Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,158,294 members, 7,836,286 topics. Date: Wednesday, 22 May 2024 at 02:55 AM

.. - Culture (73) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1831377 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (70) (71) (72) (73) (74) (75) (76) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by dominicson: 10:23pm On Apr 15, 2016
omoalade144:
Moki gbogbo ile o.Ejoo se baba Heltfirst kosi nile ni




Imule: Asefijin


A o fi ikoode kan ha adaripon kan l'enu. A o fi atare kan naa ha. A o jo, a ko ni so kale ti o ba ti jo tan, a o fi omo olo lo mo inu ape, a o wa da epo pupa die si, a o fi ekiri aran malu kan si. Ti o ba ti din(fried), a o pa ina ni idi re, sugbon a ko ni so ikoko na kale. Ti o ba ti di agogo kan oru, a o da oogun yi si enu ona, a o bo ara sile ni ihoho, a o dobale, a o so wipe:




Psalm/nafdac

Asefijin, asefijin, asefijin, ti alangba ba se igba eniyan, idobale kan soso bayi ni nfi tan. Idobale mi re o, gbogbo enia ti mo ba ti se, oso ni, aje ni, emere ni... e fi orijin mi o. E je ki ona o la fun mi, ki n ri temi se o. Plus personal prayer.

2 Likes

Re: .. by Ifatoki16: 1:13pm On Apr 16, 2016
Baaba mi Ifankaleluya.mo wari faye mo seba agba ooo.Ifatoki16 lo nkan si yin pe ke ma gbagbe mi,awon to laye ko ni gbagbe eyin na.ifa keji Imule awon Agba ti won nfi amin igba si aya wa ti mo bere lati ojo yi,eo ti fun mi.Se e nbinu simi ni? llcatz@yahoo.com
Re: .. by marv006: 11:40pm On Apr 16, 2016
PAPA LO JO MO LO TANHUN TANHUN,
OGUNNA KAN SOSOOSO LO SO ELULU DILEELE,
A DIA FUN ANRERE OMO OLODUMARE,
OMO ATENI LEGELEGE FORI SAGBEJI OMI,
NIJO ON NI O RUBO SAIKU ARARE..

.....Ifa losobe..OFUNOBARA.
Re: .. by marv006: 11:58pm On Apr 16, 2016
OWONRI IWORI

Ise ni o se gunnugun ko ba loorun,
A dia fun Owonrin omo asegilowo,
Osi nio takala ko ba leruwa,
A dia fun Iwori omo atapola sola,
awon iwo o sai la, emi o sai la,
A dia fun Alafohunfojuri omo asoru ta ra igba eru,
awon le la laye bi?
ebo ni won ni won o ru o,
igba ti won rubo ni ise ba tan, loro ba de,
nje iwo o sai la, emi o sai la,
gbogbowa la o la si rere laye o.
Re: .. by marv006: 12:12am On Apr 17, 2016
Atupuru odo ni kose fi gunyan,
Atupuru ikoko ni won fa lokun danyin-danyin-danyin,
A dia fun Ori,
Ori wa nlo ode Ajalaye,
won ni ko sakaale ebo ni sise,
Ogbebo orubo,
Nje Awede we tie o mo,
Ella ifa, we Ori mi mo,
Ogede we tie o de,
Ella ifa wa weri mi mo,
Ara kii ni ogede koma de,
Ella ifa wa weri mi mo,
Ero woo ni ti igbin,
Ella ifa wa weri mi mo.

Ise keke kan nu fun awon ti ooye ye.
Re: .. by Lero70: 9:57am On Apr 17, 2016
marv006:
Atupuru odo ni kose fi gunyan,
Atupuru ikoko ni won fa lokun danyin-danyin-danyin,
A dia fun Ori,
Ori wa nlo ode Ajalaye,
won ni ko sakaale ebo ni sise,
Ogbebo orubo,
Nje Awede we tie o mo,
Ella ifa, we Ori mi mo,
Ogede we tie o de,
Ella ifa wa weri mi mo,
Ara kii ni ogede koma de,
Ella ifa wa weri mi mo,
Ero woo ni ti igbin,
Ella ifa wa weri mi mo.

Ise keke kan nu fun awon ti ooye ye.
baba awo ekuise takuntakun teefi nse iranlowo fun gbogbowa Eledumare yiomaa ranyinlowo.
Bana momope eyinnaa mope kiise gbogbo wa ni omoawo nitorinaa ejowo emaa funwa ni awon ise yi ni pipe. Olorun konii se oore yin ni aabo
Re: .. by Nostradamus: 10:04am On Apr 17, 2016
kadunasouth:
Asiri Owo(Asiri bibo)
Eye lekeleke odidi kan ao fi orisi owo meji, eyokan lapa otun, ikan lapa osi e.g (1000 naira and 500naira) or 200/100
Ao gbe sinu agbada ao ko opolopo ewe aje lelori ti yio bomole ao wa fi odidi atare meta si ati oko atare meta ati eyo atare meta ao jo ao ma fi miliki olope lo lararo kato soro si eniyan odaju
Ise yi dara debi wipe taba lotan osukan si meji atun ma sise lo larawa, lekeleke ki rinrin idoti asiriwa yio bo, ise yi daju tobarise oti kuro ninu egbe otosi.
Danwo o confirm No repercursion
e jowo sir,e fun wa ni oogun ti omo ile iwe eko giga ti unifasiti le lo lati fi bo ri ogun carryover ki o le tete se tan pelu awon ara ti won jo ri admission nigba kan..a maa ri yin ba sir
Re: .. by Tevez83839: 11:05pm On Apr 17, 2016
Edakun nipa oso aworo ...shop mi fee dada .e salaye funmi
Re: .. by Tevez83839: 11:05pm On Apr 17, 2016
Edakun nipa oso aworo ...shop mi fee dada .e salaye funmi .nipa oso aworo
Re: .. by wale259(m): 9:42am On Apr 18, 2016
Bawo la se ma se eyele yen leyin ti a ti lo eje re tan ati wipe igbawo ni lilo re
marv006:
ASINA KEKE KAN NI O

ORI OKETE
EGBO TUDE
ERU ALAMO
EWE EJINRIN ATI
EWE EWURO.

ao jo, aolo, aoteni OTURA-OGBE.
ao fi eje eyele po, ao su si ona meta,
aofi REGAL lofunjo meta.
Re: .. by Lero70: 7:55pm On Apr 18, 2016
marv006:
OSE-IRETE ( OSE BI IRETE SI ILE AJE)

IFA O DI ALAJUBARAKA, EMI O DI ALAJUBARAKA,
BI ABA LO JUBARAKA KIO JUBARAKA, OBI OLOTOORO,
OBI OLOTEERE, OBI ONAWOFUNMIRIN, ONAWOFUNMIRIN
LO BI AJE, AJE LO BI ENIYAN, AJE DI ORE OLOKUN,
ENIYAN DI ORE IRADA,
OSE KIO SAREGEGE LO RE MU AJE WA FUN MI NI ILE OLOKUN,
IRETE KIO SAREGEGE RE IRADA LORE MU ENIYAN WA FUNMI,
APE KIO MAJE KI IRE MI PE KIOTODE, EJINRIN KIOMAJE KI
IRE MI RIN JINA KIOTODE, BI ABA GBALEGBA'NA,
AATAN LA NKORIRE SI, IRE GBOGBO KO WA BA MI NI JEBUTU,
IRE GBOGBO KO MO DARI SODO MI.

EWE IFA: ewe ape, ewe ejinrin, yerupe atan to gba igba ese, omi okun, ose, osun pupa not osun buke o, eje eyele funfun meji; okan fun ose okan fun irete, ara ogiri yara wa ni ao pari ise yi si o. Aini di gberee nu o, ifa awon baba nlawa niyio o, eyi ti alefi okete ti nse eran ifa na gbe ebo re wa.
baba eku ise o, Eledumare togbingi ogbon siiyin nikun koniije Koku, aseti kiibojo kojomayo aseti konii baayin o. Ejowo mosakiyesi wipe opo awon ise ti e nfunwa ni e nseku sikun, mosimope onidi teefi nsebee,
baba ejowo efunwa ni email yin kalemaa beere fun iyoku labe-aso. Eseepupo, Eledua konii kodi aimoose siiyin laelae.
Re: .. by Benjamite01: 11:41pm On Apr 18, 2016
Sir Healthfirst at Kadunasouth.. ejo, mofe ki e fun mi ni ise ti mole lo losi visa interview ti moma fi ri anu gba, ki wole funmi ni Visa, nitori pe mo ti gbiyanju ni a i moye igba.
Re: .. by Nostradamus: 6:48pm On Apr 19, 2016
Ifankaleluya:


e-mail po ti mo n fo esi si ni. E ma ti binu, n o da esi pada laipe.
baba mi agba,e jowo sir,e ya aworan awon odu ifa ti o wa fun wa,mi o man won te,awon odu bi EJI OGBE,OGBE OBARA,OBARA KAN ati bebe lo,ese gidi gan sir.
Re: .. by Ifankaleluya: 7:31pm On Apr 19, 2016
marv006:
OWONRI IWORI

Ise ni o se gunnugun ko ba loorun,
A dia fun Owonrin omo asegilowo,
Osi nio takala ko ba leruwa,
A dia fun Iwori omo atapola sola,
awon iwo o sai la, emi o sai la,
A dia fun Alafohunfojuri omo asoru ta ra igba eru,
awon le la laye bi?
ebo ni won ni won o ru o,
igba ti won rubo ni ise ba tan, loro ba de,
nje iwo o sai la, emi o sai la,
gbogbowa la o la si rere laye o.

Okare Babalawo

O si mu mi ranti Owonrin Olola(owonrin-were), Ki ebo fin oooooo.

Ifa ni;

Bi asinwin(re mi mi)

Bi asinwin

Bi were(do do) bi were

Bi were

Adifa fun Labalaba ti o faye so fe je,

Won ni o sakele ebo ni o se,

O gbebo nibe o si sebo

O geru atukan esu o si tu

O gbo kara ebo nibe o si ha

Igbayi lawon omo-kekere nle labalaba kiri,

labalaba o fo soke yio wipe

Bi asinwin bi asinwin,

Labalaba o tun fo wale

Yio wipe bi were-were

Bayi ni o gbe awon omode wo inu gbo lo...

Labalaba wa n faye sofe je.....

Orunmila erigi-alo ifa jia faye so fe je....!

O si mu mi ranti Isegun ota oni Owonrin-were to je wipe bi Babalawo, Onisegun, Alfa, Woli, ati whatever ba sa si eeyan. Iro ni won fi pa...!

Aboru Aboye!

1 Like

Re: .. by Ifankaleluya: 7:39pm On Apr 19, 2016
Tevez83839:
Edakun nipa oso aworo ...shop mi fee dada .e salaye funmi .nipa oso aworo

Ti o ba ti ri Ori abo-elede tutu....., Aso-funfun ti a le fi sin Oku....kan si mi!

Balawo ni emi.....emi kiise Baba-alariwo.
Re: .. by Ifankaleluya: 7:50pm On Apr 19, 2016
Benjamite01:
Sir Healthfirst at Kadunasouth.. ejo, mofe ki e fun mi ni ise ti mole lo losi visa interview ti moma fi ri anu gba, ki wole funmi ni Visa, nitori pe mo ti gbiyanju ni a i moye igba.

Ogbeni....lotito kiise awa lo ko si, Sugbon awa o gba e ni imonran. Kiise Ogun ni o nilo, Lo kesi awon Babalawo to gbo ifa yanran-yanran ki won O gba o kale ni. Leyin na ni wa wa se Eyonu gidi Oni Ogbe-yonu. Wa wa Opa-aro, Eye-orofo ati awon ewe-ifa kan ti a ko le so lori afefe, won o ti bi 13-father awon yen ki won ma fun e ni Visa.

1 Like

Re: .. by Nobody: 8:00pm On Apr 19, 2016
Ifankaleluya:


Ogbeni....lotito kiise awa lo ko si, Sugbon awa o gba e ni imonran. Kiise Ogun ni o nilo, Lo kesi awon Babalawo to gbo ifa yanran-yanran ki won O gba o kale ni. Leyin na ni wa wa se Eyonu gidi Oni Ogbe-yonu. Wa wa Opa-aro, Eye-orofo ati awon ewe-ifa kan ti a ko le so lori afefe, won o ti bi 13-father awon yen ki won ma fun e ni Visa.
Baami, e ku ise takuntakun oo.a mo riri ore yin gidi gan sir. mi tii ri esi yin si e-mail ti mo fi ranse si yin yen oo. ese pupo baba.
Re: .. by Ifankaleluya: 8:04pm On Apr 19, 2016
Won rubo rubo ebo won o fin

Omo Babalawo ni won won fi nba wi

Won se ogun se ogun, ogun won o je

Omo-Onisegun ni won fi n sun lebiran

Ile yin nikan ko wa eegba-awo, omo-olowo ni won fi n ba wi ke eti olowo o le ba gbo ni

Adifa fun Osa ti somo-ologun eru

A ki fun Iwori ti somo-ologbon(re mi do) atiwofa(do do do do)

Nijo won nbe larin Iponju

Ebo Ola(re do) ni won ni ki won o se

Won gbebo nibe won rubo

Won gba-atukan esu o si tu

Nje Osa(do mi) n lowo ooooo

Iwori(do do do) n Loro(mi do)

Eyin O mo pe ile-wa lati jo se ajumo(do do do) jo(re) la(do).

Gbogbo Ori to wa ni fanran yi ni ao jumo jo la oooo. Ase!

E ku Ile..!

Aboru, Aboye, Abo-sise!!

1 Like

Re: .. by wale259(m): 10:20pm On Apr 19, 2016
Ase!ase!!ase!!! Baba....
Ifankaleluya:
Won rubo rubo ebo won o fin

Omo Babalawo ni won won fi nba wi

Won se ogun se ogun, ogun won o je

Omo-Onisegun ni won fi n sun lebiran

Ile yin nikan ko wa eegba-awo, omo-olowo ni won fi n ba wi ke eti olowo o le ba gbo ni

Adifa fun Osa ti somo-ologun eru

A ki fun Iwori ti somo-ologbon(re mi do) atiwofa(do do do do)

Nijo won nbe larin Iponju

Ebo Ola(re do) ni won ni ki won o se

Won gbebo nibe won rubo

Won gba-atukan esu o si tu

Nje Osa(do mi) n lowo ooooo

Iwori(do do do) n Loro(mi do)

Eyin O mo pe ile-wa lati jo se ajumo(do do do) jo(re) la(do).

Gbogbo Ori to wa ni fanran yi ni ao jumo jo la oooo. Ase!

E ku Ile..!

Aboru, Aboye, Abo-sise!!


Re: .. by Truck01: 10:16am On Apr 20, 2016
Ifankaleluya:


Ogbeni....lotito kiise awa lo ko si, Sugbon awa o gba e ni imonran. Kiise Ogun ni o nilo, Lo kesi awon Babalawo to gbo ifa yanran-yanran ki won O gba o kale ni. Leyin na ni wa wa se Eyonu gidi Oni Ogbe-yonu. Wa wa Opa-aro, Eye-orofo ati awon ewe-ifa kan ti a ko le so lori afefe, won o ti bi 13-father awon yen ki won ma fun e ni Visa.
.




Baba ifakanleluya pls I need your contact phone or email
Re: .. by Legendbaba1(m): 11:45am On Apr 20, 2016
ABORU BOYE OOO PLS LET ME HAVE UR FACEBOOK ADDRESS
Re: .. by Legendbaba1(m): 12:02pm On Apr 20, 2016
BABA KEPE EJO WO TI ENIYAN BANI AYISAN Staphylococcus KINI ENIYAN LELO FUN ARUN YI MAY U LIVE LONG AMIN
Re: .. by Nostradamus: 2:34pm On Apr 20, 2016
marv006:
ASINA KEKE KAN NI O

ORI OKETE
EGBO TUDE
ERU ALAMO
EWE EJINRIN ATI
EWE EWURO.

ao jo, aolo, aoteni OTURA-OGBE.
ao fi eje eyele po, ao su si ona meta,
aofi REGAL lofunjo meta.
eku agbaale wa sir,eledumare a maa fun yin se,ejoor sir,e te OTURA OGBE ati awon odu ti oku si oju aworan tori awa ti a ko mon awon odu te.eseun pupo
Re: .. by Nostradamus: 2:40pm On Apr 20, 2016
Ifankaleluya:


Ogbeni....lotito kiise awa lo ko si, Sugbon awa o gba e ni imonran. Kiise Ogun ni o nilo, Lo kesi awon Babalawo to gbo ifa yanran-yanran ki won O gba o kale ni. Leyin na ni wa wa se Eyonu gidi Oni Ogbe-yonu. Wa wa Opa-aro, Eye-orofo ati awon ewe-ifa kan ti a ko le so lori afefe, won o ti bi 13-father awon yen ki won ma fun e ni Visa.
baba agba,ejoor mi o mon awon odu ifa te,ejoor e te sori afefe tori awon eniyan bi temi.ewe a maa je o
Re: .. by lawani: 3:06pm On Apr 20, 2016
Nostradamus:
baba agba,ejoor mi o mon awon odu ifa te,ejoor e te sori afefe tori awon eniyan bi temi.ewe a maa je o

https://oyekuofun.org/odu-ifa/
Re: .. by dominicson: 5:52pm On Apr 20, 2016
Benjamite01:
Sir Healthfirst at Kadunasouth.. ejo, mofe ki e fun mi ni ise ti mole lo losi visa interview ti moma fi ri anu gba, ki wole funmi ni Visa, nitori pe mo ti gbiyanju ni a i moye igba.



Ekolo kii kan ilekun yangi ki o to si fun, ilekun America/Germany o ya si fun emi Lagbaja omo Lagbaja...

2 Likes

Re: .. by Nostradamus: 5:56pm On Apr 20, 2016
Re: .. by Ifatoki16: 8:38am On Apr 21, 2016
Ki e pe fun wa oo baba Ifankaleluya,ori ekerin niyi ti mo ti nkan si yin pe ki e joo fun mi ni ifa ti awon aje fi nfi ami igba si aya enito ba je ifa na.mo fi ipe aago mi sori ikanni yi ati email mi,e o dami lohun.ti mo ba seyin ki e dakun dabo e dari jinmi.Orunmila yio wa pelu yin o. llcatz@yahoo.com
Re: .. by Ifatoki16: 8:56am On Apr 21, 2016
marv006:
Atupuru odo ni kose fi gunyan,
Atupuru ikoko ni won fa lokun danyin-danyin-danyin,
A dia fun Ori,
Ori wa nlo ode Ajalaye,
won ni ko sakaale ebo ni sise,
Ogbebo orubo,
Nje Awede we tie o mo,
Ella ifa, we Ori mi mo,
Ogede we tie o de,
Ella ifa wa weri mi mo,
Ara kii ni ogede koma de,
Ella ifa wa weri mi mo,
Ero woo ni ti igbin,
Ella ifa wa weri mi mo.

Ise keke kan nu fun awon ti ooye ye.
> E se oo baaba mi.Elaaarowa ooo @Ifatoki16 lo nki yin ooo. e jowo e fun mi ni email tabi nomba ipe yin. llcatz@yahoo.com 08144762240

(1) (2) (3) ... (70) (71) (72) (73) (74) (75) (76) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 77
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.