Farotika's Posts
Nairaland Forum › Farotika's Profile › Farotika's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 (of 12 pages)
Ebony-Silk:Eeeeemi Pelu ise takun takun ti mo nse, o o ri ope du, nse ni o n fimi wole ninu tireedi yi O ma se o. Je ki nwa wi fun o o, ti o ba fi orokun e mejeeji kunle fun mi, ki o si fi enu ara re so iru ise nla ti mo nse fun o ninu yara ibusun; mi o ni ba e sere ife mo lai ![]() |
dayokanu:Oro yi o se ajeji si mi rara Ti o ba mo iru ise ti mo ma nse lori omo yen ti emi ati ohun ba wa ninu yara, o maa kan sara si mi Mo maa n eroticala omo yen ni gbogbo igba ti o ba ti wa s'odo mi |
Cecilia Ibru is a great and exceptional woman. Kudos to her |
PERVERT9:Iwo omo yi pafaati gan an o. Shioooooooooooo ![]() |
@dijavu147 & hymo, Both of you can reach me via: toscotee2001@yahoo.com Chiao! |
Si debosiky, Adura ni bobo ti won npe ni goodaasi yen nfe o. Boya 'ka gbe lo si ile baba onirugbon yeuke to a ma le ri iwosan fun ![]() |
MrCrackles:Ogbeni kirakusi abi kini won npe o Se iyawo mi ni o ntasi beyen Ti o ba sora, mo ma ge koboko e yen ni ![]() Olodo nla. |
Si adumarandan mi, Jowo ma binu si mi o. Emi o kan fe ki debo se e laburu kan kan ni ![]() |
6. At the beginning of this year he has been ill, now he is fine again. 7. He had broken a leg, therefore he couldn't come to school. 8. I’m reading a book now. 6. Omokunrin naa ti nse aisan lati ibere odun yi, sugbon ara re ti ya pada 7. Ko le wa si ile-iwe toripe o kan l'ese 8. Mo nka iwe kan lowo |
for 4 and 5: 4: O wa ni idubule aisan ni odun to koja 5 - O wa ni idubule aisan ni igba ti awon obi re ko ile naa |
debosky:Je ki nso ooto oro fun o nipa goodaasi: Nigbati awon omoge elese teere yen ti bere si fi baba s'ako (nfi tage) ni o ti gba ile oloti lo ti o si fi ara re fun oti guda. Ti o ba ri bobo yen nisinyi, aanu re maa se e. Oti ti yi ori e patapata Nipa ti adumaradan temi nikan, jowo saanu iyawo mi o. Se o mo 'pe eyin agba le ma nso wipe: Omode o ni mo eko ije ki o ma ra lowo. Omode ni o nse; mo maa ba soro nigbakugba ti a ba ti wo yara lo ![]() Se o ri ogbeni dayo yen, oro e ti sun mi patapata, nitooto, won ni kinni re tobi tobee ge ti ennyluv ko jale pe oun o ni le fi i sile. Ennyluv ti di mario si dayo lorun o, nibe lo maa ku si ![]() |
Ebony-Silk:Haba iyawo mi, se arugbo ni o npe ni olori gbeske |
debosky:Baba ni debo, bawo ni ore, se o njolifikeeti. Nipa ti ogbeni judaasi, rara o , goodaasi, o dabi pe omo naa ti lo p'okunso o nitoripe o pe ti mo ti gbo nipa re gbeyin. Awon omo onidi regede yen nkan, se won o jasi sa ![]() |
FBS:Beeni o, pelu amii: mi mi mi mi do. |
bababuff:O gbe iree ![]() |
PERVERT9:Looto ni iwo omo yii ti pafaati ![]() |
fesse:No my sister, most bankers get to the office by 6am and leave for their homes at 9 - 10pm. No official closing time for most banks, it’s so pathetic. But come to think of it, this act of closing late is not a deliberate act from the management. It is something cunningly invested by lazy and hypocritical Managers or bosses to show they're really working and it gradually became part of their life. Most of them also stay back at work in other to beat traffic and they'll expect that their junior workers should also wait till they (the bosses) are ready to leave the office. The closing time diamond bank adopts is therefore a welcome development which I hope other banks will learn from ![]() |
HeatFusion:Se o l'oko (koboko) ni |
HeatFusion:GBA |
St.Funmi:Tope once had a crush on her pastor's wife. She told me herself ![]() |
HeatFusion:Se o n gbadun ara e ![]() |
HeatFusion:Se o n jolifikati ![]() |
HeatFusion:Se o ri nibi ti o ti do ashewo ri ni O je jawo ninu apon ti o yo, dayo o feran re rara, o ti ni ololufe tie. Iwo se temi leni ki o wa ri bi mo se ma fi adun s'aye e ![]() |
HeatFusion:O se jare iyawo mi ![]() |
HeatFusion:Omo ipinle Ondo lemi o, sugbon ilu mi (Ijare - ti a mo si I.J. city) pelu Ikere Ekiti dijo ni ala kan ni. Nitorinaa ede kan na ni awa ati Ekiti nso. Iwo naa mo wipe mo feran re tokan tokan, iwo saa ti se temi; mo ma fi gbogbo aye mi fun o ni ![]() |
maimota:Hi Becky, happy to have u here and u're highly welcome. How's the work over there Hope you're all experiencing peace ![]() |
Neither of you is a goat or ram or whatever, we're only trying to clarify things here. It might not be the standard practice but, it's still in existence. Believe it or not. |
Hmn, it’s very amazing to this kind of response to the question posted by this mysterious poster. But, the truth of the matter is this, Obin (Oceanic bank Int. plc) has one or two criteria which must be met before you can be eligible for employment in this great institution: You must be a graduate of a recognized university (home and abroad) with at least second class lower division. Interestingly, the bank also employ HND graduate as full staff if such candidate possesses at least upper credit as his/her graduating grade. Secondly, you must apply online at www.oceanicbanknigeria.com; a number will be given to you immediately after application, copy the number and keep it well; you might be called anytime opportunity comes. If you're so lucky to be called, you'll have to write a test (a very tough one). After the test (provided you passed), you'll be called for interview which naturally you should pass except you're not good at all. All these criteria must be met before you'll be able to work in Obin as a starter. For experienced staff: Apply on-line and wait to be called for interview. Chiao!!! |
nanaharry:Why can't we have positive thinkers in da house Believe me, most of the story you hear 'bout banks laying off are make-believes. Although the global financial crisis may affect us, but it will not break us, we will survive it. |
davidylan:Miss kini Do you know what u're saying at all O nso 'pe o n miss iyawo temi, my lover, ololufemi, ore mi, orebinrin mi abbl.Ikilo: Yara jowo lapon ti o yo, ki o lo gbomi la kana. Nitoripe, tomode ba dari sapa apa a pa, beeni tomode ba dari soroko, iroko oluwere a ko ![]() Ma je ki nri e ni odo omo yen mo o ![]() |
HeatFusion:Se yooba ekiti ni o nfe: Je kin nfun e nikan: Awe o, ko ba mo bi mo se feran re to nii ni, i lua gbon kete ihonra kuwe tele hon on ni re, kua sare ya ba mi li kia. ijare se temi, litorifo mo feran re gan ni ![]() Meaning: Ore, ti o ba mo bi mo fe feran e to, se ni o maa fi gbogbo awon ti o n sare tele yen sile, ti o maa sare wa ba mi ni wara nsesa. Jowo se temi, nitoripe mo feran re tokan tokan ![]() |

O ma se o.
Ti o ba mo iru ise ti mo ma nse lori omo yen ti emi ati ohun ba wa ninu yara, o maa kan sara si mi

Se iyawo mi ni o ntasi beyen 

