Segoye2's Posts
Nairaland Forum › Segoye2's Profile › Segoye2's Posts
1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 11 12 13 14 15 (of 22 pages)
Mo ti gba Jesu lowlow yi, sugbon mo yin n wa omo to sanra daadaa!, Jesu Loba! |
ti oluwa ni ile at ekun re, aye ati awon ti o tedo si ori re, ni tori ti ofi idi re sole lo ri okun, o si gbe kale lori awon i san omi, tani yio gun ori oke oluwa lo, tabi tani yio duro ni bi mimo re, eni tio ni owo mimo ati aya funfun, eni ti ko geb okan re si o ke si asan, ti ko si bura e tan, owun ni yio ri ibukun gba ni owo oluwa ati ododo lowo olorun igbala re, eyi ni iran awon tin se a fe ri re, awon ti n se afe ri re olorun agba'ye, egbe orin yin si oke, eyin enu ona, ani ki a gbe yin si oke, eyin ile kun aye raye, ki oba ogo ki o wo inu ile yi wa, tani oba ogo yi, olu a won omo ogun, owun na ni oba OGO! Amen. |
E kule ee oo, ema binu pe mo pe kin to dee, mo ni Datee ni, Omo yen dun ginagina, mi o ni soro fun yen loo, ehen, ogbeni Idinyun mi abi obo n yun mi, se ole ya ibiri on yun ee yen ni awora ki o so sori ero alantako mi? ani emaili mi, sugbon ooo, ti o ba sanra, gbagbe ee, ni se lo ma yun ee ku. Ire jo babalawo, sugbon babalawo dekpe ni tire, ati wipe, ko si a te gun ni idi e eee Sir. Eyin omo iya mi, mo fe ko orin kan ti a ma n ko nigba ti mo yi wa ni orile ede nigeria. Guguru a ko omo lo le, boole amo ko le, eepa a munu roni, chewing gum, ale di PA! |
O ti e ti da be yen, babalawo meji pade ra, Fire ooo, mo fe ri eni to ma wound. |
ha ha ahaha Mo san bu so sile ni shala shala, si oro si Nite Angel n so. Babalawo tuntun, ese sir, bawo lese le ran mi lowo oooo, ani, e so fun mi sir. e sa mo ohun ti mo n wa, ki ni etu tu ooo? |
Babalawo, jeka soro ti ofe ba mi so yen lori msn , ibi ti obo ba wa, e mi a wa ri ni oni, e je ka loo sa, e ku ise agbara na |
Odara la ti ma ko iwe ni ede wa, ati ojo ti mo bere si ni ko ede yoruba yi, mo tin gbona ninu ee daa daa, bee mi oti loo 5 minutes ri ni ile yoruba ni ayemi, but don't try me, nitori language student ni mi. |
if you are tired of reading Igbo language, you can join segoye2 on Hausa or Yoruba Thread. I hope am not gonna pay for ADVERT ![]() |
great one, thats the numbering in hausa. Ya ya ne, ya ma tan ka de ya ran ka, ka sa mu aiki ne ko ka na kae ni man aiki? N na de aiki, nkana ni ma n ikae. N na suwa |
Ya ya nne, ya gida de ma tan n ku? ni ne abo kin ku segoye2, ni be erebe ne, ama to, na e girima ah Kagoro, mu yi maganan mu a nam. Du kan mi daya neh! |
I nu mi dun pe o pari ile eko jiga ti a mosi Encyclopedia ti Ilu Britannica, sugbon bawo ni asele ko e ni yoruba lai si ami? ani ami oke, isale and Arin? pa pa julo ami isale isale? so fun wa jooo |
Babalawo Iro gba emaalii mi, ko de ba mi soro, okan addii mi ni,, I ro ni bobo yen so jare, tire ni mo gbagbo, so ro fun mi, bawo ni ase ma se ise na? Abi kin lo si soo si ni? |
@ nnnennnigbo, Otolo gba gbu ke e kwensu, o o maka Ikomi, n sopossu gwa gi si n ga DO E DAA DAA, but n di generous, gua mu si n bia, and n ga bia, n ga ye gi, i he a hunnn, Ikomi bu koret guy, e suppose choosu mu or ikomi, ma ka, i de cho ose two at a time, I ge loose the both of us. Meanwhile, Ibu Orobo, I mean se osanra da daa, if not, carry go, I no need ham, |
Eyin omo iya mi, ema binu si mi rara, babalawo mi fe bami soro kekere kan. |
Ma binu jare, mo se woo ni, ati wipe, mo ti acepti re, sugbo mi ko ri oo mooo ooo |
Ijoru ga oru, nga bia echi, kele wuye gi ikomi, meanwhile elo so ra yin eyin aje okuta ma mo mi won yi! |
Ikomi, if they reject you, can always find a house in my home, we love you! but you need to keep your promise to get me one Oyibo. Meanwhile, Brothers in Igbo Language, How are you doing and the rest of your self, Am cool and really crazy about the yoruba and Igbo thread, I think you guys are bomb, so bomb yourselfs ooooooooo and leave Honorable Ikomi alone Igbo Quenui OHOOOO |
Tiyin da? |
oruko mi @ hotmail dot com |
Ok, Ikomi is my friend, am ready to stand for him in place of him crusified, but mind you, am omo awon Yeye ooooooooo, and they might hunt you! |
isi anyi ekotela ebu taa too! |
you mean they need you dead instead of the items? Tell them I can afford a truck fully loaded of each mentioned items, I mean they can kill some, and place some in their warehouse, please tell them in Igbo, I think is a good deal! |
Oda,, Babalawo, Kini oruko ti anpe Mouse ni ede Yoruba? ati wipe kini pasti tensi Mango ati table, ti e ko ba gbaa ajepe, babalawo ironi ti yin! |
Ikomi, are you giving me or not? am going ooooo, with the items, u na no go beg mi ne? |
babalawo mu owun, ki ni e fe ba mi sooo, omo iya ni gbogbo wa ni bi yi, nitori na, e je ka ma so lo ni bi yi abi e le te mi ni ago lori segoye2@itsabove.com emi o ni messenja yahoo ra ra ra msn ni mo ni, |
Ogbeni Ikamefa, se ire ni babalawo daadaa, oda na, ole ran mi lowo ni yen kee |
Ikomi, Don't worry, Nge ye gi; 7 tubers of yam 7 kolanut, don't forget ose oji too 7 bottles of shnapp 4 yards of akwa ocha 3 white oke okuko + 10 live Goats Ye mu ihan, and Nge ye gi the items for your hungry finners. LOL |
Babalawo, Gbagbe bobo yi jare, ko da yin mooo. |
Oga Ikomi, Se e ti lo san ohun ti awon omo iya yin ni ki e san? We will fine him the following: 7 tubers of yam 7 kolanut, don't forget ose oji too 7 bottles of shnapp 4 yards of akwa ocha 3 white oke okuko i know he can't afford atulu, so we'll take a white goat. all in favor say aye Oro Ounje sa ni ti awon omo nna. |
Ejo oo, emi ni ore Ikomi, Iyen omo yin, mo ba soro lori obirin to sanra, mo dee fe ki eran mi lowo lati bee, abi ti e ba ni obirin to sanra, e le fun mi, Ikomi mo ohun ti mo n fe, asalaye fun yin daa daa. Ati wipe, kini e ma n fun alejo ni biyi? Meanwhili, Igbo quanu, Hey! |
Iwo ro pe, I woni kan lole so ro abi? odana, mo ti lo ba e ni beyen mo de, ba ee soro ni ede yin, abi e ni ranmi lowo sibe? |
Emi ofe ki won ku ooo, ani omo yen ati baba ee, mo kan fe ki baba e dariji mi, ko de gbagbe mi, atipe ki o ma wu omo yen lati ma see gannnn, omo yen mose gan, eyin nikan de ni mo mo ninu ile yi, I ran mi lowo ejooo. Omo wo Ikamefa? soro fun mi, se owa, bawo ni awon osise tire, se won ju si daadaa. |
