Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,152,749 members, 7,817,076 topics. Date: Saturday, 04 May 2024 at 03:29 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (197772 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (50) (51) (52) (53) (54) (55) (56) ... (100) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by C2H5OH(f): 5:10pm On Aug 16, 2009 |
baby mi oloju tuntun eweso oooo . e ku gbogbo e. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 7:00pm On Aug 16, 2009 |
IYA NGBALI:olorun o ni je ko tun fenu ko. @gbogbo ile Ki lon sele? bawo ni ojo isinmi yin se n lo? e de ku imura ibere ose tuntun. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 11:54pm On Aug 16, 2009 |
Kabiyesi oooo!! EMi Faakay lati Ilu Oko Malu ni oo! Mo tun ni kin pe ni ooo! Mo ni gbo ohun OBA ni oo Ti o baje ata la ta, Iwo ni ooo, Mo de FLorida Iwo ni ooo, mo de gbogbo e! gbogbo e!! Iwo ni ooo, awon ti London gan o gbeyin Awon eniyan kan o de yi gbo eee! Ibikibi ti o ba wa!! Kabiyesi Oba GBogbo Rapper Ti o ba ti gbo messagi mi! Ki o pe mi ni oooo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 12:56am On Aug 17, 2009 |
Mi o Shagidi! Mi o ki se tanwinji Nitoripe mo mo a, b, d |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 10:05am On Aug 17, 2009 |
ogbeni faakay, o tun ti de? @gbogbo ile eku ojumo oo, ojumo ayo fun gbogbo wa loni oo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 10:34am On Aug 17, 2009 |
IFELEKE: Egbon ki lon bo Mo sese taji ni sha, Mo lala tele ni ooo, ekaro ni ile yi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 10:51am On Aug 17, 2009 |
E n le faa ni le yi o! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 11:25am On Aug 17, 2009 |
faakay:ko si repete joo, bawo ni? o n lala ke? iyen ni wipe ala ni gbogbo ewi at orin to n ko lataaro? tubabie:bawo ni faa? se omo kwara ni e faa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 11:34am On Aug 17, 2009 |
IFELEKE: Lol. Rara mi ki n se omo kwara sugbon mo gbe ni be fun igbakan ri. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 11:54am On Aug 17, 2009 |
tubabie:tooto fa? nibo lo gbe fa? ilorin,offa,omu aran abi oro? omo ilu wo ni e gan? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 11:59am On Aug 17, 2009 |
Ilorin ni won bi mi si fa, ni yan yin ni mosi gbe dagba ki n to kuro ni ilu naa. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 12:14pm On Aug 17, 2009 |
Ilorin mesu jamba ara afonja(oriki awon omo ilorin niyen) kogi looto? se kabba ni abi okene, lokoja ni abi ankpa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 12:21pm On Aug 17, 2009 |
IFELEKE: Ooto ni , oriki won niyen Oni jamba lawon peeps yen lol Anyway kogi ni side okun ni moti wa(the yoruba side). Se oni ore lati kogi ni? odabi wipe omo die nipa ilu mi? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 12:28pm On Aug 17, 2009 |
beeni,mo ni ore lati kogi mo de ti lo si gbogbo ibi ti mo daruko yen ri. btw, ara ekiti ni okun ti jade(okun has links/ties with ekiti). . .t'o ba se akiyesi,wa'a ri wipe ede ilu yin ati ede wa l'Ekiti fe jora won. ati wipe, ado ekiti ko jina rara si ilu yin. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 12:33pm On Aug 17, 2009 |
Beeni ooto loso, ede ti iwo ati Gators and co maa n so jo ede wa gidigan ni. Ori awon govt ope fun geographical failure to pin wa si kogi lol |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 1:20pm On Aug 17, 2009 |
tooto ni, nkan buruku gbaa ni awon adari atijo se nipa pin pin ti won pin awon eeyan. se o gbo ede yin sha? igba wo lo lo ile gbeyin? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 1:26pm On Aug 17, 2009 |
mo gbo ede wa daada mo de le so die, sugbon ope ti mo lole gbeyin sha bi 2004 |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 2:03pm On Aug 17, 2009 |
odaa je ka so ede na die. . . okun awe, se ala lu e se? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 2:06pm On Aug 17, 2009 |
'Seun kaaba, alafia rin. Ka bi ti je? Ise nko? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 2:18pm On Aug 17, 2009 |
adupe, kete re lo dede ise sikan? se e gbomimu ju? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 2:24pm On Aug 17, 2009 |
IFE ati tusweetie, ba wo ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 2:29pm On Aug 17, 2009 |
Adupe, gbogbo re e lo daada @Ibkaye mo wa alright |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 2:37pm On Aug 17, 2009 |
ibk alaafia ni. . .bawo ni opin ose e se ri? ku ibere ose tuntun. @tu, adupe lo'o olorun ko da kete ria si titi di asiko yi. se wo gbero ihon ara ulu? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 2:40pm On Aug 17, 2009 |
Ahon ara ile ati ilu wa daada, adupe Beeni adupe lowo Olorun fun gbogbo nka. Ka bi oti e wa, ilu wo ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 2:54pm On Aug 17, 2009 |
mee s'use li 'lesa ni osun. iwo sikan? ibo luo ha? ku ese? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 3:11pm On Aug 17, 2009 |
Emi tika me e si li naija. Mo ha ni UK lowolowo be yin. Ka bi ti je li 'Lesa, so o in gbadun ara re? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 3:15pm On Aug 17, 2009 |
Ilesa osun state. Me e gbadun ora mi daada . . .ku e se li u.k? sukuru abi use? btw,u are surprising me real good. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 3:21pm On Aug 17, 2009 |
Lol. Sukuru ki mo ha be yin fun masters, mo to pari rin li osu e ibo Iwo iko, ku we se li 'lesa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 3:53pm On Aug 17, 2009 |
me e suse lule ifeo pamo kan lulesa. tubabie:apa ibo we'e gbe li u.k? you are really good in this |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 4:03pm On Aug 17, 2009 |
IFELEKE: Hehhehe , Inu ahan obi m dun ganni pe mo ro so ede yii Me fe ko ibi mo wa sori, se oro m ye o? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 4:18pm On Aug 17, 2009 |
oro re ye mi, btw, aworan kuo mu han mi lori tireedi ihon osun lijosi, se tere ni litooto? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 4:23pm On Aug 17, 2009 |
Titemi rin lol, se ajo oniyan rin?Ti we ba gbami gbo mo ro fi omiran han o |
(1) (2) (3) ... (50) (51) (52) (53) (54) (55) (56) ... (100)
Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá / Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 22 |