Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,104 members, 7,957,125 topics. Date: Tuesday, 24 September 2024 at 07:31 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1842183 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (87) (88) (89) (90) (91) (92) (93) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by ademotech: 7:43pm On Jan 06, 2017 |
Ifankaleluya:ESE pupo 1 Like |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:12am On Jan 08, 2017 |
belatoxx: 1. Ashina 2. Atude 3. Oso funfun |
Re: .. by dagu: 2:24pm On Jan 08, 2017 |
Ifankaleluya: Be ni baba, Mama-Agba so fun mi wipe Awure keke to n sise ni aye igba kan o fi be sise mo laye ode oni nitori wipe alujonnu owo ti po ju ni ita. 2 Likes |
Re: .. by seanjizzyayo: 2:24pm On Jan 14, 2017 |
Ifankaleluya: @IFANKALELUYA baba ifankaleluya edakun edahun ibere mi mo ti se awa ri ewe ire edakun oku awon eroja toku ejowo bi EBA le funmi ni ori tread yi email mi niyi seanjizzyayo@gmail.com edakun ti ise yi badahun makan yin Lara ejowo ti oba si je omiran le o funmi kosi eyi ti ko da. ti aba si rii eni ti o mo ogun ti omo yahoo lelo tiyo fi ma ri owo gba yala ose, ebu tabi aseje koba mi post ee ejowo @kadunasouth @healthfirst ejowo eba dasi oro yi ise onidojuru aseye le o mase oooooo |
Re: .. by seanjizzyayo: 2:26pm On Jan 14, 2017 |
Ifankaleluya: @IFANKALELUYA baba ifankaleluya edakun edahun ibere mi mo ti se awa ri ewe ire edakun oku awon eroja toku ejowo bi EBA le funmi ni ori tread yi email mi niyi seanjizzyayo@gmail.com edakun ti ise yi badahun makan yin Lara ejowo ti oba si je omiran le o funmi tabi oshole togbona kosi eyi ti ko da. ti aba si rii eni ti o mo ogun ti omo yahoo lelo tiyo fi ma ri owo gba yala ose, ebu tabi aseje koba mi post ee ejowo @kadunasouth @healthfirst ejowo eba dasi oro yi ise onidojuru aseye le o mase oooooo |
Re: .. by seanjizzyayo: 3:20pm On Jan 14, 2017 |
Lionhearted:ee add me sori whatsaap group number mi niyi 08100713615 |
Re: .. by seanjizzyayo: 4:10pm On Jan 14, 2017 |
08101646045atwp: kini itumo biscuit okin ?? |
Re: .. by fridayakanb1(m): 2:11am On Jan 15, 2017 |
Baba e jowo mo sese de ori ikan ni yi ni.Mo fe ogun iwosan roparose to daju.E seun,yio ma ju yin se o. |
Re: .. by fridayakanb1(m): 3:38pm On Jan 15, 2017 |
A ku dede iwo yi baba,ajinde yio ma je yio.Baba e ko ti dahun ibere mi,mo fe OGUN IWOSAN ROPAROSE ti o daju saka.Baba ejowo sir,eyan mi kan ni aisan yi nyo lenu,e ko ni ri ogun agbana o,Ase Edumare. |
Re: .. by ADEOSUN111(m): 8:15am On Jan 22, 2017 |
ejowo nipa EYONU AWON AGBA YEN, se omi lasan ni ao fi po ose ati awon nkan to Ku ni abi omi agbon abi kini? ejowo e yan Nana re. eseun yoo maa Ju waa se o ase |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:08pm On Jan 25, 2017 |
OSO ONITIKUTI Omo aja eyikeyi ninu ako tabi abo, aofi ewe swerepepe tutu oojo teele inu agbada, aogbe omo aja na lelori, aofi odidi atare nla 7 si legbe, aoda opolopo ewe ola le aja na mole, aowa fi ewe aje onisefun sefun bomole ti aja na koni han sita, aojo ni dede ago mejila osan, aoto epo pupa yika aro na, ti aba njo oogun yi lowo, aoma mu oti ti aofi jotan, ti aba jotan, aolo kunna, aoda sinu ado sere kan, aoran aso osunwon, aogbeko fun ojo meje kiato mafi oti lo lararo, pelu OHUN; onitikuti walole ti olowo wa, olola wa, oba ilu, ijoye, borokini ilu yi wa kiwon wafi owo owo won tamilore, kiwon wafi sanu mi, kiwon wafi bomi lasiri Ki won wa fi tiwon gbe temi lawuge etc... Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP! ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045 OR https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above! Jowo mafi number re si abe comment'o Whala'oni payin'o Add links yen si odo'e Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere. Ajuwase o |
Re: .. by Despiryer: 5:03am On Jan 28, 2017 |
keyguy59:baba se igbin to ba ni kini funfun loju? |
Re: .. by Despiryer: 5:34am On Jan 28, 2017 |
Lionhearted:mo nilo ogun ti oko olomokunrin file tobi daada |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 12:09am On Feb 13, 2017 |
fridayakanb1: OGUN IWOSAN STROKE AO toju igi osunsun,ao lo tiyo kunna dada,ao wa Sa enina ni gbere ni apa ati ese,ao fi ra. ao wa wa oge oro adete sinu igbakan,ao ju odidi eko tutu kan si,ao fo papo dada,ao mafi wo owo ati ese eni na,pelu ogo olorun alafia de niyan. STROKE¤ Ewe Ato, Eru awonka, ori, ao fi ori yii tele agbo ao fi eru yen le lori ao fi ewe ato le lori ao fi omi se jina daadaa, emeta ni mimu re lojumo. FUN IWOSAN STROKE Elowa epo jebo tioba po dada kie wa kosi inu ikoko agbo kie se ko hoo dada tio obati ho ao wa lowa akisa ori atan tabi ti ilele tojewipe erupe tinbo monle ao wamu ao gban nu ao jusi inu agbo yi ao se po tityo ho dada toba jina ao so enina yoma mu ninu agbo na akisa towa wanibe ao mafi jo gbogbo ara enina lati ori delee walahi mofi olohun bura ose kan pere lefi se ti enina yofi OGUN ROLOWOROLESE(STROKE eku asin 11,atare odidi 11,ori oka 6,oga gbigbe 11,ao wa gun ninu odo ti yoo kunna,ao gbodo fi owo ko o,ao wa gun ni agunmu,ao ma fimu eko gbigbona sibi kookan.wallahi ise nla ni koye kin yonda re,adua yin ni mo nfe.fun ibeere {User Contribution} Ogun rolowo rolese(stroke)-eku asin 11,atare odidi 11,ori oka 6,oga gbigbe 11,ao wa gun ninu odo ti yoo kunna,ao gbodo fi owo ko o,ao wa gun ni agunmu,ao ma fimu eko gbigbona sibi kookan. KI STROKE MA MUN ENIA¤ Opolopo Ayan ao jo pelu Odindi ataare kan gbere yii ifunpa waa kaa ni owo otun, Gbere yii itan Osi kaa Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP! ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above! Jowo mafi number re si abe comment'o Whala'oni payin'o Add links yen si odo'e Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere. Ajuwase o 1 Like |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 3:00pm On Feb 15, 2017 |
OSOLE GBEWA PAJAWIRI Omo yahoo na lelo daada kosi ewu Ori kanakana 3, alangba 3 atare aja 3, pelu pelu biscuit okin ati opolopo ewe ola ao jo papo ao ma fi omi alujannu lo ebu na......... N.B:- owo Ni afi ma nlo ebu na'o Iru owo ewo Ni ao maafi lo? =**** Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP! ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045 OR https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above! Jowo mafi number re si abe comment'o Whala'oni payin'o Add links yen si odo'e Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere. Ajuwase o |
Re: .. by Lokoandtq(m): 12:30pm On Feb 18, 2017 |
jamiu3209:=baba Ejowo Efun Wa Ni Awon Oogun Yii Tan,bi Ayeta Oni Chain Ati Gbetugbetu Oni Oruka Yen Tan,sebi Eyin Agba Naa Le Bo Tee Pa Owe Pe ,oju Ti Ore Mi Oju Ko Ti Mi ,pe Ai lojuti Lon Je Bee Iba Agba Oo Elee Gegun Lori Ise Naa Fun Eni Ti Oba Fi Se Ise Ibi Email Mi Niyi, Lokoandtq@gmail.Com Tabi Ebami Fi Ranse Si Ori No Yi - 07063539854 |
Re: .. by lackren(m): 4:18pm On Feb 21, 2017 |
Dear forumites, Please I need more knowledge about YES or No answer on Merindinlogun Cowries when tossed it on the ground once and form any one of the following: Eji Ogbe Eji oko Ejila shebora Odi Obara Okana sode Irosun Owonrin Ogunda Osa Irete Otura/ofun kanran Oturapon Ika Ose Ofun Opira |
Re: .. by IBAAGBA1: 12:37am On Feb 24, 2017 |
Iba Olorun,iba eniyan,iba esu lapa kan,kesu ma sewa ko ma se enikankan to sun mowa o. Iba omode,iba agba,iba gbogbo onimimo to nfi imo won tu awon eniyan sile ninu ide aye. Omode ni mo je,eyin agba onilakaye e dakun dabo e damimo omo to. Lagbara Eledua a ma ju yin se o AMIN ASE EDUMARE. |
Re: .. by IBAAGBA1: 12:52am On Feb 24, 2017 |
08101646045atwp: Iba re baba mi agbalagba,e jowo sir iru omi wo ni eyin agbalagba npe ni omi alujonnu,atipe iru owo wo la ma fi lo ebu yi,e se pupo sir. |
Re: .. by possible26: 5:41pm On Feb 27, 2017 |
baba pls i want to join isese lagba pls guide me 2ru. |
Re: .. by Nobody: 6:30am On Mar 01, 2017 |
08101646045atwp:ejowo baba, bawo ni eniyan se ma nlo olugbohun to bawa ninu iwo agbo pelu ikoti ogun lori re. Ejowo, mohun duro de idahun yin sir... e se pupo |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:56am On Mar 02, 2017 |
CallmePROF: Eku'laakaye Lori ibere yin Yi. Nitori opolopo awon ise onikoleti lo ma nje eyibti ao fi ikore banu! Nitori ise na leeje ajogun ba'o Sugbon bi ase nlo ise oniko leyi niyen'o But telomi tun le yato'o Sugbon bi mosemon Ti a nlo niyen'o Ajuwase o 1 Like |
Re: .. by Nobody: 11:02pm On Mar 02, 2017 |
08101646045atwp:ese pupo Lori alaye yin sir, modupe. Sugbon nkankan to n ru mi loju niwipe..... se ti mo bati fi ikoti ogun nah banu tan, se ma da ikoti ogun nah pada sinu olugbohun nah kin to soro si abi maa soro si olugbohun nah ki n to da ikoti ogun nah pada sinu olugbohun nah??. E se pupo sir. |
Re: .. by Mallam1910(m): 7:25am On Mar 03, 2017 |
kadunasouth:efun ati osun pelu edu kini ama lo fun |
Re: .. by olamide1247: 9:39am On Mar 08, 2017 |
ejo efun wa ni ogun aferi ati eyi ti a ma fi ma ri owo |
Re: .. by Nostradamus: 11:40am On Mar 08, 2017 |
IBAAGBA1:oti schnapp lo n je omi anjonnu (tabi kie pe ni eje anjonnu /omi aye ). |
Re: .. by Medallion500: 9:36pm On Mar 12, 2017 |
Ibaba eyin agbaagba oo. Ki iba mi se oo.. Ejo eyin agbaagba e add me si whatsapp group. Mofi eledumare beyin oo.. 08066447586 |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:57pm On Mar 12, 2017 |
OSOLE OWO TIMU OWO NLA TI ALE FI KOLE LARIN OSU META! Sugbon nigbati Emi danwo, Mio kole'o Sugbon hmmm!!! Nkan Ti mofise komabaje'o!!! :- EWE BARA MESAN TI OOJO, AOGUN MO ERU ALAMO IYEKIYE, AOPO LOSE, AOFI EJE EIYELE funfun PO OSE NA DADA, AOKO ose na SINU IGBA OLOMORI, AOGBE PAMO FUN 16DAYS. Aoma buwe lararo, pelu ogo Eledumare owo ti ama fi kole nlala yio wa larin osu meta pere. IKILO: enikeni kogbodo ri igba yi ki ojo na tope. Osole yi Koni daun daada na. Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP! ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045 OR https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above! Jowo mafi number re si abe comment'o Whala'oni payin'o Add links yen si odo'e Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere. Ajuwase o |
Re: .. by boas521: 8:46pm On Mar 14, 2017 |
Ejowo kin ni won PE ni isu dandan |
Re: .. by boas521: 4:20pm On Mar 16, 2017 |
Pls add me on WhatsApp |
Re: .. by Adewunmis(m): 8:41am On Mar 23, 2017 |
ifankealeya eku owuro ejowo kini nje ashisu |
Re: .. by Nobody: 3:26pm On Mar 23, 2017 |
. |
(1) (2) (3) ... (87) (88) (89) (90) (91) (92) (93) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 84 |