Farotika's Posts
Nairaland Forum › Farotika's Profile › Farotika's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 (of 12 pages)
**osisi:Osisi, nobody is been tribalistic here. Eating human parts is not strange in some Eastern parts and they are even very proud of it. I have I guy in my office and he's always proud to say they eat human parts in his home town. Therefore, it is a known fact. The issue of been tribalistic does not come to play at all. |
Yeeeeeeeeeeepaaaaaa |
Go awaayyyyyyyyyyyyyyyyyyyy |
Ooto ni oro re. Yooba bo won ni: Ela loro Oko ti mo nso ni awon eebo npe ni CAR E joo e ma si mi gbo o |
HeatFusion:My sweet love, aaro e nsan mi ni o. nso mi wrong gan an ni |
dayokanu:Mo mo jare ore mi daadaa. Nitooto, odo mi ni o wa ni gbogbo ojo yen. Je ki nse ofofo fun e: mo ra oko ayokele kan fun [s][/s] ![]() |
badboym:I bet u ran like mad ![]() |
E ku ojo meta o eyin eeyan mi. Se daadaa lewa Dayo, Se daadaa ni ebony iyawo mi wa. O da mo nbo, mi o tii de ![]() |
Si Olukowe, Ayun e nyun mi Aaro e nsan mi Okan mi nsaferi re Okan mi nfa si e All join means "I miss u" ![]() |
jamace:Bawo ni jare booda jagbado (jamace) ![]() Emi o sa o. Ise kan po die ni owo mi ni. Ofo si po nile oluwere, beeni ogede o le tan nile awo. Ki awon amofin ipinle ogun maa se nkan ti won nse. Ase ntedulare |
Czarskit:Gbam!!! |
dayokanu:Olorun a dariji bobo yen o |
Ogaga4Luv:Yeepa |
TOYOSI20:Se emi ni omo kekere yi nba soro kunba kungbe Se o ro pe dayo orobinrin dori ni o nba soro ni ![]() Wobi aburo, o o le fi emi sako o. Ti o ba de soro to koja enu e, ma fi nkan ti agba fi ju omode lo won e ![]() Olodo nla. |
dayokanu:Mo ti gbo o. Sa ma je ki obinrin abeyinto lasan lasan ma da e riba ribo Si debo, O to ojo meta ati abo, se tori obinrin naa lo se sa fun awa tie. O ga o. Wahala ti obinrin ma da sile, owo won o ni ka ![]() |
dayokanu:Dayo, dayo, dayo, o de fe maa se mi; ki lo de ti o fe so ara e di mugu fun omo ti won npe ni toyosi yi, se o ri obinrin miran nle ni ![]() Ako bebi yen ti fe maa po ju joo |
TOYOSI20:Toyo babe, don't tell me you find that disgusting Just tell him to slap himself 12 times for a test and see if he would not do it 24 times ![]() The guy don fall mugu for you I pity am |
dayokanu:Haba! dayo, nah so u hate me reach I thought u love Toyosi nau ![]() |
djslam:Next time u meet such girl(s), forget about pre-intimacy; bounce on her and both of you might come at the same time ![]() Chiao ![]() |
Hollysmile: |
ede (do do) - home ede (re re) - town in Osun state ede (do re) - sacred Nitorinaa e ma tori ede bede je nitoripe ede ni oro olorun ![]() |
I guess Chamotex makes use of ewe koko while dayo makes use of Toyosi's pee ![]() |
HeatFusion:Oro iwo omo yii ti sun mi patapata; nje mi o ni be awon iya lowe si e bayii ![]() |
TOYOSI20:Ko ye ki o ni iporuru okan rara. Mo nife Toyin kan an ni; sugbon dipo ki o fi ife han si mi, dayo oko re ni o nfi ife han si. Jowo ba mi so fun bi ife re ti to ni okan mi Okan mi ngbogbe fun omobinrin yen gan an ni. Shiki shiki aya re lo fe pa mi |
Ori yin ti foka sibi ![]() |
Si, dayo Ojo kejila, Osu Keji, Egberunmeji odun O le mesan, Leyin iku oluwa wa ![]() Ore mi tooto, Mo dupe gan an ni fun imoran pataki ti o fun mi. Omo yen fe ki nbinu si ohun ni, sugbon mo ti dariji Sugbon, o ku ni'bon nro o: kilo fun gidigidi pe ko ye fi mi tage lori tireedi o ![]() O digba kan naa |
@poster, God has made it so from the beginning. Man was created to rule over everything God created (think of whatever). Women on the other hand were created to assist man but not to rule over them or anything whatsoever. Our home and society will be far better than what it is today if women will be satisfied with what the were created to do and not convet what is not theirs. While we rule, you are suppose to pray for our success and help us with our children and other chores, strenthen us when we are weak and offer your strong shoulder for us to cry when we are disappointed etc. Man na Man. ![]() |
HeatFusion:Se dayo oko oloko ni o le kiri ni nigba ti mo nfi gbogbo ojo asiko mi nfi ife han si o Ti o ba je pe iranu ni o fe lati maa se, mo ma fi e sile o. Jowo je ki nmo eyi ti o fe se ki nba tete lo ba miss M ![]() |
dayokanu:dayo, dayo, dayo, eemelo ni mo pe o, O un tona wo oju ekun mi o, o si fe maa fi omi ata boju. O ye ki o mo pe emi o kii fi iyawo mi sere rara ![]() Ikilo pataki ni yi: ti Kamoteesi ba fi owo kan toyin, oko e ba pare patapata ni ![]() |
dayokanu:Amin ase edumare, ati emi na o ![]() |
dayokanu:Ogbontarigi ------- do mi do re do do Alaafia -------------- do mi mi do Olopa -------------- re mi domi. E patewo fun mi jooooooooooooooooooo ![]() |


Dayo, Se daadaa ni ebony iyawo mi wa. 

, keep tuned on to the thread, u'll learn if u are willing 
Okan mi ngbogbe fun omobinrin yen gan an ni. Shiki shiki aya re lo fe pa mi