Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,154,850 members, 7,824,537 topics. Date: Saturday, 11 May 2024 at 12:02 PM

.. - Culture (84) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1829960 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (81) (82) (83) (84) (85) (86) (87) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by ogboliagba: 5:06am On Aug 15, 2016
scholes0:


Ododo oro.
ati wipe, ni igba miran- bi awon akopa itakun yii se n ko ede Yoruba won sile ko danto rara.
Bi apere, elomiran le fe so wipe:
"Ni Igba ti mo lo si Ilu Eko, mo ri omoge arewa kan"

Ki o si ko o bayii:

"Ni gba timolo silu Eko, mori omo ge are wa kan"
Nje eyin naa rii wipe, o ma soro fun elomiran lati ka?

Baba, eku agba Otito ni wipe bi awa omo yoruba ode oni se nko ede wa ko muna doko idi ni eyi ti elomiran fi maa nsi oogun lo, ki olorun gbawa lowo awon Oyinbo tiwon wa bawa ledeje.
Re: .. by ogboliagba: 5:21am On Aug 15, 2016
ifasheun:


Mo ti dan ti akoko ti nse ti iwe na wo, mo si ri apere rere, awon eniyan nyonu si mi, even awon eniti mio mo ri ntami ni ore.
Tested vere very ok.
Baba eku agba, ewe koni ko ohun yin o, e jowo e Funmi ni oogun ti tan (IMULE AWON AGBA ) number mi niyi 08066161217.
Re: .. by ogboliagba: 5:40am On Aug 15, 2016
Baba please add me on Isese lagbara whatsapp group my number is 08066161217(ogoliagba)
Re: .. by ifasheun: 2:53pm On Aug 17, 2016
ogboliagba:

Baba eku agba, ewe koni ko ohun yin o, e jowo e Funmi ni oogun ti tan (IMULE AWON AGBA ) number mi niyi 08066161217.

Ella-boru, Ella-boye o

Emi ko ni imule agba yi lowo o
Baba wa Ifankaleluya ni won ni lowo,
e le kan si won lori emaili won.
Ifa o gbe wa o.
Re: .. by Zenlife: 9:25pm On Aug 18, 2016
X
Re: .. by Zenlife: 9:49pm On Aug 18, 2016
@Ifakanaleluya, Domnicson, kadunasouth, ayokomi 1010, etc, etc.

E kale o.

1. E jowo kini won npe ni aso ose?
Nibo la ti le ri ra?

2 Kini itunmo Sisi Teso?

3. Oogun ada Ahan?

4. Orise owo?

5. Oogun Orilu?

6. Oogun okele?

7. Oogun Ejiorosun

8. Oogun Asogbo

9. Oogun to afi de enia lewo ode

10. Oogun Aforan

11. Oogun karukusu

12. Oogun Abilu roro Agbo

13. Oogun ti afi pa gbawojo

14. Oogun abo okele

15. Bi enia banmo abu ekosa

16. Oogun epon kan

17. Oogun onfa obinrin

18. Oogun Aremo

19. Oogun oruka abo

20. Oogun Agbele pota

Eseun eyin baba agbala yi o
Modupe.
Re: .. by fai8th(m): 4:40am On Aug 22, 2016
ewe ama je fun yin baba, ejowo efunmi ni oogun aseyori
Re: .. by Abeleikare(m): 12:50pm On Aug 22, 2016
pappykay0428:

E jowo se e ni oruka aluwo to daju abi agbaseje tabi agbawo abi agbefuye ti o daju...aboru boye nile awo.
baaba ooooo mo ti darapo moyin ni nairaland bayii...ewe nbe ogun si wa pelu.... emi gangan lemi.... Abele lati ilu ikare....
Re: .. by Lionhearted: 5:25pm On Aug 22, 2016
dominicson:



Drop your number, it is already on 'Isese Lagba', our whatsapp group. I will add you. Typing is not that easy. Regards

*
Re: .. by Sego4(m): 11:11pm On Aug 25, 2016
[/color][color=]

aburo boye oo eyin aye. Mose iba omode, mose iba agbalagba. Ewe ama je o, eku ise takuntakun
Re: .. by Sego4(m): 9:17pm On Aug 27, 2016
ekale ooo gbogbo ile, ewe amaaje ooo ami, ejo bawo ni mosele ki ewe iyalode
Re: .. by dominicson: 11:07pm On Aug 29, 2016
Atayese


Efun, osun, oori, oyin, aadun, eko tutu, ewe rinrin, tete abalaye, ewe abamoda, ewe orokojiya, ewe ogbo, ewe odundun, iyo. A o ko gbogbo awon nkan yii si inu igba nla, a o pe gbolohun re si, a o gbe sinu iri di ojo keji, leyin ti a ba lo gbe won ni ojo keji, a o gun gbogbo re papo pelu ose dudu. A o ko sinu igba olomori. A o da iyere-osun le ose ti a ko sinu igba naa lori. A o te ni eji-ogbe. A o tun wa pe gbolohun re si leekeji. A o ma fi we. Oyin ni a fi ma n po ose yii, kii se omi.





Psalm:


Efun ni tun ori Olugbon se, osun ni mu iwa osun toro. Awon ni won sa igede fun Orunmila nigbati oro re daru tan. Orunmila wa to Eledumare lo. Orunmila ko ejo o ro fun Eledumare. Eledumare ni ki Orunmila lo wa Esu wa. Orunmila de ile Esu, ko ba Esu. O de ile Lapara tii se baba Esu, ko ba Esu nibe. Orunmila lo si ile Gbaroje tii se eru Esu, o ba Esu nibe. Orunmila ba ko ejo o ro fun Esu wipe oro aye oun ti daru, beeni ko si dogba mo. Esu fun Orunmila ni esi wipe: iwo ko rubo ni koje ki oro re dogba, ohun ni oro aye re ko se toro. Esu ni ki Orunmila lo wa Aadun, Osun, Efun, Oyin, Iyo, Eko-tutu, Ewe rinrin, Ewe abamoda, Ewe tete abalaye, Ewe orokojiya, Ewe ogbo, Ewe odundun, Oori. Orunmila ni ki Esu wa ba oun lo si odo Eledumare. Nigbati Esu de odo Eledumare. Esu ni mo de, Oba Alamonmotan, Oba amatiwaiye ojo, Oba amogbeyin oro, Oba ti o n tun ori eniti ko sun won se si daradara. Eledumare bi Esu lere wipe: kilode iwo Esu? Esu ni Orunmila lo wa ba oun wipe oro oun daru tan patapata, beeni oun ko ri ojutu re mo, gbogbo ohun ti oun se koje oun mo, bi oun se ogun ko je mo, oun kori owo, oun kori iyawo fe, oun ko ri omo bi, oun kori ohunrere kan gbese. Eledumare wa bere lowo Esu wipe: se iwo ko gba nkankan ni owo orunmila ni? Esu ni mo gba nkan ni owo re. Esu ni mo gba Aadun lowo re. Eledumare ni aye re (mi) yoo ma dun ni. Esu ni mo gba Eko-tutu lowo re. Eledumare ni aye re (mi) yoo ro, ko ni le fun mi laye. Esu ni mo gba Iyo lowo re. Eledumare ni aye mi yoo layo kale ni. Esu ni mo gba oyin lowo re. Eledumare ni aye mi yoo dun ni, ko ni koro, ko ni kan fun mi laelae. Esu ni mo gba Odundun lowo re. Eledumare ni laye mi ohun buruku ko ni dun ni ile mi. Esu mi mo gba Tete-abalaye lowo re. Eledumare ni gbogbo ire ni yoo ma te mi lowo. Esu mi mo gba Rinrin lowo re, Eledumare ni ile mi yoo ma tutu ni rinrin, ko ni gbona. Esu ni mo gba Abamoda lowo re. Eledumare ni gbogbo aba ti mo ba da ni araye yoo ma gba, ohun(voice) mi ni won yoo si ma fe gbo. Esu ni mo gba Orokojiya lowo re. Eledumare ni emi Lagbaja omo Lagbaja ko ni jiya mo laelae. Esu ni mo gba Ogbo lowo re, Eledumare ni gbogbo omo araye ni yoo ma gbo temi. Esu ni mo gba Efun lowo re, Eledumare ni gbogbo omo araye ni yoo ma fun mi ni ire temi. Esu ni mo gba Oori lowo re. Eledumare ni gbogbo omo araye ni won yoo ma ri mi yonu si. Esu ni mo gba Osun lowo re. Eledumare ni gbogbo ire ni yoo ma sun mi bo. Ebo naa ni emi Lagbaja omo Lagbaja gbe wa yio. Ki ara o de mi fun ire gbogbo, ki nri na, kin ri lo, kin rije, ki n ri mu (Adua)

4 Likes 1 Share

Re: .. by provostkola: 7:41pm On Aug 31, 2016
eku ise oooo.gbogbo Omo oduduwa,ise takun takun latigbe Omo Yoruba laruge. eledumare ama wa pelu yin o.ase .
Re: .. by Nobody: 11:06pm On Aug 31, 2016
Ejowo mi o le mi dada (short breathing problem) lenu ijo meta, ejowo Kini mo le lo?
Re: .. by DoctorD: 6:53pm On Sep 01, 2016
Ogun Oruka malu todaju ejowo efun wa pls
Re: .. by Zenlife: 7:20am On Sep 02, 2016
Zenlife:
@Ifakanaleluya, Domnicson, kadunasouth, ayokomi 1010, etc, etc.

E kale o.

1. E jowo kini won npe ni aso ose?
Nibo la ti le ri ra?

Kini itunmo Awon oigun wonton?

2. Sisi Teso?

3. Oogun ada Ahan?

4. Orise owo?

5. Oogun Orilu?

6. Oogun okele?

7. Oogun Ejiorosun

8. Oogun Asogbo

9. Oogun to afi de enia lewo ode

10. Oogun Aforan

11. Oogun karukusu

12. Oogun Abilu roro Agbo

13. Oogun ti afi pa gbawojo

14. Oogun abo okele

15. Bi enia banmo abu ekosa

16. Oogun epon kan

17. Oogun onfa obinrin

18. Oogun Aremo

19. Oogun oruka abo

20. Oogun Agbele pota

Eseun eyin baba agbala yi o
Modupe.


Iro mi ni wipe eko kiko ni abala yi wafun, bi o ba jebe, e dari Jimi.
Amon mo beere itunmo awon oogun oke wonyi lati bi ose meji sehin nisi, amon ninu awon oni mimo abala yi ko si ikan ninu won to fi esi kan si.
Kini idi re? Ibeere alaye ni mo beere. Mi o toro oogun ofe.
Kini o fa? se won ko man ni? Ko da bayi o.
Ko yemi ooo.
Re: .. by provostkola: 10:01am On Sep 02, 2016
ejo emu mi wo group whatup imule agba number 08025334126.
Re: .. by olusegunakintol: 11:09am On Sep 02, 2016
Baba kaduna. E joo, ise contract ni mo n se,o de ti le lodun meta bayi ti mo ti di oga ara mi. Amo se ni mo kan n joko ni office lasan ni mio ki n rise gba. Koda awon ore kan ma n wa ya irinse mi sise won ni. Isin(religion) mi ko faye gba ogun(charms),ayajo ati ofo(chants). Sugbon a nigbagbo ninu ewe ati egbo,agbo(herbs) ati ose(soaps) gege bi ase ti Olorun ti da mo won. E jowo e ran mi lowo ki n yee seru aye. Ki ona la femi naa. A maa ju yin se o
Re: .. by olusegunakintol: 11:11am On Sep 02, 2016
olusegunakintol:
Baba kaduna. E joo, ise contract ni mo n se,o de ti le lodun meta bayi ti mo ti di oga ara mi. Amo se ni mo kan n joko ni office lasan ni mio ki n rise gba. Koda awon ore kan ma n wa ya irinse mi sise won ni. Isin(religion) mi ko faye gba ogun(charms),ayajo ati ofo(chants). Sugbon a nigbagbo ninu ewe ati egbo,agbo(herbs) ati ose(soaps) gege bi ase ti Olorun ti da mo won. E jowo e ran mi lowo ki n yee seru aye. Ki ona la femi naa. A maa ju yin se o
Re: .. by jentusoul: 6:57pm On Sep 02, 2016
Ejowo baba, e add mi si imule agba group 08074522156
Re: .. by olusegunakintol: 5:42am On Sep 03, 2016
Baba kaduna. E joo, ise contract ni mo n se,o de ti le lodun meta bayi ti mo ti di oga ara mi. Amo se ni mo kan n joko ni office lasan ni mio ki n rise gba. Koda awon ore kan ma n wa ya irinse mi sise won ni. Isin(religion) mi ko faye gba ogun(charms),ayajo ati ofo(chants). Sugbon a nigbagbo ninu ewe ati egbo,agbo(herbs) ati ose(soaps) gege bi ase ti Olorun ti da mo won. E jowo e ran mi lowo ki n yee seru aye. Ki ona la femi naa. A maa ju yin se o
Re: .. by Cariz: 9:59am On Sep 03, 2016
add me to isese lagba whatsapp group pls 08104739470
Re: .. by Nobody: 12:58pm On Sep 03, 2016
ifasheun:



Ose Ebe Awon Agba yi ni mo nlo lowo,
Apere ti mo ti ri so far ni wipe,
1. Awon olopa nle mi ni oju orun, mo si ri iya kan ni ojiji( sudenly) oni ki ntele owun wipe awon olopa(police) na ko le fi mi se nkan kan,
2. Awon omo iya mi ti won ti nbami ja lati ojo pipe nfi owo ranse simi wipe ki ebi o mo pami nitori ipe mio ni ise lowo(hand).
TESTEDD CONFITMED, Ifankaleluya iba re oo.


Pls can we use ordinary toilet soap...OR its oshe dudu.....
Re: .. by olusegunakintol: 7:58am On Sep 05, 2016
Baba kaduna. E joo, ise contract ni mo n se,o de ti le lodun meta bayi ti mo ti di oga ara mi. Amo s
e ni mo kan n joko ni office lasan ni mio ki n rise gba. Koda awon ore kan ma n wa ya irinse mi sise won ni. Isin(religion) mi ko faye gba ogun(charms),ayajo ati ofo(chants). Sugbon a nigbagbo ninu ewe ati egbo,agbo(herbs) ati ose(soaps) gege bi ase ti Olorun ti da mo won. E jowo e ran mi lowo ki n yee seru aye. Ki ona la femi naa. A maa ju yin se o

gbogbo isese, e joo e ma wo mi niran. e ran mi lowo
Re: .. by Akerekoroabijawara(m): 4:25pm On Sep 06, 2016
E Ku ise.
Re: .. by olusegunakintol: 8:51pm On Sep 08, 2016
gbogbo isese E joo, ise contract ni mo n se,o de ti le lodun meta bayi ti mo ti di oga ara mi. Amo s
e ni mo kan n joko ni office lasan ni mio ki n rise gba. Koda awon ore kan ma n wa ya irinse mi sise won ni. Isin(religion) mi ko faye gba ogun(charms),ayajo ati ofo(chants). Sugbon a nigbagbo ninu ewe ati egbo,agbo(herbs) ati ose(soaps) gege bi ase ti Olorun ti da mo won. E jowo e ran mi lowo ki n yee seru aye. Ki ona la femi naa. A maa ju yin se o

gbogbo isese, e joo e ma wo mi niran. e ran mi lowo
Re: .. by Sego4(m): 11:20am On Sep 09, 2016
jades5050:
e jo sir ki ni oruko i mi ti Won tun pe ewe ola tabi ti o tun nje

igbo
Re: .. by olorymusty: 5:17am On Sep 11, 2016
add me to isese lagba whatsapp group pls. 08132486529
Re: .. by Unilevel(m): 12:00am On Sep 13, 2016
kadunasouth:



OGUN ILE KIKO odaju

Irun, ori, alakan okan aguntan, odidi atare ao jo ao pa tagiri ni pansa ao kosi tabi ka kosi inu owu tutu ao wa kosinu tagiri ao we lowu dudu ati funfun ao bomole
Ofore lowo lowo laguntan nrin ojo odun meji kipa bara, akiri kekere akan koma kole, ojo tabafa ori lama enikan kimagba torikun gbogbo ona ni kola kanmi ninu odun yi kinri owo pari ilemin Mojuba gbogbo eyin ti oloun ko ile ayele lowo iba agbagba iba omode iba okunrin iba obinrin yio ma juwa se o ase edumare

Se irun ori eni naa ni tabi ti enikeni?
Se bara nii tabi tagiri?
E se pupo.
Re: .. by Unilevel(m): 12:43am On Sep 13, 2016
kadunasouth:
Iyonu

Ibeere lori ose aseta ti a lo tako tabo edan fun yen.
Bawo ni ao se lo ose ti o wa ninu igba yen?

E se pupo.
Re: .. by miich28: 8:11pm On Sep 13, 2016
kindly add me to the group. @ 07068089504
Re: .. by miich28: 8:14pm On Sep 13, 2016
Ejowo mo nilo Oogun mayehun to gbonaa gan

(1) (2) (3) ... (81) (82) (83) (84) (85) (86) (87) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 40
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.