Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,513 members, 7,958,554 topics. Date: Wednesday, 25 September 2024 at 05:05 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1842311 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (89) (90) (91) (92) (93) (94) (95) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by akingbemi(m): 9:07am On May 21, 2017 |
Eseun |
Re: .. by ifadamilola: 4:07pm On May 21, 2017 |
ejowo gbogbo ile moni lo Ogun ti obinrin ba fiyan sile tio si pada ni KIA KIA edakun esaanu Mi aboru aboye |
Re: .. by ADABA25: 10:28pm On May 24, 2017 |
Lero70:Baba, e Jo bawo ni eniyan se le mo boya Ogun dudu ba eladare sise?? E Jo number me ni eyi boya e le ba mi beere lowo IFA olokun asoro dayo, fun ibere ,e jowo I try Lati flash number yi ma si pe pade pelu ogo olorun....07060404998 |
Re: .. by Ifakorode: 3:28am On May 26, 2017 |
e jowo baba e fun wa ni ogun gbetugbetu |
Re: .. by danjeze(m): 7:58am On May 28, 2017 |
Éjó kini eyàn lelo fun eniti nkàn ómö kunrin é o bà tobi? |
Re: .. by shakuna(m): 5:58pm On May 28, 2017 |
Zaudi:moni ogun iferan to damiloju |
Re: .. by Obaf1(m): 11:35am On May 31, 2017 |
[/quote];;;;;;;;;;ejowo sir kini oruko ti a tun pe igi nla, i mean oruko miran fun IGI NLA. Ama juyin se oooh asee |
Re: .. by Obaf1(m): 11:37am On May 31, 2017 |
KolaBELIEVE:;;;;;;;;;ejo se emo oruko miran fun igi nla. Another name for IGI NLA plz |
Re: .. by IBAAGBA1: 4:39pm On Jun 02, 2017 |
Wolad:E se pupo,mo dupe ooo,lagbara Olorun ao ni wa gbogbo eyin agbagba wonyi ti AMIN ASE!!! 1 Like |
Re: .. by Wolad(m): 1:46am On Jun 05, 2017 |
Obaf1: Asorin ni oruko miran fun Igi nla |
Re: .. by Obaf1(m): 10:35am On Jun 05, 2017 |
Wolad:;;;;;;;;;;;;;;;thanks |
Re: .. by Adewunmis(m): 2:13am On Jun 08, 2017 |
Baba lfa mo ki yin eku ifomoniyan se ajinde ara yio ma je yin o ejowo mo fe ki e fun mi number WhatsApp yin mo ni oro to important lati ba yin so |
Re: .. by Adewunmis(m): 2:23am On Jun 08, 2017 |
Ejowo Eko mi ise yi boya mari ise agba mi ko si ise kan kan lowo mi Ose Ebe Awon Agba yi ni mo nlo lowo, Apere ti mo ti ri so far ni wipe, 1. Awon olopa nle mi ni oju orun, mo si ri iya kan ni ojiji( sudenly) oni ki ntele owun wipe awon olopa(police) na ko le fi mi se nkan kan, 2. Awon omo iya mi ti won ti nbami ja lati ojo pipe nfi owo ranse simi wipe ki ebi o mo pami nitori ipe mio ni ise lowo(hand). TESTEDD CONFITMED, Ifankaleluya iba re oo.[/quote] |
Re: .. by Adewunmis(m): 2:47am On Jun 08, 2017 |
Ogun yi ope kilo de ti e fi oruko awon ewe Yen si ti ba fe se anfani ki e se oluwa lo nsan esan fun ni OBINRIN MALE KO ENIA SILE Iyimi yimi, Ewe ........... Iye igun, Eyo Atare 7, Aolopo Ao fi sin gbere meta si iwaju ori. Confirm![/quote] |
Re: .. by Adewunmis(m): 2:52am On Jun 08, 2017 |
dominicson: 1 Like |
Re: .. by realherb: 12:51am On Jun 11, 2017 |
Mo ki gbogbo Ile, ewe a maa je fun wa o. Eledua yoo maa fun wa se o. Iwaju lopa ebiti wa yoo maa resi lola alawurabi. E dakun e gbami kale, eniyan mi Kan loni aisan idi yiyo gbogbo agbo ati agunmu ti mo mo Pata ni moti lo fun ti ko si iyato. Laipe yi lowa salaye fun mi pe o tito bi odun marun to tin yo oun lenu. E dakun e fun mi ni oogun to daju ti mo tun le lo fun ki abiku re maa so oloogun mi deke. E seun modupe. |
Re: .. by lambvard: 5:59pm On Jun 23, 2017 |
. |
Re: .. by Midumighty(m): 11:09pm On Jul 02, 2017 |
shakuna:motini iferan todaju lorisirisi.mo nilo re mo |
Re: .. by Midumighty(m): 11:11pm On Jul 02, 2017 |
Obaf1:se ko si loja ni igi nla na ni wo pe. |
Re: .. by Midumighty(m): 11:17pm On Jul 02, 2017 |
shakuna:ogun owo/ibon todaju.mi koro agbalumo kan tio oba di ojo keta wa ya mo igbe,wa yo sita.ti o ba ni fe si te ate ranse sori numba yii. |
Re: .. by Obaf1(m): 9:18am On Jul 03, 2017 |
Midumighty:, i don buy am thanks, bt plz can u give me iferan to sure and beat and run, plz i really need it |
Re: .. by Obaf1(m): 9:24am On Jul 03, 2017 |
shakuna:tiyin a da baba, motise ai moye ogun ti ko sise, o si je kin ma siye meji lori gbogbo ogun toku patapata, ejoor e funmi ni ogun iferan obinrin to daju lati clear dought me, nipa ogun ile karo o jire, ise se agbe wa oooh, asee |
Re: .. by Obaf1(m): 9:32am On Jul 03, 2017 |
Adewunmis:ewe kinni baba ejoor mo need e gaaaaaannnnn ejooor sir |
Re: .. by KolaBELIEVE: 7:59pm On Jul 04, 2017 |
kadunasouth:. baba Kaduna south ejowo monilo ose arisiki owo 1 Like |
Re: .. by Oladimeji120(m): 8:06pm On Jul 04, 2017 |
Baba ejo efunmi ni isoye orin kiko todaju gan ejo baba oju konitiyin sir |
Re: .. by Oladimeji120(m): 9:53pm On Jul 04, 2017 |
Ejo baba sebi ewe areyinkosun noni olosanku abi |
Re: .. by mercysamuelson(m): 6:55am On Jul 05, 2017 |
KolaBELIEVE:@Kadunasouth: Baba, e jowo, Ki ni Afola? |
Re: .. by Midumighty(m): 11:53am On Jul 05, 2017 |
mercysamuelson:bere ni oja |
Re: .. by Midumighty(m): 12:00pm On Jul 05, 2017 |
....Ogun iferan todaju fun enikeni...,awo ewure dudu,irun abe,ewe amunimuye,odidi atare kan,ekanna owo mewewa ati ti ese mewewa,irun ipenpeju die,irun ori die a o jo po a o fi sinu ounje fun eni naa.die ninu ebu yen ni o. |
Re: .. by Midumighty(m): 12:06pm On Jul 05, 2017 |
tani o ni ogun'ibukun oluwa ni muni la'.ko jowo mo nilo re, eni tio ba ni ki so isori ogun ti o ba fe ma fun.eyiti odaju ni ma fun(tested ok) |
Re: .. by ajobi1(m): 10:29am On Jul 06, 2017 |
@ kaduna south and others ejowo kini Ogun eje riru |
Re: .. by Nobody: 10:12pm On Jul 12, 2017 |
kini itumo isuke! kii eeyan maasonu.. kini oogun e. o ti n se eeyan mikan lati ojo meta seyin........ ki ni a le lo. e seun gan. |
(1) (2) (3) ... (89) (90) (91) (92) (93) (94) (95) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 37 |