Farotika's Posts
Nairaland Forum › Farotika's Profile › Farotika's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 (of 12 pages)
chamotex:Pele o buroda Aworo. Se gbogbo eniyan lo ro pe o ri bi tie to je pe gbogbo obirin adugbo ni o nfowo ba kiri. Onisekuse ati oniranu gbaa ni mo ka e si. Shioo Nitemi, oju kan bayii ni ada ni, nitorina emi le ja, mo si le pofo nitori onitemi, adamaradan, ejiwumi, iyunade temi nikan ![]() |
dayokanu:Aja to ba ma sonu ni oro re, koni gbo fere olode. Se emi ni iwo nba leri beyen. Haaaaaa, sangba fo!!! Ti kii ba se ero ayarabiasa ti fa arifin, se iru e le maa ba emi du aya Boya lomo pe ode ti o ba gboju le fi awo egiri se gbedu laiku re. Loni, emi ati iwo ti jo wo sokoto kan naa; mo de ma fi nkan ti won npe ni agba won e. Maa je ko mo pe eran ti won fa ti ko ja ni won npe ni namo. Nipa ti Toyin (onitemi tooto), ati toje boloosa lowo, o ku baba eni ti o bo Mo ti lo ri awon obi re asi ti da ti a maa lo se mo-mi-n-mo-o sona. Ma si se seyonu, ma fi iwe ipe ranse si o ti o ba to akoko ![]() ODE NLA ![]() |
KarmaMod:Yeepa Ma je ki nfi enu mi yii se epe fun e ninu odo titun o. Ole, oponu, ole ponbele ati oniranu ni o ni lati je. Bi beeko, enu e o ni maa wa roofu si agbalagba. Shiooooooooooo ![]() U need ur attention, a lazy pussy like u ![]() |
ehie007:U dont have to turn urself into a monster to ur wife just because u want control of the house. Some men do that because of inferiority complex. What both need is understanding, togetherness, love and respect for each other. When these virtues are present, you wont even know or think of who is earning more. |
Moonstone:At least she cook however tasteless unlike our lazy KarmaMod. What a pity ![]() |
dayokanu:Yeepa Je ki n so fun o iwo omo dayokunu abi ki lo ti npe o Asa re, nkolugi, nkolope, o si fe ko lu orule o. Eye akala to see lojosi nse ni o yo gege lorun. JAWO NBEEEEEEEEEEEEEEEEEEE ![]() |
My fellow NLs, from this part of the world, women knowing how to cook is inevitable. Cooking is an art that a woman who wants a successful marriage must learn even before becoming a wife-to-be. In my own opinion, there is no difference btw a woman who does not like to cook and the one who does not like making love with the hubby. They both lack the ingredients that make a smooth and happy marriage. In fact, where sex fails, food may not. It should also be noted that cooking for once hubby does not make a woman less professional or more inferior. In fact, it endears her more to the hubby. My wife is a banker and a very busy one for that matter. Notwithstanding, she does not play with her cooking. She told me expressly that she doesn’t want me to have any reason to eat outside. Believe me honestly, this makes me love her more and more and I'm always beside her in the kitchen whenever I'm at home helping her with the cooking (cos I'm a good cook too). So, if you're a lady here and don't know how to cook, pls stop giving excuses and learn; u'll need it sooner or latter. |
KarmaMod:My sister, u dey miss oo, haba ![]() I beg repent and accept gbegiri, akpon, egusi and the likes into ur life ![]() |
Yee yee yee Africa 2ce, Africa is my home Land of blessing, Africa 2ce I'm black and proud 4ce i've travelled all over the sea and all over the land There's no place like Africa to me. Yee yee yee Africa 2ce, Africa is my home All Africa games of Nigeria, prove to all the world that Africa is a nation Africa, motherland Africa Yee yee yee Africa 2ce, Africa is my home The bright sunshine of Nigeria, makes me to believe that allover the world there's no place like Africa For Nigeria is my home Yee yee yee Africa 2ce, Africa is my home I'm black and proud 4ce i've travelled all over the sea and all over the land There's no place like Africa to me. Yee yee yee Africa 2ce, Africa is my home Blessed be thy name o Lord, I'm proud to be a Nigerian 2ce I will never, I will never, I will never, I will never forget my home Africa 3ce I will never, I will never, I will never, I will never forget my home |
*Toyinrayo:Rara o E je pe ori onitoun ti daru. Nitooto, ife re ti fe maa dami lopolo ru. Jowo onitemi, ma foju mi sona ![]() |
tkb417:Booda 419, tani iyawo yin naa E gbe si wa leti ka ri gbo, abi onishina buruku[s][/s] |
dayokanu:Booda gboromideleru, ewo ni tiyin naa Iwo gan an ni a ba pe ni onirinkunrin, mofilomindasi, gbeborun ati oniranu ![]() Se iwo fe so fun mi pe o o mo pe toko tiyawo ni emi ati omo adumaradan yen ni ![]() Ka sora o ![]() |
Baba Eledumare lole fona han ni Ayafoba mimo lole fona han wa o 2ce layeeeeee Igbekele eniyan, asan loje Ayafoba mimo lole fona han wa o 2ce layeeeeee Ori mi ma je nsilete, eda mi ma je nsise Ayafoba mimo lole fona han wa o 2ce layeeeeee |
chamotex:Ore, mo gbaa ladura pe o o ni ku sori obo o. Haba!!! |
*Toyinrayo:Ebony mi owon, nibo ni mo wa gba lo nigba ti o n kan leku O ga o. Laifa oro gun sa, ile igbafe ni eebo npe ni hotel or guest house Se daa daa lo wa sa ![]() |
Igba owuro lawa baba je kale san ni Jekale san wa o, baba je kaye ye wa Ase eledumare re ni pe ka maa bi si ka sii maa re si Ka maa gba yin in lori aye 2ce Igba owuro lawa baba je kale san ni Jekale san wa o, baba je kaye ye wa Agogo ti nka wakati ojo, wa ka wakati mi si rere o Ma je nsise, ma je nsije, ma je a silete Oju re lamiwo o baba ma je pade agbako laye Oju re lamiwo o baba ma je a se ohun ti o pe o laye, |
Oro se ni wo Kale meni to fe ni Aa nrin nile, inu belesin aa njefo sun, inu nbeleran aa nwakisa, inu nbalaso oro se ni wo Kale meni to fe mi |
Haaaaaaaaa Se iyawo mi Ebony naa lo bere tireedi yi Inu mi dun debi pe, ti e ba gun esin ninu mi, ko ni kose rara. Pe ololufe mi naa feran orin yooba naa bayii O ga o. |
Eyin olufemi ninu tireedi yii, odun titun yii a san wa sowo, a san wa somo, a san wa si aiku baale oro. Gbogbo idawole wa a yori si rere o. Amin. |
chamotex:Kamoteesi, nibo ni iwo lo lati ijo yi. Iwo gan si ni oga awon asewo o. Ki Olorun dari agabagebe re ji o ![]() |
Ebony-Silk:Ololufemi, ki lo de ti o wa tan mi Mo duro titi ni ojo keresi, sugbon o ko, o ko wa rara Se kii se pe o fe ko oju mi si orun ale bayii |
Ebony-Silk:O se gan ni iyawo mi atata. Iwo naa si to fun mi. Nipa ti oruka igbeyawo, iwo sa je ka pade ni ile igbafe ti o ba fe ki nba lee fun o ![]() |
TOYOSI20:Iwo omo yi, o je bowo fagba ki o baa le pe laye ![]() |
Ebony-Silk:Ma da bobo yen loun jare. O ma ku soro owu jije ni. ![]() |
MrCrackles:O se jare omo daa daa. Eni a san e o ![]() |
Eyin ara mi ninu foroomu yii, Mo fe fi akoko yi ki gbogbo yin ku odun keresi o. Aseyi samodun o. Odun o ni diwa mo eru lo o. Gbogbowa la tun ma peju sibi ni odun to nbo pelu alaafia ati ayo ati idunnu pelu igbega. E ba mi mu nkan ti e ba jeku fun odun wa o Si Ebony, Jowo iyawo mi tooto, mo se nreti re nile mi leni o. Obe ti o se ni o wu mi ki nje ninu odun keresi yi. Ose pupo o si ku ife aisetan ti o ni si mi ![]() |
babsongudus:Ki Olorun ma je ko je eleyi to ma ha e lofun ![]() |
How come u know soo much, were they ur sisters ![]() |
tkb417:Eyin omode wonyi, ki lo n seyin naa Obinrin po nigboro ta tie ri nkan fiwon se le wa nja lori omo kan ti won pe ni sumoofu lori tireedi yi. E je ki ori yin pe o ti e o ba fe ki n le yin kuro nibo. Eyin oloju kokoro yi. Shioooooooooooooooooooooooooo ![]() |
chamotex:Kii se obinrin ni mo wa wa o. Sugbon bo se wu Olorun lo nse ola, bi mo se de ori tireedi yi ni mo beresi n nife si omo Ebony yen. Mi o mo nkan omobirin yen fun mi je o Oruko e nikan ni mo maa nje lenu ni enu ojo meta yii. E jowo e ba mi waa ooooooooooo. Bi bee ko mo ma pa ara mi sii yin lorun ni o |
neo_welsh:What nonsense ![]() |


Inu mi dun debi pe, ti e ba gun esin ninu mi, ko ni kose rara. Pe ololufe mi naa feran orin yooba naa bayii 