Farotika's Posts
Nairaland Forum › Farotika's Profile › Farotika's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 (of 12 pages)
tkb417:Ma da awon ode meji yen loun joo. Opolo won ti yoro ![]() |
Don't know how it happened but my dad tell me say my mama nah still virgin ![]() Can u beat that ![]() |
tkb417:O se jare ore mi. A n gbiyanju ki ise maa lo. Bawo ni odo e lohun Se ise nlo bose ye Jowo ma fi aye gba awon omoge elese teere yen lati mu e se irewesi lenu ise o ![]() Eni a san e o |
dean2725:E ma da bebi yen loun jooo. Ko mo nkan ti o se rara. O digba ti o ba wa juba lodo mi ki o to le mo nkan ti o nse Olori odo ![]() |
[quote author=Ebony-Silk link=topic=48547.msg3257680#msg3257680 date=1229975657]@TOYOSI no be you I meet for here? ![]() @ oko mi owonkini nkan ti wan pke ni ago? abi o mean "Agogo ewu?" you're not slick ![]() then wa, je kin fun e ni igbati!! wa like e. . . . [/quote]Aago ilewo ni oyinbo npe ni: GSM number. Pele onitemi atata. Se o n filenijo nibi ti o wa yen? Jowo ma fi oju mi sona o. E jowo e ba mi wa Debo ati kamoteesi ooooooooooooooooooo ![]() |
tkb417:Se emi ni buroda agbaiya. Iwo naa omode ise Yooba ni "bi omode ba mo owo we, a ba agba jeun" emi ti rii daju pe o mo owo we rara, mi o de rope o le ba awa agba jeun. Ti kii ba se onitemi (Ebony) ti o be mi ni, nba ti le e kuro ni tireedi yi.O le eeeeeeeeeeee |
TOYOSI20:Mo se rii daju pe ODE NLA ni e. Bayo lo se ma pe olowo nla bi temi ni talika. O dabi pe eje ti ta si e lopolo Wa ki nko e ni bi won se nko ede Yooba ![]() |
goodass:O se ore mi tooto. Mo ti ka ireke onibudo daadaa ni kekere. Mo ti ka ADIITU ELEDUMARE naa sugbon o ti pe gan an, atipe awon oro ife inu re po gan an. Se o de mo pe mo ti nnife Ebony, mo si nfe awon oro ife nla nla ti mo le fi da ori re ru. Emi ati Ebony o tii se igbeyawo o. A kan si n sere ife ni ![]() |
romade:I concur ![]() |
Head 9 for sure!!! ![]() |
[quote author=Ebony-Silk link=topic=48547.msg3255942#msg3255942 date=1229954526]Oko mi owon, jo ma binu simi. Mo ti nkunle lowo lowo fun yin, ejo, e dari jimi ejor ejor ejor, efi mi sile ![]() Tani "Uncle" yin? [/quote]Ololufe temi nikan, ma fi oju mi sona Tete fun mi ni aago ilewo re ki nba le tete kan si e. Oju nro mi o |
Moonstone:Eeee anti gbeborun. Ta lo pe yin si oro oko ati iyawo Jowo ma ta si iyawo temi o. Emi o fi oro re sere rara. Ti oko ti o dara bi temi ba wu o, tete wa oko tire siwaju o. To ba fe mo le saye Kamoseeti fun o.Olodo buruku ![]() |
[quote author=Ebony-Silk link=topic=48547.msg3255866#msg3255866 date=1229953564]Lol, talo so fun e wipe mii le so ede mi? Emi o ki nse akata o ![]() Mo f'eron ede mi bi mo se f'eron owo ![]() lmao. . . . debo don start trouble o.To ba je wipe o f'eron mi nigbati mo ko post ye si e, oba ti so fun mi ![]() lol, I like your poem sha. . . .shugbon to ba fe ri mi, ba debosky (my PA) soro ![]() O ti daa nigbayen, ore mi tooto ni Debo, ni tooto a jo lo si ile-iwe puramari kan naa ni. O de ti so fun mi pe ki nmaa paro lo. Nitorinaa, fun mi ni aago e ki nba le pe e ni kiakia. lol, ejo oga, ambinu. Yooba ni ma ma so la te ni lo [/quote]O se iyawo mi atata. Emi naa mo pe omo daadaa ni e ati pe omo Oodua tooto si ni e pelu. |
[quote author=Ebony-Silk link=topic=48547.msg3255839#msg3255839 date=1229953225] ![]() Stop playing hide and seek with me jor, I no like am. Come out come out wherever you are [/quote]Ebony temi owon,O de fe maa doju timi sa. Ani ko ye so ede ajeji nibiyi. Bami so ede abinibi. Ti o ba jawo ati maa so awon ede eru buruku yii; mo ma ja iwe ikosile fun e o. Emi o de fe ki nkan beyen sele tori ife ti mo ni si e. ![]() Ka sora gidigidi ![]() |
tkb417:Itumo foni ni: o pani lerin ![]() tabi o darin pa ereke ![]() Olodo nla. Olodo rabata, oju eja lo mo je. Sileeti lo o ma lo o oni lo pepa. Poki!!! ![]() |
babsongudus:Nah lie My mama nah virgin ![]() |
[quote author=~smurf link=topic=48547.msg3254787#msg3254787 date=1229931221]Same here oo, I see I can learn a couple of things too, B.T.W, how u dey? [/quote]Abi ode ni awon alawe meji ti won npe ara won ni Toyosi ati Sumoofu yi ni? Se oju yin fo e o rii pe Yooba lanso nihanyi ni. E ma so ede ajeji nibi ti e o ba fe ki a leeyin kuro ni ori tireedi yi o.O digba kan na. |
[quote author=Ebony-Silk link=topic=48547.msg3254247#msg3254247 date=1229907395]Why am I just seeing this now? Sorry o, you're not my father, you don't get to give me away. . . . [/quote]Haba ololufe mi, ma doju timii. Yooba ponbele ni mo fe ki a maa so nibi yii. Jowo ma se je ki awon omo kekere wonyi wenu si e lara o |
Remii:Mo kan sara si e Remi. O se pupo. |
goodass:Judaasi, Jowo se o ti ka iwe baba Fagunwa ti o ni akole yii: ADIITU ELEDUMARE? Bi o ba je be, se o si nii lowo atipe bawo lo se le fi sowo si mi. Jawo ninu riba JUDAASI!!! |
debosky:O se ore mi atata, emi naa mo pe eyin mi ni o wa lojokojo. Emi naa ti n nife omo yen o. Mo fe ma fi enu fa kini ti o wa ni aya re yen. Jowo se o le ko mi bi mo se le se ti o ma gba lati fe mi laisi wahala rara. Jowo mo nreti esi re o. |
[quote author=Ebony-Silk link=topic=48547.msg3246874#msg3246874 date=1229720689]lmao. . . .beeni, mo n jowu e Mo ni ife fun Chamotexi hehehhe, is that okay for you? ![]() lmaoooooo, dude, you're crazy. . . .oya, mo ni ife si e nan. [/quote]Ebony mi owon,Looto, oro ife dabi oro adawo ni. Lati igba ti mo ti ka iwe pelebe ti o ko simi yii ni ife re ti ngun mi bi esin. Nse lo dabi ki nri e ki nsi ma fi ara lo e bi ologbo. Jowo ololufe mi, bawo ni mo se le ri e ki a ba le bere ere ife wa loju paali. Oloomi, onitemi, ore mi, alabaro, oju kan saa lada ni, lolaoluwa ko seni ti o ya wa (Kamoteesi). Mofe ba e darugbo, mo fe ba e kale, iwo leni ti mo fe ri lojojumo aye mi |
tkb417:E ma binu sir, 419 kan wa simi lenu ni. Won o komi ki nmaa yaju si agbalagba. E jowo sir, E fori ji omo yin. Eyin agba le npa lowe pe: "Omode o le mo eko je ko ma yi lowo". Tooto, o se bi owe eyin agba. |
Dere I:The girl nah virgin o, d only thing be say the thing sweet am no be small ![]() |
server34:Haba! so u no no say winch plenty for Calabar. I pity u o; u no no say na hin make them good for fuckmania ![]() |
I beg make una leave african Osama, oh, sorry ![]() |
tkb417:Ogbeni 419, ah! Lakotan, emi o fe ki e maa gbe nikan o, mo nfe ki o je bi le ma ku si, bi ti mario ![]() |
[quote author=Ebony-Silk link=topic=48547.msg3242587#msg3242587 date=1229636817]rotflmao. . . .Iwo gan lo ye ki Farotika sho'ra fun. Eduro nan, mo ni ibeere kan. . . .se obirin t'abokunrin no farotika? Nitoripe mo sha n wonder kini reason ti Chamotex fi nle kakiri. [/quote]Ma fi lo mi ndasi, ewo lo kan e naa? Se o njowu mi ni Ti o ba nifesi Kamoteesi, je ki a gbo o maa fi tife tife so eyin mejeeji papo. Ni idakeji, ti o ba je pe omi ni o ni ife si, mo wa fun e tigbatigba nitoripe ese meta shandi ni mo ni, mo si se ileri wipe mo maa te e pelu nkan omokunrin mi ![]() |
@ gudass, how u dey naa? che u later show ur teacher the thing wetin she do when she see am ![]() |
chamotex:Haaaa!! kamoteesi, o o se jawo ninu iwa palapala ti o nwu yii. Emi o gbo tabi ka nkankan ti o jo iru ewi yi ri o. Se baba Fagunwa abi Faleti lo koo ni. E saa ma ja emi lawe o. Oro obo ati oko ti e nso yii ti fe maa yi mi lori ![]() E ti e gbo naa eyin ore mi: kini won npe ni oko ati obo naa ![]() |
goodass:Iro nla le pa sa. Beba ko ni yooba npe "paper"; kalamu ni won maa npe nigbati won a maa pe "biro" ni gege. |
The bride tells her husband, "Honey, you know I'm a virgin and I don't know anything about sex. Can you explain it to me first?" "OK, Sweetheart. Putting it simply, we will call your private place 'the prison' and call my private thing 'the prisoner'. So what we do is: put the prisoner in the prison. And then they made love for the first time. Afterwards, the guy is lying face up on the bed, smiling with satisfaction. Nudging him, his bride giggles, "Honey the prisoner seems to have escaped." Turning on his side, he smiles. "Then we will have to re-imprison him." After the second time they spent, the guy reaches for his cigarettes but the girl, thoroughly enjoying the new experience of making love, gives him a suggestive smile, "Honey, the prisoner is out again!" The man rises to the occasion, but with the unsteady legs of a recently born foal. Afterwards, he lays back on the bed, totally exhausted. She nudges him and says, "Honey, the prisoner escaped again." Limply turning his head, He YELLS at her, "Hey, its not a life sentence, OKAY! |




