Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,152,430 members, 7,815,970 topics. Date: Thursday, 02 May 2024 at 10:31 PM

.. - Culture (90) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1828588 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (87) (88) (89) (90) (91) (92) (93) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by ademotech: 7:43pm On Jan 06, 2017
Ifankaleluya:

E lo re wa EWE-AJABO(eku gogoro ni a n pe bayen). e gbo ninu omi ti e le fi we ni e kan soso ni aro kutukutu, ki e wa ju epo igi-nla di e sinu omi yen ki e gba omi yen si ibi ti o tile ri sanmo lati aro yen di ale. ki e wa ra AJAPE eran oruko, ki e ko sinu awo-abokadale, ki e bu epo pupa si lori, ki e wa se adura si wipe Oso lo ba fe bayin ja ni, aje lo ba fe ba yin ja ni gbogbo ajogun kajogun to ba fe koju ija si yin lati de yin mole lona kan tabi lona miran, odidi eran ni e ti pa fun won yi, ki won jowo ki won yonda yin. eo ti wa efun ati osun sile, eo lo papo, eo fi omi di e po, eo wa fi pa ese yin lati orunkun da atelese, eo wa lo gbe ipese yi si orita-meta lale ti gbogbo eniyan ba wole sun tan. pi pada ti e ba pada wo inu ile ni eo wa fi omi ti e ti gbo ewe-ajabo ninu re yen sin gbogbo ara yin ti eo si wole sun.

NB; Ti ile ba mo laro ojo-keji, e gbiyanju lati se saara fun afoju meje.

Pelu ogo-olohun, eo si ja Ajabo ninu odun yi, e ki yio ri ohun ti yio da yin gunle tabi ogun atimo(do do mi). Ase!
ESE pupo

1 Like

Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:12am On Jan 08, 2017
belatoxx:
Baba 08101646045atwp(m) ko si akole kan kan lo ri ise yi ejowo e fi akole si

Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:02am On Dec 15, 2016
Ni bai ao fi epo obo Tele ape, ao Ko eeru alamon le Lori
AO Ko ewe ewuro oojo ati ewe eyeoba le ao bu omi totowe si ao gbe ka ori Ina Ni ago kan osan gerege, ao we Ni ago kan oru nitori Ti ide baja ona asi Ti ona basi arisiki owo awole
(Quote) (Report) (Like) (Share)

Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:11am On Dec 15, 2016
Bakan na ao lo kafura pelebe merin ati epo obo ao fi omi Idi igbin poo, ao maawe Ni igba kan Ni odun
N.B:- ao fi oseyi si ori kan-nkan meta, ao kunle ao we ikan, ao naro ao we ikan, ao joko ao we iketa, ao ju kan'nkan na nu, ao we be Ni ekan Ni ose akoko ose keji ati iketa, eyi Ti otun Ku odi odun miran, abawon kankan koleefo Mon eniyan
Ajuwase o
(Quote) (Report) (Like) (Share)

Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:16am On Dec 15, 2016
HMMM
eyin pepeiye mewa, eyin adie ibile mewa, a o Jo eyin mejeji sinu awo olomori funfun, ao bu iyo die si, ose lux funfun mewa, ao ha , ao ko sinu re. Ao jeki ore di ojo keji,. A o po po ninu awo yen nibe, ao ma fi we. .
N.B:- ( JOWO MASE FUN ENIA LO NINU OSE YIO ).

1. Ashina
2. Atude
3. Oso funfun
Re: .. by dagu: 2:24pm On Jan 08, 2017
Ifankaleluya:

Baba, e ma je ka tan ara wa je. EMI o gbagbo ninu Awure ti e n toka si yen. Gege bi Apere, ki eniyan kan ni ohun fe ma lo awure dalute ni ilu eko, e dakun nibo ni alujonnu awon to se alujonnu owo ma lo? E dakun, nibo ni alujonnu awon to n lo OSOLE-GBIGBONA ma lo? E ma je ka tan ara wa je, ALUJONNU ju ara won lo. won si ma n da ara won lona gege bi ole ti ma n da eniyan lona! Won da pe fun yin ni, o ni loruko miran, gbogbo n kan to ba je mo bayen gbodo ni owo awon iyami(AJE) ninu,

Be ni baba, Mama-Agba so fun mi wipe Awure keke to n sise ni aye igba kan o fi be sise mo laye ode oni nitori wipe alujonnu owo ti po ju ni ita.

2 Likes

Re: .. by seanjizzyayo: 2:24pm On Jan 14, 2017
Ifankaleluya:

Kiise ewe-Ireke. Ewe-ire ni mo n so!

@IFANKALELUYA

baba ifankaleluya edakun edahun ibere mi mo ti se awa ri ewe ire edakun oku awon eroja toku ejowo bi EBA le funmi ni ori tread yi email mi niyi seanjizzyayo@gmail.com edakun ti ise yi badahun makan yin Lara ejowo ti oba si je omiran le o funmi kosi eyi ti ko da.
ti aba si rii eni ti o mo ogun ti omo yahoo lelo tiyo fi ma ri owo gba yala ose, ebu tabi aseje koba mi post ee ejowo @kadunasouth @healthfirst ejowo eba dasi oro yi ise onidojuru aseye le o mase oooooo
Re: .. by seanjizzyayo: 2:26pm On Jan 14, 2017
Ifankaleluya:

Kiise ewe-Ireke. Ewe-ire ni mo n so!

@IFANKALELUYA

baba ifankaleluya edakun edahun ibere mi mo ti se awa ri ewe ire edakun oku awon eroja toku ejowo bi EBA le funmi ni ori tread yi email mi niyi seanjizzyayo@gmail.com edakun ti ise yi badahun makan yin Lara ejowo ti oba si je omiran le o funmi tabi oshole togbona kosi eyi ti ko da.
ti aba si rii eni ti o mo ogun ti omo yahoo lelo tiyo fi ma ri owo gba yala ose, ebu tabi aseje koba mi post ee ejowo @kadunasouth @healthfirst ejowo eba dasi oro yi ise onidojuru aseye le o mase oooooo
Re: .. by seanjizzyayo: 3:20pm On Jan 14, 2017
Lionhearted:

*
ee add me sori whatsaap group number mi niyi 08100713615
Re: .. by seanjizzyayo: 4:10pm On Jan 14, 2017
08101646045atwp:
OSOLE=Ti o ma n mun EYAN Mon AWON nlanla nileyi ati okere.(OMO-YAHOO LELO KOSI LABURU)
Eiye kannakanna tutu kan,ao fi biscuit okin si labiya otun, ao fi Odidi atare kan si labiya OSI,Ao wa ka iye re mejeji Mon Lara ki awon nkan wonyi maba bole.....ao wa ko eyin ororo meta tele ape tuntun, ao wa GBE eiye kannakanna yen le monle.....ao wa ko ewe ekuya tutu pelu sawerepepe tutu die bo monle....odi jijo.......ao lo kuna Dada,ao wa ma fi 1000naira tuntun kan ko ebu yen sinu oti ST-REMMY....Ao wa GBE si igun yara wa,ao fi 1000naira yen si legbe.
Ao wa sope:---------Owo timofi dao loko owo re ooo,kio lo ma bami WO olowo nlanla, olooro,okunrin, obinrin tiowa fun emi l omo l ni owo nlanla wasi odo mi.ADURA....
Ao ma mun diedie laro laro.
N/B******

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o

kini itumo biscuit okin ??
Re: .. by fridayakanb1(m): 2:11am On Jan 15, 2017
Baba e jowo mo sese de ori ikan ni yi ni.Mo fe ogun iwosan roparose to daju.E seun,yio ma ju yin se o.
Re: .. by fridayakanb1(m): 3:38pm On Jan 15, 2017
coolA ku dede iwo yi baba,ajinde yio ma je yio.Baba e ko ti dahun ibere mi,mo fe OGUN IWOSAN ROPAROSE ti o daju saka.Baba ejowo sir,eyan mi kan ni aisan yi nyo lenu,e ko ni ri ogun agbana o,Ase Edumare.
Re: .. by ADEOSUN111(m): 8:15am On Jan 22, 2017
ejowo nipa EYONU AWON AGBA YEN,
se omi lasan ni ao fi po ose ati awon nkan to Ku ni abi omi agbon abi kini?
ejowo e yan Nana re.
eseun yoo maa Ju waa se o ase
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:08pm On Jan 25, 2017
OSO ONITIKUTI
Omo aja eyikeyi ninu ako tabi abo, aofi ewe swerepepe tutu oojo teele inu agbada, aogbe omo aja na lelori, aofi odidi atare nla 7 si legbe, aoda opolopo ewe ola le aja na mole, aowa fi ewe aje onisefun sefun bomole ti aja na koni han sita, aojo ni dede ago mejila osan, aoto epo pupa yika aro na, ti aba njo oogun yi lowo, aoma mu oti ti aofi jotan, ti aba jotan, aolo kunna, aoda sinu ado sere kan, aoran aso osunwon, aogbeko fun ojo meje kiato mafi oti lo lararo, pelu OHUN; onitikuti walole ti olowo wa, olola wa, oba ilu, ijoye, borokini ilu yi wa kiwon wafi owo owo won tamilore, kiwon wafi sanu mi, kiwon wafi bomi lasiri Ki won wa fi tiwon gbe temi lawuge etc...

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045
OR
https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: .. by Despiryer: 5:03am On Jan 28, 2017
keyguy59:
"OGUN TI OKO OKUNRIN BAKERE TI YIO FI YO JADE TI YIO
SI TOBI" ao
wa igbin nkan toba bonu, ao ju sinu
omi fun igba die, bi iseju mewa tabi marundogun,ao
yo igbin naa pada, ao
fi sile, tobati yo ori jade funrare, ao fi ada be ori re lekan, ao wa gun po mose dudu, ao mafi fo
gbogbo ara oko wa. oko wa yojade
ti yio si gun dada.
baba se igbin to ba ni kini funfun loju?
Re: .. by Despiryer: 5:34am On Jan 28, 2017
Lionhearted:

E lo ye email yin wo. Eseun.
mo nilo ogun ti oko olomokunrin file tobi daada
Re: .. by 08101646045atwp(m): 12:09am On Feb 13, 2017
fridayakanb1:
coolA ku dede iwo yi baba,ajinde yio ma je yio.Baba e ko ti dahun ibere mi,mo fe OGUN IWOSAN ROPAROSE ti o daju saka.Baba ejowo sir,eyan mi kan ni aisan yi nyo lenu,e ko ni ri ogun agbana o,Ase Edumare.

OGUN IWOSAN STROKE
AO toju igi osunsun,ao lo tiyo kunna dada,ao wa Sa enina ni gbere ni apa ati ese,ao fi ra.
ao wa wa oge oro adete sinu igbakan,ao ju odidi eko tutu kan si,ao fo papo dada,ao mafi wo owo ati ese eni na,pelu ogo olorun alafia de niyan.
STROKE¤ Ewe Ato, Eru awonka, ori, ao fi ori yii tele agbo ao fi eru yen le lori ao fi ewe ato le lori ao fi omi se jina daadaa, emeta ni mimu re lojumo.

FUN IWOSAN STROKE Elowa epo jebo tioba po dada kie wa kosi inu ikoko agbo kie se ko hoo dada tio obati ho ao wa lowa akisa ori atan tabi ti ilele tojewipe erupe tinbo monle ao wamu ao gban nu ao jusi inu agbo yi ao se po tityo ho dada toba jina ao so enina yoma mu ninu agbo na akisa towa wanibe ao mafi jo gbogbo ara enina lati ori delee walahi mofi olohun bura ose kan pere lefi se ti enina yofi

OGUN ROLOWOROLESE(STROKE eku asin 11,atare odidi 11,ori oka 6,oga gbigbe 11,ao wa gun ninu odo ti yoo kunna,ao gbodo fi owo ko o,ao wa gun ni agunmu,ao ma fimu eko gbigbona sibi kookan.wallahi ise nla ni koye kin yonda re,adua yin ni mo nfe.fun ibeere {User Contribution}

Ogun rolowo rolese(stroke)-eku asin 11,atare odidi 11,ori oka 6,oga gbigbe 11,ao wa gun ninu odo ti yoo kunna,ao gbodo fi owo ko o,ao wa gun ni agunmu,ao ma fimu eko gbigbona sibi kookan.

KI STROKE MA MUN ENIA¤ Opolopo Ayan ao jo pelu Odindi ataare kan gbere yii ifunpa waa kaa ni owo otun, Gbere yii itan Osi kaa

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o

1 Like

Re: .. by 08101646045atwp(m): 3:00pm On Feb 15, 2017
OSOLE GBEWA PAJAWIRI
Omo yahoo na lelo daada kosi ewu
Ori kanakana 3, alangba 3 atare aja 3, pelu pelu biscuit okin ati opolopo ewe ola ao jo papo ao ma fi omi alujannu lo ebu na.........

N.B:- owo Ni afi ma nlo ebu na'o
Iru owo ewo Ni ao maafi lo?

=****
Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045
OR
https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: .. by Lokoandtq(m): 12:30pm On Feb 18, 2017
jamiu3209:

Ejowo baba efun wani Ogun yii tan, Adura yin ama gba...Mojuba oo
=baba Ejowo Efun Wa Ni Awon Oogun Yii Tan,bi Ayeta Oni Chain Ati Gbetugbetu Oni Oruka Yen Tan,sebi Eyin Agba Naa Le Bo Tee Pa Owe Pe ,oju Ti Ore Mi Oju Ko Ti Mi ,pe Ai lojuti Lon Je Bee Iba Agba Oo Elee Gegun Lori Ise Naa Fun Eni Ti Oba Fi Se Ise Ibi Email Mi Niyi, Lokoandtq@gmail.Com Tabi Ebami Fi Ranse Si Ori No Yi - 07063539854
Re: .. by lackren(m): 4:18pm On Feb 21, 2017
Dear forumites,
Please I need more knowledge about YES or No answer on Merindinlogun Cowries when tossed it on the ground once and form any one of the following:
Eji Ogbe
Eji oko
Ejila shebora
Odi
Obara
Okana sode
Irosun
Owonrin
Ogunda
Osa
Irete
Otura/ofun kanran
Oturapon
Ika
Ose
Ofun
Opira
Re: .. by IBAAGBA1: 12:37am On Feb 24, 2017
Iba Olorun,iba eniyan,iba esu lapa kan,kesu ma sewa ko ma se enikankan to sun mowa o.
Iba omode,iba agba,iba gbogbo onimimo to nfi imo won tu awon eniyan sile ninu ide aye.
Omode ni mo je,eyin agba onilakaye e dakun dabo e damimo omo to.
Lagbara Eledua a ma ju yin se o AMIN ASE EDUMARE.
Re: .. by IBAAGBA1: 12:52am On Feb 24, 2017
08101646045atwp:
OSOLE GBEWA PAJAWIRI
Omo yahoo na lelo daada kosi ewu
Ori kanakana 3, alangba 3 atare aja 3, pelu pelu biscuit okin ati opolopo ewe ola ao jo papo ao ma fi omi alujannu lo ebu na.........

N.B:- owo Ni afi ma nlo ebu na'o
Iru owo ewo Ni ao maafi lo?

=****
Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045
OR
https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o

Iba re baba mi agbalagba,e jowo sir iru omi wo ni eyin agbalagba npe ni omi alujonnu,atipe iru owo wo la ma fi lo ebu yi,e se pupo sir.
Re: .. by possible26: 5:41pm On Feb 27, 2017
baba pls i want to join isese lagba pls guide me 2ru.
Re: .. by Nobody: 6:30am On Mar 01, 2017
08101646045atwp:
OSOLE GBEWA PAJAWIRI
Omo yahoo na lelo daada kosi ewu
Ori kanakana 3, alangba 3 atare aja 3, pelu pelu biscuit okin ati opolopo ewe ola ao jo papo ao ma fi omi alujannu lo ebu na.........

N.B:- owo Ni afi ma nlo ebu na'o
Iru owo ewo Ni ao maafi lo?

=****
Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045
OR
https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
ejowo baba, bawo ni eniyan se ma nlo olugbohun to bawa ninu iwo agbo pelu ikoti ogun lori re. Ejowo, mohun duro de idahun yin sir... e se pupo
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:56am On Mar 02, 2017
CallmePROF:
ejowo baba, bawo ni eniyan se ma nlo olugbohun to bawa ninu iwo agbo pelu ikoti ogun lori re. Ejowo, mohun duro de idahun yin sir... e se pupo

Eku'laakaye Lori ibere yin Yi.
Nitori opolopo awon ise onikoleti lo ma nje eyibti ao fi ikore banu!
Nitori ise na leeje ajogun ba'o
Sugbon bi ase nlo ise oniko leyi niyen'o

But telomi tun le yato'o
Sugbon bi mosemon Ti a nlo niyen'o
Ajuwase o

1 Like

Re: .. by Nobody: 11:02pm On Mar 02, 2017
08101646045atwp:

Eku'laakaye Lori ibere yin Yi.
Nitori opolopo awon ise onikoleti lo ma nje eyibti ao fi ikore banu!
Nitori ise na leeje ajogun ba'o
Sugbon bi ase nlo ise oniko leyi niyen'o

But telomi tun le yato'o
Sugbon bi mosemon Ti a nlo niyen'o
Ajuwase o
ese pupo Lori alaye yin sir, modupe. Sugbon nkankan to n ru mi loju niwipe..... se ti mo bati fi ikoti ogun nah banu tan, se ma da ikoti ogun nah pada sinu olugbohun nah kin to soro si abi maa soro si olugbohun nah ki n to da ikoti ogun nah pada sinu olugbohun nah??.

E se pupo sir.
Re: .. by Mallam1910(m): 7:25am On Mar 03, 2017
kadunasouth:
AYAJO AWEBI, AWE-OGUN IDILE AWE-EPE etc
Efun ni baye osun je
Osun ni baye efun je
Atefun Atosun edu ni baye awon mejeji je.
Gbogbo asasi, edi, offa, aisan, epe, idiwo, arun, owo kowo, airi je, airi mu tin be lara oni kaluku wa koba je, kopa ibi da, koso dire, ki ona owo nlala ati arisiki kio la kan mi ati gbogbo ololufe Nairalanders!!! Ase odumare
efun ati osun pelu edu kini ama lo fun
Re: .. by olamide1247: 9:39am On Mar 08, 2017
ejo efun wa ni ogun aferi ati eyi ti a ma fi ma ri owo
Re: .. by Nostradamus: 11:40am On Mar 08, 2017
IBAAGBA1:

Iba re baba mi agbalagba,e jowo sir iru omi wo ni eyin agbalagba npe ni omi alujonnu,atipe iru owo wo la ma fi lo ebu yi,e se pupo sir.
oti schnapp lo n je omi anjonnu (tabi kie pe ni eje anjonnu /omi aye ).
Re: .. by Medallion500: 9:36pm On Mar 12, 2017
Ibaba eyin agbaagba oo. Ki iba mi se oo.. Ejo eyin agbaagba e add me si whatsapp group. Mofi eledumare beyin oo.. 08066447586
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:57pm On Mar 12, 2017
OSOLE OWO TIMU OWO NLA TI ALE FI KOLE LARIN OSU META!
Sugbon nigbati Emi danwo, Mio kole'o
Sugbon hmmm!!!
Nkan Ti mofise komabaje'o!!!
:- EWE BARA MESAN TI OOJO, AOGUN MO ERU ALAMO IYEKIYE, AOPO LOSE, AOFI EJE EIYELE funfun PO OSE NA DADA, AOKO ose na SINU IGBA OLOMORI, AOGBE PAMO FUN 16DAYS. Aoma buwe lararo, pelu ogo Eledumare owo ti ama fi kole nlala yio wa larin osu meta pere. IKILO: enikeni kogbodo ri igba yi ki ojo na tope. Osole yi Koni daun daada na.

Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP!
ele fi orukoyin sile si ori :- 08101646045
OR
https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS
bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above!
Jowo mafi number re si abe comment'o
Whala'oni payin'o
Add links yen si odo'e
Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere.
Ajuwase o
Re: .. by boas521: 8:46pm On Mar 14, 2017
Ejowo kin ni won PE ni isu dandan
Re: .. by boas521: 4:20pm On Mar 16, 2017
Pls add me on WhatsApp
Re: .. by Adewunmis(m): 8:41am On Mar 23, 2017
ifankealeya eku owuro ejowo kini nje ashisu
Re: .. by Nobody: 3:26pm On Mar 23, 2017
.

(1) (2) (3) ... (87) (88) (89) (90) (91) (92) (93) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 68
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.