Fileki's Posts
Nairaland Forum › Fileki's Profile › Fileki's Posts
Dejike, i read ur post o, o ga o. well, i feel u should just ask God for the strength to carry on. i cant blame anyone, it is easy for us to cast stones, forgetting that there's no one without faults. i wish u luck, be sure to bring up ur daughter in a right way, God be with u. |
a ku ojo isinmi yi o. Kabiyesi, Alaga methodman, otunba Debson, YA Oloye Desorlah, Dr ferlie,Gbogbo eniyan ni mo ki lai yo enikeni sile, E kaaaro o. o ti dara fun wa o |
a ku odun ojo ibi, Mohammad ta se koja, a si ku odun ajinde bakana. se alaafia sa ni gbogbo wa wa, nitori n ko gburo awon eniyan lo titi. ire gbogbo ko ma wa wa o Kabiyesi, ODe metodman, Dr ferlie, Aya Oloye desolar, Otunba Debson, gbogbo eniyan pata ni mo ki o. ilu yi ko ni baje o Ase. |
mine is 1st Feb, happy birthday in advance, Debson |
''omo'go ani o ma ku, tani ko mo pe ago ni yo pa omo'' |
Dr, what are my chances if i marry An AS and i wana have 2-3 kids cos i am As too |
Seventn Day Adventist Nur/Pry school, Ile Ife this is my most cherished school anthem [center]Seventh-day Nusrsery Primary Ile Ife Founded in Unity, We shall never forget our founding Pastor, serving god and humanity Anywhere everywhere we go in the world, North or South or East or West We shall never forget our founding Pastor serving God and humanity[/center] |
Alagba Metodman,o ti to ojo meta ti mo ti gburo Asiwaju dr Felie, sugbon mo ni igbagbo wi pe alaafia ni won wa, eyin nko? se ara yin le? e ku bi oju ojo ti ri? ilu yi ko ni baje o |
A ku ojumo o, o ti dara fun wa loni, Oba oke a saanu fun gbogbo wa o ase. |
e ku ojumo o, oni a dara fun gbogbo wa o, ase! Debson baba, mo ki yin o, |
if the question is ''Traditional Marriage or ''white wedding'' , then d poster is asking me to make a choice, so i chooe; Traditinal weddind |
, for u, my late sister Busayo- March 15,1979 - July 3,2000 Good nite sis |
2kids. no matter d gender |
i eat, bt if dre's no food available, i simply avoid talking wt ple cos i cld b touchy |
Snake! yummy |
hi Sagacious, I know efinrin leave, used as spice 4 cooking bt i dnt know of the stew, bt it sure tastes good wen used4 cooking meat or sauce |
A ku ojo Isegun oni o. Ire a wa wa ri o, ase! ni inu ilu yi, gbogbo wa la o ri b'atise, Kabiesi mo ki yin, Asiwaju Dr Fele,Erelu, ogboju ode Metodman, aya Oloye Desorlah, ati gbogbo eniyan.oni yo dara fun gbogbo wa |
i would have asked '' why do we have to loose the people we love dearly'' but He is God, no one can ask! |
Goat-meat! |
Alagba Metodman emi o b'inu rara. fun atunse, Fileki, Olori Fileki ni oruko mi, Ilu yi o ni baje |
Alagba Metodman, Kabiesi ki se omode, beeni won mon awon oun ti o to ati eyi ti o ye fun won lati ma lo, ati wi pe oro l'ori eto ilu nikan ni e ni eto lati fi enu si, T'owo t'owo ni mo fi royin pe ki e dakun ki e ma se mu enu lo si ibeyen rara. Ati wipe '' arabirin ye le die ooooo'' ti e so yen ni itumo , se e mon mi ri tele ni? e ma se ba oruko mi je l'aafin oro ilu l'ani ki e da si |
''Amala water'' beside book sellers @ Dugbe in Ibadan,+ Iya Ila @ Molete my God! just try it if u are close to the address and give me a feedback. |
beeing single can be so much fun at times, u have ur whole time to urself. INDEPENDENCE, no explanations of any kind to anyone, u cld b single n not lonely. i just enjoy, having 2 be ith mysef hen 'm single |
Omojowo |
Kabieesi, eyi ni wipe emi nikan ni Olori l'aafin? inu mi dun fun eyi. k'epe |
i saved it with his name, fter a settled quarrel, i saved it with* OSEME* , meaning ; ''MY OWN''. though we are both Yoruba,i just want a diffrent one |
ase o |
Kaabiesi o! E seun, mo dupe k'e pe. Olowo ori mi, e dakun mo fe mon awon olori ti mo ba l'aafin ki n le ma ye won si bi o se to.mo fe mu amoran wa, wi pe ki arabinrin Lamide so fun wa awon iwa amuye ti Erelu gbodo ni. . , Dr Felie e seun ana, Kabiesi ounje yin ti se tan, k'eepe o |
t'oba l'ase, t'aa ni mi lati so wipe n ko fe ipo to ni iye l'ori bii ti ipo Olori? e se o, ilu yi ko ni b'aje. inu mi dungan an ni. e je ki n mon awon olori ti mo ba l'aafin k'oba pe |
Baale, emi ki se oju titun ni ilu yi o. o kan ti pe die ti mo ti de ori okun yi o, o si ye ki e toro gafaara fun afoju di kekere yi. amon sa ka bi o ko si. se alafia le wa, se ara le. e jowo mo fe mon awon olori baale ilu wa yi, nitori, apon le ko si fun Baale ti ko ni olori. E ma si mi gbo o, emi ko ni ife si ipo olori o, sugbon mo fe mon pupo nipa ilu wa yi. gege bi omo ilu wa tooto, kara o le o. e ma gbagbe mo nife si oye ni ilu wa yi o, oye *iyalode* ni mo fe je. o digba. |
Sranger 26, o gbiyanju. . . sugbon lojo miran o le so wipe: e se jeje o. eyin temi , a ku odun ayajo ololufe ana o. e je ki ife ti ko ni etan ninu ki o ma bawa gbe o. ati wipe e wa o, se ko si oye ni inu ilu wa yi mon ni? emi fe je oye o, looto ilesanmi dun joye lo amo mo fe wa lara awon amulu t'oro ilu wa yi, mo fe dije fun ipo oye '' iyalode'' ti ilu wa yi. e se, lekan si, a ku ayajo odun ololufe o. e se jeje. ire o |
these replies had really been interesting . . . just want read more. |
Kaabiesi o! E seun, mo dupe k'e pe. Olowo ori mi, e dakun mo fe mon awon olori ti mo ba l'aafin ki n le ma ye won si bi o se to.