe ki o dabi wipe niwon igba ti mo ti mo awon ewe yi, mio ra mo lowo awon elewe omo mo. Se ko si aburu ti mo ba ja awon ewe yi lai san owo fun. |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 5:14pm On Apr 12, 2016 |
AdiscoPele: Koburu rara 1 Like |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by jcklsweet(f): 9:59pm On Apr 12, 2016 |
ekaale baba...ejowo sir...ogun ibile wo ni mo le lo fun athritis? |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:22am On Apr 13, 2016 |
jcklsweet:Abere topo die ao gun die alubosa ayu, kanafuru , kankadoro(ata ile) kafura pelebe ao ki lagbo pelu omin ao ma yomu ti on ba ti kawa lowo ao bu omin to gbona die sibikan ao to agboyi die si ao wa ki owo na bo pelu ogo oloun yio bayin lara mun 3 Likes |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Tevez83839: 11:48pm On Apr 13, 2016 |
Edakun babawa kadunasouth .Agbo tee sope ema bami fi sita lori oko mi to n sunki teeni gbogbo idoti yen akuro ti oko mi yoo si pada si aaye re .edakun awon ore mi n fimi se yeye pe oko mi kere sitawon |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by jcklsweet(f): 9:27am On Apr 14, 2016 |
kadunasouth:e seun gaan sir...e jowo gbogbo ile...e ma binu si mi o...can anyone please help me interpret the prescriptions I've just been given....e joor ma...e joor sir... |
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 6:42pm On Apr 14, 2016 |
jcklsweet:Copy it out into a piece of paper, give it to elewe omo tell them u are the one to take it they will prepare it 1000naira can buy all 1 Like |
(1) (2) (3) ... (8) (9) (10) (11) (12) (13) (14) ... (27) (Reply)
Causes Of Seeing Menstrual Period Twice A Month / Postinor 2 - How Effective Is It? / Doctor in the House: Free Medical Advice Available
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 40 |