Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,359 members, 7,815,766 topics. Date: Thursday, 02 May 2024 at 05:59 PM

.. - Culture (85) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1828513 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (82) (83) (84) (85) (86) (87) (88) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by miich28: 11:01am On Sep 14, 2016
@:Baba #Kadunasouth ati Baba #Healthfirst...Mi o le paro nkan ti mo n se:Omo yahoo ni mi,,,,,Ejowo,,,Mo ni lo Oogun ti mo le fi GBA owo lowo awon Clients Mi

Ewe a maa he fun yin @:Baba #Kadunasouth ati Baba #Healthfirst...Mi o le paro nkan ti mo n se:Omo yahoo ni mi,,,,,Ejowo,,,Mo ni lo Oogun ti mo le fi GBA owo lowo awon Clients Mi

Ewe a maa he fun yin
Re: .. by sirkzee: 1:39pm On Sep 18, 2016
ewe ama je ooo
Re: .. by ENOWOH: 9:18pm On Sep 19, 2016
Baba ki ni a le lo fun omode ti o ni kokoro ni gbogbo ara re. kokoro naa ma lo a tun pade.
Re: .. by dmangodwin(m): 9:38am On Sep 21, 2016
x
Re: .. by Nobody: 10:57am On Sep 24, 2016
Hello all karoojire here,

Pls,

1. How does "MAGUN" work?
2. Is it possible for someone who is not a legit husband( or anybody at all) to put it on someone else's legit wife (or on any female, married or not married)?
3. If a man places it on his wife, is he excempted from the magun spell? That is, can he mate SAFELY with his wife?
4. How to identify a female with magun
5. How to remove magun from a female with Magun
6. Is there Magun or equivalent done on males?
7. How is it prepared?

Thanks
Re: .. by olusegunakintol: 8:52pm On Sep 24, 2016
dominicson:
As herbalists, our duty is to prepare medicine that are not only effective but also safe. Safety first. We shouldn't cure impotence/weak erection and acquire stroke in its place(in the process); we shouldn't say because we want power, ki a wa se ogun ti paagun yoo fi ma da wa laamu. Desire is not bad; surfeit is. We should be safety conscious. The fact that herb-A can cure malaria and herb-B too can cure it does not mean that the combination of the two herbs will cure malaria. There are certain combinations that go together, and there are those that don't 'meet'(they rather produce adverse effect, sooner or later). So we shouldn't stop learning and researching.
dominicson:

Atayese
Efun, osun, oori, oyin, aadun, eko tutu, ewe rinrin, tete abalaye, ewe abamoda, ewe orokojiya, ewe ogbo, ewe odundun, iyo. A o ko gbogbo awon nkan yii si inu igba nla, a o pe gbolohun re si, a o gbe sinu iri di ojo keji, leyin ti a ba lo gbe won ni ojo keji, a o gun gbogbo re papo pelu ose dudu. A o ko sinu igba olomori. A o da iyere-osun le ose ti a ko sinu igba naa lori. A o te ni eji-ogbe. A o tun wa pe gbolohun re si leekeji. A o ma fi we. Oyin ni a fi ma n po ose yii, kii se omi.
Psalm:
Efun ni tun ori Olugbon se, osun ni mu iwa osun toro. Awon ni won sa igede fun Orunmila nigbati oro re daru tan. Orunmila wa to Eledumare lo. Orunmila ko ejo o ro fun Eledumare. Eledumare ni ki Orunmila lo wa Esu wa. Orunmila de ile Esu, ko ba Esu. O de ile Lapara tii se baba Esu, ko ba Esu nibe. Orunmila lo si ile Gbaroje tii se eru Esu, o ba Esu nibe. Orunmila ba ko ejo o ro fun Esu wipe oro aye oun ti daru, beeni ko si dogba mo. Esu fun Orunmila ni esi wipe: iwo ko rubo ni koje ki oro re dogba, ohun ni oro aye re ko se toro. Esu ni ki Orunmila lo wa Aadun, Osun, Efun, Oyin, Iyo, Eko-tutu, Ewe rinrin, Ewe abamoda, Ewe tete abalaye, Ewe orokojiya, Ewe ogbo, Ewe odundun, Oori. Orunmila ni ki Esu wa ba oun lo si odo Eledumare. Nigbati Esu de odo Eledumare. Esu ni mo de, Oba Alamonmotan, Oba amatiwaiye ojo, Oba amogbeyin oro, Oba ti o n tun ori eniti ko sun won se si daradara. Eledumare bi Esu lere wipe: kilode iwo Esu? Esu ni Orunmila lo wa ba oun wipe oro oun daru tan patapata, beeni oun ko ri ojutu re mo, gbogbo ohun ti oun se koje oun mo, bi oun se ogun ko je mo, oun kori owo, oun kori iyawo fe, oun ko ri omo bi, oun kori ohunrere kan gbese. Eledumare wa bere lowo Esu wipe: se iwo ko gba nkankan ni owo orunmila ni? Esu ni mo gba nkan ni owo re. Esu ni mo gba Aadun lowo re. Eledumare ni aye re (mi) yoo ma dun ni. Esu ni mo gba Eko-tutu lowo re. Eledumare ni aye re (mi) yoo ro, ko ni le fun mi laye. Esu ni mo gba Iyo lowo re. Eledumare ni aye mi yoo layo kale ni. Esu ni mo gba oyin lowo re. Eledumare ni aye mi yoo dun ni, ko ni koro, ko ni kan fun mi laelae. Esu ni mo gba Odundun lowo re. Eledumare ni laye mi ohun buruku ko ni dun ni ile mi. Esu mi mo gba Tete-abalaye lowo re. Eledumare ni gbogbo ire ni yoo ma te mi lowo. Esu mi mo gba Rinrin lowo re, Eledumare ni ile mi yoo ma tutu ni rinrin, ko ni gbona. Esu ni mo gba Abamoda lowo re. Eledumare ni gbogbo aba ti mo ba da ni araye yoo ma gba, ohun(voice) mi ni won yoo si ma fe gbo. Esu ni mo gba Orokojiya lowo re. Eledumare ni emi Lagbaja omo Lagbaja ko ni jiya mo laelae. Esu ni mo gba Ogbo lowo re, Eledumare ni gbogbo omo araye ni yoo ma gbo temi. Esu ni mo gba Efun lowo re, Eledumare ni gbogbo omo araye ni yoo ma fun mi ni ire temi. Esu ni mo gba Oori lowo re. Eledumare ni gbogbo omo araye ni won yoo ma ri mi yonu si. Esu ni mo gba Osun lowo re. Eledumare ni gbogbo ire ni yoo ma sun mi bo. Ebo naa ni emi Lagbaja omo Lagbaja gbe wa yio. Ki ara o de mi fun ire gbogbo, ki nri na, kin ri lo, kin rije, ki n ri mu (Adua)
dominicson:
As herbalists, our duty is to prepare medicine that are not only effective but also safe. Safety first. We shouldn't cure impotence/weak erection and acquire stroke in its place(in the process); we shouldn't say because we want power, ki a wa se ogun ti paagun yoo fi ma da wa laamu. Desire is not bad; surfeit is. We should be safety conscious. The fact that herb-A can cure malaria and herb-B too can cure it does not mean that the combination of the two herbs will cure malaria. There are certain combinations that go together, and there are those that don't 'meet'(they rather produce adverse effect, sooner or later). So we shouldn't stop learning and researching.

gbogbo isese E joo, ise contract ni mo n se,o de ti le lodun meta bayi ti mo ti di oga ara mi. Amo s
e ni mo kan n joko ni office lasan ni mio ki n rise gba. Koda awon ore kan ma n wa ya irinse mi sise won ni. Isin(religion) mi ko faye gba ogun(charms),ayajo ati ofo(chants). Sugbon a nigbagbo ninu ewe ati egbo,agbo(herbs) ati ose(soaps) gege bi ase ti Olorun ti da mo won. E jowo e ran mi lowo ki n yee seru aye. Ki ona la femi naa. A maa ju yin se o
gbogbo isese, e joo e ma wo mi niran. e ran mi lowo
Re: .. by olusegunakintol: 8:55pm On Sep 24, 2016

Re: .. by emmyjahzy: 11:28am On Sep 28, 2016
Mofi Olohun bura, owa daada sugbon awon yahoo won ki n moore

1 Like

Re: .. by Nobody: 6:40pm On Sep 28, 2016
add me to the group

1 Like

Re: .. by dominicson: 10:59pm On Sep 28, 2016
olusegunakintol:

gbogbo isese E joo, ise contract ni mo n se,o de ti le lodun meta bayi ti mo ti di oga ara mi. Amo s
e ni mo kan n joko ni office lasan ni mio ki n rise gba. Koda awon ore kan ma n wa ya irinse mi sise won ni. Isin(religion) mi ko faye gba ogun(charms),ayajo ati ofo(chants). Sugbon a nigbagbo ninu ewe ati egbo,agbo(herbs) ati ose(soaps) gege bi ase ti Olorun ti da mo won. E jowo e ran mi lowo ki n yee seru aye. Ki ona la femi naa. A maa ju yin se o
gbogbo isese, e joo e ma wo mi niran. e ran mi lowo

Join Isese L'agba!

1 Like

Re: .. by elegushichilling: 1:36am On Sep 29, 2016
dominicson:

Join Isese L'agba!

our God Jehovah is alive, he is fighting for us and will continue to do same. Better give ur life to christ now, tomm may be too late. Iku lo'n keyin oungbo gbo. Kini yo je erere ti oba jere gbogbo aye yi, ti osi so emi renu. Ranti wipe aye loja, orun nile. Kilode toje wipe a'un gba owo iyebiye lowo ara wa, ki ato ran ira wa lowo pelu agbara, ipo ati oye wa. A'un tan ira waje wipe okan niwa, omo ile kaaro ojire. Sioo, Iwo ti oko, ti oko se ore, seranti wipe elomiran ni olorun yo lo lati se ore eyi ni ofe, ti oun olorun fe se. Iru eni na sini yoo gba iyi re fun ogo olorun ati imuse oro olorun. Olorun ki se eniyan ti yo fi puro, tabi omo eniyan ti yo fi yipada. Otiso, unje ko ni se, otiso oro, se koni muse. Fi igbagbo re le Oluwa eledumare, ki ogba laye, ki ose iyanu layere. Igbagbo lai si ise, oku ni. Ise pelu igbagbo, emi ni. Gba olorun laye ki odari re si ibi ti igbala re wa pelu ise igbagbo re ninu oruko Jesu. Emi, Ara Olodunmare.

2 Likes

Re: .. by zenith329: 2:57pm On Sep 29, 2016
If you have it in abundant, kindly give him, he will surely appreciate it and be grateful to you, remember, this world is a small world
Re: .. by Ola4ple: 5:27pm On Sep 29, 2016
Edakun Kilo Nje Iri Ti Eko Si Ibi Ogun Atayese (iri)
Re: .. by jophins(m): 12:20am On Sep 30, 2016
mo ki gbogbo ile 08082988576 ero ibani soroo mi ni yi e add me si whatsapp group.
Re: .. by dominicson: 11:45am On Sep 30, 2016
elegushichilling:

our God Jehovah is alive, he is fighting for us and will continue to do same. Better give ur life to christ now, tomm may be too late. Iku lo'n keyin oungbo gbo. Kini yo je erere ti oba jere gbogbo aye yi, ti osi so emi renu. Ranti wipe aye loja, orun nile. Kilode toje wipe a'un gba owo iyebiye lowo ara wa, ki ato ran ira wa lowo pelu agbara, ipo ati oye wa. A'un tan ira waje wipe okan niwa, omo ile kaaro ojire. Sioo, Iwo ti oko, ti oko se ore, seranti wipe elomiran ni olorun yo lo lati se ore eyi ni ofe, ti oun olorun fe se. Iru eni na sini yoo gba iyi re fun ogo olorun ati imuse oro olorun. Olorun ki se eniyan ti yo fi puro, tabi omo eniyan ti yo fi yipada. Otiso, unje ko ni se, otiso oro, se koni muse. Fi igbagbo re le Oluwa eledumare, ki ogba laye, ki ose iyanu layere. Igbagbo lai si ise, oku ni. Ise pelu igbagbo, emi ni. Gba olorun laye ki odari re si ibi ti igbala re wa pelu ise igbagbo re ninu oruko Jesu. Emi, Ara Olodunmare.

K
Re: .. by Zenlife: 12:42am On Oct 01, 2016
Re: .. by Zenlife: 12:45am On Oct 01, 2016

Hmmmm.... Good Introspection.
Food for thought.
Well said.

1 Like

Re: .. by Zenlife: 2:40am On Oct 01, 2016
For those who claim to be in the know on this thread and those with whatsapp group, the so called babas, Awos, etc , why are valid questions ignored, such as...

Asked by 'nobody' above over a week ago...

"
Hello all karoojire here,

Pls,

1. How does "MAGUN" work?
2. Is it possible for someone who is not a legit husband( or anybody at all) to put it on someone else's legit wife (or on any female, married or not married)?
3. If a man places it on his wife, is he excempted from the magun spell? That is, can he mate SAFELY with his wife?
4. How to identify a female with magun
5. How to remove magun from a female with Magun
6. Is there Magun or equivalent done on males?
7. How is it prepared?

Thanks"

Could it be because there's no potential monetary gains in these questions?
If so, there's I guess no limit to your despicable hustle in the cloak of disguised assistance and that to me is so damn low exploitative, and apologetically dishonorable.

Using Orunmila, the deities, for the primary reason to exploit users of this forum or thread for personal monetary gains is abhorrent, humanly and spiritually disappointing.
Those who come under such umbrella should be perceived as scumbags, leaches and avoided as plagues. It shouldn't always be about money.
On here, you give a little coomon candy as though you wanna assist, but all done with ulterior motives.
When you get folks sucked in and pertinent questions asked, you give the flimsy excuse why it can't be publicly shared and asked to pm you or join your group. So I ask, those who pay you and you give these 'oogun" to, how do you know that they are worthy of it? Do you conduct a thorough background check? No you don't.
Damn shameless hustlers.
You all can go bury your head in the sand, fly a kite, or flush yourselves down the loo and kiss my black ass while at it.
Despicable, nauseating charlatans!!!

Rubbish! Oshi!!
Re: .. by Ola4ple: 9:51am On Oct 01, 2016
Edakun Kilo Nje Iri Ti Eko Si Ibi Ogun Atayese I Mean D Meaning Of Iri
Re: .. by dominicson: 5:01pm On Oct 01, 2016
Ola4ple:
Edakun Kilo Nje Iri Ti Eko Si Ibi Ogun Atayese I Mean D Meaning Of Iri

Dew
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:28am On Oct 05, 2016
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ati paapa eyin Omo June 22 to July 23 ati 2/19to3/20 haa! Afiti ori won bagbe alawore kowon nitori hmm olagbara'o ajuwase'o

Asitun nfi asikoyi sofun eyin aworo sasa todarare loju wipe anfani Ti si sile bai lati join egbe awon ojogbon Ti ape oruko'e Ni MAJEMU LAILAI on wasp.
Kajolasepe'o
Re: .. by olusegunakintol: 4:07pm On Oct 05, 2016
dominicson:

Join Isese L'agba!

add me to the group. my whatsapp number is 08182533557
Re: .. by skamoh74: 6:44am On Oct 09, 2016
08101646045atwp:
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye,
opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye
bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan
koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun
bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni
bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju
kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ati paapa eyin Omo June 22 to July 23 ati 2/19to3/20 haa! Afiti ori won bagbe alawore kowon nitori hmm olagbara'o ajuwase'o

Asitun nfi asikoyi sofun eyin aworo sasa todarare loju wipe anfani Ti si sile bai lati join egbe awon ojogbon Ti ape oruko'e Ni MAJEMU LAILAI on wasp.
Kajolasepe'o

. please add me
08085632313

thanks
Re: .. by Lero70: 2:56am On Oct 11, 2016
dominicson:

Dew
moki gbogbo eyin agbalagba ti Eledumare jogun ogbon fun ni abala yi, lagbara Eledua ogbon na konii dope, kosiniitan nibiti eti nmuu.
Ejowo mose akiyesi pe eyin agba wonyi kofibee kobiara si abala yi mo, ISESE LAGBA GROUP lorii whatsapp ti boo mole patapata, mosifekeemope awa ti a nje anfaani abala yi, sugbon ti phone wa kogba whatsapp application sipo gan, nitorinaa ejowo ebawa fun abala yi ni ijelogun bii tateyinwa. Yio maa juu yin se o ase.
Re: .. by Nostradamus: 7:37am On Oct 12, 2016
dominicson:

Dew
edakun gbogbo ile mo ni ibeere ranpe kan,ti won salaye pe ki a gun ogun kan mo ose dudu,shey a le ko ose ati ogun na si ori olo(grinding stone)ki a lo papo?mo fe se ose ebe awon agba kan ni sugbon mi o ri aye si odo but olo wa niwaju mi bayi.
Re: .. by emmyjahzy: 1:22pm On Oct 12, 2016
Beeni sugbon kodara to kia ma lo eyi ti awon iyawo wa fi nlo ata
Re: .. by bolorunfem(f): 4:28pm On Oct 13, 2016
.
Re: .. by dominicson: 11:56pm On Oct 13, 2016
Nostradamus:
edakun gbogbo ile mo ni ibeere ranpe kan,ti won salaye pe ki a gun ogun kan mo ose dudu,shey a le ko ose ati ogun na si ori olo(grinding stone)ki a lo papo?mo fe se ose ebe awon agba kan ni sugbon mi o ri aye si odo but olo wa niwaju mi bayi.

A ma n lo olo. Asi tun ma n lo odo. Nigba miran ohun ti a ba fe gun le kere ti o je wipe ti a ba lo odo, odo yoo ko je. Fun idi eyi, a ma lo olo. Nigba miran ewe, ohun ti a ba fe gun le po ju olo lo ti o je wipe odo la ma lo. Sugbon o, awon ise kan wa ti o je wipe o ma n pan dandan ki a lo ohun ti won ba ni ki a lo lati fi gun, boya odo tabi olo.

Ohun ti o tun da bi re ni wipe, a koko ma n gun eroja kunna ki a to da ose abuwe si, ki a to wa gun papo. Ohun ti o fa sababi eleyi ni wipe ki o le ba rorun lati gun papo. Isese a gbe wa o!

1 Like

Re: .. by dominicson: 12:07am On Oct 14, 2016
Lero70:

moki gbogbo eyin agbalagba ti Eledumare jogun ogbon fun ni abala yi, lagbara Eledua ogbon na konii dope, kosiniitan nibiti eti nmuu.
Ejowo mose akiyesi pe eyin agba wonyi kofibee kobiara si abala yi mo, ISESE LAGBA GROUP lorii whatsapp ti boo mole patapata, mosifekeemope awa ti a nje anfaani abala yi, sugbon ti phone wa kogba whatsapp application sipo gan, nitorinaa ejowo ebawa fun abala yi ni ijelogun bii tateyinwa. Yio maa juu yin se o ase.

O seun gan. Adura re yoo gba. Oju ko ni tie. Omo araye ko ni binu re. O o ni te oju ile mo'le. O o ni si oko ja je. Porogodo aye ko ni lu fun o jo. O wi're! Agbekale oro re fi han pe omoluhabi ni o. Oo ni je ibaje nigba kookan.

Ba mi fi omi lo kekere yi:

House arrest

Iha, damonito, koleorogba, ose dudu, a o gun papo, ita gbangba nibiti elomiran ko le ti we ni a ti ma n we. Ko si igba ti a ko le we.

Psalm:
Damonito kan kii fi ito tie dola, warawara ni koleorogba n s'oje, gbogbo eniti ba n p'ori mi nibi, oso ni, aje ni, emere ni, kenimani, babalawo, pastor, ala-laafa,abbl, Iha lo ba mi ha won mole ki won ma le jade mo. Ki won ma a gbe yara pe omo alakara.

1 Like

Re: .. by HorlarhMheporzy(m): 6:13am On Oct 14, 2016
ekaro, eku oju mon, inu mi dun lati darapo mo eyin memba ti nairaland. eku ki asa ati ise yoruba ma pa run. motun fi asiko yi ki gbogbo agbalagba ati omode to wa ni nairalandi yi ajinde ara yo maje oo inu mi dun pupo lati tun mo eniyan si lori oro alagbeka (internet).
Re: .. by HorlarhMheporzy(m): 6:19am On Oct 14, 2016
Ejo mo ni di ogun ti mofa ti ara eyan ati awon mo gbon lai ri inka iberu (scared thing) ta bi wa nibi ti oro posi (in public). so gbon mogbo pe aisan isan (vein fever) ni. eda kun mo nidi ogun yi gidi gidi gan ni.
Re: .. by rubbyplus: 2:25pm On Oct 14, 2016
Mo ki gbogbo tomode tagba lori ikani yii. Mo je olufe ikanni yiii lati
2015. Inu mi lati join finally. Ewe a ma je oo. Ase

(1) (2) (3) ... (82) (83) (84) (85) (86) (87) (88) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 91
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.