₦airaland Forum

Welcome, Guest: RegisterLoginWith GoogleTrendingRecentNew

Stats: 3,330,943 members, 8,447,834 topics. Date: Sunday, 19 July 2026 at 06:55 AM

Toggle theme

Argent's Posts

Nairaland ForumArgent's ProfileArgent's Posts

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 (of 17 pages)

CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 4:24pm On Jul 27, 2009
hotteju:
newbie ni miii ooo
ki lon shele?
Kabo si abule wa  cheesy
dayokanu:
E ku deede iwoyi o se alaafia ni e wa
alafia ni a wa o. Se alaafia ni eyin naa wa?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 8:39am On Jul 27, 2009
Gbogbo ile e ku owuro o.
Se weekend yin sweet gege bi temi naa se dun gan cheesy
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 2:04pm On Jul 25, 2009
IFELEKE:
adumaradan temi nikan, bawo ni? se ara mokun?
awon ibeji mi nko, se won to kutukutu?
that addy is wrong it's luv4real003. holla!

@gbogbo ile(debo,dayo,toyin,tope,blu,tubabie,ajenti,dokita feli,faakay,remii)
Eku popo sinsin opin ose, se gbogbo e n yotomi?
Mo yotomi oh, ariya unlimited lo n sele ni ibi ti mo wa yi.
Christianity EtcRe: Have You Praised Him Yet, Today? by argent(f): 12:15pm On Jul 25, 2009
Who can question your ways oh LORD?
RomanceRe: My Boyfriend Is Demanding Money Frm Me by argent(f): 11:09am On Jul 25, 2009
Relationships have now turned into money making ventures. O ga ju cheesy
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 9:35pm On Jul 23, 2009
FL Gators:
@argent
hahaha cheesy cheesy Jor ma binu si mi.
emi ke moh pe o lufe debosky beyi. mee binu si mi cheesy

IFELEKE is not ready available. He's now a father to be grin grin


@@post
A saying goes like this "You never know what you ave until you lose it". Now I know, where's topsy25 cry
Ha mo ni ife dbosky gan ni o, i se ni ife e ma pa mi bi oti waini ni grin
Se alafia lo wa, sukulu n ko?

debosky:
Okare lai! Mo ri awon ajasa ti o fi kun, ogbon gidi wa lori e. grin
Mabinu aya mi, ise naa ni o mu mi jina si tireedi yii, sugbon ti mo ba tun ronu ife e si mi, mo ma sare pada ni. wink

Ma je ki ise yen gbo e rara, ma ronu ife ti ajo ni ati ere ife ti ama se ti a ba dele. wink

Mo ni ebun nla fun e, oruka ati ileke nla ti won fi wura (gold) da ni mo ti ra fun e lati ilu oyinbo. cool


Daju daju oro ti o so yii oje ki ori mi wu. kiss kiss

Ko si aya miran to dara to e ni ilu nairaland yii, ojojumo ni mo ndupe lowo Eledumare to so wa po.
I cant wait, jo tete wa si ile ki a sare se ere ife die cheesy
faakay:
looll, ori gbogbo wa ni owa foka bayi ooo grin grin grin grin

Argentina abi aje buredi la gege ni oruko re grin
Ti o ba mo itumo oruko mi, lo bere dada, iwo bobo farakoigbe ewure grin grin
For your info emi ati debo a wa in lust love, a se ere gele kankan.

Dr Ferlie:
ASIWAJU dee, ki gbogbo ilu pa roro. emi okunrin ogun ti wo ilu, ki gbogbo ota wo igbo lo.

mo ki gbogbo eyin omo oduaaaaaa. e ku ojo meta oooooo.

Baale, iyalode, dobosky, ore mi pataki ###wunmi, o ku ojo meta ooooooo. grin grin cheesy cheesy
Asiwaju ti ibo ni iwo?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 3:33pm On Jul 23, 2009
debosky:
Ooto ni o so iyawo mi, ori e ti fokasibe pata pata. grin

Daa daa ni mo wa aya mi owon, eleyinju eke, adumaradan, orekelewa, ololufe mi. kiss kiss

Se wahala ise ko poju fun e sa? Mo ni ebun nla kan fun e (surprise) wink
sweets mi kiss kiss
mo se fe so wipe ki won ba mi wa e lo ni cheesy
Ise fe shake mi die, but love e ni o je ki ma feel e rara kiss
Ebun wo niyen oh, je ki gbo wink

bluespice:
faakay o gbadun rara grin grin grin grin

eyin ile e tie da mi lohun sha angry
ani ta lo ma ko mi no yooba?
Mo ma ko e ni yoruba
Bawo ni, se o wa dada?

FL Gators:
@bluespice
Maa ko e ni yoruba, while am learning ekiti tongue

B.T.W, gbe oju e yen kuro lodo IFELEKE. abi se oro pe mi ke ri o ni? Find debosky or faakay to teach you "yooba" . Our sistership no reach that level o angry angry grin
awww, all that for me?! Orimi ti wu kiss
well, alafia ni mi a, sugbon se ni mo n ni backpain and awan ibeji wa n ja bii pe jackie chan ni un. embarassed
Okiez, holla back.


Howzzzzzzzzzzzzz everyone (topsy25, ife, bluespice, argent, deboskey et all). Good morning o.
Why debosky huh ma je ki binu si e oh angry smiley . O ti like ko ma pull legs mi ju
@ bluespice ma da toyin lohun, ma ko e ni yoruba for free or
to ba je wipe o prefer okunrin Ifeleke is readily available tongue
IFELEKE:
Ololufe mi,aaayo temi nikan, iyaafin IFELEKE kiss
bawo ni? se alaafia lo wa gege bi emi se wa nibi? awon ibeji mi nko? mo lero pe wahala yen o poju sha? ile-iwe e n ko, se o n lo deede?
i'll check your message up and holla back, trust me, you'll learn wink

@faakay
Dude, you are off da hook! grin
that is the yoruba version of eddie murphy's Coming To America. . .right?
@Gbogbo Ile
E n le oo
Ifeleke, ba iyawo e soro, ki o de kilo fun gan ni. Mi o fi Debo mi se ere rara angry
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 8:55am On Jul 23, 2009
faakay:
GRIRAMA NI EDE YORUBA

Akeem: Oga ooo!! Semiu wa wo nkan oo!! ha america yi afi bi ile ni ose ri oo! afi bi idi-araba ati ajegunle, e be nikan ni oti ma ri awon aafokoko ti
awon eniyan da si oju titi bayi.

O gbo? Ede yankee gan gan ni wan so yen oo,

*********************************************************
(Ohun awon eniyan ti wan soro)
Femi: Titi ti o ma fi ku! iru nkan be yen ole sele mo

Shipulu: [/b]O da O da! John Lucy nko?

[b]Jagunlabi:
haaaaaa! John Lucifer! Elese buruku ni yen oo!

Shipulu: ehen! se otan!

Femi: Gbogbo yin oti e soro pa teshin clin! teshin clin yen gan! Ija ni!

Shipulu: ehen o le soro pa teshin clin lo to! sugbo se nkan ti teshin clin acheieve, se mohammed ali o achieve ju be lo ni?

Jagunlabi: heee! Mohammed Ali achieve ju teshin clin loto! sugbo sho mo wipe ti mohammed ali ki oto achieve nkan ti o achieve yen, ikunmu otun e fe bosi tosi.

Abi iwo ro wipe lasan ni? se oro wipe oju lasan se were ni? mohammed ali ti o je elese ti o ni agabara gan! se omo nkan ni omo buruku yen ti fa si opolo ni ki oto ma lu everybody pa ni!

Femi: [/b]E ta ayo ti e ma ta jor!

[b]Jagunlabi:
ehen, se emi ni efin pa abi? hen? eyin meteta! e pa arayin po ki e wa ta draft yi! ma fe naa yin pa ni!

**************************************************************

Back to Akeem Scenerio:
Akeem ko lekun! ko ko ko!


Baba LandLordu: ehen? kini e fe?

Akeem: E jo! A need ile ni

Baba LandLordu: E ma fi ti yin dami duro! se eni owo lowo sha?

Semiu: Owo wa! ($$$$)

Baba LandLordu: ehen, e wo ile! iru eniyan ti yin bayi ni emi wa!

Ema binu! awon eniyan jakujaku ni mo gba si ile yi tele, sugbon bi mo se ri oju ti yin, oju ti yin farabale di e,

E jo! E ma binu, iru ile wo gan gan ni e fe bayi?

Akeem: Ejo! Ile face me and face you ni afe!

Baba LandLordu: hen? mi gboooooo?

Akeem: ani ile ti owo e kani lara pupoju

*******************************************************************

(Omuti subu ni ori staircase)

Baba LandLordu: Oloshi ara e ori owo ile san! ti oba ti lo mu oti! gbogbo awon lonbo YAHOO nkankan ati awon GIN yen! wa ama subu kakiri gbogbo staircase.

Ti o ba ku lasan? sa ra ni oku ee ooo! Olofo!

*********************************************************************

E be ni ade yi ooo (Yanmu Yanmu fo kiri! hmmmmmm, hmmmmmmmm, )

Baba LandLordu: Ileyi, shalanga kan pere ni owa ni ile yi ooo

Owun ni yii! e be ni e ma ma lo ooo

Awon ayan ati idun nkankan wa ni ibi bayi oo, sugbon eyin ti e wa lati AFRICA, o je ki oti mo yin lara.

E de ma lo gun lift oo! ti e ba gun lasan? e ma payin si be ni ooo

Akeem: [/b]A gba be!

************************************************************************

(Akeem ni balcony wo aworan New York)

[b]Akeem Pariwo!!!!!!!!!!: America!!!!!!!! America! America!! America ilu ola! America Ilu oro!

America ibi ti gbogbo aiye pin si! haa! America! America!!

E ka ro eyin ara AMERICA!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!


Semiu: Ori FOKA!!!!!!!!

Akeem: beni! Ori ti ena FOKASIBE!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!



IBI NI O PARI SI NI YI!!
grin grin grin grin

Emi Faakay lati ilu awon omo changpin lu grin grin
Fakaay, o ri ti fokasibe grin grin
RomanceRe: Dating One Of My Mate Since We Were In S.s.2 by argent(f): 10:30am On Jul 21, 2009
kokoA:
How old are u?
Age has nothing to do with this.

@ poster,

If spending time with her will make you do what you dont want to do, then stop spending time with her.
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 10:16am On Jul 21, 2009
Gbogbo ile, se dada l'ewa?
Debo, ololufe mi se dada lo wa?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 5:08pm On Jul 18, 2009
debosky:
Iyawo mi ajenti, ootie dahun gbogbo oro ti mo so fun e. sad

Abi se on bami ja ni? Ti mo ba ti se e jowo dariji mi.
ololufe temi nikan, o mo pe o le se mi wink
ma binu pe mi o kie specially kiss kiss
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 3:45pm On Jul 18, 2009
PERVERT9:
o ni time gan lati ka gbogbo iro yi o ga o tongue tongue tongue
Ta lo so fun e pe mo ka?  huh
Owo ni emi ma ka, mi o ki ka ikokuko tongue
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 12:14pm On Jul 18, 2009
PERVERT9:
Eyin ara papa julo eyin omoge ti ifelepon ifeleke nparo fun ni abule yi,eyi ni leta ti iyawo ifeleke towa ni abule won kosi ni nkan bi ojo meta seyin,ede oyinbo ni o fi ko leta na, o dami loju pe gbogbo yin le o gbadun leta ohun,e ma bawa kalo o grin


No 25,alamudo street,
abule mado mi pa,
26-06-2008


Dear Ifeleke,
How is you does?i hope you are does fine?long time no seeing,long time no earing from you,why does you do me like that,you just abadoning me in the village sinse all this deys,are it good like that and you tolded me that you loving me,you efen promise promising me before i gree greeing to goes out with you and marriage you,now that you have lefting the village you are does not caring or get time for me again,you does not write to me,you does not kollling my nomba or efen flashing me like you use to does wen you does not having credit in your fone.ifeleke temi nikan what does i did to desaving all this from you,has you forgeted about me and the plenty loves that i has for you,has you forgeted all what you tolded mama eleko who helps you to toasting me when you are ashaming to even facing me to told me that you loving me,i did not greeing to your loving,you would not leaving me alone,you going to meet iya olobi,broda mukaila,iya luku,buroda kapenta and even my momo to talking to me for you,still i does not greeing for you because i am afraiding of you disappointing me uselesing me and leafing me in the village.i does not greeing you until when you broughted your momo and your olori ebi to our house to come and beging me for you,you frostrated {dobale} for my parent and promising many many thing that day,when i looked at your eyes i tooked pity on you,i even sees in your eye that you loving me and becos you have suffering too mush because of me i gree greeing for you,you tooked me to many playses to see many many pipu,you tooked me to the zoo to see monkey,inaki,ejo,erin,ekun, ijapa and elede,you tooked me to kinsway to buying plenti tins{Things} for me like cloth,pata,shuu{shoe}rist wash,bangu and provisionses you also tooked me to mr bigs and boughted for me iresi and siken{chicken}we enjoying awaself well well before you tooked me to owonikoko hotel,where we goes to enjoys awaself. cry cry cry cry cry cry

Ifeleke temi nikan,you rememba when we gotted to the owonikoko hotel,that day you beged me to greeing for you to fokying me but i rifuse you,you promising me many many thing,like moni,cloth and you promising to taking me to amerika,when i looked at your eyes i tooked pity on you and i allowing you to fokying me you fokying me well well and fokying you too well well,we both enjoying awaself bifore we going back home,we doing it gain in your hause on the mart and you promosing not to disappointing me,but sinc you going bak to lagos i does not sea or hearing from you again, mulika and seri tolded me that they seeing you in nairaland efery day,that you are now marrying anoda wife caling tubrasier,toyosi,mukina ati awon obirin mi,is it truth,ifeleke what you does to me is very very bad and i am not hapi with you i am very very anoying with you,aniway i will look for money to coming to lagos and sees you so that you can telling me if you are not loving me again or you are not interesting in our relationsheep again,but i want you to nose that i stll loves you and i would like to marriage you.

till i comes to lagos takes kia of yorself kiss kiss kiss

yours daling waif,
sikiratu bebedi kiss kiss kiss
O ni time gan lati type gbogbo iro yi. O ga o undecided

Gbobo ile se e wapa?
Dating And Meet-up ZoneRe: Nairaland's Coolest Babe Is. . . . . . . by argent(f): 12:12pm On Jul 18, 2009
This is the second thread,
just when are you going to reveal the person huh
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 2:43pm On Jul 15, 2009
TOYOSI20:
Ehen, niboni Dayokanu wa?? shocked sad. . . .and Mr Farotika himself undecided, i need to brush up on ma yoruba oo, LOL!!
Farotika is now topsy25 aka oko omo iya olobi  grin
FL Gators:
argent, darling, s'ebi o moh mi na

mo wa pelu onje lati wa ki iwo ati debo. sugbon debo so fun mi wipe o lo ri pediatrician e nitori ibeji yin. se ko si sha?

He must have finished my food and forgot to tell you. I know say ur cheeks dey shine, so bro debo is taking good care of you tongue
Se awon ibeji n kick?
Igba wo ni oko se change of name si Ifelepon? ( oruko fine gan ni grin)

?
ajenti! angry
ma je ki n binu si e oo.
mo ro oyun ore mi debo mo e lara ni, n ba binu gan. grin

@gbogbo ile
eku ojumo oo
[/quote]mi o ni like lati bi oko sis mi ninu
E ma binu sir  tongue[quote author=topsy25 link=topic=226848.msg4189789#msg4189789 date=1247648000]iya afin tubabie ti dahun ibeere re undecided
nah, i dnt want this for tubabie phulease
Christianity EtcRe: Have You Praised Him Yet, Today? by argent(f): 12:12pm On Jul 15, 2009
Thank You Jesus.
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 7:00pm On Jul 14, 2009
Debosky oko mi atata, mo ti miss e gan kiss je ka sare wo iyara grin

Tubabie ba wo ni?

Toyin, o ri mi o bere mi?

Ifelepon grin grin grin

Mr Farotika, oko omo iya olobi tongue

Pafati, jo a ki ma so isokuso ni ibi bayi

Topup, ka bo si ori eto yi smiley

Gbogbo ile, se dada l'ewa?
FoodRe: 10 Minute Nigerian Recipes by argent(f): 6:33pm On Jul 08, 2009
you can actually prepare noodles for less than 10 mins
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 6:28pm On Jul 08, 2009
Moyola:
Eyin omo kaaro ojire, se dada lew? tongue
Dada ni awa, iwo na ko, se o wapa?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 6:16pm On Jul 08, 2009
tubabie:
E n le ni tiredii yi o. Kilonsele eyin eyan mi?

Oda wipe asiko ka maa loyun kaasi ma bimo niyiii grin

Gbogbo eyin omoge tie ti loyun bi Flgator ati Argent ti o n mura naa eku ise o, ema gbe omo olomo fun elomiran o.
Olorun aa maa fun yii se.

Eyin okunrin kilosele naa, se e wa pa?
Tubbabieeee kiss kiss
mo ti miss e gan. Ibo la wa la ti ijo yi?
Se iwo naa lo fun 9 month course ni? tongue


FL Gators:
LOL, IFE and topsy, both of you are so not serious grin
I'm too young to be pregnant o shocked shocked
And I no wan play housewife. So How about 3 more years, then you can ask me how my baby is kicking tongue tongue
ko kuku si nkan to n sele. Awan okunrin mejeji ye kan fe ko mi si wahala tongue

Invite you ke? How we go forget you if you be the main main of the parrry? So should the color be, blue or pink or both? grin
too young to be kini? when you were doing it with ifeleke, o mo pe o ti kere ju abi? tongue
babe yi o ti loyun jo, stop hiding it
Ifeleke, toyin ma deny oyun e?

debosky:
Ibeji ni gatoosi ma bi - taiye ma jo farotika, kehinde si ma jo ifeleke. grin grin grin
Aya mi iwo lo nsoro bayi? Mo ti ra rolls royce fun e lati osu to koja. Abi oti gbagbe ni? Se kin tu ra iketa fun e ki o to le loyun fun mi ni?

Ma se beyen o, emi o ti setan fun e lati yokun nisiyin. Mosi fe ma gbadun e bio se da bii sisi nisiyin. kiss

Farotika? Ngbo?? So pe ko je bee - ase iwo ni o fun omo iya olobi loyun? Oma se o. sad

Mo ki yin Dokita Tomobirin ati ronkeotobee si ori oro pataki yii o. . .ayo ni e ma ba ni bi yii o! Olorun a pese aya rere ati oko rere fun yi o. Ekaabo sori eto.
kilode to se ma n fi mi sile anyhow? mi o like e oh. mo miss e gan ni kiss
O mo pe rolls royce mewa lo promise mi, abi bawo lo se fe ki won mo pe olowo l'oko mi?
E mi gan o ti redi lati bi omo kankan, mo si n enjoy something e lo naa grin grin
topsy25:
E woo, e ma da ifeleke lohun. Eni ti o mo nkan ti o nso. Ti a ba tie ni ooto ni pe mo fun omo kan l'oyun ni IJ London, iyen fi han gedegbe pe mo pe l'okunrin. Emi o dabi ore wa oke ohun ti o fun obinrin l'oyun ri. A tie mo boya o ni koboko l'abe gan tongue
oko omo iya olobi, iyawo e n ko?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 5:55pm On Jul 07, 2009
IFELEKE:
awe, se omo ti o fun loyun ni ijare lo ro wipe a n soro e ni?tope ore mii, o se o ku akitiyan ati atotonu, oyun ibeta(olosu meji abo) lo wa ninu iyawo mi,[b]lo mu risika omo iya olobi to o fun loyun nijare was sile e. . .[/b]e n le oo
Iyen ni pe omo iya olobi ni farotika fun l'oyun, oga oh shocked shocked
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 5:10pm On Jul 07, 2009
FL Gators:
((((((((((((hugssss)))))))))))))) Long time oh.
sorry, I just bumped you with my big belly, ifeleke has already done his job tongue
Didnt you notice have been missing here, the doc says am going to have twins

Anywaz, I dey. iwo nko?
Please dont miss the baby shower
Wont miss it for anything in the world tongue

kiss kiss kiss kiss mo ti miss e gan ni. Ki lo nshele?
Se o ti ya s'are bimo niyen?
Ranti lati invite mi fun naming oh, mo fe je jollof rice ati chicken.
Btw, tani baba omo larin ifeleke ati farotika  grin

topsy25:
Omo yen n kick jare. emi o mo pe omo osu meta ma nju apa ju ese bi omo yen o shocked Nitooto, omo naa ma ni agbara bi ti baba e shocked

Ajeniti, ijo wo ni iwo maa loyun fun ore mi debo huh Jowo kia o ti npe ju o
oyun ke  shocked ni'gba ti debo o ti ra rolls royce fun mi
Christianity EtcRe: Lets Celebrate The King Of Kings by argent(f): 8:55am On Jul 07, 2009
You are the greatest
The I AM THAT I AM.
The LORD of all, marvelous Jehovah.
The ONE that shuts and no man can open
The ONE that opens and no man can shut.
Who can question your ways oh LORD?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 6:25pm On Jul 06, 2009
Toyin ba wo ni?
Mo gbo pe o ti l'oyun tongue
Se baby n kick?
Christianity EtcRe: Have You Praised Him Yet, Today? by argent(f): 5:56pm On Jul 06, 2009
Thank you Jesus
Christianity EtcRe: Lets Celebrate The King Of Kings by argent(f): 5:50pm On Jul 06, 2009
Abuzola:
Praise be to Allah, lord of the world, who never die, shit nor slumber, eat nor drink, no vision can grasp him, the omnipotent who is never hungry talk of cursing a fig tree, who never cry, and will never ever be in agony, no one can dare born God,



Allah is great
you miss road?
CultureRe: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 10:00am On Jul 03, 2009
topsy25:
Eyin temi ninu tireedi yi, mo mo pe opolopo wa ni o ti ka iwe alawiye yooba ni kekere; eni ti o ba ranti awon eko inu iwe yii, ki o gbee si wa leti.

Fun Apeere:

Obe baba bo, o ba obo oba

A o ba baba be oba

A o baa bee grin cheesy
Ha mo ranti dada, a o ba bade be oba
A o ba bee.
FoodRe: Six Family Members Die After Eating 'amala' ! by argent(f): 5:40pm On Jul 02, 2009
very sad angry
Jokes EtcRe: Who Wil Be More Remembered by argent(f): 5:21pm On Jul 02, 2009
romade:
yea u deserve the dung dumped on ya head
grin grin grin
LiteratureRe: Which Genre Of Literature Is Fast Going Into Extinction? by argent(f): 5:00pm On Jul 02, 2009
Drama

1 2 3 4 5 6 7 8 9 10 (of 17 pages)