Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,163,098 members, 7,852,729 topics. Date: Friday, 07 June 2024 at 03:15 AM

Yoruba Commonwealth and Politics - Politics (91) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Yoruba Commonwealth and Politics (675629 Views)

OPC - Faseun & Adams Unite For Security Of Yoruba Commonwealth / SEUN - Re: Yoruba-commonwealth-politics / Goodluck Jonathan Returns From Commonwealth Assignment (photo) (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (88) (89) (90) (91) (92) (93) (94) ... (384) (Reply) (Go Down)

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Musiwa419: 10:06pm On Oct 30, 2015
razid:

Ti e ba wo ohun ti mo so ni ana, asiko tito fun wa lati ni olori tuntun ti yoo maa fun awa omo Yoruba ni ilana. Gbogbo awon ti o ti ju Aadota odun lo ko le se ise naa rara tori wipe opolopo won ni won ni ikunsinu si ara won. Fun apeere, kosi ibasepo to dan moran laarin ojogbon Wole Soyinka ati Oloye Obasanjo. Awon Afenifere to je odo naa tun ti koju ija si ara won. Eyin e wo Yinka Odunmakin ati awon iyoku ti won jo bere, e o ri wipe awon naa n ba ara won ja ni. Eeyan kan ti mo fe damoran ni Baba Bolanle Gbonigi, sugbon awon naa n be lara awon iran agba ti a n soro re.
Hmmmmmmm

oro na so si ni lenu otun bu iyo si
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by modath(f): 10:08pm On Oct 30, 2015
Modath ti wa si ori eto, smiley

Midolian, eyin na e wa bawa da si eto yi oo.

Ogbeni razid, asiko lati ni oludari eto omo oodua ko ti i to nitori oro oro aje ile naijiriya....

Awon yoruba bo "won ni ebi ki pa inu ki oro mi i wo... ni iwon igba ti ilu o ba ti fararo mi o ni ireti pe a le ri eniyan ti a fa ara re sile lati ja fun eto omo oodua..

Ewo idibo to koja bi awon aladeluwa se di arepiba kale, awon egbe odua people's congress na gba owo, ni won bere isokuso.....
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 10:09pm On Oct 30, 2015
E maa n so Yoruba ni'gba ti n ba ti wa l'ori nl. Ko da o embarassed
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:09pm On Oct 30, 2015
razid:

O dabi eni pe gomina Amosun ti fowosi ise ode pelu awon oyinbo kan lati pese oko oju irin ti yoo lo lati Abeokuta si Sagamu ati titi de Ijebu Ode. Bakannaa ni lati Abeokuta lo si Ilaro ati Ayetoro. Ti iru eleyi ba wa nibe, sebi n se ni ipinle Ondo yoo ko dara po mo lati Ijebu Ode lo si Ore titi gba Ondo ati Akure ni.

O ti pe tati n gbo nipa ele yi. eje ka so ooto fun ra wa.ipinle ogun o ni owo lati fi pari iru igbero yii
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 10:09pm On Oct 30, 2015
Laudate smiley
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:10pm On Oct 30, 2015
Lol see them coming in after the match grin cheesy
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by delpee(f): 10:10pm On Oct 30, 2015
E Ku igbadun asiko yi. O dara pupo lati maa so ede abinibi wa.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 10:10pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:

O ti pe tati n gbo nipa ele yi. eje ka so ooto fun ra wa.ipinle ogun o ni owo lati fi pari iru igbero yii

Bawo lo se moh?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:11pm On Oct 30, 2015
Ilekeh:

Bawo lo se moh?

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 10:13pm On Oct 30, 2015
Musiwa419:
Alaye yin ye mi dara dara. Emi na mo wipe ipinle Ogun ati ipinle Ondo ni won jijo nii. Amo kilode ti awon ipinle mejeji ose fi owo sowopo lati fi le ri wipe eto yen wa si imuse ni isiyin. Se nitori wipe egbe oselu ototo lo wa ni ipinle ogun ati ondo ni?
E seun e jana. Ipinya to waye lati ara egbe oselu won je lara nnkan ti yoo fa ti ise naa fi wole. Ti e ko ba gbagbe, Odun 2009 ni Mimiko gba ijoba lowo Agagu labe egbe Labour ti igbakeji re ni ipinle Ogun si n be ni PDP.

Lati ara bi awon mejeeji kose si ni egbe oselu kanna, ko fee si ajose to dan moran laarin won. Nigba ti Gbenga Daniel kuro lori oye ni 2011 ti ijoba bo si owo Amosun labe asia ACN, aisedeede tun tesiwaju nitori wipe Mimiko ti n fa sehin nipa ibasepo re pelu awon gomina ilu Yoruba yo ku nitori aawo to sele laarin ohun ati Tinubu. Nnkan ti mo mo ni wipe nitori Mimiko ohun ni eto DAWN ko se ni aseyori nitori wipe kosi bi won se fe yo owo Ondo kuro lawo.

2 Likes

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by midolian(m): 10:13pm On Oct 30, 2015
modath:

Modath ti wa si ori eto, smiley

Midolian, eyin na e wa bawa da si eto yi oo.
Present!

shocked shocked I no too hear yoruba o! shocked shocked

I can see yoruba everywhere on this thread
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Firefire(m): 10:14pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:

Beeni oloselu ni won.Lehin iku olori pataki obafemi awolowo ati adekunle ajasin, pa adesanya lo ropo won.Alliance for democracy loruko egbe won.awon pelu olori bola ige,ayo adebanjo,ganiyu dawodu ati bola tinubu

Ki Olorun dele fun awon eni ire.

Ni gba ti awon agbagba Ile Yoruba bi Pa Abraham Adesanya fi owo le Amojuero Funsho William lejika lati gba fun Bola Tinubu ni aye AD, o se ni laanu wipe abamo lo gbehin oro naa.

Eyin Omo Odua, oto akoko lati gbena woju awon jegudujera oloselu iwoyi. angry

2 Likes 2 Shares

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:14pm On Oct 30, 2015
I'm really dissapointed though.I was expecting to see a lot of people comment.I know they will come later to give excuses cheesy cheesy grin

We have those who are also showing up after the match . grin grin cheesy
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by modath(f): 10:14pm On Oct 30, 2015
midolian:
Present!

shocked shocked I no too hear yoruba o! shocked shocked

Ere abi awada?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 10:15pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:
Lol ilekeh i thought you said you're from ekiti

Omo Ekiti n'iya mi. Omo Ekiti ati Ondo ni baba mi. Sugbon, Ekiti ni won ti bi mi ati pe, ibe ni mo dagba si.
Mo ti so gbogbo eleyi fun e tele nau
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Firefire(m): 10:15pm On Oct 30, 2015
midolian:
Present!

shocked shocked I no too hear yoruba o! shocked shocked

I can see yoruba everywhere on this thread

Now I see... cheesy
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:16pm On Oct 30, 2015
Firefire:

Ki Olorun dele fun awon eni ire.

Ni gba ti awon agbagba Ile Yoruba bi Pa Abraham Adesanya fi owo le Amojuero Funsho William lejika lati gba fun Bola Tinubu ni aye AD, o se ni laanu wipe abamo lo gbehin oro naa.

Eyin Omo Odua, oto akoko lati gbena woju awon jegudujera oloselu iwoyi. angry

Oro nla le so yi.ki olorun ko ko wa yo
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ritchiee: 10:17pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:

Beeni oloselu ni won.Lehin iku olori pataki obafemi awolowo ati adekunle ajasin, pa adesanya lo ropo won.Alliance for democracy loruko egbe won.awon pelu olori bola ige,ayo adebanjo,ganiyu dawodu ati bola tinubu
The only person suitable for this is the pillar of arts and culture in Africa but for his little shady side.He is sagacious if I may use that word.Almost like Awo if not for that little hmmm...I think he has repented.He has Yoruba's leader quality if I must say...
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 10:17pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:
I'm really dissapointed though.I was expecting to see a lot of people comment.I know they will come later to give excuses cheesy cheesy grin

We have those who are also showing up after the match . grin grin cheesy

You guys aren't arranging this properly. Mii moh igba ti e ma so Yoruba. Let's make it the same time everyday. Mo maa n wa lori computer lati code ni gbogbo igba ti n ba wa ni ile-iwe, maa le wa nibi nigba ti e ba ti n so ede Yoruba.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:17pm On Oct 30, 2015
Ilekeh:

Omo Ekiti n'iya mi. Omo Ekiti ati Ondo ni baba mi. Sugbon, Ekiti ni won ti bi mi ati pe, ibe ni mo dagba si.
Mo ti so gbogbo eleyi fun e tele nau

Oo so nkankanfun mi tele oo.mo sese n gbo ni sin ni ooo
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by itstpia8: 10:19pm On Oct 30, 2015
Ilekeh:

Omo Ekiti n'iya mi. Omo Ekiti ati Ondo ni baba mi. Sugbon, Ekiti ni won ti bi mi ati pe, ibe ni mo dagba si.
Mo ti so gbogbo eleyi fun e tele nau

aunty, e ki i se Ekiti mo ni?

ki lo tun sele bayi?

tele, Hausa le pe ara yin, o tun ti da Ondo lakoko yi, e se kuku claim Eko?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by zimoni(f): 10:19pm On Oct 30, 2015
itstpia8:
Thread: English

Owu: Yoruba

Rara. In the sentence, he was referring to a comment made by someone on a 'thread'.

Ire ooooooo.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by midolian(m): 10:20pm On Oct 30, 2015
Firefire:

Now I see... cheesy
lol..I saw you viewing. I was expecting your mention. I am Nupe by tribe.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:20pm On Oct 30, 2015
Ilekeh:

You guys aren't arranging this properly. Mii moh igbo ti e ma so Yoruba. Let's make it the same time everyday. Mo maa n wa lori computer lati code ni gbogbo igba ti n ba wa ni ile-iwe, maa le wa nibi nigba ti e ba ti n so ede Yoruba.

We already agreed its 9pm-10pm Nigerian time.You were probably viewing as a guest. stop lyyiiing tongue tongue grin cheesy

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by midolian(m): 10:21pm On Oct 30, 2015
modath:

Ere abi awada?
lol..I mean it o! I understand when you speak and write though..to an extent
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 10:21pm On Oct 30, 2015
Aareonakakanfo:

We already agreed its 9pm-10pm Nigerian time.You were probably viewing as a guest. stop lyyiiing tongue tongue grin cheesy

lmaoooo...... rara, mo n sise lowo.
Igba wo ni yen? Se o da oruko mi?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by totit: 10:22pm On Oct 30, 2015
zimoni:

He's right.

Thread....English, Tiredi.....Yoruba.

He actually meant " ready " hence I corrected him " se'tan or gbaradi "
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:23pm On Oct 30, 2015
Ritchiee:
The only person suitable for this is the pillar of arts and culture in Africa but for his little shady side.He is sagacious if I may use that word.Almost like Awo if not for that little hmmm...I think he has repented.He has Yoruba's leader quality if I must say...

Exactly but that's not politics though, that's arts. Politics is a totally different ball game
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 10:25pm On Oct 30, 2015
bolabolakemi:
The only future for keeping Yoruba culture and people is restoration of Oduduwa Republic ... embarassed

The long and short of the British fraud is that blacks are still slaves and they divided us into two-the house slaves and field slaves. The 1967 Biafra restoration was like a recaptured slave and how can a black monkey undo what the British did? They could not believe it. YOU PROBABLY HEAR GOWON AND OTHERS SAYING OJUKWU SHOULD HAVE SURRENDERED EARLY, IF BUHARI IS DOING WHAT HE IS DOING TODAY BECAUSE HE WAS DECLARED WINNER IN AN ELECTION, DO YOU NOW SEE WHY THEY STOLE PEOPLES HOUSES AND MONEY? The land Buhari owns in Port Harcourt that he said he does not know where it is, is probably one of the houses they stole but they will blame it on Ijaws or Ikwerres.

Before you criticise Biafra please take time and ask "Is Biafra different from Scotland and the UK? When they say loss of property and so on remind them there are Igbos in Ghana and Cameroon and in London and New York - they have not lost their property and we are not one country with them. The House slaves normally sabotage every effort of the field slaves to be free - you have to choose which one you are but don’t think we are free -the British uses the Hausa/Fulani to enslave everyone. - http://combatgeno
http://elombah.com/index.php/opinion/2067-biafra-or-black-emancipation-opening-the-eyes-of-black-people

This is true and this is why every well-meaning Yoruba person should invest in the Yoruba interest and any legal Yoruba business.
We need to do all we can to lift the Yoruba nation up again!
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:25pm On Oct 30, 2015
Ilekeh:

lmaoooo...... rara, mo n sise lowo.
Igba wo ni yen? Se o da oruko mi?

If i don't mention you, who else will i mention.In fact your name was the first or are you not ilekehd anymore?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by itstpia8: 10:25pm On Oct 30, 2015
bolabolakemi:
The only future for keeping Yoruba culture and people is restoration of Oduduwa Republic ... embarassed

The long and short of the British fraud is that blacks are still slaves and they divided us into two-the house slaves and field slaves. The 1967 Biafra restoration was like a recaptured slave and how can a black monkey undo what the British did? They could not believe it. YOU PROBABLY HEAR GOWON AND OTHERS SAYING OJUKWU SHOULD HAVE SURRENDERED EARLY, IF BUHARI IS DOING WHAT HE IS DOING TODAY BECAUSE HE WAS DECLARED WINNER IN AN ELECTION, DO YOU NOW SEE WHY THEY STOLE PEOPLES HOUSES AND MONEY? The land Buhari owns in Port Harcourt that he said he does not know where it is, is probably one of the houses they stole but they will blame it on Ijaws or Ikwerres.

Before you criticise Biafra please take time and ask "Is Biafra different from Scotland and the UK? When they say loss of property and so on remind them there are Igbos in Ghana and Cameroon and in London and New York - they have not lost their property and we are not one country with them. The House slaves normally sabotage every effort of the field slaves to be free - you have to choose which one you are but don’t think we are free -the British uses the Hausa/Fulani to enslave everyone. - http://combatgeno
http://elombah.com/index.php/opinion/2067-biafra-or-black-emancipation-opening-the-eyes-of-black-people

well, they've said you folks should come and dredge/develop Imo river, but you prefer congregating here on this thread and yarning fables.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Firefire(m): 10:26pm On Oct 30, 2015
midolian:
lol..I saw you viewing. I was expecting your mention. I am Nupe by tribe.

One Nigeria bro, nothing do you. tongue

1 Like 2 Shares

(1) (2) (3) ... (88) (89) (90) (91) (92) (93) (94) ... (384) (Reply)

Kenyans Are Far Behind Nigerians In Every Aspect – Fani-Kayode / Anambra light of the nation, eastern economy power house. / Enugu, The Pride Of The East.

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 50
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.