Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,517 members, 7,958,565 topics. Date: Wednesday, 25 September 2024 at 05:24 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (201660 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (42) (43) (44) (45) (46) (47) (48) ... (100) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by hotteju(f): 1:48pm On Jul 27, 2009 |
newbie ni miii ooo ki lon shele? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrFerlie(m): 2:02pm On Jul 27, 2009 |
hotteju: hotteju, kaabo si inu ilu wa yii. se daadaa ni gbogbo ile wa? ko si wahala ninu ilu wa yi, igbadun ati alaafia ni awa. omo ilu wo ni eyin nse? se okunrin tabi obinrin ni eyin? e kaabooooooo. topsy25, awo mi, agbo to feyin rin, agbara lolo muwa. emi naa mura ija fun e |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 2:16pm On Jul 27, 2009 |
hotteju: Kaabo sinu ile baba re o. Ihanyi a san e o. Bi o ba je okunrin, awon abo to dara wa nihinyi (yato si toyin o); bi o ba si je obirin, awon gende okunrin wa nibi bii Ifelepon, dayokunnu, kamotessi, dr. feli abbl. Kaabo ooooooooo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 2:19pm On Jul 27, 2009 |
Dr Ferlie: Ibo ni agbara ohun wa. O je lo sidahun |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ibrokay(m): 2:27pm On Jul 27, 2009 |
Ekuule ooo eyin ara iwaju,ekaabo ooo eyin ero eyin. Mo ki gbogbo eyin omo kaaro oojiire to nbe ni NL. Oruko ti emi ni Sola,mo n wa Iyawo to jinle ti osi jinna ninu asa ile wa(Yoruba). Omo ti o rewa ti o si leko. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 3:53pm On Jul 27, 2009 |
E ku deede iwoyi o se alaafia ni e wa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 4:24pm On Jul 27, 2009 |
hotteju: Kabo si abule wa dayokanu: alafia ni a wa o. Se alaafia ni eyin naa wa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrFerlie(m): 4:26pm On Jul 27, 2009 |
dayokanu: Ojogbon dayo, e yin naa e kaabooooooo.alaafia ni a wa ooooooo. awon iyawo yin nko? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 4:34pm On Jul 27, 2009 |
hotteju:O Kaabo gidi gan ni. Turaka kosi maa gbadun ara e ni hanyi. dayokanu:Daada la wa, adupe. O ma to ojo meta, anirope alaafia lewa? @Argent & Dr. Ferlie Se wa pa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrFerlie(m): 4:59pm On Jul 27, 2009 |
tubabie: Omidan 2babie, ki lode to je wipe argent nikan ni o kiss mo wapa. bawo ni ise, ile ati body? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by hotteju(f): 5:02pm On Jul 27, 2009 |
gbogbo yin ese gan nii ooo modupe, inu mi dun gan |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 5:27pm On Jul 27, 2009 |
tubabie: sweets mi bawo ni, se everything wa okay? Dr Ferlie: Se o n jelosi mi ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 5:52pm On Jul 27, 2009 |
argent:Mo wa alright, ose Dr Ferlie:lol. Oya turaka kosi tun oju ese, ma frown at me mo! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrFerlie(m): 6:14pm On Jul 27, 2009 |
tubabie: ti o ba ti kiss mi ma turaka argent: mo njelosi e oooooo. bawo ni 2babie se ma kiss eee , e mi loye ko kiss now |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DrFerlie(m): 6:16pm On Jul 27, 2009 |
hotteju: omidan hotteju, inu awa naa dun gannnnnn lati gbayin si inu wa yi. se e gbona felifeli gege bi oruko yin? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 6:43pm On Jul 27, 2009 |
Ehn? ai si ni ile ologinni mi ile di ile ekutele tope-lobi! ogbeni tope, iru iwa palapa wo lo n wu leyin mi yii? awe we e b'oyami tage lere ki mo wi si o kuo gbonyami re? so rora koloun so o o! @toyin temi nikan oyami atata , se alaafia lu e se? ibeji mi sikan, se ala ni?(ekiti way of checking on my wife and babies) mo o ri yim e oo*mayb you sent to the wrong addy again). . .will b waiting. @tejutogbona feli feli(hotteju) ati ibrokay(sola) EKaabo si ile kaaro oojiire, se alaafia ni? inu wa dun pupo lati gba yin si awujo wa a de lero pe ee a gbadun gbogbo igba ti e ba lo lori tireedi yi le e kan si, E kaabo. @gbogbo ile(ajenti,tubabie,toyin,dayo,tope,dokita feli,fakaay,tejutogbona,ibrokay et al. . .) In okun oo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 7:02pm On Jul 27, 2009 |
Ifeleke, ba wo ni? o to ijo meta, se ise nlo dede? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 8:03pm On Jul 27, 2009 |
dayo, omo'luwabi ni mi a kin j'okoloko ni le wa ekuule oh gbogbo yin ori ikunle ni mo wa she daada le ji eyin ti US awon to ku, she everything nlo were were |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by oYaTo(m): 8:19pm On Jul 27, 2009 |
blue, mi o mo pe yoruba e dan moran to bayi oo, oya, ile ya, je ka lo mo awo obi mi ni waran sesa, bi ise o pa pe ni, enikan o kin pe se! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 8:27pm On Jul 27, 2009 |
ROFLMAO!!!!!! oni yeye ni e sha ko ma dupe lowo jesu pe mo si nife fun e o tie yoju sibi at all bawo lara oh she gbogbo e wa bo she ye ko wa? o ti jeun sha? beeni iya re ni mi kunle je kin gbadura fun e |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 8:29pm On Jul 27, 2009 |
@blue ba wo ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by oYaTo(m): 8:34pm On Jul 27, 2009 |
bluespice: mi o ti jeun o, mo n reti ounje to ti se de mi, ko wa fi simi lenu. . ti a ba jeun tan ka wa wo inu yara lo ka lo sere ife. . |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 9:05pm On Jul 27, 2009 |
ibukun mo wa jare iw nka? sho wa pa? sh'aran dan bo she ye? (i dunno y im in the mommy phase today ) oyato ko iranu e kuro jare amala e'nbe l'ekunle |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 9:10pm On Jul 27, 2009 |
mo wa pa baby mii, so, where is my food? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MrCrackles(m): 9:12pm On Jul 27, 2009 |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by oYaTo(m): 9:17pm On Jul 27, 2009 |
e'nkunle ke? ti aja ba lo je nko? mommy shey e ma fi onje si mi lenu? p.s: o da bi pe omidan hotteju yen wa pa gan o. .omo naa rewa gaani |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Moyola(f): 9:24pm On Jul 27, 2009 |
Ko s'oro! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bluespice(f): 9:36pm On Jul 27, 2009 |
oYaTo:o f'oju jo iya e jare |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 2:09am On Jul 28, 2009 |
Se Yoruba ni chinedoll ni tabi o gbo Yoruba? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 3:16am On Jul 28, 2009 |
IFELEKE:keede? ki lo n bi e ninu? Calm down jare, eyin okurin ekiti ti ni gra gra ju (but I no dey complain ) |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 6:46am On Jul 28, 2009 |
Bluespice, Emi lo de? Ki ni o fin se eyan? Kilode to oo le jokoloko? Oya tete ma se afira bi ise ko pe ni, enikan ki pe ise |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ibrokay(m): 7:10am On Jul 28, 2009 |
dayokanu, Kinni itunmo jokoloko? Die die ooo |
(1) (2) (3) ... (42) (43) (44) (45) (46) (47) (48) ... (100)
Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations) / HAUSALAND: Teach Me Hausa
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 34 |