Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,195,592 members, 7,958,825 topics. Date: Thursday, 26 September 2024 at 04:04 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (381191 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (115) (116) (117) (118) (119) (120) (121) ... (167) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 3:51pm On Sep 17, 2007 |
Digital:se oko mi lo doti ni abi okan mi? abeg make una no steal my slipas,i dey mosalasi dey pray for una.
|
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Aladunni(f): 5:53pm On Sep 17, 2007 |
mo tile miss eyan kan ni bi o, she admin won kin wa si bi ni. or won tii ban eyan kan nibi rara ni. e maa se pelepele sha a o. thread yi o dun gan ni o. mo proud lati je omo yoruba to the core. ilorin ilu awon alfa ni ti wa, ilu to jina sina to sunmo aljana, moti pe gan nibe sugbon igbomina ni mi sha. e kun o, e nle faaaaaaaaaaaaaaa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by penfold(m): 7:44pm On Sep 17, 2007 |
@iya aje aworan ti o gbe si afefe yi hmmmmm, o ga o, emi koba beere pe nibo ni o ti ri sugbon je ki n dake nitoripe o ye emi ati iwo wipe aworan yiiiiiii, hmmmmm, o daa na, emi o sówo re si o lati ori ero ibanisoro ti mo fi ya ti n ba ti pada de ibi ti "network"wa!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 10:18pm On Sep 17, 2007 |
iya aje, se the moon don dey bo si ta? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 1:30am On Sep 18, 2007 |
egbe ni bobo yio,onfi padlock ti slipppers maje kaye ba e gbo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 1:48am On Sep 18, 2007 |
egbe lasan lasan, o n'pe ra e ni iya aje, awon aje ma le e kuro ninu aarin won, won o like lati ma faramo egbe awon egbe e n'wa igbale ton fi ina sise (vacuum cleaner) iwo n'fi padlock si bafroom slipas, oju o tie ti e ra ra |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Digital(f): 9:11am On Sep 18, 2007 |
iya aje: Oro pa esi je, oro di huuuuuuu. iya aje oro ohun ma ga gan ni oh |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by waxyweller: 12:24pm On Sep 18, 2007 |
Eni bashe ahji wasiu Oye kaki ,OMO GBOLAHAN MI OO, Oya ebami kalo silu canada oo, *Singing KWAM 1* |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by obedz(m): 8:07pm On Sep 18, 2007 |
mo wa nibiyi o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 8:10pm On Sep 18, 2007 |
minute:no blame me,i put d padlock because of people like you. debosky:debosky sora e o,se o ro pe mi o mo pe o fe ji slipas mi ko ni mosalasi ni ojo jimoh to koja,now ti mo ti fi padlock si je ki wo bo se ma ji ko lo ile re infact mo plan lati lo ko slipas mi pamo si central bank because of you |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ssRhino: 11:23pm On Sep 18, 2007 |
Digital, Yoruba teacher |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 3:32pm On Sep 19, 2007 |
nkan tobari kofi ti-kona mi ni kolobo ---iwo loni salubata e!!! bata yen naa loti je lesese yen,otun ti fi ese e ran.lol. otun ti je labe. arinka njabataa anyway, *singing ebeneza obey* kininbe nigbo tondun mohuru mohuru mohuru. 2xe.lol bio panije kokuku panije bio si panije komashe panije .lol koye dun mohuru mohuru mohuru momi mo. inu mi dun gidi leni,morowo he!!LOL |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 10:07pm On Sep 21, 2007 |
ki le le yi o e ja so ki le le yi o, e ja so eja tutu shokoyokoto eja tutu, shokoyokoto ajashoro!!! whistling and hummming eja tutu shokoyoko |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 10:10pm On Sep 21, 2007 |
ki lo shele? o da bi pe awon won yin ni thread yi se kurukere kurukere. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 10:12pm On Sep 21, 2007 |
omoge je ki n'ko e daa daa bi won se n'ko orin yen ki le leyi o, eja osan ki le leyi o, eja osan eja tutu, shokoyokoto eja tutu, shokoyokoto emi o le je oun ti o da, kin la ju mi sile kin won wa fi mi s'aponle eleda o something something something something o, oyin momo *emi gaan ti gbagbe ipari orin naa* |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kateflow(f): 10:12pm On Sep 21, 2007 |
omo dara tan like mama iya re lo fi jo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by shakira: 10:18pm On Sep 21, 2007 |
a star has been born |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 10:20pm On Sep 21, 2007 |
kateflow bee ko ni jazzman se korin yen o omo dara just like mama iya e lo fi jo walk like mummy, talk like mummy omo dun, ati check e, iya e lo fi jo! o baby baby you drive me crazy ati bee bee lo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kateflow(f): 10:22pm On Sep 21, 2007 |
lol jo oo emi o gbo yoruba |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 10:25pm On Sep 21, 2007 |
debosky, o se gan. whistling and humming eja tutu shokoyoto, eja tutu shoko yo ko to (now ebi obe Shoko pa mi ) |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by buttyelele: 9:46am On Sep 24, 2007 |
waxywella or whatever u are called u are a bleeped up nigger. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by buttyelele: 10:18am On Sep 24, 2007 |
i studied linguistics in U.I and mother tongue was really promoted, am always impressed when our laguage is being promoted, some think the language is endangered, because it has not been passed from one generation to another, all the alo apagbe, the folklores, games we used to play in yoruba when we were younger is all gone, all the bat somi were were, the poems i.e adiye mi eyi ti mo ra, all that is gone, we are losing out big time on our heritage, ur child will never speak as good as u can, and they will pass on their substandard yoruba to the next generation until theres is no yoruba left, what can we do pls bring suggestions. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 1:42pm On Sep 24, 2007 |
buttyelele: Suggestion: Bi o tile je wipe oro isiri ati onilaakaye ni o ti ko sile, iba dara ki o tumo gbogbo ohun ti o ko si oke yi si ede yoruba, bi iwo na ba bere pelu apere rere ko ti buru ju.Oyinbo tabi ede geesi ko ni aagbon okun oro yi wa fun |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 7:56pm On Sep 24, 2007 |
Hello! Se daada ni mo ba gbobo yin, bo tile je wipe o ti se die ti mo ti wa si ori okun yii, mo lero wipe en gbadun ara yin? Nana, Ika6, Segoye2, Baale, Ikomi, etc. . . . . . se gbogbo yin ni e si wa lori okun yi? Maa tun ma kan si yin l8r, odabo naa. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 1:06am On Sep 25, 2007 |
alo ooooooooooooooooooooooooooooooooooooooooo, o dun pa po po pa po po po pa po po po praaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaaa, kini o? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 5:21am On Sep 25, 2007 |
iya aje: iso (fart) ni o, lati idi nla iya aje se mo gbaa abi mio gbaa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 6:06am On Sep 25, 2007 |
iya aje: ibon ni o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bolorunfem(f): 9:03am On Sep 25, 2007 |
E ku afere yi o, gbogbo omo kaaro o jiire, se alafia ni mo ba yin, se oode o so? Mo ki yin pe e ku ojo meta, Ayanjide, Richylaw, Ika mefa (Olugbodi ko niyen? ), iya aje, debosky, gbogbo eyin to ku patapata ni mo ki o. Se gbogbo yin nbubble? Ni se ni mo sare lo si oko etile ni ko je ki e ri gburo mi. Se e si mo pe ero ayara bi asa ko de abule . Eyin ti oke okun lohun, se otutu o po? Gbogbo wa ni a o ko ere oko dele o. E heen, ta lo ba wa gburo Segoye2 o? O dagbere pe oun fe rin irin ajo, mo lero pe o ye ko ti pada. Ti e ba pade re lori okun miran yato si eleyi, e ba mi so pe mo beere re o. Mo riyin na, o digba kan na |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by buttyelele: 12:24pm On Sep 25, 2007 |
Suggestion: Bi o tile je wipe oro isiri ati onilaakaye ni o ti ko sile, iba dara ki o tumo gbogbo ohun ti o ko si oke yi si ede yoruba, bi iwo na ba bere pelu apere rere ko ti buru ju.Oyinbo tabi ede geesi ko ni aagbon okun oro yi wa fun apere temi ko ni o se pataki, ti ko ba se opolopo awon eniyan ti ko le so ede abinibi won, papa ju lo, ede yoruba. A le so yoruba di ola, oto oro ni pe opolopo awon eniyan ni gbogbo nkan ti a ko si nairalandi yi ko ye, ko se nipa kiko orin shina peters tabi sunny ade ni afin gbo yoruba. iwo na mu akole gidi wa ka si jiroro lori re. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 3:18am On Sep 26, 2007 |
eniba she ha! enu e aya o! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 7:01pm On Sep 26, 2007 |
tafari:o si o,gbogbo yin e kan niko lori debosky:o gba o, e patewo fun omo ita agbalagba,o ti pe to ti nfi iso soge larin awujo wa ni nairaland |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 2:55pm On Oct 02, 2007 |
buttyelele: Ohun ti mo n so ni wipe ki o ye ra fun ede geesi ni ori okun yi gegebi eyi ti o koko fi gbe eronu re kale ninu oro ti o fi sowo si ori okun ni akoko. Nipa akole ti o d'amoran ko buru rara gege bi aba sugbon mo mo wipe asiko le e ma si fun o lati ka ohun gbogbo to wa lori okun yi lati oju ewe kini, iwo o ba ti ri akitiyan lati se bi o se n fe ( bo tile je wipe ara n fu mi wipe awodi re kan pa aso esin da ni). Opo igba ni a ti daba akole, opo igba ni awon ti o ni arojinle na ti gbe koko yi yewo , sugbon niwon igba ti oronro ba ti n fo po mo eran adun re a ma soro ri. Opo eniyan ni abara meji lori okun yoruba yi, won ni oruko ti won fi n hu iwa buburu, won si ni eyi ti won fi n fi oye inu won han. Sugbon niwon igba ti nomba idanimo(IP Address) wa fun ero ayarabiasa ti onikaluku, awon aseto n je ki a da iru won mo. Emi gegebi enikan , yala ni igba kan tabi omiran mo ti mu aba akole orisirisi wa , ko si si eyi ti o mu ogbon dani ti enikeni da laba ti n ko da si. Opon oro ni o wa ni iwaju iwo na yi, da ifa tire na sile ko je ki a gbo ohun to ba wi nipa akole. Gbogbo ile, eku ojo meta e si tun ku ko le da o. Bolorunfem e seun o eku ibeere mi. Emi na o ti gburo Segoye2 o, o da mi loju wipe ko le e wa larowoto ki o ma kan si ori okun ti o fi owo ara re da sile. E je ki a mu suuru ka si ma woye titi ti yio fi de. |
(1) (2) (3) ... (115) (116) (117) (118) (119) (120) (121) ... (167)
Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 40 |