Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,153,038 members, 7,818,067 topics. Date: Sunday, 05 May 2024 at 06:47 AM

Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju - Health (20) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju (558690 Views)

Civil Servant Killed By Thunder In Oro, Kwara (Photos) / Ogun Ibile To Daju / The Bad Shape Of Oro General Hospital, Kwara State (Exclusive Photos) (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (17) (18) (19) (20) (21) (22) (23) ... (27) (Reply) (Go Down)

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 1:56pm On Feb 15, 2017
IFERAN: afara oyin, iyo, ao lo papo ao po mo ose dudu ao mafi we

IPARA IFERAN: omo nile 1 ayee, atare odidi 1,ao jopo ao da sinu ipara ao mafi para.

IFERAN:- Ewe orijin, epo eyin Ti adie paku
AO lo papo
AO fi ori po, ao maa fisi oti idodo wa

N.b:- enu Ni Edie fi ntun eyin re se Lori aba
Ki gbogbo eniyan'omaafi enu Tunmise loni

IBA fun gbogbo atoni sona'o

Eyi Ti abatunse Loni kie monfi biwa'o
Omo elomii Ni kie fibi'o
Nitori use konko lake odo
Omo eja Ni won fi nbi. /+\
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 1:57pm On Feb 15, 2017
IFERAN: afara oyin, iyo, ao lo papo ao po mo ose dudu ao mafi we

IPARA IFERAN: omo nile 1 ayee, atare odidi 1,ao jopo ao da sinu ipara ao mafi para.

IFERAN:- Ewe orijin, epo eyin Ti adie paku
AO lo papo
AO fi ori po, ao maa fisi oti idodo wa

N.b:- enu Ni Edie fi ntun eyin re se Lori aba
Ki gbogbo eniyan'omaafi enu Tunmise loni

IBA fun gbogbo atoni sona'o

Eyi Ti abatunse Loni kie monfi biwa'o
Omo elomii Ni kie fibi'o
Nitori use konko lake odo
Omo eja Ni won fi nbi. /+\

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045
OR
https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 2:09pm On Feb 15, 2017
OSOLE GBEWA PAJAWIRI
Omo yahoo na lelo daada kosi ewu
Ori kanakana 3, alangba 3 atare aja 3, pelu pelu biscuit okin ati opolopo ewe ola ao jo papo ao ma fi omi alujannu lo ebu na.........

N.B:- owo Ni afi ma nlo ebu na'o
Iru owo ewo Ni ao maafi lo?

=****
Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045
OR
https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ignitereaders: 3:21pm On Feb 15, 2017
These were people that exposed other to the disease the most. Their activities caused more death than imagined.

http://blog.ebolaalert.org/superspreaders-were-the-drivers-during-the-last-ebola-outbreak/
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by adeolabilkis002: 10:32pm On Feb 15, 2017
E kale sir,e jowo kinni mo le se ki awon egbon mi merin nkan ki won le pe mi pe kinni ki awon se Funmi.Nitori won si nitosi beeni won ki gbe call Mi.
Ki ni maa se ti oko mi afi pada wa si ile nitori iya yi poju funmi pelu omo meta
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 7:37pm On Feb 24, 2017
Ekule eyin eyan mi eyin ololufe etoye mo kiyin pe oto ojo meta, mose irin ajo ranpe nio modupe lowo gbogbo eyin ti epe lati bere alafia mi ati awan to send message ati chat lori watsup adura gbogbowa yio gba lase odumare laipe eto yio bere pelu awan ogun ibile ati iwosan fun arun gbogbo, ati ona ta nfi bo ninu ide aye raye,
Mose iba eyin toloun ko ayele lowo emaje kin sise o efi ojure womi Ase ntodumare

3 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ademasta(m): 7:39pm On Feb 24, 2017
kadunasouth:
Ekule eyin eyan mi eyin ololufe etoye mo kiyin pe oto ojo meta, mose irin ajo ranpe nio modupe lowo gbogbo eyin ti epe lati bere alafia mi ati awan to send message ati chat lori watsup adura gbogbowa yio gba lase odumare laipe eto yio bere pelu awan ogun ibile ati iwosan fun arun gbogbo, ati ona ta nfi bo ninu ide aye raye,
Mose iba eyin toloun ko ayele lowo emaje kin sise o efi ojure womi Ase ntodumare
Baba o
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by CivilianJTF(m): 7:41pm On Feb 24, 2017
Baba e kaabo o...
E da'kun e gbami... Iyawo mi n binu o... Mi o le se ju iseju meji lo lori obinrin... E joor e gbami baba kadunasouth
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by EasyMind(m): 8:37am On Feb 25, 2017
kadunasouth:
Ekule eyin eyan mi eyin ololufe etoye mo kiyin pe oto ojo meta, mose irin ajo ranpe nio modupe lowo gbogbo eyin ti epe lati bere alafia mi ati awan to send message ati chat lori watsup adura gbogbowa yio gba lase odumare laipe eto yio bere pelu awan ogun ibile ati iwosan fun arun gbogbo, ati ona ta nfi bo ninu ide aye raye,
Mose iba eyin toloun ko ayele lowo emaje kin sise o efi ojure womi Ase ntodumare

Baba e kaabo o, e de ku ojo meta... Aa ma ju yin se o
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by eeby1983(m): 11:26am On Feb 25, 2017
kadunasouth:
Ekule eyin eyan mi eyin ololufe etoye mo kiyin pe oto ojo meta, mose irin ajo ranpe nio modupe lowo gbogbo eyin ti epe lati bere alafia mi ati awan to send message ati chat lori watsup adura gbogbowa yio gba lase odumare laipe eto yio bere pelu awan ogun ibile ati iwosan fun arun gbogbo, ati ona ta nfi bo ninu ide aye raye,
Mose iba eyin toloun ko ayele lowo emaje kin sise o efi ojure womi Ase ntodumare
Aboruboye oo baba, eku ojometa ogbon ati imon ti olorun funyin Koni pare orunmila a gbeyin oo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 8:53pm On Feb 25, 2017
CivilianJTF:
Baba e kaabo o...
E da'kun e gbami... Iyawo mi n binu o... Mi o le se ju iseju meji lo lori obinrin... E joor e gbami baba kadunasouth

Elora ogede agba dudu meta kie bo epore danu kie ge si 201 kie sa si orun ko gbe dada kie loma atale ati kanhun bilala die ko kuna dada kie ma fi mu ogi gbigbona iyawo yin yio gba pe okunrin lako okunrin lada eni togbamu gan okunrin ni

5 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:00pm On Feb 25, 2017
Ogun aleko ati moko tobi
Pandoro tutu ào ge kekeke ao ko sinu koko ao da eru alamo ati eru awanka le lori odidi atare to gbo dada kan si ao bu omin toma dada si ao se yio jina dada ao mamun laro ati ale die die idaji stainless cup ni odiwan mimunre tobasepe ani match tobaku awa kan aomu . Wadupe fun oloun
NB gbogbo igba taba fe mu agbo yi lao ma gbe kana

9 Likes 1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by flakings007(m): 6:19am On Feb 26, 2017
kinah:
@kadunasouth. edakun sir. ogun wo la le lo fun fibroid?
call 08134541163
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by CivilianJTF(m): 9:39am On Feb 26, 2017
kadunasouth:

Elora ogede agba dudu meta kie bo epore danu kie ge si 201 kie sa si orun ko gbe dada kie loma atale ati kanhun bilala die ko kuna dada kie ma fi mu ogi gbigbona iyawo yin yio gba pe okunrin lako okunrin lada eni togbamu gan okunrin ni
Wow! Baba e seun o, modupe gidi.

Sugbon, e joor o... Se garlic ni atale ni...
Ewo photo yi na

1 Share

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by possible26: 11:34am On Feb 26, 2017
baba eku ojo meta oooo...ejor e fun wa ni ogun aseje ririse ati aseje arisiki todaju
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by IBAAGBA1: 10:28pm On Feb 26, 2017
kadunasouth:
OGUN AWURE TI NSI ONA TIPATIPA
odindi alangba ako gbigbe kan,ewe firiganmu,girija ti ko lomo ninu ,imi orun-(imi ojo) ao gun gbogbo re po,aofi ase joo dada ,igbati aba joo tan ,ao gbon eyi ti oba kunna yen ao po mo ose dudu,sawasawa toku ni ,ao fi ma fi turari ni ale ojo monday ,ao ma we ose yen ni ojo monday ati alamisi ,ao ma sope ki ona si fun mi lona kona o tan.
E jowo sir,ewe wo ni won npe ni ewe firiganmu,atipe kilo nje girija ti o lomo ninu,e se sir

3 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by IBAAGBA1: 2:05pm On Feb 28, 2017
kadunasouth:
Turare Jalabi, Itaja, Afa orewole Odara Fun Onile ati Onirin Ajo
Ori Agiliti, ori aparo, ori musu eyi toni irun, Ewe ajade, eru alamo, koro owu kopo die, oyin bi sibi meji ao gun gbogbo re sakasaka ao mafi lararo Danwo oje bi idan

E jowo sir baba ewe wo ni ewe ajade,e se pupo sir a ma juyin se o
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 4:02am On Mar 01, 2017
CivilianJTF:

Wow! Baba e seun o, modupe gidi.

Sugbon, e joor o... Se garlic ni atale ni...
Ewo photo yi na
Ginger ni atale o then kanun bilala niwanba lema fisi nibi odiwan garlic odidi kan kogbudo jubelo
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 4:04am On Mar 01, 2017
IBAAGBA1:

E jowo sir baba ewe wo ni ewe ajade,e se pupo sir a ma juyin se o
,
Owa lodo awan elewe omo ebere wan a funyin

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:44pm On Mar 07, 2017
ATUDE
Asin odidi kan ao jo pelu odidi atare ninu isasun tuntun ao lo kuna ao fi sin gbere yipo owo wa mejeji ao fi iyoku fokomu odaju

Atude ota inu iroko pelu egbo tude ao gun yio kuna dada ao dapo ma nescafe ao to die die sinu omin gbona ao fi oyin die si bi ao se ma lo niye lararo

3 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by CivilianJTF(m): 3:45pm On Mar 08, 2017
kadunasouth:

Ginger ni atale o then kanun bilala niwanba lema fisi nibi odiwan garlic odidi kan kogbudo jubelo
E seun baba. Keepe funwa o!
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by possible26: 7:45pm On Mar 09, 2017
[quote author=kadunasouth post=54369305 IBA OMIN O!, OMIN TI INA MU TOKU OHUN NA NI OMO ENIYAN MU TOLA, MOBOJU WO APAMI OTUN WONJU BINNBIN NI, MONI BOLEJU BINNI KOJU BINNI, AJIBOWU NISE ALAGBEDE ODE ORUN, MOBOJUWO APAMI OSI WONJU BINNI BINNI MONI BOLEJU BINNI BINNI KOJU BINNI AJIBOWU NISE ALAGBEDE ODE ORUN AGBALAGBA BABALAWO KOLEBINU KOFI OMO BIBI INURE BOFA AJIBOWU NISE ALAGBEDE ODE ORUN AGBALAGBA ISEGUN KOLEBINU KOFI OMO BIBI INURE BO OSEYIN, AJIBOWU NISE ALAGBEDE ODE ORUN AGBALAGBA ALUFA ABI EWU GEREJE KOLEBINU KOFI OMO BIBI INURE PA ILEYA, AJIBOWU NISE ALAGBEDE ODE ORUN WONNI KIN MASU SEPO MOSU SEPO WAN OBAMI WI RARA, WONI KINMA TO SALA MOTO SALA WAN OBAMI WI RARA, MOWAFI IKO ODIDERE NUDI OMO OYEBE YEBE AYAMI OGBIRIGIDI MODI IRULA ORITA AYAMI OGBIRIGIDI MODI OMO OBANILE IFE ONI AYAMI OGBIRIGIDI MODI IRULA ORITA AYAMI OGBIRIGIDI INU KIBI BABALAWO KOFI AJA BO IFA INU KIBI ADAHUNSE KOFI ELEDE TE ODU , EFUN OMO OGERE IDE, EEDI OMO OGERE OJE, OGANNA NI ORUKO OGERE IDE EFUN ATI EDI WONJE ERU OBA NILE IFE, ONI NI IGBA IWASE, ERU KISIPA OMO OHOWOREJE, EDUMARE MAJE KI EFUN ATI ED OMO ARAYE OMUNMIN POPO OKUN KONI ENINI IRAWO OSA KONI GBOGBO, AKIGBE AWORAN GEGE KAMOFI OWORE BA IBIKAN LODIFA FUN YEWANDE TOFI ODUNMETADINLOGUN WASE OGBURU, OGBURU OGBARA MORE NITI APA OKUN OMOLAYO OMO AJOMITAN WUWO OSO GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO, AJE GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO, IKU GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO ARUN GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO etc OMIN WO YANRIN GERERE OMI OLAPA OMIN OLESE OMIWO IYANRIN GERERE GBOGBO ENIYAN TIN BA NDOJU OTA KOMI KI OMI AYE BAMI GBEWON LO MOBA OMIN MULE LONI, ENIKAN KIBANI MULE KOTUNSE IDANI, EWO ORISA. baba e dakun bawo lase ma lo ise yi
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by YoungAbiodun1(m): 9:55am On Mar 10, 2017
Modupe gidi gan fun idawun yin lori ibeere mi iyen (ogun fun ara tin wu)eseun gan an ni.Uhn,ajanaku koja mori nkan firi,taa ba rerin kaso wipee arerin.Ise takun takun le n se lori ikanni yii.Mo gbaa ladura wipe ki olorun oba tun bo maa se alekun ore ati ibukun fun un yin.Ejo,eniti ara re un wu yi,won ti lo ogun lorisirisi fun un sugbon ti o jasi wipe ti enina ba ti yagbe fun iye ojo die,ti arare si ti lole toba ya arare a tun bere sini maa wu pada paapa julo ikun re lo maa un wu ju ai eni imale gbe.Inu mi adun gidi gan an ti ogun ti e fun mi yi ba je ti arare kosi wu pada mon.IBA AWON TO LAYE,IBA YIN OOO
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by kadunasouth(m): 9:45am On Mar 12, 2017
possible26:
[quote author=kadunasouth post=54369305
IBA OMIN O!, OMIN TI INA MU TOKU
OHUN NA NI OMO ENIYAN MU TOLA,
MOBOJU WO APAMI OTUN WONJU BINNBIN
NI, MONI BOLEJU BINNI KOJU BINNI,
AJIBOWU NISE ALAGBEDE ODE ORUN,
MOBOJUWO APAMI OSI WONJU BINNI
BINNI MONI BOLEJU BINNI BINNI KOJU
BINNI AJIBOWU NISE ALAGBEDE ODE
ORUN AGBALAGBA BABALAWO KOLEBINU
KOFI OMO BIBI INURE BOFA AJIBOWU
NISE ALAGBEDE ODE ORUN AGBALAGBA
ISEGUN KOLEBINU KOFI OMO BIBI INURE
BO OSEYIN, AJIBOWU NISE ALAGBEDE
ODE ORUN AGBALAGBA ALUFA ABI EWU
GEREJE KOLEBINU KOFI OMO BIBI INURE
PA ILEYA, AJIBOWU NISE ALAGBEDE ODE
ORUN WONNI KIN MASU SEPO MOSU
SEPO WAN OBAMI WI RARA, WONI KINMA
TO SALA MOTO SALA WAN OBAMI WI
RARA, MOWAFI IKO ODIDERE NUDI OMO
OYEBE YEBE AYAMI OGBIRIGIDI MODI
IRULA ORITA AYAMI OGBIRIGIDI MODI
OMO OBANILE IFE ONI AYAMI OGBIRIGIDI
MODI IRULA ORITA AYAMI OGBIRIGIDI INU
KIBI BABALAWO KOFI AJA BO IFA INU KIBI
ADAHUNSE KOFI ELEDE TE ODU , EFUN
OMO OGERE IDE, EEDI OMO OGERE OJE,
OGANNA NI ORUKO OGERE IDE EFUN ATI
EDI WONJE ERU OBA NILE IFE, ONI NI IGBA
IWASE, ERU KISIPA OMO OHOWOREJE,
EDUMARE MAJE KI EFUN ATI ED OMO
ARAYE OMUNMIN POPO OKUN KONI ENINI
IRAWO OSA KONI GBOGBO, AKIGBE
AWORAN GEGE KAMOFI OWORE BA
IBIKAN LODIFA FUN YEWANDE TOFI
ODUNMETADINLOGUN WASE OGBURU,
OGBURU OGBARA MORE NITI APA OKUN
OMOLAYO OMO AJOMITAN WUWO OSO
GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO, AJE
GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO, IKU
GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO ARUN
GBEMI OTIMI MOJOMITAN MOWUWO etc
OMIN WO YANRIN GERERE OMI OLAPA
OMIN OLESE OMIWO IYANRIN GERERE
GBOGBO ENIYAN TIN BA NDOJU OTA KOMI
KI OMI AYE BAMI GBEWON LO MOBA OMIN
MULE LONI, ENIKAN KIBANI MULE
KOTUNSE IDANI, EWO ORISA. baba e dakun bawo lase ma lo ise yi

Elowa cup tabi igba funfun tabi awo funfun ti kosi fulawa larare ki ebu omin ti ebale mutan sinure ki e wa pe gboloun yi si kie gbemu kie se die ku kie fi sari ema se etoyi ekan larin ose ti ota bapo funwa ao lo lerawan fun ojo meje ASETA TO DAJU NI,

6 Likes

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by 08101646045atwp(m): 9:55pm On Mar 12, 2017
OSOLE OWO TIMU OWO NLA TI ALE FI KOLE LARIN OSU META!
Sugbon nigbati Emi danwo, Mio kole'o
Sugbon hmmm!!!
Nkan Ti mofise komabaje'o!!!
:- EWE BARA MESAN TI OOJO, AOGUN MO ERU ALAMO IYEKIYE, AOPO LOSE, AOFI EJE EIYELE funfun PO OSE NA DADA, AOKO ose na SINU IGBA OLOMORI, AOGBE PAMO FUN 16DAYS. Aoma buwe lararo, pelu ogo Eledumare owo ti ama fi kole nlala yio wa larin osu meta pere. IKILO: enikeni kogbodo ri igba yi ki ojo na tope. Osole yi Koni daun daada na.

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045
OR
https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by possible26: 11:37pm On Mar 12, 2017
modupe baba olohun o jeki e pe fun wa Amin

1 Like

Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Jummyphabulous: 8:15am On Mar 13, 2017
Ekaro sir, have when through ur post n saw that u have done great for pple. Am 27 year with 2 kids. Mo ri pe ikan osu mi polapoju, won wa ya scan funmi ni ile iwosan. Won ni moni arun iju. Sugbon okere.

Pls sir i need herbs that will shrink the fibroid so that it will not develop. Thank u
Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by ibro2much(m): 8:06pm On Mar 15, 2017
08101646045atwp:
Ise ti afi nwa nkan ti ole bajilo!
Ewe Ina ati ewe esisi ati ako alangba ao gun papo, ao Sa ti yio gbe.
Lilore: Ao wa eyin na sinu akufo ikoko ni dede ago mokanla, ao maafin Lai nije Ki o fin si Awa na Lara
Pelu gbogbo bai wipe gbogbo iyeju awon ti ogbe nkan baibai lo tabi iyeju awon ti ogbe nkan lagbaja Ki ara maani komaroju raaye Ile aye re mon'o!
Afi tobada pada
Ao Sa bee ni ijo kini ikeji ati ijo keta!

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori number yi:-ni wasp 08101646045 bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add number yen si odo'e
Kede fi orukoyin sowo ni ekun rere:-Fun apere...emi ni arole onikoyi(chief egbeji)omo bibi ilu osun ni mi,ni ilu Ikoyi,ise onisegun ibile ni mo de nse ni ijebu ode

Atipelu iye Omo odun bai nimi

Eo si fi ise ti etiseri tosi dayin loju kan tabi meji sile lobatan!

Ajuwase'o

ekuse baba o,ewe ati egbo yio ma je wa o
ejowo ibere mi ni wipe se agogo mokanla ale tabi owuro ni ao maafin ni?

(1) (2) (3) ... (17) (18) (19) (20) (21) (22) (23) ... (27) (Reply)

Causes Of Seeing Menstrual Period Twice A Month / Postinor 2 - How Effective Is It? / Doctor in the House: Free Medical Advice Available

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 65
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.